Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Wọ́n ṣì ń retí èsì láti ọ̀dọ̀ aṣojú ṣùgbọ́n kò tí ì fèsì.
0
Nídìí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ni àwọn ènìyàn mìíràn ti máa ń rí jẹ.
0
Béèyàn 'ò re Mọkà, yóó re Mọkọlá.
1
Bí a kò bá kú lógún ọdún, baba ẹnìkan o lè gbéni sin.
1
Ẹ̀gún ò bẹ́sẹ̀ rẹ́ .
1
Àgbákò gba ẹ̀ka tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ẹjọ́ tó sú yọ lórí ìdìbò sípò ààrẹ nímọ̀ràn.
0
Ẹní bá 'Jẹbú sòwò, ó bárá-ọrun se.
1
Bùkọ́lá sọ wí pé àwọn ń gbọ́ bí àwọn ọkọ̀ ofurufu ologun ṣe ń fò kọjá.
0
Ènìyàn lè yàn ju iṣẹ́ kan lọ ní ìgbésí ayé rẹ̀.
0
Àìsí àtẹ̀gùn lásìkò tí àwọn ọmọdé náà wà nínú ọkọ̀ ló pa wọ́n.
0
Ẹni ebì ń pa, kì í rankùn.
1
Bí a kò bá lè dijú kan ọmọ ẹni níkòó, ojú là ń là sílẹ̀ tí wọ́n fi ń kàn án lọ́mọríodó lórí.
1
Bádé àti Òkìkí kò wá fún ìpàdé ẹgbẹ́ wa.
0
Bá wo ni òrékelẹ́wà Dọjà ṣe jẹ́ sí Aláàfin ?
0
Ahéré o kú iwọ nìkan nínú oko, ẹrù ò bá abà níjù. Ó dijọ kan òjò, k'áhéré tó deleni.
1
Olúkóredé sọ pé kò sí ẹni tó ń gbé inú ilé náà mọ́.
0
Bí ọkùnrín réjò, tóbìrín pa á, à ní kéjò má ṣáà lọ.
1
Awuyewuye ti pọ̀ lórí bóyá Bọ́lá ni ààrẹ tuntun tàbí Abíọ́lá.
0
Àwọn onídúró rẹ̀ yóò dúró fún un.
0
Olúgbọ́n sọ pé ọ̀kẹ̀ àìmọye mílíọ̀nù làwọn ti pàdánù látàrí ikú àwọn màlúù wọn.
0
Àjàkálẹ̀-àrùn tí à ń sọ yìí kò ní àmì kan pàtó.
0
B'éégún ba léni dókè-odò kó máa dúró.Bé ógún ò bá fi dúróòkú ó ó di méjì láàrin omi.
1
Bí a 'ò bá gb'ọmọ mọra, kì í șęgbin síni lára.
1
B'éèyàn 'ò rẹni júbà yóó pòfo.
1
Bíọ́-bíọ́ tí apó ńdá, ọrán ló gbójúlé.
1
Àánú ojú ò jẹ́ ká fọwọ́ bojú; ìbẹ̀rù ejò ò jé ká tẹ ọmọ ejò mọ́lẹ̀.
1
Àwọn ọ̀daràn dojú ìjà kọ àwọn jagunjagun.
0
Owó tí àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ń gbà lóṣù kan kò tó láti gbọ́ bùkátà wọn.
0
Baálé kú, a f'olókùnrùn lédù oyè, ariwo șì kù leyìn ariwo.
1
Eegun tí a so m'ájá ľọrùn, ajá 'ò gbọdọ ję ę.
1
Ọjọ́ Àbámẹ́ta tó kọjá ni ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún wáyé ní ìlú Èkó.
0
Àwọn èèyàn sábà ń di ẹ̀bi gbígbé ọmọ àlè wálé ru àwọn ìyàwó.
0
‘‘Ọba, èmi lẹrú ẹ; Baṣọ̀run, èmi lẹrú ẹ’’; àtọba àti Baṣọ̀run, wọn ò mọ iye ẹrú tí wọ́n rà?
1
Ẹlẹ́dẹ̀-ẹ́ pàfọ̀ tán, ó ń wá ẹni rere tí òun ó fara yí.
1
Àwọn agbófinró tẹ̀lé ọmọbìnrin náà lọ sí ilé wọn.
0
Ẹ pa Ayéjẹ́nkú, ẹ pa Ìyálóde Aníwúrà; ìgbà tí ẹ pa Ìyápọ̀ ẹ gbàgbé ogun.
1
Ẹlẹ́bùìbọn ní àfọwọ́fà wà lára nǹkan tó n fa Àkúfà nílẹ̀ Yorùbá.
0
A kìí ròyìn àbíkú fún lyá-Ìgbẹkọyí.
1
Àmọlà kékeré ò ran Șàngó, omi-ilé ò tó ẹṣin-in wẹ bí kò s'omi-oko.
1
Èèyàn tí ò nítìjú ojú kan ni ìbá ní, a gbórín a tó tẹṣin.
1
Àwọn olùkọ́ mìíràn kò ní iṣẹ́ ṣe rárá.
0
Eti (ni) kì í dàgbà.
1
Ẹlẹ́bùúbọn ní èèwọ̀ ni fún ọba láti gbé Bíbélì dání dípò ifá.
0
Ọ̀nà àbáyọ yìí kò tẹ́ àwọn apá kan nínú wọn lọ́rùn.
0
Abínú ẹní foore ṣegi nígbó; ó ní kẹ́ranko mu jẹ.
1
Agbádá ya lọ́rùn, ó bàjẹ́.
1
B'ẹmìí bá gùn, ọtá ọdún mẹtàdilógún yóó dọrẹ eni.
1
Bá ò bá gbàgbé, ìjọba àpapọ̀ ṣèlérí pé àwọn yóò yá àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lówó.
0
Báwo ni, ṣé kò sí rárá?
0
Àwọn ọlọ́pàá ti ń wá àwọn olè tó jówó kó ní ilé-ìfowópamọ́.
0
Àwọn èèyàn ńláńlá, tí wọ́n nìfọ̀n léèékánná, ni ó ń bá rìn.
0
Ìròrí ọ̀dọ̀ tiwọn ni wọ́n ń gbé wá síbí, wọn ò mọ ìṣòro tiwa.
0
Mákindé ṣàlàyé pé arábìnrin náà ní tébùrù kan níwájú ìta ilé tí ó ń ta pọ̀nmọ́ lórí rẹ̀.
0
B'ọrọ bá débí 'súùú' kádiẹ ó fò ni.
1
Àwọn ìwádìì ìjìnlẹ̀ tó ṣe ràn án lọ́wọ́.
0
Dánpárá kì í mú àgbọnrín, káyùn-ún kì í yún màlúù ľẹsẹ.
1
Ẹnì t'ọn ń wò, kì í wòran.
1
‘‘N óò gúnyán, n óò bùn fún ọ́ jẹ’’; ibi ẹ̀sun la ti ń mọ̀ ọ́. .
1
Àwíjàre Ọlápòjù ni pé ọmọṣléwá náà ló dá gbogbo nǹkan tó ṣẹlẹ̀ sílẹ̀.
0
A kì í ró aṣọ ajé sídìí ká dájọ́ òdodo lẹ́bi.
1
Akọ Ológbò, mówórá.
1
Alàsejù ló ń p'ọkọ ní baba. Èèyàn kì í jọkọ ẹni, kó tún jẹ baba eni.
1
Ẹní burúkú dá ọrọ sílệ ó sá.
1
Bí àwọn ọlọ́pàá ṣe gbé Tẹjúmọ́lá lòdì sí òfin ilẹ̀ wa.
0
Bí a kò kú, a ó jẹ ẹran tó tó erin.
1
Kò sí ẹ̀dínwó lórí àwọn ọjà tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ kó dé láti ilẹ̀ òkèèrè.
0
Aáyán kì í yán ẹsẹ̀ erin; èèyàn kì í yán ẹsẹ̀ irò.
1
A kì í fi awo wé àwọ; a kì í fi àwo wé awọ.
1
Ayé jìn, kò lópin; ibi tí ẹsẹ̀ ò dé lógún ọdún ò lóǹkà.
1
Ẹnu ẹ la wà yìí,'kì í bí Olówó nínú.
1
Agbàdídà a fí ń yan ọmọdé jẹ ni.
1
Èdùmàrè Ló da dídùn mádùn.
1
Ọmọ bíbí ìlú Mọ́dẹdé ni Ràúfù.
0
Adénúgà ń fi owó rẹ ṣe ayé lóore.
0
Ẹran gbígbę kì í ni ìjànjá.
1
Àwọn aṣojú ilé-iṣẹ́ náà ni Lágbájá àti Adékúnlé olórin.
0
Gàmbàrí jẹ díẹ lóbì k'éyín tó pọn.
1
Bí Ṣàǹgó bá ń pa àràbà, tó ń pa ìrókò, bíi tigi ńlá kọ́.
1
A kì í fi àgbà sílẹ̀ sin àgbà.
1
Àìfárí kì í ṣe ọ̀bọ ní túúlu; àìjẹun lèèwọ̀-ọ rè.
1
Ààrẹ Bọ̀bádé késí ẹgbẹ́ náà.
0
Àjẹkùlóko àgbẹ̀ lọba ńjẹ lórí ìtẹ́.
1
Èèlò dun oúnjẹ náà gbogbo ojú rẹ̀ ló fani mọ́ra.
0
Ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ wà kò gba ẹ̀bẹ̀.
0
Ẹgbẹ́ tí Àyìnlá àti Rótìmí dá sìlẹ̀ ni wọ́n ń lò ó láti fi ṣàwàrí ẹni tí ìrìn rẹ̀ kò bá mọ́ lọ́wọ́ alẹ́.
0
Ẹní a pé ó wá wo gọbì, ó ní 'kí nìí gọbi; gọbi yìí?
1
Bí a bá ti lè ṣe là ń wí; a kì í yan àna ẹni lódì.
1
Afọ́jú àjànàkú, kò mọ igi, kò mọ èèyàn.
1
À ń léșu (kasu) kókò ń yí wọ ọ, èlé ni tàbí ènì?
1
B'éèyàn tí ọmọdé ní ìtì-àlàpà, ọmọ náà yóó dúró nídùúró ògiri.
1
A ti gbé ìgbésẹ̀ láti bá àwọn tí ọ̀rọ̀ náà kàn sọ̀rọ̀ láti wá ojútùú sí ìṣòro ọ̀hún.
0
Bí a kò bá pàdé lókè, a ó pàdé lódò.
1
Àwọn agbófinró rí kọ́kọ́rọ́ àdìpọ̀ kan lójúko ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé.
0
Adébáyọ̀ kò sọ pé ko máa hùwà burúkú.
0
Oṣù méje lẹ́yìn oyè ni Ọba Owólabí yan àwọn olóyè ọba.
0
Bí afẹ́fẹ́ bá ń fẹ́, koríko a máa jó.
1
Diędie l'opeeẹ jẹe là.
1
Afẹ̀fọ́jiyán di imíi rẹ̀ ládìrẹ.
1
Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ dé síbi àpérò tí ilé-ẹ̀kọ́ wọn ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.
0
Ààbà ò ṣéé kàn mọ́ ẹni lẹ́sẹ̀, àfi ẹni tí ńṣe búburú.
1