raw_text
stringlengths
2
128k
ann mukoro nigerian footballer ann mukoro jẹ obinrin agbàbọọlu orilẹ ede naigiria ti a bini 27 óṣu may ni ọdun 1975 elere naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu gẹgẹbu midfielder
dora akunyili dora nkem akunyili ofr ọjọ́ kẹrìnlá osu keje ọdun 1954 ọdun 2014 jẹ́ olùdarí àgbà fún national agency for food and drug administration and controlnafdac ti nàìjíríà láàrín ọdún 2001 sí 2008 igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ dora edemobi ni a bi ni makurdi ni ipinle benue naijiria fun oloye paul young edemobi ti o ...
toyin saraki toyin ojora-saraki llb llm bl tí a bí ní ọjọ kẹfa oṣù kẹsán ọdun 1964 jẹ́ ajijagba eto ilera lagbaye ẹlẹ́yinjú àánú lori ilera oun si ni ààrẹ ati oludasilẹ àjọ ẹlẹ́yinjú àánú kan ni ilẹ adúláwọ̀ tí wọ́n pè ní wellbeing foundation africa ibẹrẹ igbe aye ati ẹkọ rẹ̀ a bi toyin saraki ninu ẹbi awọn ọba ọjọra à...
taonere banda taonere banda ti a bi ni ọjọ karun ni osu okudu ọdun 1996 jẹ elere idaraya kan lati orilẹ-ede malawi ti o dije ni ẹka t13 fun àwọn ti o ni akudie ni ọdun 2016 banda di elere idaraya akọkọ lati ṣe aṣoju malawi ni awọn ere paralympic nigbati wọn yan lati dije ni paralympics igba ooru 2016 ni rio de janeiro ...
wendy okolo wendy a okolo jé onimo àti onowadi okò-òfurufú ní ara awon eka nasa ames research center ó jè omo nàìjirià àti amerika òun ni obinrin alawo dúdú akoko láti gba àmì èye phd ninu aerospace engineering láti yunifasiti ìlú texas ẹ̀kọ́ rẹ̀ okolo ka ìwé primary rè ní st mary primary school ní lagos highland o si ...
karim el-khebir karim el-khebir eyiti a tun pe ni karim el-khebyr ti a bi i ọjọ kerin osu kẹrin ọdun 1974 ni orilẹ-ede niger jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede niger ti fẹyìntì ti o n ṣiṣẹ bayi gẹgẹbi olukọni agba fun ndc angers ni orilẹ-ede rẹ iṣẹ-ṣiṣe el-khebir bẹrẹ iṣẹ agba rẹ pẹlu valenciennes ni ọdun 1990 ni 1999 o ti owo...
arthur moses arthur moses ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹta ọdun 1973 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede ghana tẹlẹ ti o gba bọọlu bii atamatase kan oun ni eniti o ni ati igbakeji aare bechem chelsea club career wọ́n bí mósè sí ákírà ni 1992 o jẹ asiwaju atamatase ninu premier league nigeria pẹlu goolu mokanla bi awọn ile itaja isọw...
ghani animofoshe ayotunde ganiyu anifowoshe ti a bi ni ọjọ keta oṣu keji ọdun1985 ni niamey je agbaboolu omo niger ti o n gba boolu fun kwara united fc iṣẹ-ṣiṣe anifowoshe gba bọọlu fun egbe agbabọọlu göyazan qazax lakoko 200405 ati 200506 akoko azerbaijan ati fun olimpik baku lakoko akoko 200607
sulliman mazadou sulliman johan mazadou ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kẹrin ni ọdun 1985 ni marignane france jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede niger ti o nṣere fun ẹgbẹ agbabọọlu faranse us marignane ni championnat de france amateur o jẹ ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede niger ti o gba ni 2012 africa cup of nations pelu gabon ati ọkan...
bose kaffo bose kaffo ti a bi ni ojo kerinla oṣù kọkànlá odún 1972 ni surulere ipinle eko nigeria jẹ alamọdaju agbabọọlu tẹnisi tabili ọmọ orilẹ-ede naijiria ti o dije ni e maarun ninu idije olimpiikiolympics lati odún 1992 si 2008 o jẹ obinrin keji ti orilẹ-ede naijiria ti yoo dije ni olimpiiki marun lẹyin asare mary ...
stanley awurum stanley ejike awurum ti bi ọjọ kerinlelogun osu kefa ọdun 1990 je agbaboolu orilẹ-ede naijiria ti o n gba iwaju fun egbe agbaboolu varzim ni orilẹ-ede portugal in yo a bi ni mbieri ipinle imo awurum bẹrẹ iṣẹ agba rẹ ni mozambique nibiti o ti jẹ agbaboolu ti o ga julọ pẹlu goolu mejilelogun fun fc chibuto...
ali abu eshrein ali abdallah abu-eshrein ti a bi ni ọjọ kefa oṣu kejila ọdun 1989 jẹ agbabọọlu fun orilẹ-ede sudan kan ti o ṣe asolee bọọlu fun al-hilal omdurman ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede sudan
école nationale supérieure des mines de paris école nationale supérieure des mines de paris je yunifasiti ni ilu parisi ni fránsì
kelechi iheanacho kelechi promise iheanacho speli ịhean find in igbo ti a bi ni 3 oṣu kẹwa ọdun 1996 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede naijiria ti o je agbawaju fun ẹgbẹ agbabọọluleicester city ti orilẹ-ede geesi ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede naijiria iheanacho bẹrẹ iṣẹ agba rẹ ni ilu manchester ni akoko 201516 o lọ si ẹgbẹ agba...
natalie mwagale natalie mwagale ti a bi ni oṣu kẹsan ọjọ keje ọdun 1993 jẹ agbá bọọlu inu agbọn fun orilẹ-ede kenya kan o ngba fun alaṣẹ ports kenya ati ẹgbẹ bọọlu inu agbọn ti orilẹ-ede awọn obinrin kenya ise ọjọgbọn mwagale gba fun ẹgbẹ bọọlu inu agbọn alaṣẹ ports kenya ẹgbẹ bọọlu inu agbọn ti orilẹ-ede kenya mwagale...
yasmine kabbaj yasmine kabbaj arabic ti a bi 15 oṣu kini ọdun 2004 jẹ oṣere tẹnisi ilu morocco kabbaj gba are akọkọ re wta tour ni open morocco 2022 nibiti o ti gba titẹsi waju tii kaadi egan ti eleeyanmeji pelu akegbeere ekaterina kazionova tẹnisi kọlẹji ni ọdun 2021 o ti gba fun ẹgbẹ tẹnisi awọn obinrin ti florida in...
bose samuel nigerian freestyle wrestler bose samuel je omo orile-ede naijiria ó jẹ́ olóye àmì ẹ̀yẹ fàdákà ní eré ìdárayá ilẹ̀ áfíríkà african games ó sì tún jẹ́ àmì-ìwọ̀n idẹ ní àwọn eré àjọ àgbáyé commonwealth games isé sise ni ọdun 2018 o ṣẹgun ami-eye idẹ ni iṣẹlẹ 53 kg ọfẹ ti awọn obinrin ni awọn ere agbaye 2018 wo...
modupe irele nigerian diplomat modupe enitan irele jẹ aṣoju orilẹ-ede naijiriati o si n ṣoju orilẹ-ede naijiria lọwọlọwọ si faranse di obirin akọkọ lati di ipa naa lati igba ti ile-iṣẹ diplomatic ti yan aṣoju akọkọ rẹ ni 1966 aarẹ muhammadu buhari yan obinrin ni ọjọ kedogun oṣu kẹwa ọdun 2016 o si fi iwe-ẹri rẹ han si ...
lilya hadab lilya hadab ti a bi ni ọjọ ketala osun karun ọdun 1999 jẹ oṣere tẹnisi orile-ede morocco hadab ni iṣẹ giga wta ti eleeyanmeji mi ipo 1097 ti o waye ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹsan ọdun 2016 hadab jẹyo ni wta 2017 grand prix sar la princesse lalla meryem ni ipele eleeyanmeji
loveline obiji loveline obiji ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kẹsán ọdun 1990 je omo orile-ede naijiria o dije ninu idije +61 kg ti awọn obinrin ni awọn ere agbaye 2014 nibiti o gba ami-ẹri goolu kan ni 2014 world championships o wà mi eka 86kg ami eri goolu ni soki ti igbegeti randa mahmoud ko je gbigba mo sibẹsibẹ mahmou...
rita atik rita atik ti a bi ni ọjọ kejilelogun oṣu kẹwa ọdun 1997 ni casablanca jẹ oṣere tẹnisi fun orilẹ-ede morocco ni 2013 o jẹ eniti ti o mu oke moroccan ti ipele16 fun awọn ọmọbirin ni mediterranee avenir o ti dije ni ọpọlọpọ igba ni ere idaraya ti grand prix sar la princesse lalla meryem
lina bennani lina bennani ti a bi ni ọjọ kerin oṣu keje ọdun 1991 jẹ oṣere alamọdaju ti oun gba tẹnisi fun orilẹ-ede morocco tẹlẹ ti a bi ni casablanca bennani to kopa nifed cup mẹfa fun orilẹ-ede morocco laarin ọdun 2008 si 2011 pupọ julọ bi oṣere eleeyanmeji o bori roba ẹyọkan rẹ nikan lori elaine genovese ti malta n...
yemisi edun yemisi edun ni adari àgbà ile ifowopamosi ti first city monument bankfcmb òun ni obinrin akoko ti o di ipò náà mú a yàn sípò náà ní 13 july 2021 léyìn ìgbà tí adam nuhu fi ipo náà sílè nitori èsùn biba ìyàwó elomiran sun tí a fi kan yemisi jé omobibi ìpínlè èkó èkó rè yemisi edun gba àmì-èye bachelor's degr...
cheick traoré cheick omar traoré ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu kẹta ọdun 1995 jẹ agbabọọlu alamọdaju ti o ngba ibi apa ẹhin -ọtun fun ẹgbẹ ligue 2 dijon ti a bi ni faranse o ṣere fun ẹgbẹ orilẹ-ede mali igbesi aye ibẹrẹ ni igba ewe rẹ cheick traoré gba bọọlu pẹlu arakunrin rẹ baba ni ilu abinibi rẹ pierrefitte-sur-...
edith eluma nigerian footballer edith eluma jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin ti a bini 27 óṣu september ni ọdun 1958 arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu
ugochi opara nigerian footballer ugochi opara jẹ àkọṣẹmọṣẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 27 óṣu may ni ọdun 1976 arabinrin na ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu
mavis ogun nigerian footballer mavis ogun jẹ́ ọ̀kan lára agbábọ́ọ̀lù obìnrin orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógun oṣù kẹjọ ọdún 1973 arábìnrin náà jẹ́ agbábọ̀ọ̀lú ọlọ́wọ́ ẹ̀yìn fún ikọ̀ nàìjíríà lobínrin ó wà lára àwọn agbábọ̀ọ̀lù tó kópa nínu ife ẹ̀yẹ àgbáyé obìnrin ti fifa ní ọdún 1991 1995 àti ọdún 1999
rita chikwelu nigerian footballer rita chikwelu jẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 6 óṣu kẹta ni ọdun 1988 àrabinrin na ti ṣere fun club spanish ti madrid cff atipè o ti fi igba kan ṣere fun umea ik ati kristianstads dff
oumaima aziz oumaima aziz ti a bi ni ọjọ kini oṣu kẹta ọdun 2001 jẹ osere tẹnisi orilẹ-ede morocco ti ko ṣiṣẹ aziz ni ipo-iṣẹ giga ti awọn juniors ni itf ni ipo 185 ti o gba ni ọjọ kerindinlogun oṣu kẹta ọdun 2018 o ṣe akọkọ yan re ni wta tour ni 2018 rabat grand prix ni idije eleeyanmeji alabaṣiṣẹpọ diae el jardi aziz...
habiba ifrakh habiba ifrakh ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹta ọdun 1978 jẹ oṣere tẹnisi alamọdaju ti orilẹ-ede morocco tẹlẹ ti o gba ikẹkọ ni wifaq tennis academy ni rabat ifrakh jẹ ọmọ ẹgbẹ ti morocco fed cup egbe laarin 1995 si 2009 ti o bori ẹyọkan meje ati rọba ilọpomeji kọja idije merinla o tun ṣe aṣoju fun orilẹ-ede m...
samuel okpodu samuel okpodu ti a bi ni ọjọ keje oṣu kẹwa ọdun 1962 jẹ oluṣakoso bọọlu ni orilẹ-ede naijiria okpodu jẹ olukọni agba fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede naijiria ni idije ife ẹyẹ agbaye ti awọn obinrin ti fifa ti ọdun 2003 ni oṣu kẹta ọdun 2021 okpodu ni a fun ni ise olukọni ti maryland bobcats fc ni ẹgbẹ afẹsẹgb...
patricia etteh patricia olubunmi foluke etteh tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹjọ 1953 jé omo egbe ile igbimo asojú naijiria fún ekun ayedaade/isokan/irewole lati osu kefa odún 1999 titi di osu kewaa odun 2007 ó jé omo egbe alliance for democracyad kí o tó padà darapo egbé people's democratic partypdp àárò ayé àti è...
kafayat oluwatosinkaffy kafayat oluwatoyin shafau tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1980 tí òpòlopò ènìyàn mọ̀ sí kaffy jé oníjó àti olùkọ́ni nípa ijójíjó oun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ ilé-isé ijó imagneto ó gba àmì ẹ̀yẹ guinness world record fún longest dance party ní nokia silver bird danceathon ti ọdun 2007 àárò ayé àti...
joan onyemaechi mrakpor joan onyemaechi mrakpor tí a bi ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdun 1966 je ajihinrere onigbagbo kristieni àti olósèlú omo orile-ede naijiria ó se asojú ekùn aniocha north-aniocha south-oshimili àti north-oshimili south ní ilé ìgbìmò asojú ní odun 2015 labe egbé oselu people's democratic partypdp ṣaaju k...
nene dorgeles nene dorgeles ti a bi ni ọjọ ketalelogun oṣu kejila ọdun 2002 jẹ agbabọọlu alamọdaju ti orilẹ-ede mali kan ti o ṣe bọọlu bii agbabọọlu aarin fun ẹgbẹ agbabọọlu austrian bundesliga sv ried ti wọn ya lawin lati ọdọ red bull salzburg ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede mali dorgeles bẹrẹ iṣẹ rẹ pẹlu fc guidars ati ...
bamidele abiodun bamidele abiodun tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù keje ọdun 1966 jé onisowo olufuni àti ìyàwó dapo abiodun eniti o jé gomina ìpínlè ogun nàìjíríà àárò ayé àti èkó rè a bí abiodun ní july 16 1966 sí inú idile ojogbon oladipo oduye ígbákejì adari yunifásitì ìlú ìbàdàn teleri àti ologbe abimbola wosilat ...
florence iweta nigerian footballer florence iweta jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti a bini 29 óṣu march ni ọdun 1983 arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu gẹgẹbi defender
gloria usieta nigerian footballer gloria usieta jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti a bini 29 óṣu june ni ọdun 1977 arabinrin naa ti ṣere fun órilẹ ede naigiria gẹgẹbi midfielder
patience avre nigerian former football forward patience avre jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti a bini 10 óṣu june ni ọdun 1976 arabinrin na ti ṣere fun ọrilẹ ede naigiria gẹgẹbi ipo forward
vera okolo nigerian footballer vera okolo jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5 óṣu january ni ọdun 1985 arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin ilẹ naigiria ti national lori bọọlu
blessing edoho nigerian footballer blessing edoho jẹ agbabọọlu lobinrin naigiria ti a bini 5 óṣu september ni ọdun 1992 arabinrin naa ṣere fun órilẹ ede naigiria gẹgẹbi defender
elizabeth adekogbe oloye elizabeth adekoge1919 - 1968 jé olósèlú ajafun ètó obinrin àti ajafun ominira nàìjíríà nígbà ayé rè òun ní adari ajo women council ti nàìjirià ní odun 1959 ajo náà darapo pèlú women's improvement league láti di egbé national council of women societies egbé tí óún jà fitafita fún ètó obínrin ní ...
patoranking nigerian musical artist patrick nnaemeka okorie ti a bi 27 may 1990 ti gbogbo eniyan mọ nipasẹ orukọ ipele rẹ patoranking jẹ akọrin reggae-dancehall naijiria ati akọrin ti a bi ati dagba ni ilu ijegun-egba satellite patoranking hails lati onicha ipinle ebonyi o fowo si iwe adehun igbasilẹ pẹlu k-solo's igbe...
mulikat adeola akande mulikat adeola akande tí a bí ní 11 november 1960 jé òtòkùlú olósèlú àti oludije fún ipò senato omo orílè-èdè nàìjíríà a dibo yan si ile igbimo asoju láti se asojú ogbomoso north south àti orire constituency labé egbé oselu people's democratic partypdpni odun 2007 a tun yàn ní odun 2011 àárò ayé à...
jadesola olayinka akande jadesola olayinka akande con ofr 15 november 1940 29 april 2008 je agbẹjọro naijiria onkowe ati omowe ti o ti wa ni bi awọn akọkọ obinrin ti o je nigerian professor of law ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ ọmọ bíbí ní ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ jadesola parí ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìbàd...
bimbo odukoya abimbola rosemary bimbo odukoya née abimbola rosemary segun-williams september 12 1960 december 11 2005 je pásítọ̀ àti ajíhìnrere ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ti fẹ́ olùdásílẹ̀ ìjọ fountain of life taiwo odukoya odukoya ti a maa n pe ni pastor bims jẹ olugba ti o ju 60 awọn ami-ẹri orilẹ-ede ati ti kariay...
halima tayo halima tayo alao tí a bi ní ọjọ́ kẹfà oṣù kejìlá ọdún 1956 jé ayaworan ilé àti minisita teleri fún eto adugbo àti ilé nígbà sáà isejoba ààre umaru yar'adua o dipò náà mú larin ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù keje ọdun ọdún 2007 sí ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ̀wá ọdún 2008 àárò ayé àti èkó rè a bí halima tayo alao ní d...
simi johnson simisola olayemi onibuwe johnson 1929 2000 jé dókítá eyín àti ajafeto okunrin àti obínrin ó sì tún jé minisita fún idagbasoke awujo àti àsà o jé alaga teleri tí allied bank àti èka national council of women societies ti èkó johnson àti grace goubadia di dókítá eyín ní 1957 èyí mú kí àwon méjèjì jé obinrin ...
timaya nigerian singer inetimi timaya odon ojoibi 15 august 1980 ti gbogbo eniyan mo si ti oruko re n je timaya je olorin ati akorin naijiria o wa lati odi bayelsa ipinle oun ni oludasile dm records limited iṣẹ adashe rẹ bẹrẹ ni ọdun 2005 pẹlu itusilẹ ti “dem mama” eyiti o tun han lori awo-orin akọkọ rẹ itan otitọ ti t...
the voice nigeria reality television singing competitionvoice nigeria jẹ ẹya nigeria ti awọn tv jara the voice
runtown douglas jack agu ti a bi 19 august 1989 ti a mọ si nipasẹ orukọ ipele rẹ runtown jẹ akọrin naijiria akọrin ati olupilẹṣẹ a bi runtown ni ojo kokandinlogun osu kejo ​​odun 1989 ni ipinle enugu ni naijiria o ti ko eko alakobere re ni ilu eko lẹhinna o gbe pẹlu iya rẹ si abuja lẹhin ikú baba rẹ ni ọdun 2007 o ṣe i...
amina titi atiku-abubakar amina titilayo atiku-abubakar jé òkan lara awon ìyàwó atiku abubakar èni to jé ígbákejì ààre orílè-èdè nàìjirià teleri ó jé oluja feto àwon obinrin àti omodé oun ni olùdásílè àjo women trafficking and child labour eradication foundationwotclef oun ni ojé obinrin ekejisecond lady tí nàìjirià lá...
olajumoke okoya-thomas olajumoke abidemi okoya-thomas jé omo ile igbimo asojú teleri o soju lagos island/federal constituency ti ìpinlè eko labé egbe oselu all progressive congressapc o lo sáà meta nípò asojú àárò ayé àti èkó rè olajumoke jé omo oloye molade okoya-thomas eni to jé asoju oba eko a bi ní 20 january 1957 ...
lateefat okunnu lateefat modupe okunnu tí a bí ní december 3 1939 jé osise ìjoba nàìjíríà tí o ti feyinti ó sì jé ígbákejì gomina ti ìpinlè eko larin odun 1990-1992 okunnu jé ara àwon omo egbé àkókò ti federation of muslim women's associations in nigeria fomwan àárò ayé àti èkó rè a bí okunnu silu èkó kí o tó dipe olo ...
omotayo oduntan omotayo aramide oduntan tí a bí ní ọjọ́ kàrún oṣù kẹfà ọdún 1957 jé olósèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń se asojú ekun alimosho ii ní house assembly ìpinlè èkó o jé omo egbé oselu all progressive congressapc ayé rè àti isé rè a bi omotayo oduntan ní ìpinlè èkó orílè-èdè nàìjíríà nibi tí o ti pari ìwé ...
gift otuwe nigerian footballer gift otuwe jẹ agbabọọlu lobinrin òrilẹ ede naigiria ti a bini 15 óṣu july ni ọdun 1984 arabinrin naa ṣere fun bobruichanka ni premier league belarusia
halimatu àyìnde nigerian footballer haimatu àyinde jẹ àkọṣẹmọṣẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 16 óṣu may ni ọdun 1995 arabinrin naa ṣere fun eskilstuna united dff ati team awọn obinrin lapapọ gẹgẹbi midfielder arabinrin naa tifi igba kan ṣere fun western new york ni united states ati delta queens ni ó...
osinachi ohale nigerian footballer osinachi ohale jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 21 óṣu december ni ọdun 1991 elere naa ṣère fun spanish primera division club deportivo alaves ati apapọ team awọn obinrin ti órilẹ ede naigiria
helen ukaonu nigerian footballer helen ukaonu jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini 17 óṣu may ni ọdun 1991 arabinrin na ṣere gẹgẹbi defender nibi o ti jẹ àṣoju team awọn obinrin ti national ni órilẹ ede naigiria
chima nwosu nigerian footballer chima nwosu jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin ti a bini 12 óṣu may ni ọdun 1986 àrabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun inneh queens ni órilẹ ede naigiria
ajuma ameh nigerian footballer ajuma ameh jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 1 óṣu december ni ọdun 1984 elere na ṣere fun pelician stars gẹgẹbi midfielder ajuma ameh ku ni ọjọ kewa óṣu december ni ọdun 2018 ni ọmọ ọdun mẹtalelọgbọn
folake solanke oloye folake solankeojó kokandinlógbon oṣú kẹta ọdún 1932 san con jẹ agbẹjọro orilẹ-ede naijiria kan alabojuto ati alariwisi awujọ òun ni alágbàwí àgbà obìnrin àkọ́kọ́ ti nàìjíríà àti agbẹjọ́rò obìnrin nàìjíríà àkọ́kọ́ tí ó wọ ẹ̀wù ẹ̀wù siliki gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn àgbà o jẹ komisona akọkọ ti western sta...
christie george christie george ti a bi ni ọjọ kewa osu kaarun ọdun 1984 je agbaboolu teleri omo naijiria ti o n gba iwaju o jẹ ikan l'ara awon ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede awọn obinrin naijiria ni olimpiiki igba ooru 2008
funmilayo olayinka olufunmilayo aduni olayinka orúko abiso rè ni famuagun tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹfà ọdun 1960 tí o sì di ologbe ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin 2013 jé akawo ilé ifowopamo àti olósèlú nígbà ayé rè o jé okàn lara awon ígbákejì gomina ìpínlè ekiti teleri àárò ayé àti èkó rè a bí olayinka ní ìlú ado-ekiti ìpinl...
yetunde onanuga yetunde onanuga tí a bí ní 11 september 1960 jé òtòkùlú olósèlú ní naijiria àti ígbákejì gomina ipinle ògùn teleri ayé rè a bí onanuga ní ilé iwosan adeoyo ìlú ibadan olú-ìlú ìpínlè oyo oruko baba rè ni fabamwo o koko kàwé ní ipinle ogun ko to dipe o kawe ni ìlú eko nibi to ti gba owe eri fún isé olukon...
adejoke orelope-adefulire victoria adejoke orelope-adefulire tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù kẹsàn-án ọdún 1959 jẹ́ olóṣèlú ní orílè-èdè nàìjíríà ó jẹ́ igbákejì gómínà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀rí láti ọdún 2011 sí ọdún 2015 kó tó di pé ó wọlé gẹ́gẹ́ bíi igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ èkó òun ni ó jẹ́ kọmíṣọ́nà fún ètọ́ àwọn obì...
école nationale de la statistique et de l'administration économique école nationale de la statistique et de l'administration économique ensae je yunifasiti aladani ni ilu parisi ni fránsì
bahia mouhtassine bahia mouhtassine ti a bi ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹjọ ọdun 1979 jẹ osere tẹnisi alamọdaju orilẹ-ede morocco tẹlẹ iṣẹ rẹ jẹ ti gbe de ipo no139 ti o gba ni ọjọ kerinlelogun oṣu kẹfa ọdun 2002 o jẹ elere idaraya ti o ga julọ ni ipo ti orilẹ-ede morocco igbesiaye mouhtassine jẹ oṣere orilẹ-ede morocco ob...
folashade sherifat jaji folashade sherifat jaji ti a bi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdun 1957 jé osise ìjoba ati akowe fun ijoba ìpínlè eko o tún jé akowe fún ijoba eko lori eka to un ri soro owó fun awon osise ijoba to ti feyinti o ran ijoba orílè-èdè nàìjirià lowo láti mu iyipada rere ba owó ti a fi pamo fún ilo awon osise...
women of owu women of owu jẹ iwe 2006 ti femi osofisan kọ ati ti a gbejade nipasẹ oxford university press plc iwe naa ti a mu lati inu euripides’ the trojan women apapo awọn akọrin orin ati ijó lati ṣe afihan itan awọn eniyan ijọba ọwu lẹhin ti awọn ologun ti ife ọyọ ati ijebu ti yabo ilu ọwu fun ọdun meje ti wọn pa gb...
sarah adebisi sosan sarah adebisi sosan jẹ́ olùkọ́ni tẹ́lẹ̀ rí àti igbákejì gómìnà èkó láàrin ọdún 2007 sí 2011 nígbà tí babatunde fashola jẹ́ gomina ìpínlè eko ìpìlẹ̀ a bí sarah sí ìpínlẹ̀ èkó ní 11 febuary 1956 sínú ìdílé olóyè àti ọmọọba durosinmi ti ì̀lú irewe ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ojo badagary ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọọba...
biodun stephen biodun stephen jẹ oludari fiimu naijiria kan onkọwe ati olupilẹṣẹ ti o ṣe amọja ninu ere ere ifẹ ati awọn fiimu alawada o ti ṣe akiyesi fun gbigba awokose fun akọle awọn fiimu rẹ lati awọn orukọ kikọ akọkọ bi a ṣe fihan ninu fiimu pẹlu tiwa baggage ovy's voice ehi's bitters ati sobi's mystic gẹgẹbi awọn ...
kehinde kamson kehinde kamson tí àwọn mìíràn mọ̀ sí kjwa bi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ ọdun 1961 ni ipinle eko naijiria je onisowo ati olufini omo naijiria oun ni oludasile ati oludari ilé-isé sweet sensation confectionery limited ilé-isé náà jé okan lara a won ilé-isé to ún se ounje atete sefast food samson bèrè ilé-isé...
folorunsho alakija folorunsho alakijatí a bí ní ọjọ́ kàrúndínlógún oṣù keje ọdun 1951 jẹ́ onísòwò àti olùfifúni ní nàìjíríà ó ń ṣe òwò àwọn ìkan ọ̀sọ́fashion epo rọ̀bì àti ilẹ̀ títa òun ni olùdarí rose of sharon group àti ígbákejì alága famfa oil limited gégé bí ọ̀kan lára àwọn àtẹ̀jáde ilé ìròyìn forbes nípẹ́ òun ni o...
adefunmilayo tejuosho adefunmilayo tejuosho orúko abiso rè ni smith tí a bi ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kàrún ọdun 1965 jé òtòkùlú olósèlú ni nàìjirià o tun jé asoju agbegbe mushin ní house of assembly ìpinlè eko oun ni alaga house of assembly eko ti o un rí si ètò owó àárò aye àti èkó rè a bi tejuosho ni ipinle eko s...
felicia eze nigerian footballer felicia eze jẹ agbabọọlu lobinrin órile ede naigiria ti a bini 27 óṣu september ni ọdun 1974 arabinrin naa ku lẹyin aisan ranpẹ ni 31 óṣu january ni ọdun 2012 si ipinlẹ anambra
ulunma jerome nigerian footballer ulunma jerome jẹ agbábọ́ọ̀lù obìnrin órilẹ èdè nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹrin ọdún 1988 ó n gbá bọ́ọ̀lù jẹun gẹ́gẹ́ bí adilémú lọ́wọ́bẹ̀yìn fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù pitea tí ó wà ní sweden damallsvenskan
tawa iṣhọla nigerian footballer tawa iṣhọla jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 23 óṣu december ni ọdun 1988 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin ti national lori bọọlu
lilian cole nigerian footballer lilian cole jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 1 óṣu august ni ọdun 1985 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun apapọ team awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu
diae el jardi diae el jardi ti a bi ni ọjọ ketala oṣu kẹwa ọdun 2000 jẹ alaiṣiṣẹ tẹnisi orile-ede morocco ti ko ṣiṣẹ o ti ṣere fun orile-ede morocco ni fed cup nibiti o ti ni iṣẹgunipadanu ti 27 ni ìdíje àwọn ojewewe el jardi de ipo 59 ni ọjọ karundinlogun oṣu kinni ọdun a⁰ 002018
tawa ishola tawa ishola tí a bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kejìlá ọdún 1988 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan tí ó gbá bọ́ọ̀lù lọ́wọ́ àárín fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin agba orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní olimpiiki ní ọdún 2008
salem elmslaty salem fathi elmslaty ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu kẹwa ọdun 1992 tl a le ko ati sipeli bi salem al-musallati ati ti a mọ ni ibigbogbo bi salem roma jẹ agbabọọlu libyan kan ti o n gba bọọlu fun al-nasr gege agbabọọlu agbaowoiwajun awọn ikun ati awọn abajade ṣe atokọ awọn ibi-afẹde libya ni akọkọ
akram zuway akram zuway arabic ti a bi ni ọjọ kerinlelogun oṣu kejila ọdun 1991 jẹ agbabọọlu libyan kan ti o nngba bọọlu fun kazma bi agbabọọlu awọn ikun ati awọn abajade ṣe atokọ awọn ibi-afẹde libya ni akọkọ ọdun 201617 ọdun 201617 awọn ọlá arab club figagbaga 2017 ipo keji
ngozi okobi nigerian footballer ngozi okobi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 14 óṣu december ni ọdun 1993 arabinrin naa ṣere fun swedish club eskilstuna united dff gẹgẹbi ipo forward
glory iroka nigerian footballer glory iroka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 3 óṣu january ni ọdun 1990 arabinrin ṣere fun river angels ati team awọn obinrin apapọ ilẹ naigiria lori bọọlu gẹgẹbi midfielder
adanna nwaneri nigerian footballer adanna nwaneri jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ 31 óṣu august ni ọdun 1975 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun team awọn obinrin apapọ ilẹ naigiria lori bọọlu
ogonna chukwudi nigerian footballer ogonna chukwudi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 14 óṣu september ni ọdun 1988 arabinrin naa ṣere fun italian club lazio ati apapọ team awọn obinrin gẹgẹbi midfielder àṣeyọri ogonna kopa ninu fifa cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2011 nibi ti o ti ṣoju órilẹ ede naig...
eniyan bwatiye awọn eniyan bwatiye ti wọn n pe ni bachama ni ọpọlọpọ awọn eniyan ti o le rii ni numan demsa ati lamurde awọn ijọba ibilẹ ni apa gusu ti ipinle adamawa ati ni diẹ ninu awọn orilẹ-ede cameroons republic ipilẹṣẹ ipilẹṣẹ awọn eniyan bwatiye le ṣe itopase pada lati ọdọ awọn eniyan gobir gẹgẹbi itan awọn eniy...
peter aluma peter aluma ti a bi ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹrin ọdun 1973 - ọjọ keji osu kejí ọdun 2020 jẹ agbá bọọlu inu agbọn ọmọ orilẹede naijiria lati ipinle eko lẹhin ile-iwe giga re ti o ka ni okota grammar school ni isolo nigeria ile- iṣẹ 208-m 6'10 di irawọ ni ile-ẹkọ giga liberty ni virginia amẹrika o sina ami ay...
mohammed muyei mohammed muyei ti a bi ni ọjọ keje oṣu keji ọdun 1975 ni niamey je agbaboolu omo orile -ede niger lọwọlọwọ o nṣere fun new edubiase united iṣẹ-ṣiṣe muyei gba bọọlu lati ọdun 2001 si ọdun 2003 fun sekondi hasaacas fc ni iṣaaju o tun gba bọọlu fun kelantan fa 01072003-01012005 ati ni ọjọ iwaju fun stade ma...
abdel zagre abdel rachid zagré ti a bi ni ọjọ kẹsán oṣu kẹta ọdun 2004 jẹ agbá bọọlu afẹsẹgba burkinabè kan ti o nṣere lọwọlọwọ fun fc sion ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede burkina faso ise re zagre jẹ akeko jade ti ile-ẹkọ js konsa o ṣe ere ikẹhin rẹ ti bọọlu inu ile ni rail club du kadiogo ti premier league burkinabé ni ...
loveth ayila nigerian footballer loveth ayila jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini 6 september ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere fun river angels gẹgẹbi ipo forward
halimatu ayinde halimatu ibrahim ayinde ti a bi ni ọjọ kerindinlogun oṣu may odun 1995 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede naijiria ti o nṣere bii agbabọọlu fun eskilstuna united dff ati ẹgbẹ agbabọọlu obinrin naijiria o ṣere tẹlẹ fun western new york flash ni amẹrika ati delta queens ni nigeria ise egbẹ agbabọọlu halimatu ayind...
uchechi sunday nigerian footballer uchechi sunday jẹ àgbàbọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 9 september ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere fun nojimastella kanagawa sagamihara ni we league gẹgẹbi striker
igi pako ìgi pákò jẹ́ ohun tí a má ní ló láti fọ eyin ni ile yorùbá èyí tí wá kí ohun tí àwọn aláwọ̀ funfun má ń pé ni búrọ́ọ̀ṣì brush ó tó dé ó ní ará igi kàn tí wọn tí máa ń gbé pákò jáde ní ilé yorùbá wá gbàgbó pé ìrun pákò a máa jẹ kí eyin bó funfun bákan náà igi pákò yìí náà máa ń jẹ́ gbígbà àgbò fún àpeere ẹnití ...
kunle adeyanju kúnlé adéyanjú ti a tún mọ si “ọkàn bíi kìnìún” jẹ́ ọmọ orilẹ-ede naijiria ogbontarigi akọṣẹmọṣẹ nipa alùpùpù wiwa si ni pẹlu bakanna oun ni aare aṣẹṣẹ yan fun awọn ẹgbẹ alaanu ti a n pe ni rotary club ni agbegbe ìkòyí ni orilẹ-ede nàìjíríà kunle adeyanju ti ṣe apejuwe ara rẹ gẹgẹbi alaya gbangba ti ohun...
cynthia uwak nigerian footballer cynthia uwak jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15 óṣu july ni ọdun 1986 arabinrin naa ṣere lọwọ fun aland united ni naisten liiga finland
nkechi mbilitam nigerian footballer nkechi mbilitam jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15 óṣu april ni ọdun 1974 arabinrin naa ṣere fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu
judith chime nigerian former football goalkeeper judith chime jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 20 óṣu may ni ọdun 1978 arabirin naa jẹ ẹni ti o ti gba jẹ goalkeeper bọọlu ri fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria ti bọọlu
blessing igbojionu nigerian footballer blessing ogbojionu jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 26 september ni ọdun 1982 arabinrin naa ṣere fun pelician stars gẹgẹbi ipo forward