raw_text
stringlengths
2
128k
yemi blaq nigerian film actoryẹmí blaq tí orúkọ ibí rẹ̀ jẹ́ fọláyẹmí ọlátúnjí jẹ́ òṣèré fíìmù nàìjíríà olùdá fíìmù akọ-orin àti módẹ́ẹ̀lì ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ yẹmí ọ̀gbẹni ọlátúnjí blaq bí ní ìpínlẹ̀ òǹdó nàìjíríà yẹmí blaq dàgbà sí ìpínlẹ̀ èkó níbi tó ti lọ àti parí ilé-ìwé pámárìlì àti ilé -ìwé fáṣítì ó lọ sí ...
yemi blag
olórin orílẹ̀-èdè nàìjíríà
wurld sadiq onifade tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí wurld jẹ́ olórin àti akọ-orin nàìjíríà wọ́n bi ní ìpínlẹ̀ èkó nàìjíríà wurld padà lọ sí atlanta georgia láti lépa ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírí rẹ̀ àti láti tẹ orin jáde ó pe bátànì orin tirẹ̀ ní ẹlẹtiro-fúíṣọ̀nì ó kọ ep rẹ̀ àkọ́kọ́ tó pè ní evolution ní ọdún 2013 ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ lórí or...
slimcase ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹ́jọ ọdún 1982 ni wọ́n bí olúfẹ́mi ọládàpọ̀ tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí slimcase olórin akọrin akígbe àti òṣẹ̀ré ni ó jẹ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ohun tí ó sọ ọ́ di ìlú-mọ̀-ọ́-ká ní àwọn orin tí ó kọ pẹ̀lú àwọn olórin ẹgbẹ́ rẹ̀ bí i orin d'banj 'issa banger' àti 'gucci snake' láti ọwọ́ wizkid pẹ...
mo' hits records mo'hits records tí ó gbajúgbajà gẹ́gẹ́ bí i mo'hits jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde ní orílèdè nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ń ṣe ti d'banj àti don jazzy gẹ́gẹ́ bí i àjọ tó ń rí sí gbígba orúkọ àwọn ilé-iṣẹ́ sílẹ̀cacilé-iṣẹ́ mo'hits jẹ́ èyí tí wọ́n dálẹ̀ ní 2006 tí d'banj jẹ́ olórin àkọ́kọ́ ti ilé-iṣẹ́ náà ní don jazzy...
vanguard vanguard jẹ ìwé iroyin ojoojumọ ti vanguard media ma ún gbejade vanguard media kalè sí ìpínlè èkó nàìjíríà oniroyin sam amuka-pemu pèlú àwon òré rè méta lódá vanguard media silẹ ni ọdun 1984 vanguard media tún ma ún gbé ìwé iroyin ojojumo náà sí orí ayelujara fún àwon ènìyàn lati káà níbè iwe irohin naa jẹ ọka...
mo'hits records
guarantco guarantco jẹ ile-iṣẹ ti o ṣe idoko-owo ni awọn amayederun ati atilẹyin idagbasoke ti awọn ọja inawo ni awọn orilẹ-ede ti owo-wiwọle kekere ni esia ati afirika itan guarantco ti dapọ ni ọdun 2005 ni port louis mauritius lati ṣe inawo awọn iṣẹ amayederun ati ṣe iranlọwọ idagbasoke awọn ọja inawo agbegbe ni awọn...
daily times daily times jẹ iwe iroyin tí olu-ilese won wà ni ìpinlè eko adá ilé-isé iroyin náà kalè ní odun 1926 ósì padà di ilé-isé ìwé iroyin tí o gbajugbaja julo ní nàìjíríà fun òpòlopò igba
thisday thisday jẹ́ òkan lara àwon iwe iroyin ní orilẹ-ede naijiria a tèé ìwé iroyin thisday jáde fún ìgbà akoko ni ọjọ 22 oṣu kini ọdun 199522 january 1995 olu ile-iṣẹ rẹ wà ni apapa ìpínlè eko oludasile ilé-isé iroyin náà ni nduka obaigbena òun ni alaga egbe thisday media ati ikanni irohin arise thisday ni ilé-isé mé...
bob mcgrath robert emmet bob mcgrath june 13 1932 je osere ara amerika
nigerian tribune ìwé ìròyìn nigerian tribune jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé-ìròyìn olójoojúmọ́ tí wọ́n ń tẹ̀ jáde láti ilú ìbàdàn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà alàgbà ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ni ó dá ìwé ìròyìn yí sílẹ̀ ní ọdún 1949 ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé ìròyìn tí ó pẹ́ jùlọ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní àsìkò àmúnisìn ìwé ìròyìn yí ni...
kefee kefee obareki don momoh ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì 1980 ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà 2014 tí wọ́n tún máa ń pè ní orúkọ ìtàgé rẹ̀ kefee jẹ́ olórin obìnrin àti a-kọ-orin nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbésí-ayé wọ́n bí i ní sápẹ́lẹ́ ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì 1980 sínú ìdílé andrew obareki tí wọ́n fi ìgbà kan jẹ́ díkọ́ọ̀nì nínú ìjọ t...
muraina oyelami olóyè muraina oyelami tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 1940 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì jẹ́ ayàwòrán àti onílù ti ìran yorùbá ó wà lára àwọn tó kọ́kọ́ gboyè ní osogbo school of art ní ọdún 1960 ó wà lára àwọn onílù àti òṣèré fún ègbé tíátà ti duro ladipoe ó kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní orin àti ...
peruzzi tobechukwu victor okoh tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejìlá ọdún 1989 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ peruzzi jẹ́ olórin àti akọ-orin sílẹ̀ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọmọ ọdún méje ló wà nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin ó di gbajúgbajà òṣèré nígbà tí 2face idibia ṣe àfihàn rẹ̀ nínú orin 'amaka' tó kọ iṣẹ́ rẹ̀ ó ni ìyàwòran ...
union bank building union bank building jẹ́ ilé gíga ti ori re ri perese ti o wa ní ìlú èkó ilé yi je olu ile-ise apapo fun ile ifowopamo union bank ni orile-ede nàìjíríà
george mother
ìdòwú phillips
chike chike-ezekpeazu osebuka tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 1993 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ chike jẹ́ akọrin òǹkọ̀wẹ́ akọrinsílẹ̀ àti òṣèré orílẹ̀-èdè naijiria chike jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn akópa nínú ìdíje àwọn akọrin project fame west africa lẹ́yín ìdíje yìí ni ó gba ipò kejì ni àṣekágbá ìdíje the voice ...
rema divine ikubor ibí 1 may 2000orúkọ orí itage rẹ̀ ń jẹ́ rema akọrin ti orílẹ-èdè nàìjíríà ayé mo rema nígbà tí ó gbé orin tí àkọlé rẹ ń jẹ́ iron kan èyí tí ó jẹyọ nínú summer playlist ti barack obama ni ọdún 2019 bákan náà ní 2019 ó sí fọwọ́ sí láti bá jonzing world ṣíṣe èyí tí ó wa labẹ mavin records ìbẹ́rẹ́pẹ́pẹ́ ...
ifedayo olarinde nigerian on air personalityifedayo olarinde wọ́n bí i ní oṣù karùn-ún ọdún 1976 tí gbogbo ayé mọ̀ ní daddy freeze jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ọmọ ilè nàìjíríà àti romania àti olùdarí eto tí wọ́n tí ń fi ọ̀rọ̀-jomi-toro ọ̀rọ̀ lórí rédíò ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ifedayo olarinde sí cluj-napoca ní orílẹ̀-èdè...
bella shmurda nigerian singerabiola ahmed akinbiyi tí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ bella shmurda jẹ́ ólórin àtí éní tí mán kó órín ní ìlú nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ nígbà tí orin rẹ̀ vision 2020 jáde pẹ̀lú àtúnkọ tí ó kọ pẹ̀lú olórin nàìjíríà tí ó ń jẹ́ olamide
reekado banks nigerian musician ayoleyi hanniel solomon bí ní ọjọ́ kẹfà osù kejìlá ọdún 1993 tí a mọ̀ sí reekado banks ó jẹ́ olórin àti akọrin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó darapọ̀ mọ́ mavin records ní ọdún 2014 ó fì mavin records lẹ̀ ní ọdún 2018 orúkọ tí ó kọ́kọ́ jẹ́ ni spicy kó tó di pé ó darapọ̀ mọ́ mavin records
ìlù bàtá ìlù bàtà jẹ ìlù kan ti o ni oju meji ikan ni iwaju ikan lẹyin amọ oju ilu ti o wa ni iwaju fẹ̀ ju ti ẹ̀yìn lọ ọdun ibilẹ ọdun òrìṣà sàngó ilu santería ní cuba láti ọdún 1800s àti ní puerto rico àti ni orílẹ̀-èdè amẹríka láti ọdun 1950s ni a ma n lo ilu yi fun bakan naa ni wọn tun ma n loo fun oriṣriṣi ayẹyẹ ni...
ijo ibile ijó ìbílẹ̀ jẹ́ àwọn ijó tó rọ̀ mọ́ àṣà ìṣe àti ìgbàgbọ àwọn ọ̀wọ́ ènìyàn tí wọ́n jọ́ gbé ní ibìkan
burna boy damini ebunoluwa ogulu tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣụ́ keje ọdún 1991 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jé burna boy jẹ́ olórin ti oríl̀-èdè naijiria ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó kọrin like to party ní ọdún 2012 èyí tó wà nínú àwo-orin rẹ̀ life tó jáde ní ọdún 2013 ní ọdún 2017 ó tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú bad habits/ atlantic records ...
ààfin ààfin ni ibùgbé àwọn ọba gẹ́gẹ́ bí orikì tí ìwé atúmọ̀ èdè fún ààfin ipò ọba kì í ṣe ipò yẹpẹrẹ rárá fún ìdí èyí ibugbe wọn máa ń yàtọ̀ sí ti àwọn ará ìlú àárín ìlú ni ààfin máa ń sábà wà ààfin ọba benin ààfin ọba benin jẹ́ ọkan lára àwọn ààfin ilẹ̀ yorùbá inú ààfin yìí ni ọba àti àwọn ebí rẹ̀ má ń gbé ọba ewedo ...
hec paris hec paris je yunifasiti aladani ni ilu parisi ni fránsì
rey rey rodriguez rey paul rodriguez ti a mọ julọ ni rey rey rodriguez jẹ oluyaworan ilu amẹrika olorin onise iroyin ati otaja ti o jẹ oludasile ti the mind of rey rey eyiti o jẹ ile-iṣẹ tita kan ti o da ni south florida iṣẹ rẹ ti ṣe afihan ni ọpọlọpọ awọn iwe iroyin pẹlu onisowo forbes the good men project vogue huffi...
broda shaggi samuel animashaun perry ti a bi ni oṣu kẹsan ọjọ 19 ọdun 1993 ti a mọ si broda shaggi jẹ apanilẹrin naijiria kan oṣere akọrin ati akọrin nígbà tó wà lọ́mọdé ó nífẹ̀ẹ́ sí eré ìtàgé bí bàbá rẹ̀ tó ti kú tó jẹ́ olùkọ́ eré ìdárayá ṣe nípa lórí rẹ̀o jẹ olokiki fun awọn ere satirical rẹ eyiti o pin lori instagra...
sciences po sciences po je yunifasiti aladani ni ilu parisi ni fránsì
amy okonkwo amy nnenna okonkwo ti a bi 26 august 1996 jẹ oṣere bọọlu aju sinawon ọmọ naijiria fun saint-amand hainaut basket ni ligue féminine de basketball ati ẹgbẹ orilẹ-ede naijiria iṣẹ ọmọ ẹgbẹ orilẹ-ede naijiria amy ṣe aṣoju naijiria ni olimpiiki igba ooru 2020 ni ilu tokyo nibiti o ṣe aropin 27 ojuami ati 1 rebou...
ify ibekwe ifunanya debbie ti ọpọlọpọ eniyan mọ si ify ibekwe ti wọn bi ni ọjọ karun un oṣu kẹwa ọdun 1989 je ọmọ orile-ede naijiria ati amerika ti o agbabọlu alapẹrẹ fun ikọ ati iko agbaboolu alapere orile-ede naijiria wnba seattle storm yan ibekwe sinu ipele idije elekeji 2011 wnba draft 24th overall elekeji national...
leia dongue leia tânia do bastião dongue tit ọpọ̀ èniyàn mọ̀ si tanucha ti a bi ni ojo kerinlelogun osu kaarun odun 1991 ni maputo mozambique jẹ oṣere bọọlu inu agbọn mozambique kan o jẹ ọdun 185 cm 6'07 ati ki o dun bi kekere siwaju ni may 2013 o ti wole nipasẹ primeiro de agosto tanucha ni a dibo mvp ni ajumọṣe bọọlu...
fúnmiláyọ̀ ransome-kútì oloye funmilayo ransome-kuti mon ni a bí ni frances abigail olufunmilayo thomas ni ọjọ kẹẹdọgbọn oṣu kẹwa ọdun1900 ó sì jade laye ni ọjọ́ kẹtala oṣu kẹrin ọdun1978 a tun mọ si funmilayo anikulapo-kuti ó jẹ́ olukọni oloṣelu alagbọrandun ati a jà-f'ẹtọ awọn obinrin ni orilẹ-ede naijiria ìlú abeoku...
nolene conrad nolene conrad tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndílọ́gbọ̀n osù keje ọdún 1985 jẹ́ asáré -ọ̀nà tó jìnà ti ilẹ̀ south africa kan ní ọdún 2013 ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà ní iaaf àgbáyé jákè jádò orílẹ̀ èdè ti ọdún 2013 tí ó wáyé ní bydgoszcz poland ó parí pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gọ́rin ní ọdún 2015 ó kópa nínú ìdíj...
kesaoleboga molotsane kesaoleboga molotsane tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní ọdún 1992 jẹ́ olùsáré ọ̀nà jińjìn ti orílẹ̀ ède south africa kan ní ọdún 2019 ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà ní 2019 iaaf world cross country championship tí ó wáyé ní aarhus denmark o pari pẹ̀lú ipò kejìlélógójì ní ọdún 2017 ó kópa nínú ìd...
adepeju jaiyeoba nigerian social entrepreneur adépéjú ọpẹ́yẹmí jayéoba tí wọ́n bí lóṣù kọkànlá ọdún 1983 jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ àti oníṣòwò àwùjọ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ brown button foundation àti mother's delivery kits èyí àjọ tí ó máa ń pèsè àwọn nǹkan ọmọ àti oògùn fún àwọn aláboyún ni owó pọ́kú ní ...
ìyanya nigerian singer' ọjọ́ kankànlélọ́gbọ̀n oṣù ọ̀wàwà ní wọ́n bí iyanya onoyom mbuk tí orúkọ ìtàgẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ iyanya olórin tàka-súfèé orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni ìyanya ó di ìlú-mọ̀ọ́ká nígbà tí ó gbégbá orókè nínú ìdíje project fame west africa àti wí pé orin rẹ̀kukere tún jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ ó pawọ́pọ̀ dá ilé-iṣ...
onome ebi nigerian footballer onome ebi jẹ àgbààbọlu óbinrin defender ti a bini ọjọ kẹjọ oṣu may ni 1983 si ipinlẹ eko ni órilẹ ede naijiriaàràbinrin naa gba bọọlu lọwọ fun fc minsk ni belarusian premier league team naigiria nigbogbo orilẹ ede ati super falcons
esther sunday nigerian footballer esther sunday jẹ agbaabọọlu obinrin ti oun gba bọọlu fun dijon ninu division 1 fèminine oti fi igba kan gba bọọlu fun sunshine queens pelician stars ati fc minsk
wuraola esan nigerian activist olóyè wuraola adepeju esan tí a bí ní ọdún1909 tí ó sì kú ní ọdún1985 fìgbà kan jẹ́ olùkọ́ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ajàfẹ́tọ̀ọ́mọbìrin àti olóṣèlú ó pa iṣẹ́ ìṣèlú rẹ̀ pọ̀ mọ́ àwọn adarí ìlú gẹ́gẹ́ bíi iyalode ìlú ibadan ìtàn ayé rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí wuraola adepeju e...
dolapo oni nigerian tv host dolapo oni tí àwọn ènìyàn mọ̀ nígbà mìíràn sí marcy dolapo oni jẹ́ òṣèré nàìjíríà olóòtú tẹlẹfísọ̀n aláwòkọ́se àti mii sí ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ oni jẹ́ ọmọ àbíkẹ́yìn nínu ọmọ mẹ́rin tí àwọn òbí rẹ̀ bí ó lo ogún ọdún ní ìlú aya-ọba kí ó tó padà wá sí ìlú nàìjíríà ní ọdún 2010 gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọdún mẹ́...
stella oduah-ogiemwonyi stella oduah ogiemwonyi tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kinni ọdún 19625 january 1962 jé òkan lára àwon asofin agbasenato nàìjirià àti minisita ofurufu tẹ́lẹ̀rí o bura wolé sí ipò minisita ofurufu ni ojó keji oṣu keje ọdun 2011july 2 2011 ṣugbọn a yọọ kuroní ipo náà ní ọjọ kejila oṣu keji ọdun 2014...
gloria oloruntobi nigerian comediennegloria oloruntobi tí wọ́n bí ní oṣù kejì ọjọ́ kẹfà ọdún 1997 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí maraji jẹ́ òṣèré apanilẹ́rìn-ín nàìjíríà ó bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ pẹ̀lú vídíò lip sync àti kọ orin olórin maraji ṣeré nínu àwọn vídíò apanilẹ́rìn-ín kékeré àti lo àwọn ẹ̀ka-èdè àti ohùn oríṣiríṣi láti...
ayo omidiran nigerian politician and lawmaker ayo hulayat omidiran tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣú kọkànlá ọdún 1965 jé olóṣèlú ti orílè-èdè naijiria àti aṣòfin ti ìjọba ìbílẹ̀ ayedaade/irewole/isokan ní ipinle osun ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ egbé all progressive congress ọmọ ìlú ikire ní ipinle osun ni ó ti wá ètó-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ...
fatima azeez titilayo fatima azeez tí a bí ní ọjọ́ kọkànlelógún osú kejìlá ọdún 1992 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù badminton ti orílè-èdè naijiria ní ọdún 2010 ó parí summer youth olympics ní singapore ní ọdún 2011 ó jẹ èbùn ti all-africa games ní maputo mozambique àwọn àṣeyọrí rẹ̀ all-africa games ìdíje àwọn obìnrin méjì ìdíje ti ...
tosin damilola atolagbe nigerian badminton playertosin damilola atolagbe tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje ọdún 1994 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lụ̀ badminton àwọn àṣeyọrí rẹ̀ àṣeyọrí ti ilè african obìnrin nìkan àdàlú è bwf international challenge/series obìnrin nìkan àdàlú è àdàlú è
peace orji peace orji tí a bí ní ọjọ́ kogún oṣù kejìlá ọdún 1995 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton ó kópa nínú ìdíje ti ilẹ̀ africa ní ọdún 2019 ó sì gba ẹ̀bùn fún ipò alákọ̀ọ́kọ́ ó sì gba ẹ̀bùn fún ipò kẹta nínú ìdíje àdàlú tí wọ́n ṣe àwọn àṣeyọrí rẹ̀ eré ti ilẹ̀ african àdàlú ẹ̀ àṣeyọrí ti ilẹ̀ a...
dorcas ajoke adesokan dorcas ajoke adesokan tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣụ́ keje ọdún 1998 jẹ́ ọmọ orílẹ-èdè naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton iṣẹ́ rẹ́ ní ọdún 2014 ó jẹ ẹ̀bùn fún ipò kẹta ní ìdíje ti ilẹ̀ africa ní oṣù kẹfà ó jẹ́ olúborí nínú ìdíje ti lagos international tournaments ní ọdún 2019 ó kópa nínú ìdíje ti i...
rose okoji oko olóṣèlú ni nàìjíríà19562020 rose okoji oko 27 kẹsán 1956 23 march 2020 je oloselu áti asofin agbasenator naijiria nigba ayé rè ó jẹ́ okàn lara àwon ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba àpapọ̀ lábé ẹgbẹ́ òṣèlú people’s democratic party pdpó si ṣe asojú agbegbe yala/ogoja ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin keje ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ...
adaora elonu nigerian basketball player adaora elonu jẹ ọkan lara agbabọọlu inu agbọn obinrin ninu naigiria ti a bini 28 oṣu april ni ọdun 1990 jẹ aburo fun àkọṣẹmọṣẹ agbààlọlu lobinrin inu agbọn tì orukọ rẹ n jẹ chinemelu elonu adaora ni asiko yi gbààbọọlu fun cb avienda
ezinne kalu american-born nigerian basketball player ezinne kalu ni ọkan ninu awọn agbabọọlu inu agbọn obinrin ni naigiria ti à bini 26 oṣu june ni ọdun 1992 ni newark njojẹ obinrin ti oun gba bọọlu fun lansmderneau ni ilu france nibi lọwọ lọwọyi
ayomide bello nigerian canoeist ayomide emmanuel bello tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kẹ́rin ọdún 2002 jẹ́ awa akọ̀-ojú-omi fún ìdíje ti ọmọ nàìjíríà ó díje ní women's c-1 200 metres ìdíje tí wọ́n ṣe í ọdún 2020 súmà òlípíkìsì tí wọ́n ṣe ní tokyo japan ní ọdún 2018 ó gba oyè wúrà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní african youth games n...
funmilayo adebayo nigerian evangelistfunmilayo adebayo co ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí mmy go isjẹ́ ẹ̀váńjẹ́lísìtì nàìjíríà tì àríyànjiyàn pọ̀ lórí rẹ̀ àti olùdásílẹ̀ rapture proclaimer evangelical church of god láti ìpínlẹ̀ èkìtì wàásù rẹ̀ lóri bí òun ṣe lo ọdún 990 ní ìjọba òkùnkùn lọ káàkiri nàìjíríà àti wí pé èyí gbá ọkàn à...
aishatu dahiru ahmed aishatu dahiru ahmed ojó ìbí rè ni 11 august 1971 ti a tun mo si binani jẹ òkan lara àwon sẹnatọ nigeria labe egbe oselu all progressives congressapc o nsoju agbegbe adamawa central senatorial district o jẹ ara awon ile igbimo asofinhouse of assembly larin odun 2011-2015 lábé egbe oselu people's de...
bunmi kayode nigerian footballerbunmi kayode tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹ́rin ọdún 1985 jẹ́ obìnrin abábọ́ọ̀lù afẹsẹ̀gbẹ́ nàìjíríà káríayé tó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bíi dìfẹ́ńdà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn nigeria women's national football team ó wà lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ 2003 fifa women's world cup
evelyn akhator evelyn akhator àkọṣẹ mọṣẹ agbàbọọlu inu agbọn lobinrin fun flammes carolo ti a bini ni ọjọ kẹta oṣu febuary ni ọdun 1995arabinrin naa sign pẹlú spanish cb avenda ni ọjọ marundilogun ni ọdun 2019
ìyábọ́ òjó
sofiat arinọla obanishola sofiat arinọla jẹ ikan lara awọn elere badminton lobinrin ni orilẹ ede naigiria ti a bini ni 16 óṣu september ni ọdun 2003 arabinrin na ti kopa ni ere idijè badminton ni kakiri orilẹ ede ati ókè okun
olamide toyin adebayo tóyin ọlamide jẹ ọkan lara obinrin awọn elere badminton naigiria ti à bini 22 ọṣu june ni ọdun 1976arabinrin na kopa ni ibf championship àgbaye ni ọdun 1995 ati 1999
uche ekwunife uche lilian ekwunife orúko abiso rè ni ogudebe ti a bi 12 january 1970 jẹ oloṣelú omobibi orílè-èdè nàìjirià ó wà lara awon ti ọmọ ile igbimọ aṣosenato kesan ti nàìjirià óún se a o ṣoju awọn eniyan anambra central senatorial district ti anambra àárò ayé àti èkó rè a bi ekwunife ni 12 december 1970 ni ilu ...
bọlaji ẹniọla maryam ẹ̀niọla maryam jẹ àkọṣemọṣẹ elere badminton orilẹ ede naigiria ti à bini 21 óṣu september ni ọdun 2005 ni ilu ibadan ṣugbọn ó dàgbà si ipinlẹ kwara naigiria arabinrin na fi oju si ere tennis tẹlẹ tẹlẹ ki oto wa dipe o pada si ère badminton aṣeyọrì bọlaji jẹ ẹni akọkọ ni ilẹ afirica lati gba gold ni...
alaba lawson olóyè alaba lawson tí a bí ní omidan alaba oluwaseun lawson ni ọjọ kejì-dín-lógún oṣú kínní ọdún 1951 jẹ ọmọ orilẹ-èdè naijiria olokoowo nla oniṣowo agba ati ọmọwe sì ni pẹlu òun ni ó jẹ́ obinrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ aarẹ ẹgbẹ naccima ati alága ìgbìmọ̀ awọn alakoso ti ile ẹko gbogboniṣe moshood abiola ni ìpínlẹ...
ayotunde phillips ayotunde phillips tí wọ́n bí ní oṣù kéje ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n ọdún 1949 jẹ́ agbẹjọ́rò nàìjíríà àti olórí adájọ́ sẹ́yìn wàá rí ìpínlè ̀ èkó ayé rẹ̀ wọ́n bí ayotunde phillips ní oṣù kéje ọjọ́ kẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ọdún 1949 ó jẹ́ àkọ́bí olóǹgbé adájọ́ james oladipo williams àti henrietta aina williams adáj...
maria braimoh maria hajara braimoh tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kìíní ọdún 1990 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń gbá badminton ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ ti nàìjíríà tó gbá badminton ní ọdún 2007 àti ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ afrika ní ọdún 2011 braimoh tún kópa nínú ìdíje ti commonwealth tí wọ́n ṣe ní odún 2010 ní new d...
grace daniel grace kubi daniel tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejì ọdún 1984 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ń gbá badminton àwọn àṣeyọrí rẹ̀ géèmù ilẹ̀ african àwọn obìnrin nìkan àdàpọ̀ àwọn àgbábọ́ọ̀lù àdàpọ̀ àwọn àgbábọ́ọ̀lù àwọn olúborí ti ilẹ̀ african àwọn obìnrin nìkan àdàpọ̀ àwọn àgbábọ́ọ̀lù àdàpọ̀ àwọn àgbábọ́...
dayo oyewusi dayo oyewusi tí wọ́n bí ní ọdún1966 jẹ́ abábọ́ọ̀lù badimíítìnìbadminton nàìjíríà ó díje ní ọdún 1994 commonwealth games ní victoria canada ó gbé ipò kìíní ní ọdún 1991 ní ìdíje tí wọ́n ṣe ní kenya fún àwọn obìnrin méjì papọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà bíi ni kan tí ẹni kejì rẹ̀ jẹ́ obiageli olorunsola àwọn oyè ibf inter...
bolanle austen-peters nigerian lawyer and business woman bolanle austen-peters tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kejì ọdún 1969 jẹ́ olùdarí fíìmù/tíátà nàìjíríà àti agbẹjọ́rò òun tún ni olùdásílẹ̀ àti olùdarí fún terra kulture ilé-iṣẹ́ tó ń ṣètò nípa àṣà tó wà ní ìpínlẹ̀ èkó ilé-iṣẹ́ fíìmù àti tíátà rẹ̀ bap productions tí ...
apaokagi maryam apaokagi maryam tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ taaooma tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjidinlogbon oṣù kejì ọdún 1999 jẹ́ gbajúgbajà aláwàdà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú wọ́n bí apaokagi maryam lọ́jọ́ kejilélógbon oṣù kejì ọdún 1999 si ilu ilorinipinle kwarao lo iléẹ̀kọ...
lebogang phalula lebogang phalula tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀san oṣù kejìlá ọdún 1983 jẹ́ olùsáré ọlọ́nàjínjìn fún orílẹ̀ ède south africa kan ní ọdún 2009 ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà fún iaaf world cross country championships ti 2009 tí ó wáyé ní amman jordani o pari pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gbọ̀n ní ọdún 2009 ó kópa nín...
àanu ayègbusi àanu ayègbusi jẹ elere tennisi lobinrin ni orilẹ ede naigiriya ti a bini 30 óṣu november ni ọdun 1993 arabinrin na jade ni ile iwe giga ti ilu port harcourt
bukunmi oluwashina bukunmi oluwashina jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ oke-imesi ní ìpínlẹ̀ ekiti lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ bukunmi oluwashina jẹ́ ọmọ keta nínu ọmọ meje tí àwọn òbí rẹ̀ bíó lọ sí yunifásítì ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ níbi tó ti gba oyè nínu ere ori itage
sarah àdegoke nigerian tennis player sarah adegoke ni elere tennis lobinrin ni orilẹ ede naigiria ti a bini ọdun 1997 ti o si dagba si ibadan nibi ti o sì kọ tennis lati ọwọ baba rẹ ọgbẹni adegoke adedapọ arabirinin naa ni ẹni ti a rank ju ninu elere tennis lobinrin ni orilẹ ede naigiria
georgia oboh georgia oboh jẹ elere golf lobinrin to jẹ ọmọ british-naigiria ti ó jẹ ọmọ ogun ọdun arabinrin naa wa lati idile èlere golf nibi ti baba rẹ si jẹ ọkan ninu èlere golf naa ni central london arabinrin naa jẹ akikanju èlere golf larin awọn obinrin afirica ti o si jẹ naigiria akọkọ lati qualify fun tour awọn ọ...
betty apiafi betty jocelyne okagua - apiafiti a bi ní 19 january 1962 jẹ onimọ-ọrọ-aje olukorede àti òtòkùlú olósèlú ní nàìjirià apiafi wà lara àwon senato nàìjirià óún se asoju rivers west senatorial district o tun se aṣoju fun abua/odual-ahoada east federal constituency ní ilé igbimo asofin kekerehouse of representat...
adunni oluwole adunni oluwole 1905-1957 jẹ́ òṣèlú nàìjíríà kí wọ́n tó gba òmìnira àti ẹni tó máa ń jà fún ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn tó wí pé ó lòdì sí òmíràn nígbà náà wọ́n bi ní ìlú ibadan ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àti dàgbà sí aroloyo ìpínlẹ̀ èkó ó jẹ́ oníwàásù tó máa ń jáde kiri tí ó sì ẹ̀bùn láti sọ̀rọ̀ dáadáa láwùjo èyí wà lára àwọn ...
jumoke odetola jumoke odetola jẹ́ òṣèrébìnrin órílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́ wọ́n bí jumoke odetola lọ́jọ́ kerindinlógún oṣù kewa ọdún 1983 si ilu èkó jumoke jẹ́ abikeyin ninu ọmọ meje tí àwọn òbí rẹ̀ bí ó lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ abati nur/pry school ní ìpínlẹ̀ èkóti o si lo ile -iwe girama ti o w...
ile alapa ile alapa je ile ti o ti gbo ti o si tko si bojumu fun awon eniyan lati gbe
ilé ìdáná space primarily used for preparation and storage of food ilé ìdáná jẹ ìyára kan nínú ilé tí a tí ń ṣe oúnjẹ tàbí ipalemo oúnjẹ ni ilẹ kàn tabi ilẹ oúnjẹ títà nínú ilé ìdáná ayé àtijó a má ṣe àwárí awọn nǹkan bí àbò igi ìdáná ijoko àmù ikòkò àti bẹebeelo
ile iidana
ilé alámọ̀ ilé alámọ̀ jẹ́ àwọn ilé tí wọ́n fi amọ̀ ìyẹn iyẹ̀pẹ̀ pupa kọ́ àwọn ibi tí wọn kò tí fi bẹ́ẹ̀ lajú ni a ti máa ń bá àwọn ilé tí wọ́n fi amọ̀ kọ́ wọ̀nyí pàdé gẹ́gẹ́ bí i ilé tí wọ́n ń gbé àwọn mìíràn ti ẹ̀ máa ń kọ́ ilé alámọ̀ ní ìlànà ìlàjú tí ó tún rẹwà ju àwọn èyí tí a máa ń bá pàdé ní àwọn ìlú tí wọn kò tí...
ile aye atijo ile aye atijo je irufe awon ile ati ibugbe ti won n ko ni aye atijo paa paa julo ni awon igberiko ati aroko ni aye atijo
wẹ̀rẹ̀ wèrè jẹ́ ènìyàn kan tí kò gbádùn tàbí tí a lẹ̀ wí pé kò mọ ohun tó ń ṣe mọ ilée wèrè ilée wèrè jẹ́ ilée kan tí ó jẹ́ wí pé oríṣiríṣi nǹkan ni ènìyàn máa ń bá níbẹ̀ àwọn nǹkan bíi pàǹtí sáábà máa ń wà níbẹ̀ àwọn wèrè máa ń sáábà kó àwọn pàǹtí àti nǹkan mìíràn láti ibi tí wọ́n bá ń gbà jọká lọ sí ilée wọn ibẹ̀ dẹ̀...
agboilé ní agbo-ilé yorùbá àtijọ́ àwọn mọ̀lẹ́bí tí wọn kì í ṣẹ́ tí ìyá bàbá àti àwọn ọmọ nìkan ni wọ́n máa ń gbé ní bẹ̀ ọkùnrin tí ó dàgbà jù lọ ni ó máa n jẹ olórí ebí kòsí àníàní pé àwọn ọkùnrin máa ń ní ìyàwó púpọ̀ ní ayé àtijọ́ tí ìyàwó kọ̀ọ̀kan sì máa n ní ìyàrá ti rẹ̀ lọ́tọ̀ wọ́n máa ń kọ́ ilé náà ni onílé pẹ̀tẹ́...
wèrè
ilée wèrè
aba oko aba oko je ibi ti awon eniyan ma n pada leyin ti won bati sise ninu oko lati reju ranpe ati fun jije pelu mimu
arò arò je òun tí a má ń ló lati fi dáná oúnjẹ jíjẹ tí a bá fé kò arò a má ń ló igi gbigbe òkúta èyí tí a má tó pọ̀ tí a ó sì dáná sí òun tí a má ń fi arò ṣe ní ìdáná awọn kan a má kò ilé fún arò àwọn kan á sì má lo gbangba ìta ile wọn lati fi ṣe arò idana ikòkò ní a má ń gbé sí orí aró
àgò àgò dúró gẹ́gẹ́ bí i ìhámọ tí wọ́n fi igi pẹ̀pẹ́ tàbí irin kọ́ a máa ń fi àgò dá àbò bo nǹkan tàbí ènìyàn àgò tún wà fún nǹkan tàbí ènìyàn tí a fẹ́ fi sí ìkáámọ́ a máa ń lo àgò fún ọ̀pọ̀lọpò nǹkan bí i fífi ẹranko tàbí àwọn ènìyàn sí àkámọ́ àti pé àgò ni wọ́n máa ń fí ṣàfihàn àwọn eranko ní ibùgbé-ẹranko-tí-a-kọ́-s...
ile ẹrù ilé ẹrù ni ó jẹ́ ilé tí wọ́n ma ń kó àwọn ǹkan oko sí nígbà tí wọ́n bá dé láti oko sí wọ́n ma ń lo àwọn ilé ẹrù fún oríṣiríṣi bíi ibùgbé àwọn ẹranko ibùgbé ẹṣin tàbí ilé óunjẹ
eran aja nígbà tí a bá pá ajá àwọn ọ̀wọ́ ènìyàn kan wà ní ilé yorùbá tí wọn a má jẹ́ ajá yálà fún ìgbádún ìpanu tàbí fún oúnjẹ ilé léyìn tí wón bá pá ajá tan wọn á ge lẹyìn náà ní wọn má ń yan ẹran rẹ fún jíjẹ tàbí fún títà
ọkọ̀ akérò lórí ilẹ̀ ọkọ̀ akérò jẹ́ ọkọ̀ ọkan lára àwọn tí àwọn ènìyàn máa ń wọ̀ lọ sí ibikíbi tí wọ́n bá lọ àwọn ènìyàn nífẹ̀ẹ́ sí kọ́ ma wọ ọkọ̀ akérò gan-an bẹ́ẹ̀ náà sì ni àwọn ènìyàn máa ń rà á láti fi ma kó èrò àwọn owó tí wọ́n bá rí níbi yìí ni wọ́n máa ń fí bọ́ àwọn ẹbí wọn nílé
mọ́tọ́ọ̀ agbègbè
ilé-ikán ilé-ikán tàbí òkìtì-ọ̀gán jẹ́ ìtẹ́ àwọn ikán tí ó jọ òkìtì tí àwọn ikán tàbí kòkòrò kọ́
òkè kò sí oríkì kan pàtó tí ó wà fún òkè àmọ́ ohun tí a lẹ̀ sọ ni pẹ́ òkè jẹ́ ilẹ̀ tí ó ga jùlọ ní agbègbè rẹ̀ oríṣiríṣi òkẹ̀ ló wà ní ilẹ̀ yorùbá àpẹẹrẹ ni òkè olúmọ ni òkè kan tí ó wà ní ilẹ̀ ẹ̀gbá ìlú abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ ògùn ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà òkè olúmọ jẹ́ ibùsálà fún àwọn ará abẹ́òkúta...
mọ́tọ́ò agbègbè
apẹja apẹja jẹ́ ẹni tí ó ń fi ẹja pípa ati áwọn ẹranko inú omi míràn ṣe iṣẹ́ ṣe
ọkọ̀ akérò