Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àwọn ènìyàn lè gbìyànjù ohun tí wọ́n bá fẹ́. | 0 |
Àwọn ọmọdé mẹ́rin ọ̀hún sì wà nínú ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́. | 0 |
Ẹlòmíìran ń fi irú ọyàn wa tọrọ. | 0 |
A-tọ̀run-wáá-dọbẹ̀-síná, eégún-un sálà. | 1 |
Kò sí bí Bọ́lá ṣe lè fa ọwọ́ aago sẹ́yìn nípa ọ̀rọ̀ náà. | 0 |
Adébọ́lá sọ pé kí ilé ẹjọ́ tètè tú àwọn ká. | 0 |
Ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn ènìyàn ni wọ́n kú ní Òṣogbo. | 0 |
Akínigánín, àbùkù l'ára ẹ ló wà. | 1 |
Àwọn iṣẹ́ tí ó ń ṣe ń mówó wọlé fún un. | 0 |
Àdìgún sọ wí pé àwọn òṣìṣẹ́ ààbò yóò bẹ̀ wọ́n wò. | 0 |
Wọ́n fi ẹ̀sùn fífi àwọn ènìyàn ṣe òwò ẹrú kan Adébísí. | 0 |
Dágundágun Kàlètú tí í kán ìbejì lápá-ijó. | 1 |
Akínjídé sọ pé òun yóò ṣe ètò amóríyá. | 0 |
Ẹni ayé ń fẹ, bó f'ewé dewù yóó yẹ ę. | 1 |
Èjìká jìnà ș'ọrùn, igi-imú jìnà sórí. | 1 |
Aláyọ̀tẹ́tí fi ipá bá àbúrò mi sùn. | 0 |
Báa báf'asowásọ, a ó kánná síkan. | 1 |
Fẹmofeyàá; b'ó bá rọjóo rẹ yóó jàre. B'Ọmọ tì ń gba iwájú-iléwọlé, nìya (ẹ) ń gba eyìnkùnlé. | 1 |
Ìbò ti Oyètọ́lá ni yóò pọ̀jù bí àwọn aráàlú bá fẹ́ kí ó máa ṣe gómìnà wọn lọ. | 0 |
Ó ní igbá-kejì Búsàrí ni Yẹmí ń ṣe. | 0 |
Ináọlájí ti ṣíṣe ọmọ ogun fún ọdún mẹ́rìndínlógún. | 0 |
Agbada 'ò gbóná, àgbàdo 'ò ta. | 1 |
Àwọn oníròyìn jábọ̀ rẹ̀ pé àwọn ọmọ-ogun ti lùgbàdi àrùn. | 0 |
Apajájẹ ní ẹ̀rù adìẹ ń ba òun. | 1 |
Ààrẹ yan Adékúnlé gẹ́gẹ́ bi igbákejì ẹni tí ó gbégbáarókè. | 0 |
Eyín-ijobi; bó bá se n d'eyín-ljahùsá; eto ni kéléyín ó fura. | 1 |
Bàbá mi gbà láti fi ọwọ́ kún iṣẹ́ náà láì ka iye tí yóò ná a. | 0 |
Bámgbọ́lá sọ wí pé òun kò fipá bá obìnrin lò pọ̀ rí. | 0 |
Abíọ́dún ti ṣe ìrànlọ́wọ́ ńlá fún mi. | 0 |
Obìnrin kan ṣoṣo ni yóò díje nínú ìdìbò Ìpínlẹ̀ Òndó tó ń bọ̀ lọ́nà. | 0 |
Bùnmi kò lè dìde mọ́ lẹ́yìn tí ṣọ́jà gún un lọ́bẹ. | 0 |
Ẹ ṣàtìlẹ́yìn fún ìjọba tó wà nípò: Abíọ́lá Ajímọ́bi. | 0 |
Ẹni tí kò l'óyún rí, kò lè mọ bí obí se ń tẹni. | 1 |
Àwon ọmọ àti ìyàwó Olóògbé Adébáyọ̀ sunkún níbi ìsìnkú náà. | 0 |
Bí ilẹ̀-ẹ́ bá rorò, tó pa ọ̀wẹ̀, orí olóko ni yó dàá lé. | 1 |
Àǹfààní yìí yóò pèsè àwujọ tó dára fún àwọn tó bá fẹ́ dáṣẹ́ sílẹ̀. | 0 |
Ìjọba ní Olúkàrẹ́ kò gbọdọ̀ kó àwọn ènìyàn jọ sí ààfin rẹ̀ fún ohunkóhun. | 0 |
Ẹkọ tí ò léwé làgbàá gbà. | 1 |
Ìjọba Àpapọ̀ kò ní òye tó kún tó láti bá ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ sọ̀rọ̀. | 0 |
Ìpàdé ìgbìmọ̀ tó wáyé ní ọjọ́ Ajé parí ní ọjọ́ Ìṣègùn. | 0 |
Bí a kò bá lówó aládìn-ín, à jẹun lójúmọmọ, à gbálẹ̀ sùn wàrà. | 1 |
Làmídì ti kéde ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alága ẹgbẹ́ lẹ́yìn ìdájọ́ ilé ẹjọ́. | 0 |
Ẹni ra ni lẹrú; a ìí gbé eé mì. | 1 |
Kò pẹ́ tí àwọn Mùsùlùmí fi mọ́ṣáláṣí sílẹ̀ lẹ́yìn ìrun àárọ̀ ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé. | 0 |
Dòsùnmú ní isẹ́ abẹ náà wáyé. | 0 |
Ení rí akeboję k'ó f'oore se é, torí ojú ló pọn ọn ló se ń kẹbọ jẹ.Akẹbọję 'ò mọ ọ lólè. | 1 |
‘‘Má ta omi sí mi lára’’ kì í dé odò; ‘‘Má fara kàn mí’’ kì í wá ọjà. | 1 |
Àwọn ọ̀daràn mẹ́ta tí ọwọ́ tẹ̀ ti wà lákàtà àwọn àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́. | 0 |
Ení fọ koto-ejò,fúnra rẹ ní yóó gbè e. | 1 |
Àgbà òṣìkà ń gbin ìyà sílẹ̀ de ọmọ-ọ rẹ̀. | 1 |
Oríṣiríṣi ohun ìjà olóró ló wà lọ́wọ́ àwọn ọlọ́kadà náà. | 0 |
Aforó yáró kì í jóró ó tán. | 0 |
Ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò dára púpọ̀ fún ara wa. | 0 |
Ó dà bíi ẹni pé Ojúọlápé mọ̀ pé inú ń bí Jókòótádé. | 0 |
Ẹ máa gbàdúrà fún àwọn adarí wa. | 0 |
A kì í gbé odò jiyàn-an ọṣẹ́ hó tàbí kò hó. | 1 |
Àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ń jà sí ilé kan ṣoṣo tí bàbá wọn kọ́. | 0 |
Ìjọba àpapọ̀ ti kéde àwọn àkànṣe iṣẹ́ tuntun tí yóò bẹ̀rẹ̀ láìpẹ́. | 0 |
Bí alẹ́ bá lẹ́, à á fi ọmọ ayò fún ayò. | 0 |
Àwọn ará ìlú ń kígbe kíkan-kíkan látàrí bí àwọn ọlọ́pàá ṣe ń hùwà. | 0 |
Àwọn ọmọdé tó ń tọrọ bárà ò lọ ilé-ìwé. | 0 |
Kí ènìyàn máa ṣe ohun ìyanu bí ó bá ń fẹ́ ìyanu. | 0 |
A-ṣòro-ó-bini, ìjà àná. | 1 |
Ìgbésẹ̀ tí Gómìnà Adélékè gbé ti di fà-ń-fà-á láàárín àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú. | 0 |
Ajá tún padà sí èébì-i rẹ̀. | 1 |
Ìbàdàn ni wọ́n bí Olúkáyọ̀dé sí. | 0 |
A kì í fi ẹ̀jẹ̀ dúdú sínú tutọ́ funfun jáde. | 1 |
Abanijẹ́ ò níí gbayì. | 1 |
Aká (adẹtẹ) rà kàrà wọn ní kí ó dúró gbènì, ó ní èyí t'óun f'ojú-owó rà, óun tíì r'ọwọ kó o ná? | 1 |
Bilù bà ń dún 'Mà pani, mà pani' mẹlọ-mẹlo là á jo o. | 1 |
Àwọn olùdíje fún ipò gómìnà àti àwọn alátìlẹ́hìn wọn ń fi òkò ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ síra wọn. | 0 |
Ẹni ó gbani nímọràn owó ló yá ni. | 1 |
Kọmíṣọ́nà ọ̀rọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ àti oyè jíjẹ ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn oníròyìn. | 0 |
Bí a bá rántí ọjọ́ kan ìbálé, ká rántí ọjọ́ kan ìkúnlẹ̀ abiyamọ, ká rántí kan abẹ́ tí ń tani lára. | 1 |
Aìkú ni ọjọ́ àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀. | 0 |
F'ara ti mí, ki ń f'ara tìọ bí yèrèpè se ń f'ara ti eèsún. | 1 |
Ìpadàbọ̀ àwọn ọmọ ogun yóò mi gbogbo ìlú tìtì. | 0 |
Adìẹ ń làágùn; ìhùùhù ni ò jẹ́ ká mọ̀. | 1 |
Àwọn ìgbésẹ̀ tó lè mú kí ọmọ àlè wọnú ìdílé pọ̀. | 0 |
Àwọn mọ̀lẹ́bí ọmọ náà ní kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà. | 0 |
Bí a bá f'ọtún p'ọmọ nìgbè (bọmọ wí) kí a f'òsì fà á mọra. | 1 |
Abarapá ti gbogbo èèyàn; òkùnrùn tẹnìkan ṣoṣo. | 1 |
A-bèèrè kì í ṣìnà. | 1 |
Àwọn ìjọba kọ́ ni wọ́n ni owó ìlú. | 0 |
Àwọn òṣìṣẹ́ ẹ̀ṣọ́ ààbò ojú pópó ń ṣe iṣẹ́ àṣelàágùn. | 0 |
Adára-mánìí-șùgbọn kan ò sí. | 1 |
Àdìgún Olówe Yorùbá tó ń pa òwe Yorùbá ọgbọ̀n lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo. | 0 |
·Eni t'ọn n wò kì i wòran. | 1 |
Àwọn ènìyàn máa ń fi owó mọ́ tọkọtaya lórí lásìkò ìgbéyàwó wọn. | 0 |
Àwọn Pásítọ̀ àti Àlùfáà kò lè ya ara wọn kúrò lára àwọn Òrìṣà. | 0 |
Ese kúkúrú nironí. | 1 |
B'éégun bá l'óun ò ri Gonto, Gonto á lóun 'ò réégùn. | 1 |
Àwọn ilé-iṣẹ́ aládàáni epo pẹtiróò ló ń ṣe èyí tó wù wọ́n. | 0 |
Bí ebí bá kúrò nínú ìṣẹ́, ìṣẹ́ bùṣe. | 1 |
Eso níí mẹsin-ín níyì. | 1 |
Iṣẹ́ alágbẹ̀dẹ ni bàbá Àyìnlá Ọmọwúrà ń ṣe. | 0 |
Èké ò ku ni, ìkà ò pé a má là; àmọ ọjọ-àtisùn logun. | 1 |
Ajá tó gbé iyọ̀, kí ni yó fi ṣe? | 1 |
A rí i bó ṣe jẹ́ pé Akínkúnmi ni ó kọ́kọ́ wájà. | 0 |
Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ owó ni wọ́n fi gba àwọn ènìyàn sílẹ̀. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.