Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Àwọn èèyàn máa ń bu iyì fún àwọn ọba aládé.
0
A kì í lẹ́ni ní Mọsàn ká mu ìgán.
1
‘‘Bùn mi n bùn ọ’’ lọ̀pọ̀lọ́ ń ké.
1
Modúpẹ́ ni abẹnugan fún àjọ àgbáríjọpọ̀ òṣèlú.
0
Enu asosokọ kì í tọrọ.
1
Ẹgbẹ́ òṣèlú Onígbàálẹ̀ sọ wí pé ìlànà ìdìbò tààrà làwọn fẹ́ lò lọ́wọ́ yìí.
0
Àro ń purọ, kò tó tỌdọfin. Àró lóun gbọndò òun p'Òdù-Ọyà.Ọdọfin, l'oun kun pápá, òun p'ẹja ńlá, bí apá, bíi itan. Ọdọfin ní eja se dé pápá ni Mẹsùn- àgbò? Àró ni Òdù-Ọyà se dòdò níMoláoke?
1
Ọkọ̀ àjàgbé tó sọ ìjánu rẹ̀ nù yà wọnú mọ́ṣáláṣí kan.
0
Akínkúnmi ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìwé rẹ̀ tuntun kan.
0
Awọ ẹnu ò ṣéé ṣe ìlù.
1
Ẹni tí 'ò jẹ gbì, kì í kú gbì.
1
Wọn kò lè kéde pé ẹnikẹ́ni ló wọlé àyàfi kí ó bá ní ìbò tó tọ̀ nílùú Àbújá.
0
Àgbàlagbà tó w'ẹwù tó kọ jú ẹ sẹyìn, b'ó bá n dára ó wà l'ọrùn ẹ.
1
Àwọn ọmọ Nàìjíríà fapájánú lórí ọ̀rọ̀ ìmọ̀ràn àjọ ayánilówó àgbáyé.
0
Kò sẹ́ni tó lè sọ ohun tó ṣokùnfà ikú ọkùnrin náà.
0
Àwọn ọlọ́pàá ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ti fọn sóde, ti wọn si bẹrẹ si i tọpasẹ kẹ̀kẹ́ náà kiri.
0
Bímpé lúgọ sí ẹ̀yìn ilé láti sá fún iṣẹ́.
0
Kò sóòótọ́ kan nínú ohun tí wọ́n ń sọ fáráyé gbọ́.
0
Eèyàn ki í kọ iwájú, kó kọ eyìn.
1
B'ẹdàá 'ò bá lè pọn koko, ó yẹ kó pọn bàibài.
1
Adágún-omi 'ò gbEre!
1
Wọ́n sáré lọ sí ilé ẹjọ́.
0
Bí a bá ń díje lenu ișę, owọ a máa yáni.
1
Ęyin adiẹ tí ń bẹ lọnà; ilé la fií ke.
1
Ẹ kú iwájú là á k'ára iwájú. Ẹ máa kálọ là á se èró eyin.
1
Ẹbẹ là ń bẹ ayé, ayé 'ò mà fẹ kó yẹni.
1
Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú mi nítorí ọlọ́run.
0
Ṣèbí o sọ pé a máa tún tébùrù rẹ ṣe bí ó bá bàjẹ́.
0
Àyànmọ́ ò gbóògùn.
1
A kì í fi àì-mọ̀-wẹ̀ mòòkùn.
1
Bí a kò ṣe àṣenù, a ò lè ṣe àṣejẹ.
1
Àìmoye ọkọ̀ àti ẹ̀mí ló ṣòfò ní Bẹ́gà nínú ìjàm̀bá ina tó ṣẹlẹ̀.
0
A gbọ́ pé àwọn ọlọ́pàá ìsọ̀rí kìíní ti ìlú Ìjẹ̀ṣà ni wọ́n padà mú Ọládipúpọ̀.
0
Aṣòroófinúhàn bí èké.
1
Àbọ̀ là ń ya ilé ọ̀rẹ́ tí kò wuni.
1
Ààrẹ Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ tí fásitì ni Oṣódẹkẹ́.
0
B'ítọ bábale, itọ a nípa.
1
Alukoro ọlọ́pàá ní ọkùnrin náà kú sí ilé ìwòsàn lórí àìsàn tó ní í ṣe pẹ̀lú kíndìnrín.
0
Àpọ́n sàn ju òkóbó; bó pẹ́ títí àpọ́n yó fẹ̀ẹ́ obìnrin.
1
Ẹní p'ówùú 'ò wíwo iwọn tó fẹ fi tanná ló mú ni.
1
Wọ́n ti fi Fọlọ́runṣọ́ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n títí tí wọn yóò fi parí ẹjọ́.
0
Bí 'ò bá rẹ'jà; wọn kì í là á.
1
‘‘Fọ́ ẹ̀kọ ká jọ mu ú,’’ kò tó ọkọlóbìnrin-ín ṣe ni.
1
Adájọ́ ṣàánú rẹ̀ fún nítorí ẹ̀rí ọ̀rọ̀ tí ó mú wá.
0
Adénúgà kì í ṣe ọ̀lẹ láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀.
0
Ẹni à n sọ 'ò pẹ mùú.
1
Fákẹ́yẹ sọ wí pé ẹ̀rù pé kó máà ba wá fi ọlọ́pàá mú òun lòun ṣe gbẹ̀mí rẹ̀.
0
Àwọn ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ọ̀ọ̀ni Ilẹ̀ ifẹ̀ tuntun nìyí.
0
Owó oṣù tó kéré jùlọ tí ìjọba ń san tẹ́lẹ̀ ti dópin.
0
Wọ́n ti dóòlà ẹ̀mí àwọn èèyàn mẹ́ta tí wọ́n há sábẹ́ ọkọ̀ àjàgbé kan.
0
Wọ́n rí igbó tí wọ́n pọ́n sínú ìwé pélébé gbà lọ́wọ́ àwọn ọ̀daràn.
0
Ataà mi dandan. lyọo mi dandan, ààrẹ èpè.
1
Bí ó ti wù kó pẹ́ tó, olóòótọ́ ò níí sùn sípò ìkà.
1
Àwòdì òkè ò mọ̀ pé ará ilẹ̀ ń wo òun.
1
Ení dé Áámọyo bu llọrin dé.
1
Àwọn ará ìlú ń bẹ̀rù kì àwọn darandaran máà ká àwọn mọ́lé.
0
Ẹni a 'ò fẹ; ààlọ 'ò ràn án.
1
A kì í dára k'á má kù síbìkan. Ibi ó bá kù sí ni ẹ wí.
1
‘‘N óò wọ́ ọ kágbó’’ ẹ̀hìn-in rẹ̀ ni yó fi lànà.
1
Àgbéré àwòdì ní ń ní òun ó jẹ ìgbín.
1
Àró ìká kì í jajá. Ọdọfin Ìká kì í jàgbò.Oníkàámògún kì íjòbúko.
1
Ẹrú 'ò dájo, iwọfà 'ò ta'jà àwìn.
1
Ọ̀gá ọlọ́pàá tí ó mú Fọlọ́runṣọ́ ló sọ̀rọ̀ nípa ìwà rádaràda tí obìnrin náà hù.
0
Eyín lèèkàn ewà.
1
Àdó olóró ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí sekú pa èèyàn mẹ́wàá ní Ìlerọ̀.
0
‘‘Gbà jẹ’’ ò yẹ àgbà.
1
B'éèyàn bá ń mùkùn l'ọgbẹlẹ, e ní kí ó nàyá (nàró).
1
Àkèekèé rìn tapó-tapó.
1
Bìrí bìrí layé ń yí; ìgbà kan ò lo ilé ayé gbó.
1
Àirífà,àirófò, ogba.
1
Bi tálikà 'ò sun; olówó ò leè fojúbá oorun.
1
Adénúgà pé ẹni ogún ọdún láyé.
0
Èèyàn méjì kì í bínú egbìnrìn, bí ẹnìkan bá7dì-enikan a tú u.
1
Ó fẹ́ rẹ Àbẹ̀kẹ́ díẹ̀ tori ńà ni mo ṣe dúró tì í.
0
Ẹlẹ ò j'óbìnrin ó kùtà.
1
Ilé àwọn ẹni tí mo mọ̀ ni mo máa ń lò sí púpọ̀ jù.
0
A fi páńpẹ́ mú u l’Ọ́jọ́bọ̀.
0
Àwọn jàǹdùkú tó padà wá kò bá ẹnikẹ́ni nígbà tí wọ́n dé..
0
Èèyàn méjì kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ tó wáyé ní Òwòrò.
0
Ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan ló sọ fún un pé ọ̀rẹ́kùnrin òun sọ pé iṣẹ́ kan wà.
0
Àìgbọ̀ràn, baba àfojúdi.
1
Agbára odó kò jọ agbára ìkòkò; bí a gbé odó kaná a jó; bí a sì gúnyán nínú ìkòkò a lu.
1
Ìlú Òmìnira yóò bẹ̀rẹ̀ sí í kó àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò ní ọjọ́ Àbámẹ́ta.
0
Òfin kò tako sínsin oríṣiríṣi ẹran àti ọ̀sìn mìíràn nínú ilé ẹni.
0
Àgbólà ni tàgbọ̀nrín; ọjọ́ tí àgbọ̀nrín bá gbó ni ọjọ̀ ikú-u rẹ̀ ń yẹ̀.
1
Abẹ́rẹ́ ò ṣéé gúnyán.
1
Adénúgà ní bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ń fi ẹ̀mí àwọn wéwu nítorí ọwọ́ àwọn ọ̀daràn ni ìlú wà.
0
Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ Yorùbá ni Olóyè Adéyẹmọ.
0
A fi ọ́ jọba ò ń ṣàwúre; o fẹ́ jẹ́ Ọlọ́run ni?
1
Bàtà já'kùn ó dì'kàlę.
1
Àwọn àkàndá ẹ̀dá náà ní inú àwọn kò dùn.
0
Ọmọ Balogun ṣe àfiwé bí àwọn gbajúmọ̀ òde-òní ṣe máa ń nífẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ wọn
0
Ilé-iṣẹ́ ìfọpo rọ̀bì ní agbègbè ọ̀hún ní àwọn ní ìrètí pé epo rọ̀bì yóò pọ̀ láìpẹ́.
0
Ẹgbẹ ayé; ó yá ju ẹgbẹ ọrun lọ.
1
Bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ènìyàn ń kú káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.
0
Bí àgbà kò bá ṣe ohun ẹ̀rù, ọmọdé kì í sá.
1
Gbongbọn mọ ẹni òún kàn.
1
Bí kúkúrú ò gbọ́n, èyí gbọgbọrọ ńkọ́?
1
Àpéjọ àdúrà náà wáyé lásìkò ìgbéyàwó àbúrò ààrẹ.
0
Adéníran ni alága fún ẹgbẹ́ òṣèlú tuntun.
0