Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
À ń pète Olóko, Olóko ń pète àmọdún.
1
Gbẹdógbédó ti gbèdó tán, ó kú sowọo gbęnugbẹnu.
1
Obìnrin kan àti ọmọdébìnrin tó wà nínú ọkọ̀ tó ní ìjàmbá kú lójú-ẹsẹ̀.
0
Apèjin là á pAwúrelà nljębu. Awúrelà, awo rere.
1
A kì í fi gbèsè sọ́rùn ṣọ̀ṣọ́ .
1
Káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé ni àwọn afurasí arúfin ẹ̀dá wà.
0
Ayò mẹ́ta sí oókan ni a na àwọn tí a kojú.
0
Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ní fásitì ti ṣèlérí pé ìyanṣẹ́lódì yóò tẹ̀síwájú.
0
Àwọn aṣòfín ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti yọ Abẹnugan Ilé bí jìgá.
0
A-pẹ́- -jẹ kì í jẹ ìbàjẹ́ .
1
Ẹni tí ń tan ni jẹ, ò șài gbọn juni lọ.
1
Ẹkún ìyàwó ṣe pàtàkì ní ọjọ́ ìgbéyàwó.
0
A-jí-má-bọ̀ọ́jú: tí ń fi ojú àná wòran.
1
Bí a kò bá ṣe fún ilẹ̀, a kì í fi ọwọ́ sọ ọ́.
1
Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ àwọn ènìyàn ni àjàkálẹ̀-àrùn pa láàárín ọjọ́ díẹ̀.
0
Àì-fẹ́-àlejòó-ṣe là ńwí pé ‘‘ Ọ̀rẹ́ ọ̀rẹ́ -ẹ̀ mí dé’’; ká ṣáà ti wí pé, ‘‘ Ọ̀rẹ́-ẹ̀ mí dé.’’
1
Ẹni iká gbè níí j'Ọba llá (níí jỌrọgún)
1
Ẹyìnkùlé l'ọtá wà, ilé l'áseni ń gbé.
1
Àgbà tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ a lọ́gbọ́n nínú.
1
Àwọn ẹlẹ́rìí níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà ní Adéníyì jẹ̀bi.
0
Așèbàję șe bí tòun là ń wí, așeburúkú o kú araáfu.
1
“Àsejù 'ò pọ!” níí kẹyìn, 'bẹệ ní tíẹ ríí'.
1
Àigbàgbé ní í je ọgbọn.
1
Bákan-náà lọmọ ńṣorí lẹ́hìn ìyá-a rẹ̀.
1
Aláàárù kì í ru ẹṣin.
1
Báwo ni a ṣe lè mọ ohun tí ó yẹ kí a ṣe bí ọ̀rọ̀ bá rí bí ó ti rí yìí?
0
Òṣìyẹmí fi àwọn nọ́mbà ìbánisọ̀rọ̀ síta fún àwọn èèyàn láti pè
0
Wọ́n nírètí pé àwọn agbófinró yóò tú iṣu dé Ìsàlẹ̀ ìkòkò lórí ikú oníbàárà wọn.
0
Adé ti sọ tẹ́lẹ̀ pé àìbìkítà àwọn ẹbí ìyá náà ló pa ìyá òun.
0
Ajerò sọ ọ́ di mímọ̀ pé ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ kò ní yí ohùn rẹ̀ padà.
0
Bí ó bá ku obìnrin láhéré, ìfé ni yóó màa sú l'oodẹ ọkọ rę.
1
Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ Ìbò ti rọ gbogbo ọmọ ilẹ̀ wọn láti padà wá sí ilé.
0
Bíṣọ́ọ̀bù Olúwafèyírọ́pò rí ẹ́wọ̀n he fẹ́sùn ìfipábánilòpọ̀.
0
Àwọn aráàlú ò rí oúnjẹ jẹ.
0
B'éèyàn bá ríkú Ẹfúnjì, kò tún je sęșin l'óore.
1
A-bánigbé-má-mọ̀wà-ẹni, ọ̀tá ẹni ni.
1
Àrokò-ó ti bàjẹ́ láti Iléṣà wá; wọ́n ní kí wọ́n mú ẹrú fún Lọ́wá, kí wọ́n gbé obì fún Ọọ̀ni.
1
Adé fẹran láti máa kawèé lọ́pọ̀lọ́pọ̀.
0
Adete sọrọ méjì, ó fikan purọ. Ò lóun gbá ọmọ òun ní ìkúùkùtítí; ìgbà tínú bí òun, òun tún já a léèkánná kárí-ara. Níbo l'adetẹ ti réèkáná fi já ọmọ?
1
Àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ń fẹ́ kí èrè òṣèlú alágbádá yíká gbogbo ẹ̀sìn.
0
B'ágbàlagbà bá n kun igbe kan bí kò bá jó; idí ę ló ye k0bá
1
Eèwọ; ẹnìkan kì í fáwọ ẹtu j'ógbìn l'ọdọ Òrìșà.
1
Olùkọ́ rere ni ọ̀gá mi Ọlábọ̀dé ní Fáfitì Èkó.
0
À-ró-kanlẹ̀ laṣọ ayaba; à-wà-kanlẹ̀ ni ti yàrà.
1
Adìẹ ìrànà náà tóbi dáadáa ìyẹ́ rẹ̀ náà sì funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú.
0
Ẹni àkọ́kọ́ tí àrùn náà pa kú lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀.
0
Bí a bá bu omi sórí, ó ń wá ẹsẹ̀ bọ̀.
1
Àwọn alágbàtọ́ ló ń ṣe èyí tó pọ̀ jù níbi títọ́ ọmọ.
0
Àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ṣe ìgbésẹ̀ máṣàfira lọ́jọ́ Àìkú.
0
Bí ojú alákẹdun ò dá igi, kì í gùn ún.
1
Mákindé àti bàbá rẹ̀ ti wà ní akóló àwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ní ìpínlẹ̀ Ògùn.
0
Alábàárù kì í wẹ àwúre.
1
A kì í rí búburú lẹ́hìn Agà.
1
Àwọn àṣìṣe lè wáyé láti ipasẹ̀ ẹ̀rọ.
0
Akíntúndé kò ní bàbá ìsàlẹ́ nínú òṣèlú.
0
Ẹni tí 'ò dani lókòwò, tí ò yáni lówó șișę, bó búni, à á bu u. Bós'ọrọ tí 'ò tẹni lọrùn, kí á sọ fún un.
1
Kété táwọn olùdíje kan ti ṣàkíyèsí bí nǹkan ṣe ń lọ lọ́jọ́ ìdìbò ni wọ́n ti lahùn.
0
Ẹni à ń wá lọ, ọnà là á kò ó.
1
Agbófinró ti gbé òkú géńdé náà lọ sílé ìwòsàn ní Yábàá fún àyẹ̀wò.
0
Bí ògbó ẹni ò bá dánilójú, a kìífigbárí wò.
1
Àjò kì í dùn kódídẹ má rè Ìwó.
1
Ẹfẹ dẹfẹ ìyàn; gbá mi létí kí n gbèrú isu.
1
B'éèyàn 'ò șe fùnlẹ; kó leé r'ọwọ fi sọ ọ.
1
Ọ̀gá ọlọ́pàá kò mẹ́nu bà á bóyá wọ́n gba ẹlòmíràn sílẹ̀ nínú àwọn arìnrìn-àjò yòókù.
0
Àwọn ènìyàn kan gbà pé olóògùn paraku ni Adéyẹmọ Ìgbòho.
0
Eré Álápà bó șe dára tó, imú rẹ tungunnu ló bà á jẹ.
1
Àgbà kì í ró kádún.
1
Lára ẹ̀sùn tí wọ́n tún fi kan àwọn ọlọ́pàá ni pé àṣìta ìbọn lè ba àwọn ọmọdé.
0
Ẹ sọ fún Bọ́lá pé kó sòótọ́ fáráyé gbọ́.
0
Bí èèyàn bá ní kò seni tó òun, ẹ pé kí ó gbé Orò lọ sí Ìjan.
1
Ìpínlẹ̀ Èkó ni yóò jẹ́ olùgbàlejò ìdíje.
0
A kì í ṣe méjì ní M kà: a kì í kírun ní Mẹ́kà, ká tún nájà ní Mẹ́kà.
1
Àgbò kì í șièrè k'ó má m'ojú eléèrí.
1
Àyìnlá sọ pé àwọn ti ọjà màlúù pa láti lè dáàbò bo àwọn aráàlú.
0
A-ríre-báni-jẹ, àgbọ̀n ìsàlẹ̀; òkú kú láàárọ̀, àgbọ̀n-ọ́n yà kó tó dalẹ́ .
1
Màríà sọ ìrírí rẹ̀ nígbà tó ń bá ìwé ìròyìn Elétí-ọfẹ sọ̀rọ̀ nípa ìrìn-àjò rẹ̀.
0
A kì í ș'oore tán kí a lósòó tì í.
1
Alájàpá ò lẹ́ran láyà.
1
Ìjà tó ń lọ lọ́wọ́ ti gba ẹ̀mí àwọn ènìyàn irínwó.
0
Kò dára kí àbùkù kan ẹni tó ti nìyí tẹ́lẹ̀.
0
A kì í f'orí-ade bale fenikan.
1
Àwọn tó farapa níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì ń pè fún ìrànlọ́wọ́.
0
Akọ̀wé Iléeṣẹ́ kẹ̀kẹ́ ló fi tó àwọn agbófinró létí nígbà tí àwọn jàǹdùkú wọ ṣọ́ọ̀bù rẹ̀.
0
Àfi ohun tí a kì í tà lọ́jà lẹrú kì í jẹ.
1
Àlááfíà tó péye ni àkókò àlááfíà tó pẹ́.
0
Àlùfáà àgbà ìjọ Ìràpadà ti Kírísítì ni Adébóyè.
0
A ò fẹ́ kí ẹ̀jẹ̀ ọmọ náà wà ní ọrùn wa nítorí a mọ̀ pé kò dáràn.
0
Bọ́lá ra ife oníke titun fún àbúrò rẹ̀.
0
Àwọn afurasí náà jẹ̀ olùgbé ìlú Bàbáńlá.
0
Ėérí là á wẹ, kò s'éèyàn tó ń wẹ ilara.
1
Asínrín ni ìkandù (Ìkamọdù) ń rùn.
1
Ẹgbèrún mẹta làwọn ará ìlú yóò máa wọ ọkọ̀ ojú irin.
0
A kì í gbà lọ́wọ́-ọ ‘‘Mé rì í.
1
Bí a kò bá tí ì jókòó, a kì í nasẹ̀.
1
Adéwuyì ní àwọn ma ri dájú pé àwọn tilẹ̀kùn mọ́ àwọn àgùntàn wọn ní alaalẹ́.
0
Bí ìgbá ò so kúdu-kùdu, kí lọmọ ẹrankó ó jẹ?
1
Dùndún fọ̀ràn gbogbo ṣàpamọ́ra.
1
Àìfinipeni, àìfèèyànpèèyàn lará oko-ó fi ńsán ìbàǹtẹ́ wọ̀lú.
1
A gbọ́ wí pé Òkìkíọlá kọlu ọlọ́pàá kan tí ó sì ṣe é léṣe.
0
Àǹfààní ńlá ni ìfọwọ́sowọ́pọ̀ náà yóò jẹ́ fún àwọn méjèèjì.
0