Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Ẹni tó gbọn kì í sę ljọba. (bọ ajá)
1
Àwọn alákoso fásitì Èkó ní kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ má tẹ̀síwájú nínú ìwọ́de.
0
·Gbíngbin eégún-ilé, kòje kerùu gbingbin eégun-oko 'ò bani.
1
Àìlówó Olówu, a ò lè fi wé ti aṣẹ́gità.
1
Akẹ́kọ̀ọ́-gboyè ojósí, Adébísí Adéoyè tí wọlé sí iléèwé gígá ní Èkó.
0
A kì í f'òfófó serí orọ.
1
Bírí lolongo ń yí; a kì í bá òkùnrùn ẹyẹ lórí ìtẹ́ .
1
Bí a bá ń bú etù, orí a máa rawó. (ro awó)
1
Aṣèyìí ó wù ú lọlọ́run, dákún má ṣe búburú fáwa.
0
Kò ní pẹ́ tí ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó yóò fi máa múlele lórí àwọn aláìgbọràn tó ń gba ojú-irin.
0
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ.
1
Àìná halẹ̀ mọ́ baálé rẹ̀ pé tí ó bá fẹ́ ìyàwó kejì òun máa gún pa.
0
Òṣìṣẹ́ kan lè máa gba ẹ̀bùn náà bí ó bá ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ bí ó ti yẹ.
0
Bí ọwọ́ bá tẹ ẹlòmíràn tó hu ìwà mìíràn ni a tó lè gbàgbọ́.
0
Ọláfisóyè ṣàlàyé pé òun wà nítòsí nígbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún wáyé.
0
Baba sọ̀rọ̀ lórí ìgbà tí ìsìnkú Òrìṣàbùnmi yóò wáyé.
0
Ilé alájọgbé kan ni Tolúlọpẹ́ ti gún alámùúlégbè rẹ̀ pa.
0
B'ọde ti lè wù ó lóògùn ìgbẹ tó, onífèrè ò ní jẹ ó m'ẹran délé.
1
·Bía bá fetísí ohun ayé n wí, a ó bàá kòríkòsún eni módì.
1
Ayẹyẹ ìfinijoyè àwọn ọba aládé ìpínlẹ̀ Oǹdó yóò wáyé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta.
0
Ìgbésẹ̀ yìí wáyé lẹ́yìn ọjọ́ méjì tí adarí ẹgbẹ́ kọ̀wé fi ipò rẹ̀ sílẹ̀.
0
Èèyàn búburú ba èèyàn rere jẹ́ .
1
Awọn ikọ̀ tí ó wà ní agọ́ ọlọ́pàá Ìdí Ayùnrẹ́ ló wá yọjú sí agbègbè ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti ṣẹ̀.
0
Bákan náà ni àwọn méjèèjì ṣe máa ń jẹun.
0
Alágbàro kì í gbin ọgẹdẹ.
1
Gbogbo àwọn ọmọ-bíbí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ni wọ́n ń gbé sàdáńkátà fún lórí ìbò tí ó kọjà.
0
B'ẹwàa Șàngó 'ò bá tètè jiná kì í s'enu Onibàtá la ó ti gbọ o.
1
Àyinfo làá yìnkòtó.
1
Adébóyè ní kí a máa gbàdúrà fún Nàìjíríà.
0
Ọkọ Fúnmiláyọ̀ kì í ṣe ọkọ gidi rárá nítorí kò tọ́jú rẹ̀.
0
Àwọn aláṣẹ ìjọba ìpínlẹ̀ sọ pé àwọn kò gbúròó wọn rárá nínú igbó.
0
Kò fi bẹ́ẹ̀ sí àwọn ènìyàn púpọ̀ lójú pópó ní ọ̀sán òní.
0
A ti oko ìroko de oko ìrokòtò.
1
À ń fọ̀tún t ní, à ń fòsì tú ṣòkòtò, obìnrín ní a kò bá òun gbọ́ tọmọ.
1
Àjàlá, ta ní nà ọ́? Ìwọ náà kọ́ un?
1
Filà l'obìnrin, kì í bánií wọ abẹ ìtí.
1
À-bí-ì-kọ́; à-kọ́-ì-gbà; òde ló ti ń kọ́gbọ́n wálé.
1
Ayọ̀ àyọ̀jù làkèré fi ń ṣẹ́ nítan.
1
A kì í fisó gíńngín bàdí ję.
1
Àkísà tí wọ́n máa ń fún àwọn obìnrin ni láti fi dí ẹ̀jẹ̀ tó ń dà.
0
A kì í fi àìmọ̀nà dá pàdé-ǹ-pàdé.
1
Ẹni dán an wò, á á dán an tán.
1
Àwọn oníṣègùn ti gba àwọn èèyàn níyàjú láti máa ṣe àyẹ̀wò.
0
Ààrẹ rọ àwọn ọ̀dọ́ kí wọ́n máa gbé pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ àlááfíà.
0
Àwọn mọ̀lẹ́bí òkú ti lọ yẹ̀ ẹ́ wò ní nǹkan bí ọ̀sẹ̀ mẹ́ta sẹ́yìn.
0
Bí a bá finú wenú, a b jewo. (je iwo)
1
Àṣá wo ìgbín kọ̀rọ̀; ìkaraun-un rẹ̀ ò jẹ́ kó gbé e.
1
Elédùà gbà fún àwọn òṣèré Yorùbá.
0
Ọ̀gá ọlọ́pàá rọ àwọn ará ìlú láti gba ẹ̀mí ìfẹ́ láàyè láàárín ara wọn.
0
Àyúnbọ̀ lọwọ́ ń yún ẹnu.
1
Baálẹ̀ àgbẹ̀-ẹ́ ní òun ò ní nǹkan-án tà lọ́run, kí owó ọkà òún ṣáà ti pé.
1
Àìmọ̀ọ́jó ni kì í jẹ́ kí àlejò ó jó.
1
Ẹlẹ́rù ní ń gbé ẹrù ká tó ba ké ọfẹ.
1
Ẹ̀kọ tí kò bá léwé làgbà ń gbà.
1
Ìfẹ́ àti-ṣiṣẹ́ tí àwọn olùkọ́ ní ni ó ṣì ń mú wọn wọ yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́.
0
B'éti 'ò gbo yìnkín, inú kì í baję.
1
Bí a bá bá aṣiwèrè gbé, a ó gba odì ọlọgbọ́n; bí a bá bá ewé iyá ṣọ̀tẹ̀, a ó ṣẹ ẹlẹ́kọ.
1
Adàgbàkọlà; ríré níí ré.
1
A kì í toríi pé a mọo jó, kí a mú rùkẹrẹ kúrò l'ágbo relé.
1
Ajá siàn tó fi d'éyín, àgbò siàn tirọrọ tirọrọ. Ajá òyìnbó siàn ó ku atisode.
1
Gbogbo àwọn ọmọ náà làwọn jàǹdùkú kó pátápátá láì ṣẹ́ku ìkankan.
0
Àwọn ọ̀dọ́ ní láti bọ̀wọ̀ fún àwọn àgbàlagbà.
0
Bí ẹkọ́ bá ní kókó, kì í ṣẹjọ́ alágbàdo.
1
B'Ọlọrà 'ò bá ì tíì f'ojúrinjú pẹ l'Ólójùdó ní í pe ara rẹ l'Ọlọjà.(loba)
1
Àrùn tí ńṣọ̀bọ ò ṣegún: igún pá lórí; ọ̀bọ́ pá nídìí.
1
Báa yó làá règbọnse, ta ní ję su lójú ebi!
1
Àgbà ò sí nílùú ọ̀kẹ́rẹ́ .
1
Díẹ̀-díẹ̀ nimú ẹlẹ́dẹ̀ fi ń wọgbà.
1
Àwọn agbófinró sọ pé eré àsápajúdé ló ṣokùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ọ̀nà márosẹ̀ Ìjẹ̀bú-òde.
0
Àlọ la rí; a ò rábọ̀.
1
Adékúnlé wòye pé kìí ṣe Tinubu nìkan ló jẹ̀bi ọ̀rò tó ń lọ.
0
A bími l'Ékòó ò dowó.
1
Ìtumọ̀ tí ènìyàn bá fún ìṣẹ̀lẹ̀ kì í sáábà rí bí a ṣe lérò.
0
B'ọpọlọ bá f'ẹyìn lele nnkankan ló ń se é.
1
Igbó tí wọ́n gbà lọ́wọ́ àwọn arákùnrin méjì ọ̀hún tó odidi ilé kan.
0
Púpọ̀ nínú àwọn ọmọdé òde-òní ni kì í jẹ oúnjẹ òkèlè.
0
Àwọn agbésùnmọ̀mí tún n gbọnwọ́ èkuru sínú àwo táńganran.
0
Wọ́n ti kó òkú èèyàn méjì lọ sí ilé ìwòsàn ìlú ìlarò fún ìtọ́jú.
0
Kò sẹ́ni tó mọ kókó ohun tí àwọn jàǹdùkú agbébọn náà fẹ́ gbà.
0
Ìgbìmọ̀ afọbajẹ Ọ̀yọ́ fẹ́ kí ìjọba ṣe ètò gbogbo láti gbé Aláàfin tuntun gorí ìtẹ́.
0
Àkàlàmàgbò má yọjú ọrẹe mi, ojú a á túnra rí.
1
Ọmọdékùnrin kan ti di ọ̀gá àgbà tuntun.
0
Àwọn agbófinró ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí kíákíá lórí ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣekúpani ilégbèé Fásitì Ifẹ̀.
0
Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ sọ wí pé ariwo lásán ni gbogbo nǹkan tó ń lọ nínú ààfin.
0
A bu omi lámù a rí eégún; kí ni ẹni tó lọ sódò lọ pọnmi yó rìí?
1
Afàìmọ̀ kí àwọn aṣòfin àti ìjọba Èkó má tẹsẹ̀ bọ ṣòkòtò kan náà pẹ̀lú Gómìnà.
0
Àwọn eré-ìdárayá wà lóríṣìíríṣìí fún àwọn àkàndá ẹ̀dá.
0
Ogun tó ń lọ́wọ́ ní ìlú Súnmọ́mi ti tó oṣù mẹ́ta báyìí.
0
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ajíṣafẹ́ kò sọ pé ìṣẹ̀lẹ̀ náà kò wáyé.
0
Àlejò tí kò wá là ń pa àgbà àgùntàn dè.
1
Ọjọ́ mẹ́ta ni wọn yóò fi kó àwọn ènìyàn kúrò.
0
Aláàfin ikú bàbá yèyé ti filẹ̀ ṣaṣọ bora.
0
Bí Tàfá bá jẹ olórí àwọn jàndùkú, kò sí ẹni tí á lè kojú ẹ̀.
0
Ajedé kì í je'kan simi.
1
Bíșẹ 'ò bá le; a kì í bẹ ọwẹ tì í.
1
Abẹ́rẹ́ ajẹsára yìí ní ipa ńlá láti mú kí ìfúnpá àti ìtọ̀ ṣúgà èèyàn wá sílẹ̀.
0
Bí a kò bá jà a kì í rẹ́ .
1
Ẹșín rógun jó, ọkọ r'ógun yo sęsę.
1
Bí a l'ọgbọn nínú bí a bá kọ tá ò lò ó ńșe làá dọgbẹrì súù. Bí a sì l'ágbára, l'ókun, bí a 'ò lò ó; ọlẹ lẹnlẹ là á dà.
1
Eégún ò na obìnrin lágọ̀; obìnrín tú kíjìpá ìdí-i rẹ̀, ó fi na eégún.
1