raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
ajíbọ́lá bàṣírù surajudeen ajíbọ́lá bàṣírù phd tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù keje ọdún 1972 1-07-1972 jẹ́ ọmọ ilé aṣojú-ṣòfin àgbà tí ó ń ṣojú fún ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní ilẹ̀ nàìjíríà ó tún fígbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ kọmíṣánà ní abẹ́ ministry of regional integration special duties ní oṣù kẹjọ ọdún 2010 sí oṣù kọkànlá ọdún 2014 ó ti fì... |
tam david-west tamunoemi sokari david-west tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí tam david-west ni a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1936 tí ó sì kú ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 2019 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti mínísítà-ana ọ̀jọ̀gbọ́n yìí ṣaláìsí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 2019 ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló dárò ikú rẹ̀ pàápàá jùl... |
ọdún ọlọ́jọ́ ọdún ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún ìbílẹ̀ kan pàtàkì tí wọ́n máa ń ṣe ní ilé-ifẹ̀ ní ìpínlè ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọdún tí wọ́n máa ń ṣe ní ilé-ifẹ̀ láti ṣe ìrántí ọjọ́ akọ́dá ayé èyí ni ọjọ́ tí olódùmarè kọ́kọ́ dá ilé-ayé ìgbàgbọ́ àwọn tí wọ́n ń ṣodún ọlọ́jọ́ ni pé o jẹ́ ọdún tí wọ́n fi ń bọ olódùmarè àwọn t... |
aṣọ ẹbí aṣọ ẹbí nílẹ̀ yorùbá jẹ́ aṣọ́ ẹgbẹ́jọdá tí wọ́n ń lò nígbà ayẹyẹ tàbí ọdún wọ́n máa ń lo aṣọ ẹbí fún oríṣiríṣi ayẹyẹ bíi ìsìnkú àgbà ìkọ̀mọjáde ìṣílé ìgbọ̀mìnira lẹ́nu isẹ tàbí onírúurú ayẹyẹ mìíràn àsìkò tí a lè dá aṣọ ẹbí gbogbo ọjọ́ ayẹyẹ tàbí ìgbà ọdún ni a lè dá aṣọ ẹbí àwọn orísirísi ayẹyẹ tàbí ọdún tí a ... |
àjèjì àjèjì ni ààrè àlejò arìnrìn-àjò tí kì í ṣe ọmọ bíbí àgbègbè ìlú tàbí orílẹ̀-èdè tí ó bá wà tàbí rìnrìn àjò lọ |
ìgbéyàwó ìgbéyàwó jẹ́ ìdarapọ̀ṣọ̀kan ọlọ́mọge tó ti bàlágà tàbí obìnrin adélébọ̀ àti àpọ́n tàbí ọkùnrin géńdé tó tójú bó láti di ọkọ àti aya ọjọ́ orí tó tọ́ láti ṣe ìgbéyàwó nílẹ̀ yorùbá ọkùnrin tàbí obìnrin níláti bàlágà tàbí tójúbọ́ kí wọ́n tó lè dábàá ìgbéyàwó ó kéré tán ọkùnrin tàbí obìnrin níláti tó ọmọ ọdún méjìd... |
ìṣọ̀lá oyènúsì ìṣọ̀lá oyènúsì tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dọ́kítà oyènúsì dr oyènúsì jẹ́ ògbóǹtarìgì adigunjalè tó fìgbà kan yọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà lẹ́nu kí ọwọ́ ṣìnkún òfin tó tẹ̀ ẹ́ iṣẹ́ adigunjalè tó yàn láàyò jẹ́ kó di ìlúmọ̀ọ́kà lọ́dún 1970s nígbà ayé adigunjalè rẹ̀ oyènúsì gbajúmọ̀ nínú dídigunjalè ilé ìfowópamọ́ ... |
ibrahim olanrewaju layode ibrahim ọláńrewájú láyọdé ni a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1973tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ oil jẹ́ òṣèlú ọmọ yorùbá láti ìlú badagry ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn méjì tó ń ṣojú ìjọba-ìbílẹ̀ badagry nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ èkó sáà ẹ̀kẹ́rin ló ń lórí àléfà gẹ́gẹ́ ... |
ẹkún ìyàwó ẹkún ìyàwó jẹ́ ewì-àbáláyé nílẹ̀ yorùbá ó jẹ́ ẹkún tí omidan tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ lọlé ọkọ máa ń sún láti dárò bí ó ṣe fẹ́ filé àwọn òbí rẹ̀ sílẹ̀ lọlé ọkọ àti láti súre fún wọn fún titọ́ ọ dàgbà di àkókò náà ẹkún ìyàwó jẹ́ pàtàkì àṣeyẹ nínú àṣà ìgbéyàwó láwùjọ ọmọ oòduà ọjọ́ wo ni ẹkún ìyàwó máa ń wáyé nílẹ̀ yor... |
àwọn ènìyàn gbagyi gbagyi or gbárí plural - agbagyi jẹ́ orúkọ àti èdè àwọn ẹ̀yà gbagyi/gbárí tí wọ́n ni olú ìlú àbújá tẹ́lẹ̀ tí ààrin gbùngbùn nàìjíríà tí wọ́n tó mílíọ́nù mẹ́jọ niye tí wọ́n ń sọ èdè náà gwari ni àwọn ẹ̀yà hausa fúlàní àti àwọn gẹ̀ẹ́sì amúnisìn ń pè wọ́n lásìkò ìkónilẹ́rú nílẹ̀ nàìjíríà ámọ́ àwọn ẹ̀yà ... |
bookshop house bookshop house tí wọ́n tún dá pè ní css bookshop ni ó jẹ́ ilé kan ní ìpínlẹ̀ èkó ní agbègbè lagos island tí ó bẹ wà ní broad street ní òpópónà ọdúnlámì ọ̀gbẹ́ni godwin and hopwood architects ni ó ya àwòrán ilé náà |
abiodun olujimi abiodun christine olujimi jẹ́ olósèlú nàìjíríà a bi ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1958 ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin orílẹ̀ ẹ̀dẹ̀ nàìjíríà tí ó sojú fún agbègbè gúúsù ẹ̀kìtì àti olórí ìpín kékeré ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin ní nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ ti àjọ ìbáraenisọ̀rọ̀ ti orílẹ̀ èdè nàìjírí... |
dino mélayé dino melaye tí a bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1974 jẹ́ sínétọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò apá ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ kogí lọ́wọ́́lọ́wọ́ lábẹ́ àsíyá peoples democratic party kí ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn to da ìbò tí ó gbé e wọlé nù tí ó sìn pàṣẹ kí àtúnd... |
àṣà ìsọmọlórúkọ nílẹ̀ yorùbá àṣà ìsọmọlórúkọ nílẹ̀ yorùbá ́ jẹ ọ̀nà tí wọ́n ń gbà láti sọ ọmọ tuntun lórúkọ láyé àtijó ọjọ́ keje ní yorùbá máa ń sọmọbìrin lórúko tí wọ́n sì máa ń sọmọkùnrin lórúkọ lọ́jọ́ kẹsàn-án ṣùgbọ́n ẹ̀sìn àjèjì kiriyó àti ìmàle tí yí èyí padà ọjọ́ kẹjọ là ń sọmọ lórúkọ nílẹ̀ yorùbá lóde òní oríṣir... |
bùkọ́là sàràkí olubukola abubakar saraki tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1962 jẹ́ òṣèlú àti ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà orílẹ̀ èdè nàìjíríà láti ìpínlẹ̀ kwara ó ti fìgbà kan jẹ gómìnà ìpínlẹ̀ kwara fún ọdún mẹ́jọ gbáko bẹ̀rẹ̀ lọ́dún 2003 di 2011 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú people's democratic party pdp ní... |
david lyon olóṣèlú david lyon tí wọ́n bí ní ogún jọ oṣù kejìlá ọdún 1970 jẹ́ olùṣòwọ àti olóṣèlú ọmọ ìpínlẹ̀ bayelsa lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó yàtọ̀ sí david lyon ọmọ ti orílẹ̀ èdè west indies tí ó jẹ́ gbajúmọ̀ olùṣòwò àti òṣèlú bákan náà david lyon tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé gẹ́gẹ́ bí gómìnà-aṣẹ̀ṣẹ̀-yàn ní ìpínlẹ̀ bay... |
ọdún egúngún ayẹyẹ ọdún egúngún jẹ́ ayẹyẹ àjọyọ̀ ilẹ̀ yorùbá bákan náà ni ó jẹ́ ohun àṣà àdáyé bá àtìran-díran àqọn yorùbá wọ́n nígbàgbọ́ wípé ọdún yí ma ń mú ìdàgbàsókè ìrẹ́pọ̀ ìfẹ́ àti ìrú gọ́gọ́ ètò ọrọ̀ ajé si ní àwùjọ gbogo ilẹ̀ yorùbá ni wọ́n si ma ń ṣayẹyẹ ọdún egúngún láì fi tẹ̀sìn òun ẹ̀yà kan kan ṣe egúngún j... |
david lyon |
àjọ elétò ìdìbò lorílẹ̀-èdè nàìjíríà àjọ elétò ìdìbò lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ni a dá sílẹ̀ ní ọdún 1998 ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè nàìjíríà da a sílẹ̀ láti mójú tó ètò ìdìbò gbogbo lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ìtàn bí àjọ yìí ṣe bẹ̀rẹ̀ ìdásílẹ̀ àjọ yìí bẹ̀rẹ̀ kí nàìjíríà tó gba omìnira wọ́n dáa sílẹ̀ láti ṣètò ìdìbò lọ́dún 1959 wọ́n... |
sálíù adétúnjí ọba sálíù adétúnjí tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1928 - oṣu kẹta ọjọ 2 ọdun 2022 jẹ́ ọba aládé lórílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni olúbàdàn tí ìlú ìbàdàn lọ́wọ́́lọ́wọ́ ó gorí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí olúbàdàn ókànlélógójì lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2016 ìtàn ayé rẹ̀ ni ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí kábíyèsì sálíù adétú... |
victoria island lagos victoria island vi tí a lè ṣògbufọ̀ lédè yorùbá sì erékùṣù victoria jẹ́ àgbègbè tó gbajúmọ̀ nílùú èkó ní ìjọba-ìbílẹ̀ etí-osà ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ àgbègbè tí omi ọ̀sà àti òkun yíká àwọn olówó àti gbajúmọ̀ orílẹ̀ èdè nàìjíríà lo ń gbé tàbí ní dúkìá ní ìbẹ̀ erékùṣù victoria fẹ̀g... |
saliu adétúnjí |
overland airways overland airways ó jẹ́ ilé iṣẹ́ pápákọ̀ òfurufú tí ó fìsí kalẹ̀ sí ìlú an airline based in ìkẹjà ìpínlẹ̀ èkó olú ilé iṣẹ́ wọn wà ní pápákọ̀ òfurufú murtala muhammed international airport ní ìkẹjà tí wọ́n si ní ẹ̀ka sí pápákọ̀ òfurufú nnamdi azikiwe international airport ní ìlú àbújá ìtàn rẹ̀ ilé iṣẹ́ b... |
àtòjọ àwọn ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀-mágbèsì ilẹ̀ nàìjíríà èyí ni àtòjọ àwọn ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀-mágbèsì ilẹ̀ nàìjíríà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ tí wọ́n wà lápapọ̀ pẹ̀lú asọ̀rọ̀-mágbèsì orí ẹ̀rọ ayélukára áàpù asking radio wà lori google play store àti apple store àwọn áàpù yí ni ó jẹ́ ti oníròyìn bbc kan ọgbẹ́ni king james yiye ẹni tí ó ti g... |
saliu adetunji |
ọba sálíù adétúnjí |
iganga iganga jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní apá ìlà oòrùn orílẹ̀ èdè uganda ibẹ̀ ni ó jẹ́ ilé agbára àṣ àṣẹ ìjọba uganda ìlú yí náà ni ó tún jẹ́ pẹpẹ ọrọ̀ ajé jùlọ fún àwọn ènìyàn ilẹ̀ uganda ibi tí ìlú yí wà iganga wà ni erékùṣù ilẹ̀ uganda tí ó ní ilẹ̀ tí ó tó ìwọ̀n márùndín láàádọ́ta 45 kilometres ìyẹn 25 mi tí a bá rí ojú... |
abúlé abẹ́òkúta ní jamaica abúlé abẹ́òkúta jẹ́ ibi ìgbà fẹ́ tó rẹwà lọ́pọ̀lọpọ̀ ní orílẹ̀-èdè jamaica ó yàtọ̀ sí abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ibi ìgbafẹ́ tí ó kún fún àwọn ohun ìgbé-ayé àtijọ́ tí kò lábàwọ́n àwọn ohun-èlò ọ̀làjú ayé òde òní wọ́n dá abúlé abẹ́òkúta ní ibi tí wọ́n ń ... |
apata katampe àpata katampe je akọ okuta o wa ni ilu abuja olu ilu orile ede naijiria |
ile gbigbe mambilla ilẹ̀ gbígbe mamìbíllà wà ní gémbù ìjọba ìbílẹ̀ sáúdánà ní ìpínlẹ̀ tàrába ní oríĺ èdè nàìjìríà ile gbigbe yii je itesiwaju arewa orile ede naijiria ti oke ile okeere kameruunu ó wà ní agbede ìgbéga 1600meters 5249ft ìpele odò tí ó sọ di òkè tí ó ga jù ní orílẹ̀ èdè nàíjíríà àwọn abúlé tí ó wà ní orí ... |
ile itaja jabi ile itaja jabi wa ni ilu abuja olu ilu orile ede naijiria |
sola sobowale ṣọlá ṣóbọ̀wálé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1963 jẹ́ òṣèré sinimá àti adarí eré ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di olókìkí ní ọdún 2001 nínú ìṣàfihàn ti ìtàn-àkọọ́lẹ̀ super story oh father oh daughter iṣẹ́ rẹ̀ ó dara pọ̀ mọ́ eré orí ìtàgé nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tí ẹgbẹ́ awada kẹrikẹri ṣ... |
tóbi oyinlolá tóbi oyinlolá ojó ìbíojó kewàá osù kaàrún odún 1992 ni ilú ìbàdànìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nàìjíríà omo bíbí orílè èdè nàìjíríà tí ó jé onísòwò àti òjògbón ó lààmìlaaka lénu isé rè pèlú ilé-isé rloop incorporated ilé-isé tí ó n gbìmò pò láti rii dájú pé àlá ìlanà ìrin àjò oní ìpele kaàrún ti elon musk se agbáterù rè ... |
patience ozokwor patience ozokwor tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1958 jẹ́ òṣèré sinimá-àgbéléwò akọrin ìyìn rere àti olùránṣọ ọmọ bíbí ìlú ngwọ ní ìpínlẹ̀ enugu lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ nípa ṣíṣe ère tí ẹ̀dá-ìtàn rẹ̀ sáàbà máa ń burú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àmín ẹ̀yẹ ló ti gbà lórí siniá-àgbéléwò ṣíṣe lára w... |
ìdòwú philips ìdòwú philips ni a bí ní ọjọ́ kẹrìndílógún oṣù kẹwàá ọdún 1942 26-10-1942 òun ni a mọ̀ sí ìyá rainbow jẹ́ gbajúgbajà òṣeré kan tí ó jé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ a bí ìyá rainbow ní ìlú ìjẹ̀bú-òde ní ìpínlẹ̀ ògùn tí ó jẹ́ apá gúsù ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ naijiria orúkọ àpèjẹ orí ìtàgé rẹ̀ ni... |
ogun àgbẹ̀kọ̀yà ogun àgbẹ́kọ̀yà ni ìjà ìfẹ̀hónú àwọn ẹgbẹ́ àwọn àgbẹ̀ tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 1968 sí 1969 nílẹ̀ yorùbá nígbà ìṣéjọba ẹlẹ́kùnjẹkùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn àgbẹ̀ adáko kòkó ló ṣe agbátẹrù ìjà ìfẹ̀hónú yìí tí àwọn àgbẹ̀ yòókù sì dára pọ̀ láti tako ìṣèjọba aninilára ní àsìkò ìjọba ológun lápá iwọ̀-oòrùn nàìj... |
níji àkànní níji àkànní jẹ́ ọmọ orilẹ-èdè nàìjíríà òṣeré ìtàgé olùdarí alákòóso àti olùgbé fíìmù jáde ni ìtàn ilé ẹ̀kọ́ rẹ̀ àkànní gba ìwé ẹ̀rí àkọ́kọ́ ti yunifásítì nínú ìmò ìjìnlẹ̀ ère ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga yunifásítì ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ni ilé-ifẹ̀ àti ìwé ẹri kejì ti yunifásítì nínú ìmò ìjìnlẹ̀ fíìmù ṣíṣe láti y... |
robert adéyínká adébáyọ̀ robert adeyinka adebayo tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán-án oṣù kẹta ọdún 1928 tí ó sì fáyé lẹ̀ ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹta ọdún 2017 jẹ́ ọ̀gágun àti gómìnà ètò ìṣèjọba-àná ní ìwọ-oòrùn ilẹ̀ yorùbá lórílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ọdún 1966 sí 1971 òun náà ní adarí àwọn òṣìṣẹ́ ológun àti ọ̀gá àgbà ilé ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ à... |
joseph ayọ́ babalọlá joseph ayọ́ babalọlá ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1904 tí ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n osun kẹfà ọdún 1959 jẹ́ ajíyìn rere àgbà àti olùdásílẹ̀ christ apostolic church tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí cac nígbà ayé rẹ̀ babalọlá ní wọ́n gbàgbọ́ pé ó ní agbára iṣẹ́ ìyanu nítorí ọ̀pọ̀lọp... |
odò ògùn odò ògùn jẹ́ alagbalúgbú omi tí ó ń ṣàn kan ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń ṣàn lọ sínu lagoon ní ìlú èkó ṣíṣẹ̀ àti ṣíṣàn rẹ̀ odo ògùn lò bẹ̀rẹ̀ láti river rises in ìpínkẹ̀ ọ̀yọ́ ní ìtòsí ìlú ṣakí tí fífẹ̀ rẹ̀ sì tó nkan bí tí ó sì ń ṣàn gba flows through ìpínlẹ̀ ògùn ọjá lọ sí inú odò ọ̀sà ní ìpínlẹ̀ èkó wọ́n d... |
babatunde hunpe babátúndé húnpẹ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1963 jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìlú àgbádárìgì badagry ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-aṣòfin nàìjíríà tí ó ń ṣojú ìjọba ìbílẹ̀ àgbádárìgì badagry federal constituency lọ́wọ́́lọ́wọ́ ìgbé-ayé rẹ̀ lágbo òṣèlú kí ó tó di ọmọ ... |
ibùdó ogunléndé ibùdó ogunléndé jẹ́ ibùdó pàjáwìrì tí wọ́n kọ́ láti pèsè ilé àbọ̀ oúnjẹ ìlera àti àwọn nǹkan mìíràn fún àwọn tí ó móríbọ́ ní agbègbè ìlú tàbí orílẹ̀ èdè tí ogun ń jà tàbí tí wàhálà kan bẹ́ sílẹ̀ sí nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀ ó lè máà jẹ́ ogún kí ó jẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá pàjáwìrì bíi ìjì búburú iná ìṣẹ̀lẹ̀ ẹṣin-ò-kọ... |
guru maharaj ji guru maharaj ji tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ mohammed ajírọ́batán jẹ́ olùdarí ilé ìjọsìn kan tó fìkàlẹ̀ sí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó júwe ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá ẹ̀dá-àlàyè tó mọ́ jùlọ ó sì tún pe ara rẹ̀ ní jésù dúdú ó ní òun lágbára láti ṣe ìwòsàn àti gbogbo nǹkan tó bá ń da ènìyàn... |
aríṣekọ́lá àlàó arisekola abdulazeez àlàó tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1945 tí ó sì kú ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kàrún ún ọdún 2014 jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣòwò láti ìlú ìbàdàn ó joyè ààrẹ mùsùlùmí tí gbogbo ilẹ̀ yorùbá èyí wáyé nípa ìrànlọ́wọ́ lóríṣiríṣi tí ó máa ń ṣe láti gbé ẹ̀sìn mùsùlùmí ga ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ́ṣáláṣí ló kọ... |
aina gold aina gold tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹta ọdún 1963 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ó tún jẹ́ gbajúgbajà onímọ̀ káràkátà ilé àti ilẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àìná gold kàwé gboyè ni ilé ìwé gíga ti yaba tech ní ìlú èkó ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà gẹ́gẹ́ bí olúkọ́ṣẹ́ lábẹ́ òṣùmàrè theatre grou... |
lola alao lola rhodiat alao tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1970 jẹ́ òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ ìgbìrà ní ìpínlẹ̀ kogí lórílẹ̀-èdè nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí òṣèré ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè yorùbá àti gẹ̀ẹ́sì tí ó ju ọgọ́rùn-ún lọ ìgbà èwe rẹ̀ ní ìgbà èwe rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà ni army children scho... |
allen onyema allen ifechukwu onyema tí wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ olùṣòwò àti agbẹjọ́rọ̀ ọmọ ìpínlẹ̀ anambra lórílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni alága àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ ọkọ̀ òfurufú tí wọ́n ń pè ni air peace airlines ilé ìṣe ọkọ̀ òfuurufú rẹ̀ ló ṣètò gbígbé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà lọ́fẹ̀ẹ́ láti south africa padà sí il... |
gemma chan gemma chan jẹ́ òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ crazy rich asians lọ́dún 2018 ló sọ ó di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà káàkiri gbogbo àgbáyé ìgbé-ayé rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n bí gemma chan sì ìlú london ṣùgbọ́n ó dàgbà sí ìlú kent ó kàwé ní ilé ìw... |
commonwealth youth council = ìgbìmọ̀ ọ̀dọ́ ti commonwealth = cyccommonwealth youth council jẹ́ onírúurú àwọn àjọ tí ó tóbi jùlọ ní àgbáyé àwọn olórí ìjọba ti commonwealth ti kọ́kọ́ gba ìdásílẹ̀ ọ̀dọ́ ti commonwealth wọlé ní agbègbè perth ní oṣù kọkànlá ọdún 2011 kí wọn tó wá se ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ ọ̀dọ́ yi ní ọdún 2013 pẹ... |
iyabo ojo nigerian actressìyábọ́ alice òjó tí a bí ní ọjọ́ kọnkànlélógún oṣù kejìlá ọdún 1977jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré tó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́jọ òun náà sì ti ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò tó tó mẹ́rìnlá ìgbà èwe ... |
eden hazard eden michael hazard tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kìíní ọdún 1991 jẹ́ agbá-bọ́ọ̀lù àfẹsẹgbá-jẹun ọmọ orílẹ̀ èdè belgium ẹgbẹ́ agbá-bọ́ọ̀lù real madrid ní orílè-èdè spain ló ti ń gbá bọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ lọ́wọ́́lọ́wọ́ báyìí ìgbà èwe rẹ̀ ìlú la louvière ni wọ́n bí eden hazard sí ṣùgbọ́n wọ́n tó o dàgbà ni braine-le-co... |
efunsetan aniwura oloye ẹfúnṣetán aníwúrà c1820sjune 30 1874 je iyalode keji ti ìbàdàn ati ọkan ninu awọn oniṣowo ẹrú ṣáaju ni ọrundun 19th ibadan ti a bọwọ fun bi onijaja ati onijaja aṣeyọri ipa rẹ ni ayika iṣelu ologun eto-ọrọ aje ati awọn agbegbe ẹsin ibadan ó jẹ́ olókìkí nítorí pé ó jẹ́ alágbára jù lọ àti pé ó dájú... |
opeyemi ayeola ọpẹ́yẹmí ayéọ̀la tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1977 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré-bìnrin sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú ṣàgámù ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti kópa nínú oríṣiríṣi sinimá àgbéléwò ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà gẹ́gẹ́ bí gẹ́gẹ́ bí òṣèré nínú eré àgbéléwò nínú ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán tí wọ́n ... |
ọ̀rọ̀-orúkọ èdè yorùbá ọ̀rọ̀ orúko ni ọ̀rọ̀kọrọ̀ nínú gbólóhùn èdè yorùbá tí ó jẹ́ orúkọ tàbí tí ó ń tọ́ka sí orúkọ ènìyàn ẹranko ìlu nǹkan ẹlẹ́mìí tàbí aláìlẹ́mìí nǹkan afòyemọ̀ nǹkan aṣeékà aláiseéka ọ̀rọ̀ orúkọ ni olùwà fún àbọ̀ àwọn àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-orúkọ *bọ́lá shadè adé wálé - ọ̀rọ̀-orúkọ ènìyàn *ewúrẹ́ ajá - ọ̀rọ̀-o... |
mambilla plateau ilẹ̀ gbígbẹ màmbíllà jẹ́ òkè ní ìpínlẹ̀ tàrábà ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ilẹ̀ náà jẹ́ ìtẹ̀síwájú àrìwá ti orílẹ̀ èdè nàìjíríà ti àwọn òkè gíga bameńdà ní orílẹ̀ èdè kamerúúnù mambilla plateau náà ní àgbède ìgbẹ́ga tí ọ́ tó bií ní èyí tí ó sọ di òkè tó ga jù nàìjíríà àwọn abúlé rẹ̀ wa ̀ni ́ orí òkè tí ó gb... |
pete edochie oloye pete edochie mon tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1947 jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ gbajúmọ̀ àti ìlúmọ̀ọ́kà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ ẹ̀yà ìgbò láti ìpínlẹ̀ anambra lorílẹ̀-èdè nàìjíríà sinimá àgbéléwò lédè gẹ̀ẹ́sì àti ìgbò ló ti ń kópa wọ́n kà á sí àgbà òṣèré sinimá-àgbéléwò tó lẹ́bùn eré sinimá ṣíṣe jùlọ ní... |
marcel quinet marcel alfred quinet 6 keje 1915 - 16 oṣu kejila ọdun 1986 jẹ olupilẹṣẹ ilu ati ara ilu belijiomu itan igbesiaye o kọ ẹkọ ni ile mons conservatory ni ṣoki ati lẹhinna brussels conservatory nibiti o ti gba awọn onipokinni fun isokan ni 1936 counterpoint ni ọdun 1937 fugue ni ọdun 1938 ati iwe abinibi piano... |
kọ́lá òyéwọ̀ kọ́lá òyéwọ̀ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1946 jẹ́ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò àti olùkọ́ ilé ìwé ifáfitì ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lóríṣiríṣi sinimá kan gbòógì tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ jáde ní orogún adédigba bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ tíátà náà ló ń ṣíṣe olùkọ́ ó ti jẹ́ olùkọ... |
ẹ̀wà àgànyìn ẹ̀wà àgànyìn jẹ́ oúnjẹ àdúgbò tí ó wọ́pọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà pàá pàá jùlọ ìpínlẹ̀ èkó wọ́n ma ń sábà se ẹ̀wà yí kí ó rọ̀ tàbí kí ó fọ́ dára dára wọ́n sábà má ń jẹ́ ẹ̀wà yi pẹ̀lú ata díndín tí wọ́n fepo gbá àmọ́ ata náà ń ta gidi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń ṣe ìkékúrú orúkọ ẹ̀w... |
vlekete ọjà ẹrú vlekete ọjà okowò ẹrú jẹ́ ọjà tí wọ́n ti ń ṣe káràkátà ẹrú ní ìlú àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí badagry ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà nigeria wọ́n dá ọjà yìí sílẹ̀ lọ́dún 1502 òrìṣà kan tí wọ́n ń pè ní vlekete ni wọ́n fi orúkọ rẹ̀ dá ọjà náà ó jẹ́ ọjà ẹrú tó gbajúmọ̀ gidigidi nílẹ̀ adúláwò ní... |
òrìṣà vlekete òrìṣà vlekete jẹ́ òrìṣà omi-òkun àwọn ẹ̀yà ògù ní ìlú àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí badagry ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ojúbọ òrìṣà yìí wà ní ibi kan ni ìlú náà tí wọ́n ń pè ní ojúbọ vlekete ojúbọ yìí ni wọ́n fi sọ orúkọ ọjà ẹrú náà tí wọ́n ń pè ní ọjà vlekete ni àgbádárìgì ọjà vlekete jẹ́ ọj... |
ìlù sàtọ́ ìlù sátọ́ jẹ́ ìlú ìbílẹ̀ pàtàkì ní ìlú àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí badagry ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ìlú kan tí ó gbajúmọ̀ jùlọ láwùjọ àwọn ẹ̀yà ògù ní badagry ìlú sátọ́ jẹ́ ìlù méjì tí ó tóbi tí gíga rẹ̀ ju ènìyàn lọ ní ìdúró ó jẹ́ ìlú tí wọ́n fi ń ré ibi dànù láyé àtijó ṣùgbọ́n lóde ò... |
ilé alájà àkọ́kọ́ lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé alájà àkọ́kọ́ lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ni wọ́n kọ́ sí ìlú àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí badagry lọ́dún 1845 ìtàn sọ wípé ọdún 1842 ni àwọn òyìnbó tí wọ́n kọ́kọ́ gbé ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tí a mọ̀ sí ẹ̀sìn kírísítẹ́nì wá sí orílẹ̀-èdè nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé alájà náà tí wọ́n s... |
rilwan akinolú ọba rilwan babátúndé oṣùọlálẹ́ àrẹ̀mú akiolú tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1943 ni ọba ìlú èkó àti alága gbogbo ọba aládé tó wà ní ìpínlẹ̀ èkó akiolú gorí ìtẹ́ ọba ìlú èkó ni ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹjọ odun 2003 ọba adéyínká oyékàn ló jọba tí ó sìn wàjà kí akiolú tó gorí ìtẹ́ ìgbé-ayé èw... |
ọba síkírù adétọ̀nà ọba síkírù káyọ̀dé adétọ̀nà awùjalẹ̀ tí ìlú ìjẹ̀bú pátápátá tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù karùn-ún ọdún 1934 ni ọba aládé tí ó ga jùlọ nílẹ̀ ìjẹ̀bú ni ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀ èdè nàìjíríà awùjalẹ̀ gorí ìtẹ́ àwọn bàbá rẹ̀ lọ́dún 1960 ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú wọ́n bí ọba sí... |
awùjalẹ̀ tí ìjẹ̀bú awùjalẹ̀ jẹ́ orúkọ oyè ọba ti ó nílẹ̀ ìjẹ̀bú ìjẹ̀bú-òde ni ààfin ọba awùjalẹ̀ tèdó sí ọba síkírù káyọ̀dé adétọ̀nà ọ̀gbágbá ii ni awùjalẹ̀ ìlú ìjẹ̀bú tí ó wà lórí ìtẹ́ lọ́wọ́́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí awùjalẹ̀ tí ilẹ̀ ìjẹ̀bú pátápátá ìdílé ọlọ́ba aníkìláyà ló ti wá àwọn ìdílé ọlọ́ba tí wọ́n máa ń jẹ́ awùjalẹ̀ ... |
ọba abdulrasheed adéwálé àkànbí oba abdulrasheed adéwálé àkànbí oluwo tì ilẹ̀ ìwó tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà ọdún 1967 jẹ́ ọba ìlú ìwó ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó wà ìtẹ́ lọ́wọ́́lọ́wọ́ bí ó ṣe jọba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ òye láti ìdílé ọba ni ìlú ìwó ni wọ́n du oyè ọba olúwòó kí orí tó bá ọba adé... |
akin lewis akin lewis tí wọ́n bí ní ọdún 1957 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè nàìjíríà akin lewis bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 1973 ìgbà èwe àti aáyan rẹ̀ nínú iṣẹ́ tíátà gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú akin lewis jẹ́ ọmọ bíbí ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìlú za... |
bimbo oṣin bím̀bọ́ ọ̀ṣìn tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1971 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ oǹdó lorílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú pé wọ́n bí bím̀bọ́ ọ̀ṣìn lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1971 ni ìpínlẹ̀ oǹdó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kàwé gboyè dìgír... |
jíbọ́lá dábọ̀ jíbọ́lá dábọ̀ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1942 jẹ́ gbajúmọ̀ oǹkọ̀wé adarí olóòtú àti òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ oǹdó ṣùgbọ́n tí wọ́n bí sí ìlú èkó lorílẹ̀-èdè nàìjíríà nigerian actor ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ jíbọ́lá dábọ̀ dàgbà sí ìlú èkó gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú ìl... |
tony elumelu tony onyemaechi elumelu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta ọdún 1963 jẹ́ pàràkòyí oníṣowò onímọ̀ ètò ọ̀rọ̀ ajé ati afowóṣàánú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni alága àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ heirs holdingstranscorp at ilé ìfowópamọ́ the united bank for africa bẹ́ẹ̀ náà òun ni olùdásílẹ̀ tony elumelu found... |
united bank for africa uba united bank for africa uba plc jẹ́ ilé ìfowópamọ́ tí ó ga jùlọ nílẹ̀ áfíríkà tí olú ilé iṣẹ́ rẹ̀ gúnwà sí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ilé ìfowópamọ́ tó dáńgájíá jùlọ nílẹ̀ áfíríkà tí ó sì wà káàkiri orílẹ̀ èdè ogún nílẹ̀ áfíríkà àti lórílẹ̀ èdè faransé gẹ̀ẹ́sì àti new york ní orílè-èdè amẹ́ríkà... |
ẹ̀yà ara ènìyan the entire structure of a human being anatomy of the human body túndarí síbí yìí fún the textbook ẹ wo gray's anatomy ẹ̀yà ara ni a tún lè pe ní àtò tàbí ìrísí ọmọ ènìyàn ẹ̀yà ara ọmọ ènìyàn yí kún fún oríṣiríṣi àti onírúurú it is composed of many different types of sẹ́ẹ́lì tí ó jẹ́ pé wọ́n kóra pọ̀ di ... |
funke akindele funke akindele tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1977 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jennifer jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n bí fúnkẹ́ sí ìlú ìkòròdú ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà eré orí tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ i need to know ló mú un di gbaj... |
mercy aigbe mercy aigbe ojo akoko osu kinni odun 1978 je oserebirin ara nigeria oludari ati obinrin onitowo oje gbajumo fun awọn fiimu abinibi abinibi rẹ igbesi aye ibẹrẹ a bi ni ojo akoko oṣu kini ọdun 1978 ni ipinle edo o wa lati ilu benin eyiti o jẹ olu-ilu ti ipinle edo o jẹ ọmọ keji ni idile ti marun o lọ si maryl... |
ibrahim gambari ibrahim agboola gambari cfr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún osu kẹta ọdún 194424-03-1944 ní ìlú ìlọrin ní ìpínlẹ̀ kwara orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ chief of staff aṣẹ̀ṣẹ̀-yàn ààrẹ muhammadu buhari kí ó tó di àsìkò yìí ó jẹ́ onímọ̀ àti aṣojú orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti fi ìgbà kan jẹ mínísítà ... |
soundcity radio network soundcity rédíò network jẹ́ ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì kan ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ma ń ṣe àtòjọ àwọn orin ovójì tó lààmì laaka jùlọ ní ilẹ̀ nàìjíríà lábẹ́ àṣe àti alákòóso alphavision multimedia tí ó jẹ́ ẹ̀ka considated media associates cma olú ilé iṣẹ́ wọn wà ní ìpínl èkó ilé iṣẹ́ yí ma ń gbó... |
ẹ̀yà àwórì ẹ̀yà àwórì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìran yorùbá tó sẹ̀ wá láti ilé-ifẹ̀ a lè rí àwọn àwórì ní ìpínlẹ̀ èkó àti ògùn ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn àwórì babańlá àwọn àwórì ọlọ́fin ògúnfúnminíre ni ìtàn sọ wípé ó kúrò ní ilé-ifẹ̀ tí ń ṣe orírun àwọn yorùbá nígbà tí ó fẹ́ rìnrìn àjò náà odùduwà tí ń ṣe babańlá wọn fún un ní àw... |
anthony olúbùnmi okogie anthony olúbùnmi okogie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹfà ọdún 1936 jẹ́ kádínà ìjọ kátólíkì àti bíṣọ́ọ̀bù-àgbà-àná ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà |
mathew hassan kuka mathew hassan kuka tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1952 jẹ́ bíṣọ́ọ̀bù àgbà tí olu-ìjọ kátólìkì tí ìpínlẹ̀ ṣókótó ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ wọ́n bí bíṣọ́ọ̀bù kukah lọ́jọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1952 ní ìlú anchuna tí ikulu ní ìjọba-ìbílẹ̀ zangon kataf ní ìpínlẹ̀ kaduna l... |
adéwálé àyúbà adéwálé àyúbà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù karùn-ún ọdún 1966 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ mr johnson jẹ́ gbajúgbajà olórin fújì ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà nigerian singer mr johnson túndarí síbí yìí fún òmíràn ẹ wo mr johnson ìṣojútùú |
george weah george weah tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ george manneh oppong weah ọjọ́ìbí 1 oṣù kẹwàá ọdún 1966 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ tẹ́lẹ̀ àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè liberia òun ni ààrẹ ilẹ̀ làìbéríà lọ́wọ́́lọ́wọ́ wọ́n dìbò yàn án lọ́dún 2018 kí ó tó di ààrẹ jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà tí orílẹ̀ èdè náà kí ó tó di òṣè... |
ẹ̀pà ẹ̀pà jẹ́ ohun jíjẹ eléso ti a ń rí láti inú ilẹ̀ tí àwọn ọmọ rẹ̀ sì ma ń wà nínú apó tàbí èpo pord òun àti ẹ̀wà pèlú gbogbo ìran tí wọn bá pín sí jẹ́ ọmọ ìyá kan náà oríṣiriṣi orúkọ ni àwọn elédè àgbáyé ń pèé |
igi àgbọn igi àgbọn tí ìnagijẹ rè ń jẹ́ cocos nucifera ní èdè latin jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí igi tí ó ń jẹ́ arecaceae tí ó sì njẹ́ ọ̀kan ṣoṣo tí ó ṣẹ́kù nínú àwọn igi ti wọ́ ń pè ní genus cocos èso àgbọn wúlò púpọ̀ nítorí ẹgbàá-gbèje ìwòs̀an tí ó sòódó sínú rẹ̀ níbi jíjẹ mímu omi rẹ̀ lílò rẹ̀ láti fi ṣe oògùn tàbí ìpara... |
omi àgbọn omi àgbọn ni omi tí ó mọ́ kangá tí a má ń rí nínú àgboṇ tí ó bá ti gbó dára dára bí agbọn ṣe ń gbó sí ni ẹran inú àgbọn ma ń yíra padà sí omi àgbọn yàtọ̀ sí wàrà milk àgbọ́n wàrà àgbọn ni wọ́n ma ń rí láti ara rírẹ́ tàbí híha tinú àgbọn pọ̀ mọ́ra wọn tí wọ́n sì fún kí omi inú rẹ̀ ó lè jáde ìwúlò omi àgbọn omi... |
kẹ́mi afọlábí kẹ́mi afọlábí tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1978 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin oǹkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ ìpínlẹ̀ ògùn ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ kẹ́mi bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé a-z international school àti... |
lateef adedimeji lateef adedimeji tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 1986 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré oǹkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ògùn ṣùgbọ́n tí wọ́n bí sí ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà lọ́dún 2013 ni ìràwọ̀ rẹ̀ gbòde kan lẹ́yìn látàrí ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ kud... |
bukky wright bukky wright tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gangan ń jẹ́ olúwabùkọ́lá sekinat àjọkẹ́ wright tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1967 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin olùṣòwò ọmọ bíbí ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn lorílẹ̀ èdè nàìjíríà aáyan iṣẹ́ sinimá àgbéléwò àti okowò rẹ̀ bukky bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dú... |
anthony joshua anthony olúwafẹ́mi ọláṣeéní jóṣúà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹwàá odun1989 jẹ́ gbajúmọ̀ ajẹ̀ṣẹ́ ọmọ bíbí ṣagámù ni ìpínlẹ̀ ògùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó ń ṣojú orílẹ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí ajẹ̀ṣẹ́ òun ni ajẹ̀ṣẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ẹ́ afẹ̀ṣẹ́ kù bí-òjò tó lágbára jùlọ ni àgbáyé lọ́wọ́́lọ́wọ́ báyìí lá... |
pẹ́pẹ́yẹ pẹ́pẹ́yẹ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹyẹ omi abẹ̀mí tí ó lè gbé ní orílẹ̀ àti nínú omi oríṣiríṣi ọ̀nà ni pẹ́pẹ́yẹ pín sí nínú ẹbí wọ́n tí ó ń jẹ́ anatidae ọ̀pọ̀lọpọ̀ pẹ́pẹ́yẹ ni wọ́n lè gbe ní inú omi iró àti omi iyọ̀ kan wà tí wọ́n pẹ́pẹ́yẹ ní akọ bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ní abo ìrísí wọn pẹ́pẹ́yẹ jẹ́ ẹyẹ tí ó gùn lọ́rùn ẹnu wọ... |
kòkó fatty seed of theobroma cacao which is the basis of chocolate èso kòkó tàbí kòkó ni wọ́n tún ń dà pè ní ẹ̀wà kòkó ni ohun ọ̀gbìn kan tí ó so sí ara igi tí ìrísí rẹ̀ fẹ́ fara pẹ́ èso igi obì orúkọ èso yí wá láti inú èdè spain tí wọ́n pé ní cacao tí àwọn náà mú orúkọ yí láti inú ọ̀rọ̀ nahuatl ọ̀rọ̀ cacahautil yí wọ́... |
kunle afolayan kunle afolayan tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí yorùbá ní ìgbómìnà láti ìpínlẹ̀ kwara lórílẹ̀-èdè nàìjíríà bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé adeyemi afolayan tí gbogbo ènìyàn ... |
gabriel afolayan gabriel afolayan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1980 tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí g-fresh lágbo orin jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti akọrin ìgbàlódé tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni gabriel àti kunle afolayan àgbà eléré tíátà nì adeyemi afolayan tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ade love nígbà ayé rẹ̀ ní bàbá wọn |
muhammad nami muhammad mamman nami tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdun 1968 jẹ́ alága fún àjọ ìjọba-àpapò lórílẹ̀-èdè nàìjíríà tó ń ṣe kòkárí fún owó-orí gbígbà firs lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kejìlá ọdún 2019 ni ààrẹ muhammadu buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ fi orúkọ rẹ̀ ránṣẹ́ sí ilé-ìgbìmọ̀-aṣòfin-àgbà fún ìfọwọ́sí nami ni yóò rọ́pò babátúnd... |
babátúndé fowler ọ̀mọ̀wé babátúndé fowler tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1956 jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ètò nípa kòkárí owó-orí àti òṣìṣẹ́ ìjọba ó ti fìgbà kan jẹ́ alága yányán fún ilé iṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ èkó lagos state internal revenue service lirs àti ti ìjọba àpapọ̀ federal inland revenue service firs tí ó ń ṣe kòká... |
federal inland revenue service federal inland revenue service tí apèkúrú rẹ̀ ń jẹ́ firs jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ó ń ṣe kòkárí ètò owó-orí àti gbígbà rẹ̀ ọ̀gbẹ́ni muhammad nami ni alága-aṣẹ̀ṣẹ̀yàn fún ilé iṣẹ́ agbowó-orí yìí ààrẹ muhammadu buhari kéde yíyàn rẹ̀ lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kejìlá ọdún 2019 ẹni tí ó wà nípò ... |
yẹmí ṣóladé yẹmí ṣóladé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1960 jẹ́ gbajúmọ̀ àti arẹwà ọmọkùnrin òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú wọ́n bí yẹmí ṣóladé lọ́jọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1960 sí ìlú èkó lorílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà... |
yọ̀mí fash-láńsò yọ̀mí fash-láńsò tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1968 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbìyànjú iṣẹ́ tíátà rẹ̀ yọ̀mí fash-láńsò kàwé gboyè dìgírì nínú imọ̀ nípa okowò ní ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ èkó university of lagos gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé yọ̀mí... |
jayé kútì jayé kútì tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje ṣùgbọ́n tí kò jẹ́ kí ọdún rẹ̀ hànde jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí yewa ayétòrò ní ẹ̀gbádò ìlaròó ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ìròyìn tí kò fẹsẹ̀ múlẹ̀ kan gbòde nígbà kan pé ìyàwó gbajúmọ̀ olórin fújì alhaji wàsíù àlàbí pàsúmà... |
dẹ̀jọ túnfúlù túndé mákindé tòkunbọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí dẹ̀jọ túnfúlù jẹ́ gbajúgbajà òṣèré orí ìtàgé tí a bí ní ojọ́ kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù karùnún ọdún 1969 31-05-1969 sí ìdílé ọ̀gbẹ́ni abbas mákindé ní ìlú abẹ́òkúta |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.