Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Arìnrìnàjò kan ṣàlàyé bí orí ṣe ko yọ lọ́wọ́ ajínigbé.
0
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ti yan Ọ̀jọ̀gbọ́n Táíwò gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gá àgbà àkọ́kọ́ fún fásitì Ifẹ̀
0
Olùṣírò owó ilé iṣẹ́ búrẹ́dì ọ̀hún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n ṣiṣẹ́ láabi náà.
0
B'Áwúsá bá ní àrùn kan ń șe òun, bí a bá ní o mọ oògùn rẹ, a ábi e pé se àrùn náà se o rí, bí o bá ní kò se ọ rí, yóó pèé kí o fowọ mú oògun rẹ náà.
1
Àṣeyọrí ìjọba ṣe pàtàkì sí gbogbo àwa ará ìlú.
0
Àì-mọ-orín-ín-rùn kọ́ làṣá fi pọ́n léhín; Ọlọ́run ló ṣẹ̀dá-a rẹ̀ bẹ́ẹ̀.
1
Ó sọ wí pé àwọn rí i dájú pé gbogbo rẹ̀ di eérú kí àwọn tó kúrò níbẹ̀.
0
Atàgòkęyin aparo, ohun toju wa lojú rí.
1
Bíṣọ́ọ̀bù náà sọ níwájú adájọ́ pé òun kò jẹ̀bi.
0
Dẹ́rẹ́bà ọkọ̀ àjàgbé dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run pé àwọn ènìyàn ti kúrò ní mọ́ṣáláṣí.
0
Àkẹ́jù tí ń ba ọmọ olówó jẹ́ .
1
B'ádìrẹ ti níyì tó; eyìn ló ń tọ aso-òfì.
1
Àwọn ẹ̀rí máa jẹ́mi nìṣó wà lórí ìfẹ́ ilé-iṣẹ́ náà sí àsà àti ìṣe.
0
Èèyàn a máa ṣìwà hù bí inú ẹni bá dùn ládùnjù nígbà mìíràn.
0
Alukoro ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí sí ojú òpó ìkànnì ayélujára rẹ̀.
0
Bàbá náà sọ̀rọ̀ yìí ní ibi ayẹyẹ àádọ́rin ọdún tí wọń gba òmìnira.
0
Àwọn olùdíje gbọ́dọ̀ fọ̀rọ̀jomitoro fún ọ̀rọ̀ wọn láti ye ara wọn.
0
Ìtọ́jú tó péye yẹ fún ẹni tó bá lùgbàdi àjàkálẹ̀-àrùn.
0
B'áyé bá já kò lónso. Báyé bá ya kò lónrán.
1
Ìbínú hàn ní ojú olùpẹjọ́ bí ó ti tẹjú mọ́ ọn.
0
A kò lè ṣàì má rántí àwọn nǹkan ńlá tí Ọlọ́run ti ṣe láyé wa o.
0
Awọ fẹ́ẹ́rẹ́ bo inú, kò jẹ́ ká rí ikùn aṣeni.
1
Àwọn jàǹdùkú lu akẹ́kọ̀ọ́ Fásitì Ifẹ̀ pa nítorí pé ó jí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ gbé.
0
Báyìí, ìpínlẹ̀ Èkó àti agbègbè rẹ̀ náà ti ń fojú winá ọ̀dá epo.
0
Àṣírí tí ènìyàn bá fẹ́ kó bò ló máa ń bò.
0
Àwọn ènìyàn púpọ̀ bú Gbọ́láhàn lórí ẹ̀rọ ayélujára.
0
Eran.esin níí kúnni l'enu tete.
1
Aríjàmálàjà, ọ̀tá Ọlọ́run.
1
Àgbọ́kànlé ò pani lébi.
1
Àwọn òyìnbó sọ Túndé padà sí ìlú rẹ̀ nítorí ó tàpa sí òfin.
0
Ele òfi bàntì lájé, ibi Opelenge tì ń ș'ayaba lỌrọgidigbà tí n saya agbále.
1
Baálẹ̀ Ìròkò-ó yan tiẹ̀ tẹ́lẹ̀; ó ní bí ẹ rọ́kùnrin ẹ ṣá a; bí ẹ róbìnrin ẹ ṣá a.
1
Awakọ̀ àkọ́kọ́ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ajétọ́mọbí ni ìbọn náà kọ́kọ́ bà, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ló sì kú.
0
Àjàsá ní òun kò ní dẹ́kun láti máa tako àwọn tó bá ń ìlú òun jẹ́.
0
Àgbà to lò ó kan? ó lẹni òun bá bá nílé.
1
Àgbéré laáyán gbé tó ní òun ó jòó láàárín adìẹ.
1
Àwọn ènìyàn ń ké pé inú ewu ni àwọn wà.
0
A kì í mọ ilẹ̀ ọjà-á gbá.
1
Àárín oṣù méje ni àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àti ọ̀mọ̀wé náà gbẹ́mìí mì.
0
Ìjọba sọ wí pé ìyàtọ̀ yóò wà láìpẹ́.
0
Àwọn gómìnà kan tilẹ̀ ń jẹ owó oṣù àwọn òṣìṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ wọn.
0
Bí ó ṣe ń ṣètò ìṣèlú ní ìlànà tó ń kó gbogbo ènìyàn mọ́ra dára.
0
Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn agbègbè náà mọ Tọ́pẹ́ bí ẹni ń mọ owó.
0
B'éèyàn sọro egàn yóó gbọro òdì. Béèyàn sọrọ òdì, yóó gbọrọegàn.
1
Àwọn ènìyàn lè wo fọ́nrán náà ní sinimá.
0
A kì í gbọ́ ‘‘gbì’’ ìràwé.
1
Àṣetán ló níyì; a kì í dúpẹ́ aláṣekù.
1
Adájọ́ ilé ẹjọ́ gíga ìlú Aáwẹ̀ da ẹjọ́ ìgbìmọ̀ afọbajẹ Ọ̀yọ́ nù pátápátá.
0
B'ẹlejọ bá tí ń fẹnu piibo, àfàimọ bí kó bá ti mẹjọ ẹ lẹbi.
1
Àbúrò gàǹgà tó l'óun ó ó ṣíji bo ẹ̀gbọ́n; ara rẹ níí yọ lẹ́nu."
1
Àkosẹbá níí jẹję àmọdún.
1
A kì í dá aró nÍṣokùn; àlà là ń lò.
1
B'áa ș'òwò-Ògún ajá làá ní. B'áa d'ọkọ, à kání.
1
B'okọ bá d'óko a'á rí se.
1
Aláwo á kú; oníṣègùn á rọ̀run; adáhunṣe ò níí gbélẹ̀.
1
A kì í ro rere ká má ro búburú.
1
Ògúnrónbí kò rí nǹkankan rò.
0
Àșeélẹ, òhun làbọáábá. Ẹní șu s'ọnà l'álọ; yóó b'éșinșin lábọ.
1
Èèyàn kì í j'ọmọ Orónnà lásán, bí 'ò bá rugi, áá se'fe lágbo.
1
Wọ́n sọ wí pé àǹfààní tó wà nínú ṣíṣe àwárí epo rọ̀bì ni àwọn fẹ́ jẹ.
0
Gbogbo òkìtì kọ ló ń hu olú-ọgán, ġbogbo ọmọ Olóyè kọ ló ńróyè je.
1
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ.
1
Àwọn ènìyàn kan ò mọ ipa àti ẹ̀bùn tó ni.
0
Ẹledẹ tó bá n jòkú, a kì í tà á sílé.
1
B'órogún ìyá eni bá jùyá eni lọ, ìyá là á pè é.
1
Bàntẹ 'ò kápàá (kájú ìpá).
1
Àbíkẹ́ fi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ sun olùkó rẹ̀.
0
Èsù tó se eèsàn ń bọ wá se ìgbín. Èyí tó se Rótì yóò s'Àbú.Èyí tó ș'òní yóó ș'ọtúnla ọmọ àpá ẹbù.
1
Ahéré mokoó sọ ni kò leè mólè/Ahéré ș'óko má mólè.
1
Ààrùn àìmọ̀ kan ni wọn ló pa ààrẹ tẹ́lẹ̀ náà.
0
Níṣe ni àwọn onítòmátò, aláta, oníṣu á máa kó ọjà wọn lọ́fẹ̀ẹ́ sínú ọkọ̀ bàbá mi.
0
Ilé-ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ni yóò di ṣíṣí ní ọ̀la.
0
Òun fúnrarẹ̀ ló gbójú lé ọ̀nà àlùmọ̀kọ́rọ́yí kan níbì kan.
0
Àwọn ìyáálé ilé jáde síta wọ́n tẹ́wọ́gba ìyàwó tuntun.
0
Bí a bá jẹ ààbọ-ẹkọ kù, Ọmọ ẹni làá fún.
1
Àwọn òbí Àjíún ń gbé Bámgbọ́lá ṣépè ní ọgbà ẹ̀wọ̀n tó wà.
0
Ẹnu tígbìn-ín fi bú Òrìsà yóó fi lọlẹ.
1
Àgbaǹgbá ṣe bẹ́ẹ̀, ó làwo lórí san-san.
1
Eégún mọ ni kí ó tó na ni.
1
Ajírọba àti Asùntọba, ẹnì kan ló máa kọkọ rọba nínúu wọn.
1
Ẹni tọn gbé gun elẹdẹ, ìwọn ni kó yọ mọ; ẹni tọn gbé g'ẹșin ilẹló ń bo.
1
Àwọn tó lọ dìbò ní àwọn ìpínlẹ̀ bẹ́ẹ̀ kò gba gbẹ̀rẹ́ rárá.
0
‘‘Mú wá, mú wá’’ lapá ẹyẹlé ń ké.
1
Bí ọ̀bẹ ò bá mú, òun ìpọ́nrin ni yóò mọ̀.
1
A kì í fi ọ̀nà ikùn han ọ̀fun.
1
Bílíọ̀nù mẹ́rin náírà ni wọ́n máa fi kọ́ kìlómítà ọ̀nà Èkó kọ̀ọ̀kan
0
Bèèyàn bá ju kùmo s'ẹlòmíràn, k'ó máa retí ìdàrọ.
1
Ọ̀gá iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ló pàṣẹ mímú afurasí lọ sí ẹ̀ka ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́.
0
A kì í purọ mọni ká tún máa sẹjú sí ni.
1
‘‘Wá jẹun.’’ ‘‘N ò jẹ.’’ Ó fọgọ́rùn-ún òkèlè tọ́ ọbẹ̀ wò.
1
Bí ọ̀nà-á dé orí àpáta, níṣe ní ń pin.
1
Bí ojú onílé bá mọ tíntín, tí ojú àlejòó tó gbòǹgbò, onílé ní ń ṣe ọkọ àlejò.
1
Ẹsẹ tí kò jẹ ki wọn ó lọ Ìmẹsi-Ìpólé lọ jagun, ó jẹ kí wọn ó lọ siléAwóyemí lo jiyán.
1
Àdá tó dáni l'ójú làá fì ń gbárí tèèkùtèèkù.
1
A-wọ́n-bí-ọgbọ́n, aṣòroódà bí àgbà.
1
Gege-ló-se, aya Olúáwo.
1
Abẹnugan ọlọ́pàá sọ bí ọ̀rọ̀ náà ṣe ṣẹlẹ̀.
0
Èèyàn méjì àti ọpọ ọkọ̀ ló jóná níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ọkọ agbépo tó gbiná.
0
Ẹlẹ́ṣẹ̀ kan kì yóò lọ láì jìyà.
0
A kì í mọ ibi tí à ń lọ kí ọrùn ó wọ ẹni.
1