Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Ẹnu ya Òjó pé àkóbá ni wọ́n fi ikú awakọ̀ rẹ̀ ṣe fún un.
0
Bí oníṣú bá fi iṣu-u rẹ̀ se ẹ̀bẹ́ , ọgbọ́n a tán nínú a-tu-èèpo-jẹ.
1
Kò sí ẹni tí ó lè sọ ní pàtó ohun tí wọ́n sọ níbi ìpàdé.
0
Àbosę kì í se ișę òòjo, ișę olúwa ęni níi gba odìdì ojo ęni.
1
Aláràjẹ ò mọ ọdún; a biṣu ta bí igi.
1
Abuké sùnkákà bí ẹní ta síná.
1
‘‘Fi ojú kàn mí’’ àna kì í ṣe lásán; bí kò fẹ́ẹ́ gba owó, ó fẹ́ẹ́ sọ nǹkan.
1
Àgùntàn kì í yọ̀wo.
1
Díẹ̀-díẹ̀ leku ń jawọ.
1
Ẹní m'ojú Eji ló ń mú u. Ẹní mojú ljì ló ń rọ ọ.
1
Ìjọba ti kéde ìséde nílùú Súnmọ́mi.
0
Eló lo ní lọwo tó fẹ lọ lọko ní Tedé?
1
Àti kékeré làràmàjà-á ti ń lalé kọ́.
1
A kì í kọ ẹlẹ́ṣin ká tún lọ fẹ́ ẹlẹ́sẹ̀.
1
Abilékọ kan ṣàlàyé lórí ìdí tó fi gb'oyún láti ìta wá sọ́ọ̀dẹ̀ ọkọ
0
Bí a bá torí igi gba odì, a ṣe iná fúnni yá.
1
Bí igí bá wó lu igi, tòkè là ń kọ́ gbé.
1
Eni kòitíì kù,a kì i rí èje e.
1
A kì í tó ara ẹni bá rìn ká má tó ọ̀rọ̀ bá ara wa sọ.
0
Mọ̀lẹ́bí bu ẹnu àtẹ́ lu ilé ẹjọ́, Iléeṣẹ́ ọgbà ẹ̀wọ̀n lórí ikú Táyé.
0
Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣèwádìí ìwà ọ̀daràn náà
0
Àwọn alátakò ń yin ìbọn sí àwọn ọkọ̀ ofurufu tí wọ́n ń fò lọ.
0
Dọ́kítà ní kí ìyá àti ọmọ ti yè ló ṣe kókó jùlọ.
0
Àgbà-ìyà tí ń mùkọ ọ̀níní: ó ní nítorí omi gbígbóná orí-i rẹ̀ ni.
1
Arákùnrin ọlọ́kadà ń du ọ̀kadà rẹ̀ nínú àgbàrá omi.
0
Àwọn ọlọ́pàá yóò ṣe àyẹ̀wò fún òkú Ògúnrónbí.
0
Bádàá 'ò bá l'éèkù nídǐí mọ, a sì d'àlùgbọnńdánrán.
1
Ẹni tí a ó tà, là á bọ.
1
Kò sẹ́nìkan tó mọ ìdí tàbí ohun tó fà á tó fi gbé ìgbésẹ̀ bẹ́ẹ̀.
0
Ebí ń pa ejò, ahún ń yan.
1
Eégún ni baba lọ́run; Pààká ni baba nígbàlẹ̀.
1
Bí olÓrò-ó májá, owó oúnjẹ olówó-o rẹ̀ ló dínkù.
1
Ahe-ìrẹ kì í he tẹgbẹ e.
1
Bíná onílé bá kú, t'olojò làá gbàá tàn.
1
Bí a bá fi dídùn họ ifàn, a ó họra dé eegun.
1
Ilé ìfowópamọ́ ti rí ọ̀nà àbáyọ sí ìwà jìbìtì.
0
Àrò kì í rẹrù kó má sọ̀.
1
Ẹran ló ń gbọjọ-ikú e tó tún ń jewé.
1
·Èrò Ote ki i te.
1
Àtisùn ẹ̀dá ò ṣẹ̀hìn Olódùmarè.
1
Aràrá kì í yin Ọlọ́run, àfi bó bá rárọ tí ń rákò.
1
Mò ń ta àwọn àkàrà òyìnbó yìí àtàwọn nǹkan mìíràn tí ẹnu ń jẹ.
0
Aì í lúweé puro.
1
Ateyin kọgbọn agétí ajá. A gé e létí tán ó lọ n fọbẹ pamọ.
1
A ti fi yé ìjọba pé àwa kìí ṣe àtẹ̀mẹ́rẹ̀ tí wọ́n lè ṣe bàṣùbàṣù.
0
Ęsin ni 'ò tẹșin ni, àbí èèyàn tó gùn ún nì 'ò téèyàn!
1
Ààre lọ kí àwọn ẹbí àwọn ọlọ́pàá tí wọ́n bá ogun lọ.
0
Ẹni orí yọ, ó dílé.
1
Àpèjúwe làgbẹdẹ ń ro.
1
A kì í dé Màrọ́kọ́ sin ẹlẹ́jọ́ .
1
Bíríkòtó, bìríkòtó làá pilẹ àwọn, bó bá d'ókè tàn a gbodó, a gbọlọ; a gbodù kẹnkẹ baba àmù.
1
Akọkọlúkọ ẹbọ ní ń pa igún lẹ́rù.
1
Ọmọ ogun tẹ́lẹ̀rí sọ̀rọ̀ lórí àbá kẹ́ta.
0
Bálàá bá lelálejù;Olú-igbó làá rọ o fún.
1
Kí wọ́n sì má ṣe kún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ lórí ìwà ìbàjẹ́.
0
Adẹ́tẹ̀-ẹ̀ ní òun sẹ́ ọ̀ràn kan de àwọn ará ilé òun; ó ní bí òún bá lọ sídàálẹ̀, wọn ò j fi kàn-ìn-kàn-ìn òun wẹ̀.
1
Bí a 'ò bá já'wé lé Àséwélé, a kì í gba t'ara e.
1
Àkọbí ẹni, àbúrò eni ni.
1
Ajàkàṣù ò mọ̀ bí ìyàn-án mú.
1
Kò sí ìgbéyàwó mọ́ níwọ̀n ìgbà tí kò sí ìfẹ́ mọ́ láàárín wọn.
0
Agbépolájà 'ò ja'lè bí ẹní gbà á l'ọwọ 'ę sílę.
1
Olóyè Ọláyíwọlá Àdìgún ni olórí ìbọ òrìṣà ìlú Ọ̀ṣun.
0
Bída 'ò bá sunàn; kí á ponída kó tún ìda gún.
1
Ibi tó sá pamọ́ sí ni wọ́n ti fín in jáde bí òkété.
0
Atúmálọ̀ọ́yún, aràmáṣèdin, agbẹmánìí-ṣẹ̀ẹ́pẹ́ .
1
Ẹni tí 'ò níyàwó, àna rẹ kì í kú.
1
B'éèyàn bá pẹ ní Badà, yóó je Asípa.
1
B'óti wù k'ọmọ ikókó pé l'ọrun tó, yóó wáyé wá bá iyà tirẹ níbe.
1
A kì í fi títóbi jẹyẹ.
1
Ẹni tí ó fi ọmọ rẹ silẹ àitọ, tí ó ń kọ ọmọ òpiję, Olóko-ẹșin lọmọrẹ yóo dà.
1
Àjọ ìdáwò àṣekágbá gbẹ́sẹ̀ lé èsì ìdánwò àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
0
Bí a bá rọ l'árojù ìyà níí fi í jeni.
1
Àwọn ènìyàn ń pe eré-ìdárayá náà ní ẹṣin gígùn.
0
Wọ́n lu awakọ̀ náà pẹ̀lú ọ̀kan-ò-jọ̀kan ohun tí ọwọ́ wọn bà.
0
Àwọn ènìyàn tó ti sá kúrò níbẹ̀ ti tó ẹgbàá.
0
Awo ní ńgbe awo nígbọ̀nwọ́; bí awo ò bá gbe awo nígbọ̀nwọ́ awo á tẹ́.
1
Gbogbo ọmọge ló mọ'bẹ tí kò ní yọ, mélòó ló mọ'bèé sè nínúu won.
1
Dọ́kítà kan ní iṣẹ́-abẹ kìí ṣe ọ̀nà àbáyọ gbígbẹ̀bí.
0
Adarí ìpínlẹ̀ Èkó gbóṣùbà fún ilé-iṣẹ́ ológun fún ìpèsè àlàáfíà.
0
Ẹkẹ́ òtòṣì kì í tó ilé lówùúrọ̀.
1
Ení ș'ọkò s'órùlé ló fẹ tẹnu oníléé gbọ.
1
Ràúfù jẹ́ apàṣẹ wà á láàárín ọdún mẹ́ta nígbà ayé rẹ̀.
0
Bùkọ́lá sọ wí pé àwọn ti fohùn ránṣẹ́ sí aṣojú tó wà ní Súnmọ́mi.
0
Ẹni a bá gbé là á fìwà jọ. Fúlàní fiwà jo màlúù.
1
Ẹlẹkọo-gbóná ò fiyọ si i tíí fíí wu nií mu.
1
Gbọn-ọngbọn-ọn kan 'ò sí, afi ẹni ń ti ara rẹ.
1
Adìẹ bà lókùn; ara ò rọ okùn, ara ò rọ adìẹ.
1
Abanijẹ́ ba ara ẹ̀ jẹ́ .
1
Èyí ni ó sì mú kí ọ̀pọ̀ sọ wí pé kò sí ohun kan tí ìjọba lè ṣe sí èyí.
0
Àjọ ètò ìlera gbọ́dọ̀ máa polongo ọ̀nà àti gbé ní àláàfíà.
0
Wọ́n ní Dámilọ́lá há nìyẹn bí ó bá fi bímọ fún Òkìkíọlá.
0
Adájọ́ ilé ẹjọ́ gíga pàṣẹ fún ọkùnrin kan pé kí ó pa àkùkọ adìẹ rẹ̀ kí ó tó di ọjọ́ Ẹtì.
0
Àwọn ènìyàn kò dúró mú ìwọ̀nba dúkìá tí wọ́n ní.
0
Eégún tó bá máa d'Orò; áá jẹ k'óbìnrin lo.
1
Àpápá ni wọ́n ti ń gbé epo wá fún ilé-epo náà.
0
Bí a bá nínúu re, ọmọ ọlọmọ ma ń ďọmọ ẹni ni.
1
Bí kò tó ẹ̀rù, kò tó ìsájú?
1
Àyà mi ò já láti bí ìbeji ni Kọ́lá sọ.
0
Àwọn ará ìlú tí ń palẹ̀mọ́ ti ààrẹ tí ó ń ti àjò padà bọ̀.
0
Edá ló ń woșę, Olúwa Ló ń wokàn.
1