Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
‘‘Mo ti wí?’’ ‘‘Bẹ́ẹ̀ lo wí!’’ Ẹ̀ẹ̀kannáà làwọn méjèèjì ń gbẹ́nu sókè.
1
Àwọn aláṣẹ ilé-ẹ̀kọ́ fásitì Èkó ti ṣe àgbékalẹ̀ tuntun.
0
Ẹsín tí wèrè yóò se ni kì í jẹ kí wọn kú ní rèwerèwe.
1
A dúpẹ́ pé àwọn elétò ìlera ti gbà láti dá ìyanṣẹ́lódì náà dúró.
0
Ìjọba fowó kún owó ìná fáwọn èèyàn tí nǹkan kò ṣẹnuure fún ní Nàìjíríà.
0
” Ebi kì í jé a pawó àná mọ.
1
Eyìn l'ọgbọn ti ń wá.
1
Ẹbọ díẹ̀, oògùn díẹ̀, ní ń gba aláìkú là.
1
Gbogbo wa nìșòwò-ògún, bẹja bá sọ lódò a mọye tó tó.
1
Ìjà bẹ̀rẹ̀ láàárin àwọn ikọ̀ ọmọ ogun méjì.
0
Adelé Gómìnà bá àwọn tí wọ́n pàdánù èèyàn wọn sínú ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún kẹ́dùn.
0
Èèyàn ló ń j'Áníbiírì, Ọlọrun 'Ò rebìkan.
1
Wọ́n jù ú sílẹ̀ láti máa bá tirẹ̀ lọ nígbà tí kò sí ẹ̀rí kankan.
0
Gbà-ràn-mí dẹlẹrù, ajínifẹ dọkọ ẹni.
1
B'éji ó ó tiẹ pani, a b'ásọọrè l'ára ẹni.
1
Àwọn àgbẹ̀ ni igi lẹ́yìn ọgbà orílẹ̀-èdè.
0
Àlááfíà ti dé bá igbákejì ààrẹ báyìí.
0
Àwọn ìlúmọ̀ọ́ka tó ti jọ́sìn ní ijọ olùṣọ́ ni wọ́n gbàá sílẹ̀.
0
Ara 'ò niwọfà bí onígbowọ, abánikówó ľ'ara ńni.
1
Àwọn aráàlú wí pé olórí ọ̀dọ́ ìlú leku ẹdá ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù Baálẹ̀ ọkọ ìlú.
0
Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ wà láàárín àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò agbègbè tẹ́júoṣó.
0
Bíkàn bá s'oríkodò, aa wewù-eję.
1
Ìjọba buwọ́lu ṣíṣe Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn tí yóò bójútó irinṣẹ́ tí wọ́n ń lò ní pápákọ̀ òfurufú.
0
Ó yẹ kéèyàn sá bí wàhálà bá ń bọ̀.
0
Èdè gbogbo la gbọ, a kò gbọ Yorùbá bọrọ.
1
Àmì ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ tí Tóbi gbà jẹ́ ohun ìwúrí.
0
Àwọn òsìsẹ́ lọ ṣe àyẹ̀wò lóri bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ó ṣe máa lo káádì ìdánimọ wọn.
0
Bí kò bá tíì rẹ ìjà, a kì í là á.
1
A kò lè sọ bóyá olósèlú ló ní ọkọ̀ ńlá tó kó ìrẹsì wá sí ìlú wa.
0
Ọmọ Balógun sọ pé bàbá òun sọ fún òun pé obìnrin ṣòro láti ṣẹ̀
0
Ìjàmbá ọkọ̀ wáyé nílùú Àkúrẹ́ láàárọ̀ ọjọ́ Ajé.
0
Àjíún bẹ́ dìde nígbà tí ó gbúròó ẹsẹ̀ àbúrò rẹ̀.
0
B'ébi bá ń pawo, iyà a je ogbẹrì lápojù.
1
Alátìíkè kì í gbélé, ẹni tó ń w'ọmọ kì í sùn.
1
Àìjẹunsùn àkàlàmàgbò, a ò lè fi wé ti àtíòro.
1
Àwọn òṣìṣẹ́ alágbàṣe mẹ́ta ti kó sí páńpẹ́ ọba.
0
Ẹlẹrù lò kọkọ ń kọfẹ, kí a tó bá a gbè e.
1
Kò yẹ kí ìran òde-òní má mọ ìtàn Eégún Mọgají.
0
Ẹni fẹ jẹ moonmọnon, ó gbọdọ se tìítìí.
1
Ajóbíewé ló fẹnu ara rẹ̀ sọ èyí.
0
Àlejò tó wọ̀ nílé-e Pọ́ngilá, Pọ́ngilá ní, ‘‘Ìwọ ta ni?’’ Àlejò-ó ní òun Bugijẹ; Pọ́ngilá ni, ‘‘Tòò, lọ́ dájú igi-i tìrẹ lọ́tọ̀.’’
1
Àjọ elétò ìlera sọ pé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì ló nílò.
0
Bí ẹnikẹ́ni bá fi gba tòsí ọkùnrin yìí kọjá ni yóò fi àdá lé wọn.
0
Agbada ní í kọ àgbàdo ní títa.
1
Àlùfáà tó ń yọlẹ jẹlẹdẹ jàre (rẹ), ìwọnba lòfin 'má se' ń mọ.
1
Owó tí àwọn òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ búrẹ́dì lu ọ̀gá wọn pọ̀ débi pé wọn kò lè ṣe ìṣirò rẹ̀.
0
Àwọn oníṣẹ́ ìlera ṣe ìwọ́de lórí àìsan owó oṣù wọn.
0
Bíná bá gorí òrùlé; a fejú toto.
1
Àwọn ẹ̀sùn nípa ìwà ìbàjẹ́ tí àjọ náà gùnlé ni wọn yóò ri i pé wọn yanjú rẹ̀.
0
Arákùnrin Tolúlọpẹ́ gún alámùúlégbè rẹ̀ pa nílùú Èkó.
0
Ayé lẹ́yín báhọn bẹnu; bérìgì.
1
Ẹsọ, ẹșọ làgbàlagbà fi ń rìnrìn ọgànjọ, torí kó má baà subú.
1
B'ódídẹrẹ bá se hàà! Aya rẹ a șe hòo!
1
Èló ni owó ilé ní Akọkà?
0
Onídàájọ́ ní kí àwọn afurasí méjèèjì lọ fi ẹ̀wọ̀n oṣù méjì-méjì gbára.
0
Àpá kò jọ àwọ, ojú-ọgbẹ kò le è jọ ojú-ara.
1
Bí a kò bá forí sọ, a kì í mọ ìrẹ̀-ẹ́ bẹ̀.
1
Alukoro ọlọ́pàá fi kún un pé ìwádìí ṣì ń tẹ̀ síwájú lórí ọ̀rọ̀ náà.
0
Àbàtàbútú ojú ọ̀run ò hu koríko.
1
Àlejò șòròó șe níyàn.
1
Kò ní sí ààyè fún àtúnṣe bí ìwé yìí bá fi dé ọ̀dọ̀ ọ̀gá àgbà.
0
Apárí ní ń fojú di abẹ.
1
Òkìkíọlá sọ pé arungún ni ìyàwó òun bó ṣe kọ̀ láti bímọ fún òun.
0
Àhésọ pátápátá ni ọ̀rọ̀ tí àwọn kan ń sọ pé òun fẹ́ pa èèyàn púpọ̀.
0
Ęgbẹ eni làá gúnyán ewùrà pè.
1
Bí a bá ń kí àgbàlagbà pé wọn kú etọ-ìlú,ó yekí a kí olóde p won kú òde.
1
B'ọbùn 'ò tiẹ mèrè, ó yẹ k'ó mojú-owó.
1
Olálẹ́yẹ Àdìó àti àwọn mìíràn ni onígbọ̀wọ́ fún àwọn agbésùmọ̀mí.
0
A kì í ṣìpẹ̀-ẹ ‘‘Nàró’’ fábuké.
1
Èérí là á wẹ, ẹnìkan kì í wẹ ìrira.
1
Àwọn aráàdúgbò tún fìdí orúkọ awakọ̀ àná múlẹ̀.
0
Ení ń gb'eyinkùnlé ń reti ohùn; ó n b'ara re nínú je.
1
Eji wẹ́rẹ́-wẹ́rẹ́ ní ńlé ọmọ wọlé; àgbàrá òjò ńlá ní ń mi ọ̀gọ̀rọ̀ tìtì lẹ́sẹ̀.
1
Àìmọye ìgbà ni Aláàfin àná fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn sí Ògúndépò.
0
Fákẹ́yẹ sọ wí pé òun rí Rìnsọ́lá nígbà tí ó ń bọ̀ láti ibi iṣẹ́ ní alẹ́ ọjọ́ náà.
0
Àṣìta ìbọn ti sọ ọkùnrin alágbe kan di èrò ọ̀run lójijì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.
0
Èkúté ilé ò lẹ́nu bá alákàá wíjọ́.
1
Wọ́n ti kó òkú àwọn ọmọdé náà lọ sí itẹ́-òkú.
0
Àwọn ènìyàn ń ké ìrora káàkiri gbogbo orílẹ̀èdè àgbáyé.
0
Àwọn ènìyàn ni wọ́n sọ wí pé arákùnrin ọ̀hún máa fi àdá lé àwọn ènìyàn.
0
Àpagbé lOrò ń pagi.
1
Àìkọ́wọ̀ọ́rìn ejò lọ́mọ́ aráyé fi ń fàdá pa wọ́n.
1
Ariwo ilé eni kì í dini létí.
1
Bọ́lá yóò dé orílẹ̀-èdè Faransé nínú ìrìn-àjò tó lọ.
0
Awakọ̀ sọ pé àwọn adigunjalè méjì ọ̀hún ṣílẹ̀kùn ọkọ mọ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́.
0
Ajẹ̀bimágbà ní ńkógun wọ̀lú.
1
Ẹni ẹgún gún lọwọ, gún lẹsę ọrọ ẹ gbà'jókòó.
1
B'ómi igbór íbi rógún (dó) sí a ní òun enini.
1
Àwọn ọlọ́kadà kan fara ṣèṣe lásìkò làásìgbò ọ̀hún.
0
A kì í dá ẹ̀rù okó ń lá ba arúgbó.
1
Agbọ́pàá àlùfáà ní ìjọ Kátólíkì ni Ajímọ̀bí.
0
Abuké kú ișẹ dé. Òkú tí kò ní sun ilẹélẹ àforí-igi.
1
Ekòló ń mì gbàgọ̀, inú ń bí adìẹ sùú-sùú.
1
·Bi 'ò bá sí fújà;ki l'olówó ń se tenikan 'ò se!po:;iyán a le.
1
Àmọ́ ọlọ́pàá ọ̀hún bu ọlọ́kadà so, ó sì fẹ́ gba ọ̀kadà lọ́wọ́ rẹ̀.
0
Àkúúkúùlákùnún, ó sàn sẹ àkún-ìyà lọrùn.
1
Bó pẹ tOyòo tí n wọ sílé eni, bí a bá wọ sílé Ọyo náà kò léèwo.
1
Bójú bá se méjì, a wòran rekete. Bèbè-ìdí se méjì wọn a jòkólení,
1
Wọn yóò wọ́ afurasí lọ sí ilé ẹjọ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọdé àti ìbálòpọ̀.
0
Àsékún ni kì í jẹ kí owó ó tán.
1