raw_text
stringlengths
2
128k
obi obì jẹ́ èso kàn nílé yorùbá tí wọn fi máa ń ṣe àlejò yálà ni ayẹyẹ tàbí láàrin ọ̀rẹ́ nígbà tí wón bá rírà won obì náà sì wà fún jíjẹ bóyá okunrin tàbí obìnrin ọmọdé tàbí àgbà ṣùgbón òbí jẹ́ òun ìpanu tí àwọn àgbàlagbà arúgbó má ní sábà jẹ jù obì yàtọ̀ sí tábà tàbí orógbó
igi-ìdáná igi-ìdáná jẹ́ igi tí a máa ń fi ń dáná wọ́n tún máa ń lo igi-ìdáná láti fi pa òótù
ilé-itán
makoko makoko je ibugbe ni agbegbe afara eleketa ni ipinle eko
mákòókó mákòóko jẹ́ ibùgbé àìtọ́ ní 3rd mainland bridge tí ó wà ní èkó orí omi ní ìdá mẹ́ta agbègbè yìí wà tí ìyóókù ní orí ilẹ̀ awọn egun tí wọ́n kúrò ní ìlú badagary àti republic of benin tí iṣẹ́ wọn jẹ́ pẹja-pẹja mákòókó ni wọ́n máa ń pè ní venice of africa èyí ri bẹ́ẹ̀ torí orí omi tí ìɔú náà wà iye àwọn ènìyàn ti ...
àlàpà àlàpà jẹ́ ihò tí àwọn ẹranko kékèké máa ń hù bí i eku àti aláǹgbá ní ọ̀pọ̀ ìgbà
bisola aiyeola nigerian actress and singer bisola aiyeola jẹ́ òṣèrébìnrin ati akoorin órílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n bí lọ́jọ́ kokanlelógún oṣù kinni ọdún 1986bisola je okan lara oludije eto monmaworan big brother naija ti odun 2017 bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ bisola ti lọ si national open university of nigeria nibiti o ti kọ ẹkọ iṣako...
obudu cattle ranch obudu mountain resort tí wọ́n tún ń pè ní obudu cattle ranch ni ó jẹ́ ibi tí a dá sílẹ̀ fún àwọn ẹranko ní ìlú obudu ní ìpínlẹ̀ cross river state ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
ahéré aáré jẹ́ ilé ìgbẹ́ kékeré kan tí wọ́n fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun-èlò ṣe aáré jẹ́ ilé tí àwọn ènìyàn mìíràn rí gẹ́gẹ́ bíi ilé àìtọ́ fún àwọn tó máa ń ya ètò ilé nítorí wí pé wọ́n máa ń lo àwọn ohun èlò tó n wà tẹ́lẹ̀ bíi igi òkúta koríko igi ọ̀pẹ ara igi àti amọ̀ ní lílo àwọn ọ̀nà tí wọ́n ń lò láyé àtijọ́
obudu oko ìsìn ẹranko obudu mountain resortòun tí wón ń pé tẹlẹ ni obudu cattle ranch je oko ẹran ọsin ati agbègbè ní obudu plateau ní cross river state ní orílé èdè nàìjíríà
obudu cattle ranch
aáré
ògùṣọ̀ ògùṣọ̀ ni a lè pè ní ohun ìdáná kan láyé àtijọ́ tí a rí mú jáde láti ara ihá ẹyìn lẹ́yìn ti a yọ kúrò lára epo nígbà tí kò tíì sí epo ̀idáná bí kerosiini kuro lara re
obudu ọkọ ìsìn ẹranko
glenrose xaba glenrose xaba tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kẹẹ̀wá ọdún 1994 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède south africa tí ó n sáré ọlọ́nà jínjìn ó parí ìdíje ti ipò àgbà fún àwọn obìrin ní iaaf world cross country championships ní ọdún 2019 tí ó wáyé ní aarhus denmark ó parí ní ipò kẹtàdínláàádọ́rin iṣẹ́-ṣíṣe ó kópa nínú ìdí...
aéré
dayo amusa dayo amusa tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù keje ọdún 1983 jẹ́ òṣèrébìnrin àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó sì tún jẹ́ oludari ere ori itage ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí dayo amusa lọ́jọ́ kedógún oṣù keje ọdún 1983 si ilu èkó dayo jẹ́ akobi ninu ọmọ tí àwọn òbí rẹ̀ bíò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ...
akon eyakenyi akon etim eyakenyi tí a bí ni 24 february 1960 ni urue-offong/oruko nàìjíríà je òtòkùlú olósèlú ní naijiria òun ló ún se asoju akwa ibom south senetorial district ti ìpinlè akwa ibom ní ilé igbimo asofin àgbàa wón diboyan sí ipo náà ní odun 2019 o jawe olúborí pẹlu ibo 122412 lapapo kí o to di pe ayan sí ...
maimunat adaji hajiya maimuna usman adaji tí àwon ènìyàn mò si maimunat adaji 1957 2019 jẹ́ olóṣèlú nàìjíríà nigba ayé rè a kọkọ diboyan fun ile igbimo aṣoju ni ọdun 2003 a tun dibo yan lẹẹkansi ni ọdun 2011 lábé egbé oselu all nigeria people's party igbé ayé rè adaji jẹ́ olûkó ó sì ní ilé ẹ̀kọ́ kan ó sì tún jẹ́ olóṣèl...
gbemi olateru-olagbegi nigerian on air personality gbemi olateru-olagbegi jẹ́ olugbohunsafefe ọmọ órílẹ̀-èdè nàìjíríàgbemi ni ọmọ ọmọ ọlọ̀wọ́ ti ọ̀wọ̀ sir olateru-olagbegi ii kbe ti o wàjà ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí gbemi olateru-olagbegi lọ́jọ́ kejidinlógún oṣù keje ọdún 1984 si ile banke ati yemi olateru-o...
feyisetan fayose philanthropist and human right activist feyisetan fayose jẹ́ onínúure-tí-ń-ta-ọ̀pọ̀-ènìyàn-lọ́órẹ ọmọ bíbí ilẹ̀ nàìjíríà tí ó tún jẹ́ olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn ẹ̀dá ènìyàn àti pé obìnrin-àkọ́kó ti ìlú ekiti state nígbà kan rí ni gẹ́gẹ́ bí i aya ayọ̀ fáyọ́ṣe wọ́n bí feyisetan fayose ní ọjó kẹ̀jọ osù kínní...
máyọ̀wá nicholas
máyọ̀wá adégbilé
jumoke akindele nigerian lawyer jumoke akindele jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó sì tún jẹ́ obìnrin olórí àkọ́kọ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ ondo ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ jumoke akindele ni wọ́n bí ni okitipupa ilu kan ni ipinle ondo ni guusu ìwò òòrùn nàìjíríà o lọ íle ẹ̀kọ́ alakobere re ni st john's p...
funmi falana funmi falana jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà bẹ́ẹ̀ ẹni tí ń ṣiṣẹ́ òfin ni ó jẹ́ àti pé olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ni ó jẹ́ funmi falana ni aya femi falana tí ń ṣe agbẹjọ́rò àti olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwon ẹ̀dá ènìyàn ti ilẹ̀ nàìjíríà òun náà ni ó bí ọkùnrin akọrin àti òṣèré ilẹ̀ nàìjíríà falz ilé-ẹ̀kó girama st lou...
foluke adeboye foluke adenike adeboye jẹ́ ọmọ bíbí jacob adelusi adeyokunnu tí wọ́n bí ní ọjọ́ ìsẹ́gunoṣù kèje odún 1948 ó ma jẹyọ pé bàbá folukejacob adeyokunnu ó jẹ́ ọmokùnrin àkọ́kọ́ bàbá ti ẹ̀ tí ó sì tan mọ́ ìdílé oyè ọwá obòkun oji ti ilẹ̀ ìjèṣà èyí fi hàn pé ọmọọba ni foluke jẹ́ olùkọ́ ìwé àti olùkọ́ ẹ̀sìn kìrìt...
àdùkẹ́ alákijà
bola are bola are wọ́n bi ní ọjọ́ kínní oṣù kẹ̀wá ọdún 1954 ó jẹ́ olórin ẹ̀sìn kìrìtẹ́ẹ́nì ti orílèdè nàìjíríà àti pé ó ti jẹ́ adarí ẹgbẹ́ àwọn olorín ẹ̀sìn kìrìtẹ́ẹ́nì ti nàìjíríà rí ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi bola ní ọjọ́ kínní oṣù kẹ̀wá ọdún 1954 ní erio ìlú ìwọ̀-oòrùn ìjọba agbègbè ekiti ti ìpínlẹ̀ èkìtì gúúsù-mọ́-ì...
myrtle bothma myrtle bothma ìròyìn ara ẹni orílẹ̀ èdè south africa ojọ́ ìbí ọjọ́ kejìdínlógún osù kejì ọdún 1964 ọdún méjìdínlọ́gọ́ta eré ìdárayá ilà-oòrùn london south africa eré ìdárayá eré orí pápá ọgọ́rún mẹ́rin mítà eré sísá oní fífò myrtle bothma tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún osù kejì odún 1964 jẹ́ olùsáré oní fíf...
bukola oladipupo nigerian actor eg mtv shuga bukola oladipupo ti won bi ni may 23 1994 jẹ òṣèrébìnrin ọmọ órílẹ̀-èdè nàìjíríà ti o bẹrẹ ere ori-itage re lori mtv shuga ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ ilu london ni won bi oladipupo si sugbon ilu eko ni o ti kàwé oladipupo ka eko alakobere re ni bellina nursery and primary...
barbara burke barbara burke burke ní apá ọ̀tún níbi eré ìjọba ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ti ọdún 1938 ìròyìn ara ẹni ọjọ́ ìbí ọjọ́ kẹtàlá osù kaàrún ọdún 1917 norwood greater london uk ọjọ́ tí ó kú ọjọ́ kẹjọ osù kẹjọ ọdún 1998 ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rinjohannesburg south africa gíga 177 cm 5 ft 10 in ìwòn 63 kg 139 lb eré ìdárayá er...
anneri ebersohn anneri ebersohn ìròyìn ara ẹni ọjọ́ ìbí ọjọ́ kẹẹ̀sán oṣù kẹjọ ọdún 1990 ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n ẹ̀kọ́ university of pretoria gíga 168 m 5 ft 6 in ìwọ̀n 57 kg 126 lb eré ìdárayá eré ìdárayá track and field events 400 metres hurdles anneri ebersohn tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀sán oṣù kẹjọ ọdún 1990 jẹ́ olùsáré ...
francisca ikhiede nigerian volleyball player francisca ikhiede jẹ obinrin elere fóólibọọlu ti ilẹ naigiria ti a bini 17 óṣu january ni ọdun 1996 si ilu kaduna elere naa ti ṣere fun team custom ilẹ naigiria ati team awọn obinrin naigiria ti national
yvonne wavinya yvonne wavinya jẹ obinrin elere fóólibọọlu ti ilu kenya fun kenya prisons elere fóólibọọlu naa ni a bini ọdun 1996 si makueni
phosca kasisi phosca kasisi jẹ elere foolibọọlu lobinrin ilu kenya ti a bini 14 óṣu febuary ni ọdun 1993 si ilu nairobi arabinrin naa ṣere fun commercial banki ilẹ kenya elere naa si tidi captain team awọn beach foolibọọlu
tochukwu oluehi nigerian footballer tochukwu oluehi jẹ elere agbabọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ keji óṣu may ni odun 1987 àrabinrin naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun rivers angels
alaba jonathan alaba jonathan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹfà ọdún 1992 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ní ìlú calabar ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù alaba jonathan bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bọ́ùlọ̀lù gbígbá lábẹ́ ẹ̀ka ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ agbábọ́ọ̀lù navy angels lẹ́yìn tí ó kùnà láti pegedé sínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù aagbà ikọ...
adaku okoroafor nigerian footballer adaku okoroafor jẹ àgbàbọọlu lóbinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 18 óṣu november ọdun 1974 nibi ti o ti jẹ elere fun national awọn óbinrin agbabọọlu orilẹ ede naigiria arabinrin na jẹ ara team fifa awọn óbinrin agbaye cup ni ọdun 1991 ati 1995
bolaji odofin bolaji odofin jẹ olutayo nínú ka kọ eré ní orílé èdè nàìjíríà o jé oníṣe ìròyìn ati akéde fún iroyin magazine publisher nígbà kan rí ṣugbọn ní sìn yí odofin ń ṣíṣẹ́ fún àwọn ilé iṣé aladani tí wọ́n kìí gbowó 
aina adeogun aina adeogun je ọ́jọ́gbọn ọ̀mowé tí o gbọyé bsc msc ati phd ní ibadan ní orílé èdè nàìjíríà àwọn ibí pàtàkì tí ọ̀jọ̀gbọ́n tí ń ṣíṣe ni hydrobiology and fisheries aquatic toxicology lára àwọn iṣé pàtàkì tí ọ̀jọ̀gbọ́n ń ṣíṣe lọwọlọwọ ni https//sciuiedung/sites/default/files/research_13pdf àti lára àwọn iṣé t...
kehinde smith kehinde smith jẹ́ òǹtajà tó ní àṣeyọrí lórí okòwò rẹ̀ bákan náà ni ó jé olùdarí ati olùdásílẹ̀ beauty brand tí wọn ń pè ní my extensionz tí ó dá sílẹ̀ ní orílé-èdè united atare láti bí ọdún mẹ́fà sẹyìn àti ní orílé èdè nàìjíríà kehinde smith tẹ̀síwájú láti tún bẹrẹ fẹ́ my extension lójú sí ní orílé èdè nà...
maria oyeyinka laose maria oyeyinka laose je asojú orílé-èdè nàìjíríàn sí orílè-èdè austria lati ọdún 2011 to 2013 laose tí ṣíṣe ní ilé iṣé àjèjì embassy tí nàìjíríà ni orílẹ̀-èdè vienna laose sí jẹ́ ẹni àríyànjiyàn tí àwọn ọmọ naijiria tí wọn ń gbé vienna ó ń ayé àti rí tàbí básọ̀rọ̀ wọn fi abel adelakun ayoko rọ́pò l...
abel adelakun ayoko abel adelakun ayoko jẹ́ asojú orílé èdè nàìjíríà sí austria and slovakia ìgbé aye ayoko ibí 14 february 1957 jẹ́ ẹni tí ó gbà oyè master's degree ní international law and diplomacy ó ṣe ìsìn ní nigerian embassy ti vienna gẹ́gẹ́ bí senior counsellor láti ọdún 1998 2002 ayoko jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ondo ní ...
bimbo balogun bimbo balogun ti a n pe ni abimbola balogun nigba miiran je gbajugbaja obinrin onisowo ọmọ órílẹ̀-èdè nàìjíríào jẹ oga ati oludasile ti bimbeads concept ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ bimbo balogun wa lati idoani ni ipinle ondo nigeria bimbo lo iwe girama ti federal government college idoani ni ipinle ondo...
folashade oluwafemiayo nigerian paralympic athlete folashade alice oluwafemiayo tí wọ́n bí ní ọdún 1985 jẹ́ eléré paralípíkìsì nàìjíríà ayé rẹ̀ wọ́n bí oluwafemiayo ní ìlú jos àti wí pé ó fẹ́ ọkùnrin òníparalípíkìsì tí wọ́n ní ọmọ kan
banke meshida lawal olabanke banke meshida lawal je make-up artist àti olùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé iṣé bmpro makeup group èyí tí ó jẹ́ ilé iṣé make-up ati cosmetology ní nigeria ó gba àmì ẹ̀yẹ brand of the year ní ọdún 2009 ní eloy awards àti tí nigerian event awards ní ọdún 2012 fún best makeup artist àti makeup artist...
ayodeji osowobi nigerian women's rights activist oluwaseun ayodeji osowobi jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà tí ó ń já fún ètò àwọn ọmọbìnrin ó je olùdásílẹ̀ stand to end rape ster ní ọdún 2019 ọ jé ẹnìkejì lóbìnrin tí orúkọ rẹlẹ̀ jẹyọ nínú time 100 next àti nínú commonwealth young person of the year ní ọdún 2019 ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ ay...
surita febbraio surita febbraio tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀noṣù kejìlá ọdún 1973 jẹ́ olùsáré oní fífò ti orílẹ̀ èdè south africa ó gba áámì-ẹ̀ye fàdákà all-africagames ti ọdún 1999 níjohannesburg tí ó sì pari pẹ̀lú ipò kẹjọ ní world championships ti ọdún 2003 ní paris ó gba ààmìẹ̀yẹ african championships ti ọdún 200...
nike adeyemi nike adeyemi wọ́n bi ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ̀rin ọdún 1967 ó jẹ́ òǹkòwé ilẹ̀ nàìjíríà òjíṣẹ́ ọlọ́run olùkọ́ni nípa ilé-ayé gbígbé igbákejì olùṣọ́àgùntàn àti ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ìjọ daystar christian centre òun náà ni olùdarí real woman international àti aya olùṣọ́àgùtàn sam adeyemi olùdarí gbogbogbò ...
augustina ebhomien sunday augustina ebhomien sunday tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1996 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton ó kọ́ èkọ́ gboyè nínú èdè gẹ̀ẹ́sì ní benson idahosa university ní ọdún 2015 ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní summer universiade ní ìlú gwangju ní orílẹ̀-èdè south korea àwọn àṣeyọ...
tolulope akande-sadipe tolulope akande-sadipe je òtòkùlú oloselu omobibi ìpínlè oyo orile-ede naijiria tí a bi ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdun 1966 òun ni óún se soju agbegbe oluyole federal constituency ni ile-igbimọ aṣoju ó jé omo egbe òsèlú all progressive congressapc èkó àti isé rè akande kékó gboyè ninú ìmò i...
ngozi ezeocha nigerian footballer ngozi ezeocha jẹ ọkan lara awọn agbabọọlu lobinrin ilẹ naigiria ti a bini 12 óṣu october ni ọdun 1973arabinrin naa jẹ defender fun team awọn obinrin agbabọọlu national orilẹ ede naigiria
faith ikidi nigerian footballer faith ikidi jẹ obinrin agbabọọlu ilẹ naigiria ti a bini 28 óṣu febuary ni ọdun 1987 si ilu port hacourt arabinrin naa jẹ defender fun super falcons ilẹ naigiria ati piteà if ni sweden
precious dede nigerian footballer precious dede ti a bini 18 óṣu january ni ọ̀dun 1980 jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ naigiria ti o si ti ṣiwọ ìṣe goalkeeper naa ti ṣiṣẹ fun óriṣirìṣi club bi delta queens fc ibom queens and arna-bjorna
uchechukwu deborah ukeh uchechukwu deborah ukeh tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 1996 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton níọdún 2014 ó kópa nínú ìdíje ti africa youth games ó sì gbé ipò àkọ́kọ́ ní èẹ̀meejì ní ọdún 2016 òun ló gbégbá orókè ní ìdíje gbogboogbò tí ó wáyé ní ivory coast ó sì tún ...
susan ideh susan funaya ideh tí a bí ní ojọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 1987 jẹ́ ọmọ orílè-èdè nàìjíríà tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton ó kópa nínú ìdíje ti commonwealth tó wáyé ní ọdún 2010 ní new delhi ní orílẹ̀-èdè india ní ọdún 2015 ó gbapò kìíní ní ìdíje gbogboogbò ti ilè africa ní maputo ní mozambique àwọn àṣeyọrí rẹ̀...
nike hamzat adenike hamzat tí a tún mọ̀ gẹ́gẹ́ bí i nike hamzat jẹ́ òṣèrè yorùbá nàìjíríà tí ó gbajúgbajà fún eré ṣíṣe aṣàgbéjáde eré ẹni tí wọn wò ṣe fún ẹ̀ṣọ-aṣọ àti ti ara aṣoju àwon ohun lóríṣiríṣi onídánilójú fún àwon ohun ìtà oníṣòwò a tún mọ̀ ọ́ fún àwọn ipa ajọnilójú tí ó máa ń kó nínú àwọn eré rẹ̀ nike jẹ́ ẹni...
olajumoke bodunrin olajumoke bodunrin tí wọn bi ní ọjọ́ kèje oṣù kejì ọdún 1945 ti gba ìsinmi gẹ́gẹ́ bí i eléré-ìdárayá ti ilẹ̀ nàìjíríà òun ni wọ́n pè ní obìrin africa tí ó yára jùlọ nínú eré-sísá nígbà eré-sísá rẹ̀ olajumoke gba góòlù ní all-africa games1965 ní brazzaville orílẹ̀-èdè olómìnira òṣèlú ilẹ̀ kóngò kí ó t...
nkoyo toyo nkoyo esu toyo ti a bi ni ọjọ́ kàrún oṣù kọkànlá ọdún 1958 jé agbejoro ajafun idagbasoke ati òtòkùlú oloselu ní orílè-èdè nàìjirià a diboyan si ilé igbimo asofin láti se aṣojú ekùn calabar-odukpani ti ìpinlè cross rivers nàìjíríà ní odun 2011 kó tó dipe o darapo mó ilé igbimo asofin o jé aṣojú nàìjirià sí or...
esther ajayi esther ajayi tí a tún mọ̀ sí ìyá àdúrà orúkọ rẹ̀ ní kíkún ni esther abimbola ajayi wọ́n bi ní ọjọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 1963 esther jẹ́ wòólì-bìnrin tilẹ̀ nàìjíríà onínúúre-tí-ń-ta-ọ̀pọ̀-ènìyàn-lọ́ọrẹ olùsọ́àgùtàn eni ọ̀wọ̀ olùdásílẹ̀ àti olùdarí gbogbogbò ìjọ cathedral of love of christ generation church c...
grace gabriel grace gabriel ofodile tí a bí ní ọjó karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton ó gbégbá orókè nínú ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ áfríkà ti ọdún 2012 àti 2013 gabriel tún gbégbò keta ní ìdíje ti ilẹ̀ áfríkà tó wáyé lọ́dún 2011 àti 2015 iṣẹ́ rẹ̀ bíi agbábọ́ọ̀lù ba...
zainab momoh zainab momoh tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣú kọkànlá ọdún 1996 jẹ́ ọmọ orílè-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton iṣẹ́ rẹ̀ ó kópa nínú ìdíje ti ilè africa ní ọdún 2017 àti 2018 ó sì wà lára àwọn tó gbégbá orókè àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ìdije ti ilẹ̀ africa àdàpọ̀ ìdíje àwọn ọ̀ọ́ ti ilè africa àdàpọ̀ ìdíje gbogboogbò t...
amin yop christopher amin yop christopher tí a bí ní ọjọ́ kefà osù kejìlá ọdún 1993 jẹ́ ọmọ orílè-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ní ilè yìí àti nilẹ̀ òkèrè ó gbégbá orókè nínú ìdíje rabat ti ilẹ̀ africa tó wáyé ní ọdún 2019 ní casablanca ní morocco àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ìdíje ti ilẹ̀...
ola fagbemi ebenezar olaoluwa fagbemi born 20 october 1984 jẹ́ ọmọ orìlẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ africa ọkùnrin nìkan àdàpọ̀ african championships ọkùnrin nìkan àdàpọ̀ àdàpọ̀ ìdíje gbogboogbo ti ọkùnrin nìkan àdàpọ̀ mixed doubles
mercy ebosele mercy ebosele jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí mercy ebosele si ipinle oyo mercy jẹ́ ikẹ̀fà ninu ọmọ méjé tí àwọn òbí rẹ̀ bíò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti memorial primary school ní ìlú oyoó lo si ile-eko girama ti oba adeyemi secondary school nilu oyo bak...
patricia etteh
janet akinrinade janet akinrinade 1930 - 1994 fìgbà kan jẹ́ olóṣèlú orílẹ̀-èdè naijiria òun sì ni mínísítà ìlú lásìkò ìjọba shehu shagari ní àsìkò ìdìbò ti ọdún 1977 òun nìkan ni obìnrin tí wọ́n dìbò wọlé fún ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ìlú iseyin ni wọ́n bí janet sì wọ́n bí i sínú ìdílé ọlọ́mọ mẹ́rin òun ni àbígbẹ̀yìn òun s...
franca afegbua franca afegbua jẹ́ oníṣẹ̀-ewà àti olóṣèlú tó ṣe aṣojú fún bendel north ní ọdún 1983 wọ́n yàn-án gẹ́gẹ́ bíi sẹ́nátò national party of nigeria òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tó wà níipò náà ìlú okpella ní ipinle edo ni wọ́n bí afegbua sí o parí ètò èkọ́ rẹ̀ ní ìlú sofia ní orílẹ̀-èdè bulgaria kó tó dìgbà ìjọba ...
kofoworola bucknor kofoworola bucknor-akerele tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n osù kẹrin ọdún 1939 jẹ́ olósèlú àti igbákejì gómìnà ipinle eko nígbà kan rí òun ni igbákejì gómìnà nígbà ìjọba gómìnà bola tinubu láàrin ọdún 1999 wọ ọdún 2003 ìbèrẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ọjọ́ ọgbọ̀n osù kẹrin ọdún 1939 ni wọ́n bi ilé-ìwé cms girls school ni...
bisi komolafe bisi komolafe je òṣèrébìnrin oludari fiimu ati olupilẹṣẹ omo-orile ede naijiria àwọn eniyan mọ julọ fun ipa rẹ ninu awọn sinima igboro ti daru ati aramotu bisi dagbere faaye ni odun 2012 ni ile iwosan university college hospitalibadan igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ bisi komolafe jẹ ọmọ keji ti a bi ni ọdun 1986...
catherine chikwakwa catherine chikwakwa ti a bi ni 24 osu keje 1985 ni blantyre jẹ asare-jinna jijin ara malawi kan o ti ṣe aṣoju orilẹ-ede rẹ ni ona meji ni olimpiiki sydney 2000 ati olimpiiki athens 2004 bakanna pẹlu awọn ere agbaye lọpọlọpọ arabinrin naa jẹ ami-eye fadaka 5000 mita ni 2004 world junior championships...
ibrahim hamadtou ibrahim al husseini hamadtou ti a bi ni ojo 1 osu keje odun 1973 ti a tun mọ si ibrahim elhusseiny hamadtou jẹ aṣaju tẹnisi tabili para ti ara ilu egypt ti o gba ọpọlọpọ amin ọla ni opoo ọdun pẹlu ami-ẹri fadaka ninu idije tẹnisi tabili tabili para ti afirika ni ọdun 2011 ati ọdun 2013 hamadtou padanu ...
ferdinand omurwa ferdinand omanyala omurwa tí a bi ni ọjọ kéji oṣu kini ọdun 1996 jẹ́ elere-ije ara fún orílẹ̀-èdè kenya ti o ṣe amọja ni àwọn ipele 100m àti 200m o hun naa lọwọlọwọ l'o jẹ́ olugbasilẹ igbasilẹ afirika ati ọkunrin 8th ti o yara ju gbogbo akoko ni mita 100 lẹhin tito akoko kan tí 977 ni ọjọ 18th oṣu kẹsa...
akani simbine akani simbine ti a bi ni ojo 21 oṣu kẹsan ọdun 1993 jẹ ẹlẹsẹ-ije south africa kan ti o ṣa ere mita 100 o gbe ipo karun ni olimpiiki igba ooru 2016 ni mita 100 ti awọn ọkunrin ati pe o jẹ eniti o fi itanbalẹ 100 mita afirika pẹlu iṣẹju aaya 984 ti a ṣeto ni oṣu keje ọdun 2021 titi di igba ti ferdinand omur...
john anderton athlete john anderton 28 kejìlá 1929 24 may 1991 jẹ́ asare ilẹ̀ south africa o dije ninu ere mita 400 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru ni 1952
agnes tirop agnes jebet tirop a bi ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹwa ọdun 1995 - kẹ̀talá oṣu kẹwa ọdun 2021 jẹ́ elere olona jinjin ara ni orílẹ̀-èdè kenya kan ti o dije ni mita 5000 àti ṣiṣiṣẹ orilẹ-ede agbekọja ni 2015 iaaf world cross orilẹ-ede championships o di ẹlẹẹkeji goolu ti o kere ju lailai ninu idije àwọn obinrin l...
luxolo adams luxolo adams a bi ni ojo kini oṣu kẹjọ ọdun 1996 jẹ ẹlẹsẹ-ije south africa kan ni oṣu kẹta ọdun 2018 o ṣiṣẹ ti ara ẹni ti o dara julọ ti awọn aaya 2001 fun 200 m ni paarl o bori ami-ẹri fadaka kan ni awọn ọkunrin 200 m ni ife agbaye ti awọn ere idaraya akọkọ ni ọdun 2018 ni 2018 o dije ni 2018 african cham...
erica ogwumike erica erinma ogwumike ojoibi september 26 1997 jẹ́ elere bọọlu inu agbọn ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà oun gba bọọlu bọọlu inu agbọn kọlẹji fún rice owls ni oṣu keje ọdun 2020 o kede ipinnu rẹ lati ṣere fún ẹgbẹ bọọlu inu agbọn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni olimpiiki tokyo yàtọ̀ sí eré ìdárayá ogwumike tún jẹ́ oníṣ...
oyeniyi abejoye oyeniyi abejoye a bi ni ojo kerindilogun osu kinni odun 1994 jẹ́ eleré ìdárayá àti pápá orílẹ̀-èdè nàìjíríà kan ti o ṣe amọja ninu àwọn idiwọ mita 110 ati pe o tun dije bi asare o dije ni awọn ere agbaye 2018 ni idiwọ mita 110 ni awọn ere afirika 2019 o dije ninu idiwọ mita 110 o gba ami-ẹri fadaka kan ...
lusapho april lusapho lesly kẹrin a bi ni may 24 1982 jẹ asare -oni mita jijin south africa kan a bi i ni uitenhage o dije ninu ere-ije ninu ere olimpiiki igba ooru 2012 ni ilu lọndọnu ṣugbọn o gbe 43rd lẹhin ti o ṣubu aarin-ije o ṣeto igbasilẹ orilẹ-ede ni 25 km opopona nṣiṣẹ 11502 ni 2010 o jẹ olubori igba meji ni er...
khadija abbouda khadija abbouda ti a bi ni june 14 1968 jẹ elere idaraya lati ilu morocco ti o dije ni tafàtafà ni olimpiiki igba eerun 2008 ni ilu beijing abbouda pari ipo rẹ pẹlu apapọ awọn aaye 539 eyi fun ni ipo 64th fun akọmọ idije ipari ninu eyiti o dojuko irugbin akọkọ park sung-hyun ni alaakọkọ tafàtafà ti o wa...
kenza tazi kenza tazi arabic ti a bi ni ojo kefa osu kínní 1996 jẹ omo moroccan ti a bi ni ilu amẹrika ti o je elere idaraya skier alpine o dije fun ilu morocco ni olimpiiki igba otutu 2014 ni slalom ati slalom nla igbesi aye ibẹrẹ kenza tazi ni a bi ni ọjọ 6 kínní 1996 ni boston massachusetts si awọn obi ilu morocco t...
naima el-rhouati naima el-rhouati ti a bi ni ọjọ kankandinlogun osu keje odun 1976 je elere idaraya ara ilu moroccan o dije ni awọn iṣẹlẹ marun ni olimpiiki igba ooru 1996
youssra karim youssra karim ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹta ọdun 1997 jẹ elere-ije ara ilu morocco kan ti o ṣe amọja ni awọn ere idaraya oni jiju o ṣe aṣoju ilu morocco ni awọn ere paralympic karim ti njijadu ni agbara gbigbe iwuwo ni ẹya 58 kg ni olimpiiki igba ooru ti awon odo 2014 karim ṣe aṣoju ilu morocco n...
stella mbachu nigerian footballer stella mbachu jẹ ọkan lara awọn agbàbọọlu lobinrin naigiria ti a bini 16 óṣu april ni ọdun 1978 ni mgidi èlère àgbàbọọlu naa ti ṣere fun super falcons ati river angels
rita nwadike nigerian footballer rita nwadike jẹ ọkan lara awọn agbabọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria tẹlẹ ti a bini 3 óṣu november ni ọdun 1974 àrabinrin naa ti ṣere fun team awọn agbabọọlu obirin naigiri ti national ni olympic ọdun 2004
gift showẹmimọ nigerian footballer gift showẹmimọ jẹ ọkan lara naigiria agbabọọlu lóbinrin ti a bini 24 óṣu may ni ọdun 1974 arabinrin naa ṣere gẹ̀gẹbi forward fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu àfẹsẹgba
fatima el allami fatima-zahra el allami ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹta ọdun1989 ni meknes jẹ ojogbon ninu ere tẹnisi ti ilu morocco tẹlẹ ise tẹnisi ninu iṣẹ rẹ el allami gba awọn akọle ida'se mẹta ati awọn akọle mejila ni circuit itf ni ọjọ kini oṣu kọkanla ọdun 2010 o de ipo 433 ni tii ida'se ti o ga julọ ti a...
nadia lalami nadia lalami laaroussi ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn osu kẹrin ọdun 1990 ni casablanca jẹ olugbaa tẹnisi fun orilẹ-ede morocco tẹlẹ ninu iṣẹ rẹ o bori awọn akọle ida'se meji ati akọle ajose meji lori circuit obirin itf ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2011 ó dé ipò ada'se tó dára jù lọ ní àgbáyé ni i...
lucia chandamale lucia chandamale ti a bi ni ọjọ kejidinlogun osu kefa ọdun1988 ni lilongwe jẹ elere idaraya ara malawi kan ti o nsare ona jijin o ṣe aṣoju malawi ni olimpiiki igba ooru 2008 ni ilu beijing o si dije fun mita 5000 ti awọn obinrin o sare ni ooru akọkọ ti iṣẹlẹ naa pelu awọn oludije mẹrindilogun miiran pẹ...
nike oshinowo-soleye nike oshinowo-soleye je olootu eto ori-afefe omo orile-ede naijiria o je olubori idije obinrin to rewa ju ni naijiria ni odun 1991 mbgn 1991 igbesi aye ibẹrẹ ati awọn oju-iwe oshinowo dagba ni ilu ibadan ati england nibiti o ti lọ si ile-iwe igbimọ botilẹjẹpe o ti pinnu lati di agbalejo afefe tabi ...
funke abimbola funke abimbola mbe jẹ́ oníṣòwò tí orílé èdè nàìjíríà àti agbẹ́jórò ó jẹ́ alágbàwí fún onírúurú nípa iṣẹ́ amòfin ní orílé èdè uk abimbola lọ sí newcastle university láti lọ ní ìmọ nípa òfin láé ó sí bí ọmọ ọkùnrin kan nígbà tí ó ń ba campbell hooper ṣíṣe ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ ayé àti ìwé kíkà rẹ abímbólá je ẹnik...
funke abímbọ́lá
mouna sabri mouna sabri ti a bi ni ọjọ keji osu kínní odun 1984 jẹ agba tẹnisi morocco tẹlẹ ti gba ife fed ni ilu morocco ni ọdun 2003 sabri ni ipo awọn juniors itf ti o ga julọ pẹlu ami 577 ti o waye ni ọjọ keta oṣu kini ọdun 2000 o ṣere ni ile-ẹkọ giga drury ni ọdun 2007 o gba ẹbun apejọ apejọ nla lakes valley ti ọdu...
lina qostal lina qostal arabic ti a bí ni ọjọ kankanla osu keta ọdun 1997 jẹ́ eniti oun agbá tẹnisi ará morocco qostal ti jawe olubori ni eeyanmeji ni irin-ajo itf ninu iṣẹ rẹ ni ọjọ kankandinlogun oṣu karun ọdun 2014 o de ipo awọn ẹyọkan ti o dara julọ ti nọmba agbaye 1165 ni ọjọ kewa oṣu kọkanla ọdun 2014 o gbe ni nọ...
tereza master tereza master ti a bi ni ọjọ kankanlelogun oṣu kẹsan ọdun 1988 jẹ asare jinjinna ara orilẹ-ede malawi kan ti o je ojogbon ni ere-ije o dije ninu idije ere-ije obinrin ni olimpiiki igba ooru 2016 nibiti o ti pari ni ipo 98th pẹlu akoko 24834 itan titun fun orilẹ-ede kan
dami olonisakin dami oloni olonisakin jẹ olukọni lori ibalopo ati oludamọran ibatan o nṣiṣẹ bulọọgi simply oloni ati adarọ-ese kan olonisakin wà ninu okayafrica ’s 100 women list ìgbésí ayé olonisakin ti gbé ni united kingdom a tọ́ ọ dàgbà nínú ilé nàìjíríà àti kristẹni o ni arabinrin aburo kan gẹ́gẹ́ bí ọmọdé kò gba ẹ...
rebecca kalu nigerian footballer rebecca kalu jẹ agbààbọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 12 óṣu june ni ọdun 1990 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team national u-20 lori bọọlu ni ọdun 2008
rachael yamala nigerian footballer rachael yamala jẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 12 óṣu febuary ni ọdun 1975 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu
prisca emeafu nigerian footballer prisca emeafu jẹ̀ àgbààbọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 30 óṣu march ni ọdun 1972 arabinrin na ṣere gẹgẹbi defender fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu