raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
sẹ́ríkí ń góómà seriki n gooma sẹ́ríkí ń góómà ọba mẹ́wàá ìgbà mẹ́wàá ìgbà kan ò lolé ayé gbó sẹ́ríkí ń góómà sànmọ́nì góómà ìgbà ti lọ ńlẹ̀ yìí ohun gbogbo ti yí padà ni wàràwàra ejò ìgbà ti wọ́ kúò níbi tàná ìgbà tó dé làwá ń lò ẹ̀bi wa kọ́ rárá ọ̀pọ̀ èèyàn tí ò bá fẹ́ bágbà yí ló le máa jàgbùrín èṣí lọ́bẹ̀ mo rántí ... |
fáwẹ̀lì yorùbá fáwẹ̀lì yorùbá fáwẹ̀lì ni ìró tí a pè tí kò sí ìdiwọ́ fún afẹ́fẹ́ tàbí èémí tí ó ń ti inú ẹ̀dọ̀ fóró bọ̀ wá sí ọ̀nà ẹnu bí àpẹẹrẹ a e ẹ i o ọ u an ẹn in ọn un gbogbo ìró fáwẹ̀lì èdè yorùbá ló jẹ ìró akùnyùn èyí ni pé tán-án-ná gbọ̀n rìrì nígbà tí a pè wọ́n oríṣi méjì ni fáwẹ̀lì èdè yorùbá àwọn ìsọ̀rí méj... |
áfríkà áfríkà ni orile keji titobijulo ati toni awon eniyan julo lagbaye leyin asia ni bi 302 egbegberun km² 117 million sq mi lapapo mo awon erekusu to sunmo ile re je 6 apapo gbogbo oju aye ati 204 gbogbo ile aye pelu egbegberunkeji kan eniyan ni 2009 e wo tabili ni awon agbegbe 61 eyi je bi 1472 gbogbo iye eniyan ag... |
ìjálá ìjálá sísun nípa àkókó ìjálá fún àkókò kan nípa ìgbésí ayé àwùjọ kan ni èyí ma ń sábà bá mu asùnjàlá tún lè yi padà bí ó bá fẹ́ lòó fún àwùjọ mìíràn ìjálá tí asùnjàlá bá sun ma ń ṣàfihàn bí àwùjọ náà ṣe rí nípa ìrísí ìhùwàsí àwọn ènìyàn ibẹ̀ àṣà ìbáṣepọ̀ ètò ìṣèlú àti ètò ọrọ̀ ajé àwùjọ náà ewì nípa ẹyẹ àti ẹrank... |
konskowola |
èṣù èṣù jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà tí àwọn ìran yorùbá ń bọ ó wà lára àwọn òrìṣà tí olódùmarè rán láti ìkọ̀lé ọ̀run wá sí ayé èṣù ni a lè pè ní olópàá tàbí agbófiró àwọn òrìṣà yòókù tí olódùmarè rán ìdí nipé òun ní o máa rí i dájú pé wọ́n tèlé òfin bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé orúkọ eṣù tí yàtọ̀ láti orílè-èdè kan sí òmíràn ọ̀nà t... |
ọba lájìwọwọ oba lajiwowo ranse ijaya ọba lájìwọwọ ránṣẹ́ ìjayà wọn ní ọjọ́ tí a ò bá dá ni kì í pé bí ilẹ̀ ti ń mọ́ tó n ṣú bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ń lọ geere bíi kẹ̀kẹ́ ológeere bí ọ̀sùpá ti ń ràn lálaalẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ń yọ́ gèèrègè bí òrí ọjọ́ tí kábíèsí dá ku oṣù kan péré jìjì kò tí ì rí ẹni tó mọ nǹkan tó fẹ́ràn jù kò gbọ́... |
ajọfọ̀nàkò àsìkò káríayé utc ni ede geesi duro fun universal time coordinated eyi tumosi ajofonako asiko kariaye |
dna dna duro fun deoxyribonucleic acid ni ede geesi eyi tumosi deoksiribonúkléì kíkan dna tabi dnk dna je núkléì kíkan ti o ni awon ilana abimo ti a n lo fun idagbasoke olounalàyè gbogbo awon iru ahamo emi lamolara dna je alolara eleemeji awon apa dna to ungbe awon ilana wonyi ni a unpe ni abimo sugbon awon itelentele ... |
ribonúkléù kíkan ribonúkléù kíkan tabi ásìdì ribonúkléù ribonucleic acid tabi rna je ikan ninu awon horogigun agba meta lapapo mo dna ati awon proteini ti won se koko fun gbogbo iru awon ohun alaye bi dna rna na je dida pelu ewon gigun to unje nukleotidi nukleotidi kookan ni ipilenukleu pipe nigba mi ni ipile oloponitr... |
sáyẹ́nsì sáyẹ́nsì tabi imo ijinle |
aids aids ni ede geesi duro fun acquired immune deficiency syndrome eyi tumosi àrọ́lù àìsàn ìdébá àìtó àjẹ́sára je arun sístẹ́mù àjẹsára ninu eniyan ti èràn àìtó-ìgbóguntàrùn ènìyàn n fa |
èràn àìtóagbóguntàrùn ènìyàn hiv ni ede geesi duro fun human immunodeficiency virus eyi tumosi èràn àìtóagbóguntàrùn ènìyàn ni ede yoruba je erantiotio to n fa okunrun aids |
umaru musa yar'adua |
tẹlifísàn tẹlifísàn tabi àfigbéwòran tv je afigbebanisoro amohunmuaworan to un se igbejade ati to n se igbawole aworan arekoja ki ba je alawo funfun ati dudu tabi ti alawo orisirisi |
oyo oyo ni naijiria le je ilẹ̀ọba ọ̀yọ́ tabi iluoba ayeijoun ipinle oyo ipinle kan ni naijiria ọ̀yọ́ ilu ni naijiria tabi oyo kongo |
ìlú ẹ̀yọ ilu eyo kiki egba ìlú ẹ̀yọ kìkì ẹ̀gbà oorun oorun oorun oorun ti ń gba tọwọ́ ọmọdé tọwọ́ ọmọdé nìkan ló ha ń gbà nì n ò mọ ìgbà tí oorun tún rá mi lọ pàfe mo wá tẹ́ra sílẹ̀ bí àtẹ ọ̀rúnlá tàbí bí obìnrin tí ń sàníyàn ọkọ mo nawọ́ mú oorun yìí lójú páálí àlá àkọ́kọ́ ni mo rí tí mò ń wí gbankọgbì nit i ìkejì tí ... |
john augustus otunba payne awon agbejoro omo yoruba àwọn lọ́ọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ yorùbá a kọ ọdún tí wọ́n di looya sí òkè orúkọ wọn christopher alexander sapara williams o di looya ni 1880 christopher alexander sapará williams òun ni ọmọ nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di lọ́ọ́yà rotimi olusola alade o di... |
fàájì àwon yorùbá jé eni tí ó féràn fáàjì dárá dara won a maa se ere idaraya bii tita ayo olopon ere ijakadi ati bee bee lo |
kurt waldheim kurt josef waldheim ti o je akowe agba fun united nation organisation uno laarin odun 1972 - 1982 ti o si tun wa di aare president austria ni 1986 ku ni 14/6/2007 nigba ti o di omo odun mejidinlaaadorun-un 88 |
àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú èdè áti lítíréṣọ̀ lédè yorùbá yoruba professors ojogbon yoruba awon ojogbon onimo ede yoruba awon ojogbon onimo litireso yoruba |
michael kearney michael kearney òun ni ó kéré jù láti gba oyè ní yunifásítì ọmọ ọdún mẹ́fà àti oṣù méje ni ó jẹ́ nígbà tí ó wọ santa rosa junior college california ní ilẹ̀ amẹ́ríkà ní 1990 ní ọdún 1994 ni ó gba oyè ba nínú anthropology ní university of south alabama ní ilẹ̀ amẹ́ríkà nígbà tí ó jẹ ọmọ ọdún mẹ́wàá àti oṣ... |
lichtenstein castle lichtenstein castle legbee honau ni swabian alb baden-wurttemberg jẹ́mánì ni 'castle' yii wa itumo oruko ti won n sapejuwe re yii ni ede geesi ni 'light cloured stone' iyen ni okuta ti awo ara re ko po fun ekunrere alaye nipa 'castle' yii wo link title |
odò amasónì odo amasonini odo to tobijulo lagbaye awon oniwadii kan ni ile brazil ti so pe odo amazon ni o gun ju ni agbaye teletele odo amazon ni a mo pe o ni omi ninu ju lo ni gbogbo agbaye ti o si je pe odo nile ni o gun ju sugbon awon oniwadii yii so pe mismi ni ile peru ni amazon ti bere ati pe o gun ni iwon 6800 ... |
sunita williams sunita williams ojoibi september 19 1965 jẹ́ ajagun ojú omi ti ìlẹ̀ amẹ́ríkà tí ó sì tún jẹ́ òṣìṣẹ́ nasa |
shannon lucid shannon matilda wells lucid ojoibi january 14 1943 je asekemistrialaye ati arinlofurufu fun nasa ara amerika |
kathryn thornton kathryn ryan cordell thornton phd ojoibi august 17 1952 in montgomery alabama je onimosayensi ati arinlofurufu tele fun nasa ara amerika to ti lo wakati 975 ni ofurufu lowolowo ohun ni igbakeji olori eko fun awon eto iparieko ni ile-eko iseero ati sayensi alamulo ti university of virginia |
lẹ́yìn ọdún mẹ́ta leyin odun meta lẹ́yìn ọdún mẹ́ta ohun t’ó bá gba ni lọ́jọ́ ogun òun l’ó yẹ ká wárí fún bíi gbanigbani ohun t’ó bá gba ni sìlẹ̀ lọ́jọ̀ ọ̀ràn òun ló yẹ ká sátọ̀ bíi olùgbèjà ṣéb’olùfọ̀n ni kò jógun ó jà l’ẹ́rìn ṣeb’ájàlá ṣàngó ni kò jógun ó kó kòso àní ‘hun t’ó bá gba ni làá sin ṣùgbọ́n òbìrí ayé ti yí... |
asiko |
vilma espin vilma lucila espín guillois tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1930 tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 2007 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ kuba bẹ́ẹ̀ sì ni ó tún jẹ́ ìyàwó raul kastro ààrẹ ilẹ̀ kuba ó kó ipa tí ó ṣe kókó nínú ìjà gbára ilé cuba |
alan s kaye alan s kaye kaye ti o je gbajugbaja onimo eda-ede ku ni 31/5/2007 kaye ti sise ti o po lori ede semitic ibi ti o ti n fi isinmi re se iwadii ni united arab emirate ni won ti ri i pe o ni kansa cancer ni 1/5/2007 ti omo re jeremy kaye si gbe e wa si ile ni 22/5/2007 |
jeremy kaye |
pẹ̀lẹ́ pele pẹ̀lẹ́ mo kí ìyáálé ilé kan pẹ̀lú ọ̀wọ̀ níjọ́sí mo ní ‘ẹ pẹ̀lẹ́ mà~’ ó bá bínú ó ní ‘mo jẹ́gbẹ́ ẹ kọ́ bùọ̀dá tó fi ń ṣe mí ní “ẹ pẹ̀lẹ́ mà” ó ṣe mí ní kàyééfi mo bẹ̀bẹ̀ gán-ín mo ní ‘ẹ jọ̀wọ́ ẹ má mà bínú tinútinú ni mo fi kí i yín kú akitiyan’ èyí wá mú mi rántí ọ̀rọ̀ àwọn àgbà irahun aja kan aja irahun ìr... |
ojú oju jẹ́ ẹ̀yà ara tí ẹranko àti ènìyàn ń lò láti ríran ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ gbogbo ẹranko ló ní ojú ṣùgbọ́n àwọn ẹranko kan wà tí kò lójú fún eniyan àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko àwòrán tí ojú bárí á lọ sí ọpọlọ ọpọlọ á sì túnmọ̀ àwòrán náà ènìyàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko ní ojú méji àwọn ẹranko inú odò tí a tún ń pè ní copepods ní oj... |
etí etí jẹ́ ẹ̀yà ara èyí tí ènìyàn àti ẹranko fi ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ènìyàn àti ẹran ọ̀sìn tí òyìnbó ń pè ní mammals ní etí méjì a lè pín etí sí ẹ̀yà mẹ́ta etí ìta etí àárín àti etí inú awon ẹ̀yà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ń ṣiṣẹ́ papọ̀ láti mú kí ènìyàn tàbí ẹranko gbọ́rọ̀ ìjàm̀bá sí etí pàápàá jù lo ìlù etí le fa àìgbọ́ràn tàbí ìṣòro p... |
ọkọ̀-àlọbọ̀ òfurufú atlantis ọkọ̀-ayára òfurufú atlantis ti o ti lo si inu ofurufu lati nnkan bi ose meji ni o pada si ile aye ni edwards airforce base california usa ni oni ojo ketalelogun osu kefa odun 2007 gbogbo awon mejeeje ti won wa ninu re ni won ba a de sunita williams naa ti gunle si ile aye oun ni obinrin ti ... |
àwọn orin ilẹ̀ yorùbá orin jẹ́ àṣà pàtàkì nínú àṣà yorùbá oríṣiríṣi orin ni àwọn yorùbá máa ń kọ fún oríṣiríṣi nǹkan tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ yòóbá a máa kọrin kẹ́dùn wọn á máa kọrin ṣayẹyẹ wọ́n máa ń kọrin ṣe ìkìlọ̀ bẹ́ẹ̀ wọ́n sìn máa ń kọrin bú ènìyàn yorùbá a máa forin rẹ ọmọ lẹ́kún wọn á máa forin ki oríkì ẹni àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ ... |
orin wéré orin wéré jẹ́ orin ìtara àti ìtaníjí nínú ẹ̀sìn mùsùlùmí ni a gbọ́ pé ìpilẹ̀ṣẹ̀ eré ajíwéré nígbà tí àwọn olúfọkànsìn kan máa ń lọ káàkiri àdúgbò ní ìdájí láti jí àwọn mùsúlùmí lati kírun àárọ̀ èyí ni aáyan láti má jẹ́ kí àwọn ènìyàn sùn gbàgbera kí wọn sì jí wéré láti ṣàdúrà òórọ̀ àwọn ohun èlò eré jùjú nígb... |
orin sákárà orin sakara orin sákárà ìfáàrà ẹ̀dá ìtàn méjì ní a gbọ́ tí ó rọ̀ mọ́ bí eré sákárà ṣe bẹ̀rẹ̀ ọkan ní pé ni ìlú ìlọrin ní sákárà tí bẹ̀rẹ̀ láti ọwọ́ àwọn mùsúlùmí kan kí a to mú un wá sí ìbàdàn lásìkò baálẹ̀ sítú tí ó jẹ́ olúbàdàn láàrin ọdún 1914 sí 1925 ẹ̀dà ìtàn kejì ní pé eré kerekérè ni ó pilẹ̀ eré saká... |
ali hassan al-majid ali hassan al-majid ti won maa n pe ni chemical ali ti o je ara ile ti o je ara ile sadam hussein ni won ti dajo iku fun ipa ti o ko nitori ipolongo ti o se tako awon kurds ni 1988 |
professor sir lawrence bragg |
william lawrence bragg sir william lawrence bragg ch obe mc frs 31 march 1890 1 july 1971 ni o kere ju ninu awon eni ti o ti gba nobel prize titi di odun 2001 omo australia ara britani ni omo odun marundinlogbon ni o je nigba ti o gba nobel prize ninu fisiksi ni odun 1915 |
sir lawrence bragg |
colin maclaurin colin maclaurin 1698 - 14 june 1746 ni ojogbon ti o kere ju lo omo odun mokandinlogun ni nigba ti o di ojogbom matimatiiki ni marischa college ni aberdeen ni scotland ni ogbon-ojo osu kesan-an odun 1717 leyin eyi ni o lo di ojogbon matimatiiki ni edinburgh ni scotland ni 1725 sir isaac newton ni o ni ki... |
nobel prize |
tòmátò tòmátò ní irúgbìn tó po ti o si kéré ó da fún ara wa tí ó bá ti pón ó ma n pupa bi ósͅe n pón lósì ma ma tóbi orísͅìrisì tòmátò ló wà ní àgbáyé wón ma n pe tòmátò ni èso nítorí pé ó ní ìrúgbìn tó pòͅ sͅùgbóͅn àwoͅn ènìyàn ma n pé tòmátò l’ágbàye ni èfóͅ wóͅn sì dèͅ má n se bi èfóͅ bí oúnje tòmátò je eso kan ti a... |
biafran war |
àfin ilé-ìṣọ́ egeskov egeskov castle oruko miiran ti a n pe egeskov castle ni danish egeskov slot castle yii wa ni gusu erekusu funen ni denmark omi ipamo igba 'renaissance' ti o wa nibe ni o dara ju ni ilu oyinbo itan castle naa ti bere lati nnkan bii senturi kerinla eni ti o ya aworan castle naa ni frands brockenhuus... |
tony blair anthony charles lynton tony blair ọjọ́ìbí 6 may 1953 jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ britani tó jẹ́ alákòóso àgbà orílẹ̀-èdè ilẹ̀ọba ìṣọ̀kan ti britani nínlá àti irelandi apáàríwá láti ọjọ́ 2 may ọdún 1997 títí di ọjọ́ 27 june ọdún 2007 |
gordon brown james gordon brown 20 february 1951 jẹ́ alákòóso àgbà orílẹ̀-èdè ilẹ̀ọba ìsọ̀kan ti britani nínlá àti irelandi apáàríwá united kingdom of great britain and northern ireland tele |
ilu |
èkánná èkánná ri bi iwo ni ori ika-owo tabi ika-ese omo eniyan |
cameroon orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù tàbí orile-ede olómìnira ilẹ̀ kamẹrúùnù ni orílẹ̀-èdè àsọdọ̀kan ni arin ati apaiwoorun afrika o ni bode mo naijiria ni iwoorun tsad ni ariwailaorun orile-ede olominira apaarin afrika ni ilaorun ati guinea alagedemeji gabon ati orile-ede olominira ile kongo ni guusu |
naijiriya |
ìwéìròyìn ìwé-ìròyìn ni itejade iroyin wiwopo |
omi omi jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ohun ẹlẹ́mìí omi ò lóòórùn kò ní àwọ̀ àti bẹ́ẹ̀ ni kò ní adùn ó jẹ́ èròjà tó pọ̀ nínú afẹ́fẹ́ ilẹ̀ àti òkun omi tún wà nínú ara gbogbo ohun ẹlẹ́mìí tí ó ma ń yòrò omi ni orúkọ àdàpè tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pèé ní h20 ní ipò ṣíṣàn ní ipò yìí omi lè di ohun tí ń rọ̀ bíi òjò tàbí ohun ... |
martin luther king jr <ns>0</ns> <revision> <parentid>531487</parentid> <timestamp>2023-03-06t102126z</timestamp> <contributor> <username>marvelousola01</username> </contributor> <comment>two reference column exit in the article removing one</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> martin luther k... |
malcolm x malcolm x pípè /ˈmælkəm ˈɛks/ may 19 1925 february 21 1965 abiso malcolm little bakanna bi el-hajj malik el-shabazz lárúbáwá je omo ile orile-ede amerika |
malcom x |
nelson mandela nelson rolihlahla mandela xoˈliɬaɬa manˈdeːla ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje ọdún 1918 - ọjọ́ karùn-ún oṣù kejìlá ọdún 2013 jẹ́ ààrẹ gúúsù áfíríkà láti ọdún 1994 títí di ọdún 1999 bẹ́ẹ̀ sì ni òun ni ààrẹ gúúsù áfíríks àkọ́kọ́ tó jẹ́ ẹni àdìbòyàn nínú ìdìbò-yani tòṣèlú ará ìlú aṣojú yanyan kí ó tó di ààrẹ man... |
thabo mbeki thabo mvuyelwa mbeki tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 1942 18 june 1942 jẹ́ ààrẹ àná orílẹ̀-èdè guusu áfíríkà láti ọdún 1999 títí dé 2008 |
gúúsù áfríkà orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ gúúsù áfíríkà wà ní ẹnu igun apá guusu áfíríkà ó ní ibodè pẹ̀lú orílẹ̀-èdè namibia botswana àti zimbabwe ní àríwá mọ́ mozambique àti swaziland ní ìlà òòrùn 2798 kilometres 1739 mi etí odò ní okun atlantiki àti okun india ti lesotho si budo je yiyika pelu re àwọn ìgbèríko gúúsù áfí... |
ìgè opadotun olátúnjí ọ̀pádọ̀tun ewì fún àwọn ògo wẹẹrẹ ìwé kejì ige ìgè ìgé adùbí ìsa àdùbí oníkẹ̀ẹ́yẹ ẹni ti kò màdùbí a lóníkẹ̀ẹ́yẹ̀ ṣánpọ́nná iké ṣeé yẹ̀ lẹ́yìn ẹni ìgè àdùbí asaare èèyàn tó bẹ ìgè àdùbí níṣẹ́ ojo òjó òjó olúkù-lóyè igbe kíké níṣẹ́ ẹyẹ òjó àdìó alájòóòsinmi tóo jó láruru tóo sì jó ní kọ̀bì ajayi àj... |
brasil brasil lóníbiṣẹ́ bíi orílẹ̀-èdè olómìnira aparapọ̀ ilẹ̀ bràsíl federative republic of brazil ni orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ ní gúúsì amẹ́ríkà àti ní agbègbè amẹ́ríkà látìnì òkòwò rẹ̀ ni ìkaàrún tótóbijùlọ lagbaye gegebi àlà jeografi àti bii alabugbe pelu 193 million eniyan brasil ni orile-ede eledeluso totobijulo lagb... |
òkun òkun je gbogbo omi oniyo ati eyi to se pataki ara ile-aye bi 71 oju ile-aye ni okun bo mo le |
orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà |
òjò òjò jẹ́ omi tí ó ń rọ̀ láti sánmọ̀ tí ó ṣì ń di omi ní orí ilẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní ni omi tí ó ń sọ̀kalẹ̀ yí ń ṣe fún ọmọ ènìyàn lára rẹ̀ ni a ti ń pèsè iná mọ̀nàmọ́má ó wúlò nínú ilé ó wúlò fún mímu ìdáná àti ìtọ́jú oúnjẹ ó wúlò fún ìwẹ̀ àti bẹẹ bẹẹ lọ síwájú sí omi òjò tún wúlò fún ìdàgbàsókè àwọn ǹkan ọ̀gbìn wá ... |
fẹlá kútì fẹlá aníkúlápó kútì orúkọ ìbí olúfẹlá olúṣégun olúdọ̀tun ransome-kútì october 15 1938 - august 2 1997 tàbí fẹlá jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún jẹ́ adìjà-gbara fún àwọn ọmọ orílè- èdè nàìjíríà ó sì tún ma ń kọ orin wón mọ̀ó ṣí ẹni tí ó ò síwájú orin àwọn aláwọ̀ dúdú orúkọ mìíràn tí won a máa pe felá ... |
desmond tutu desmond mpilo tutu ojo ibi 7 october 1931 - 26 december 2021 je omo orile-ede guusu afrika |
ẹ̀bùn nobel ẹ̀bùn nobel ẹ̀bùn nobel ní èdè gẹ̀̀ẹ́̀si àti nobelpriset ní ède sweden norwegian nobelprisen ní àwọn èbùn odoódún káríayé tí àwọn ìgbìmọ̀ ará scandinafia ń fún ni fún ìdámọ̀ ìmúlọsíwájú àṣà àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ wọ́n jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1895 latowo ara sweden onímọ̀ ẹ̀kọ́ ẹ̀lá kẹ́místri alfred nobel olúṣé dyna... |
dìde èyin ará wikisource has original text related to this article nigeria's present national anthem arise o compatriots was adopted in 1978 arise o compatriots nigeria's call obey to serve our fatherland with love and strength and faith the labour of our heroes past shall never be in vain to serve with heart and might... |
odò odò jẹ́ ojú-ọ̀nà fún omi tó ń ṣàn ní orí ilẹ̀ láti ibi gíga sí ibi ìsàlẹ̀ |
odò ọya odò niger tabi odò ọya ni èdè yorùbá je odo gbangba ni apa iwoorun afrika ti o gun to maili 2500 bi 4180 km |
ọ̀sẹ̀ ọ̀sẹ̀ kan je ọjọ́ meje ninu kàlẹ́ndà giringori awon ojo wonyi ni ede yoruba ni a mo si ojo-aje ojo-isegun ojoru ojobo ojo-eti ojo-abameta ojo-aiku ọ̀sẹ je eyo àsìkò ti o tobi ju ọjọ́ kan lo sugbon ti o kere ju osù kan lo |
àsìkò àsìkò tabi àkókò je esese isele lati ibere titi de opin tabi lati igba eyin titi de isinyi ati titi de igba to n bo niwaju |
tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry ararussia dimitri mandeleev ni odun 1869 mandeleev fe tabili yi lati s'afihan igba isele bi a se n da awon apilese mo atunse ti bo si iy... |
tábìlì ìgbà standard this is a standard display of the periodic table of the elements for more information on its contents and history see the article periodic table <onlyinclude> notes </onlyinclude> |
orin fújì fújì jẹ́ orin tó gbajúgbajà láàárín àwọn yorùbá ó jáde látara orin wéré tí wọ́n tún ń pè ní ajísàrí tó máa ń jí àwọn musulumi nígbà àwẹ̀ sikiru ayinde barrister ló sọ orin yìí di gbajúmọ̀ ní 1950 sí 1960 ó sì yí orúkọ rẹ padà sí fuji barrister sọ ọ́ di mímọ̀ pé ìwé alẹ̀móde kan ni òun rí ní pápá ọkọ̀ òfurufú ... |
ọjọ́ ajé day of the week ọjọ́ ajé jẹ ọjọ́ tí ó wà láàrin ọjọ́ àìkú àti ọjọ́ ìṣẹ́gun gégé bí àjọ international organization for standardization's iso 8601 se sọ ọjọ́ ajé ni ọjọ́ àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè míràn tí ó ka ọjọ́ àìkú sí ọjọ́ àkókò inú ọ̀sẹ̀ sì ka ọjọ́ ajé sí ọjọ́ kejì inú ọ̀sẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ni ó sọ... |
ọjọ́ àìkú ọjọ́ àìkú je ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ti o tele ọjọ́ àbámẹ́ta sugbon ti o siwaju ọjọ́ ajé |
ọjọ́ ìsẹ́gun ọjọ́ ìsẹ́gun je ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ti o tele ọjọ́ ajé sugbon ti o siwaju ọjọ́rú |
ọjọ́ rú ọjọ́ rú je ọjọ́ ọ̀sẹ̀ tí ó tẹ̀lé ọjọ́ ìsẹ́gun ṣùgbọ́n tí ó ṣíwájú ọjọ́bọ̀ ní ìbámu pẹ̀lú àjọ àgbáyé ti iso 8601 òun ni ọjọ́ kẹta nínú ọ̀sẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè tó fi ọjọ́ àìkú ṣe ọjọ́ àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà nínú ẹ̀sìn islam àti àwọn ará júù ọjọ́ rú ni ọjọ́ kẹrin wọn |
ọjọ́bọ̀ ọjọ́bọ je ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ti o tele ọjọ́rú sugbon ti o siwaju ọjọ́ ẹtì |
ọjọ́ ẹtì ọjọ́ ẹtì jẹ́ ojú kan láàrin ọsẹ tí ó wà láàrin ọjọ́bọ̀ àti ọjó àbámẹ́ta ní àwọn orílẹ̀-èdè èdè tí wọn ń ló ọjọ ìṣẹgun gẹgẹ bí àkọkọ́ ọjọ́ nínú ọ̀sẹ̀ ọjọ ẹtì jẹ́ ọjọ karún nínú ọ̀sẹ̀ amọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ọjọ ẹtì ní ojú kẹfà nínú ọ̀sẹ̀ fún àwọn tí wọn ń ló ọjọ àìkú gẹ́gẹ́ bí àkọkọ́ ọjọ nínú ọ̀sẹ̀ |
ọjọ́ àbámẹ́ta ọjọ́ àbámẹ́ta tabi satide tí wọ́n tún ń pe ní saturn's day je òpin ọjọ́ ọ̀sẹ̀ tí ó wà láàrín ọjọ́ ẹtì àti ọjọ́ àìkú ọjọ́ àbámẹ́ta ni ọjọ́ keje tí ó kẹ́yìn nínú ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ní ilẹ̀ yorùbá |
ọjọ́ ọjọ́ kan je eyo asiko to je wakati 24 ki i se eyo si |
gbéringbérin gbéringbérin je ohun yiowu ti ni papa gberigberin papa gberingberin yi ko se foju ri sugbon ohun ni un fa ini pataki gberingberin kan agbara la ti fa awon eroja gberingberin ferro bi irin be ni o si un fa mora tabi sun sohun awon gberingberin miran |
ìlú ayétẹ̀ olúgbóyèga àlàbá onírúurú àròfọ̀ gboyega alaba ilu ayete ayete ìlú ayétẹ̀ ojú-ìwé 17 kò sẹ́ni tí ò níí kú kò sẹ́ni tí ò níí rọ̀run ẹ jọ̀wọ́ ẹ má fi kú yọ̀ wá gbogbo wa la sá jọ ń lọ ẹní bá wáá fẹ́ kó yá ilu tapa ni ibarapa tapa ibarapa ìlú tápà ní ìbàràpá ojú-ìwé 18 ẹ tẹ́tí ẹ gbọ́n ná jànmán-àn mi ìrọra àtòk... |
ìlú igbó-ọrà olúgbóyèga àlàbá onírúurú àròfọ̀ gboyega alaba ilu igboora igboora ìlú igbó-ọrà ojú-ìwé 13 ìdèrè jẹ́ ìlú pàtàkì tó ṣe kókó gan-an ní bàràpá tó jẹ́ ẹ̀yà oòduà kan ẹ̀gàn àtàwàdà ni wọ́n ń sọ̀rọ̀ “ọ̀bọ ìdèrè” kò mà mà sọ́bọ ní dèrè ní pàtó ilu idere idere ìlú ìdèrè ojú-ìwé 14-16 ayétẹ̀ jẹ́ ìlú pàtàkì tó dúró ... |
ìlú ìgàngàn ilu igangan je ilu kekere ni ipinle oyo ni naijiria |
brazil |
sm raji àti ji ogunranti sm raji ji ogunranti ọ̀pẹ̀ ń fọ dídùn 1 orin ifá akojopo orin ifa ajemodu odu àkójọ̀pọ̀ orin ifá ajẹmọ́dù ojú-ìwé 91-110 lílé olówó tutu dodo ó ó ó ẹ̀là tutu nini in in ilé olúwẹri kì í gbóná ègbè olówó tutu dodo ó ó ó ẹ̀là tutu nini in in ilé olúwẹri kì í gbóná orin yorùbá ojú-ìwé 1-3 orin ni ... |
kùrìtíbà kùrìtíbà je ilu ni apaariwa ile brasil ati oluilu ipinle parana |
èdè gẹ̀ẹ́sì èdè gẹ̀ẹ́sì |
kwame nkrumah kwame francis nwia kofie nkrumah 21 september 1909 - 27 april 1972 je oloselu ati alakoso agba akoko fun orile-ede ghana lati march 6 1957 titi di 1 july 1960 nkrumah je oloselu pataki ni ile afrika be sini o se ipolongo fun iferan larin gbogbo awon omo afrika kakiri |
gánà gánà gánà jẹ́ orílẹ̀-èdè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ afíríkà ní ìfọwọ́sí republic of ghana jẹ́ orílẹ̀-èdè kan pẹ̀lú gulf of guinea àti òkun àtìláńtíìkì ní orílẹ̀-èdè ìwọ̀-oòrun afíríkà gbígbà ibi-ilẹ̀ kan ti 238535 km2 92099 sq mi gánà ń ko ivory coast ní ìwọ̀-oòrun burkina faso ní àríwá tógò ní ìlà-oòrun àti gulf of g... |
kano kano jẹ́ olú ìlú ìpínlè kano àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà lẹ́yìn ìlú ìbàdàn àti ìlú èkó gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006 kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè nàìjíríà àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — kano municipal fagge dala gwa... |
ìlú-ìjélè <ns>0</ns> <revision> <parentid>379273</parentid> <timestamp>2017-09-13t133754z</timestamp> <contributor> <username>blahmabot</username> </contributor> <minor /> <comment>replacing unicode code points from the private range u+e000 to u+f8ff by the proper combining accents</comment> <model>wikitext</model> <fo... |
joseph okefolahan odunjo joseph òkéfọláhàn ọdúnjọ je olukowe omo ile naijiria lítírṣọ̀ adíláwọ̀ ti di ìlúmọ̀miká báyìí ó ti gbayi ni ilé ó ti gbayì lóko bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti gba iyì ní ìdálẹ̀ ju ilé lọ ọ̀pọ̀ òyìnbó ni ó ti fi ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lítíréṣọ̀ adúláwọ̀ gboyè ìjìnlẹ̀ ìwé pupọ ninu awọn ọmọ adúláwọ̀ lo si ti di o... |
òwò ẹrú brasil adeyemo akinloye steve àkọ́sílẹ̀ díẹ̀ lórí i ìgbé ayé ọmọ yorùbá ilẹ̀ brazil kan tí ó fi ìgbé ayé rẹ̀ tako òwò ẹrú láti ọwọ́ asa j davis alága gbogbo ẹ̀yin ọ̀fọ̀ọ̀kùn iyì ńlá ni fún mi láti wà ní ìjókòó lónìí láti sọ̀rọ̀ lórí ‘ìlàjú yorùbá’ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo ṣiṣẹ́ rí ni ọgbà fásitì ìbàdàn n kò rò wí p... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.