Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
A-gbáhéré-yáná ni a-gbénú-oko-yá òòrùn. | 1 |
A kì í gbọ́n ju ẹni tí a máa dÍfá fún. | 1 |
Gbọnìngbọin t'ó dì m'ẹșin l'ọrùn ni 'ò j'ẹșin 'ò jẹko. | 1 |
Ọmọọba ìlú Ìjẹ̀sà ni Adégbémilé ń ṣe. | 0 |
Àwọn ará Òǹdó ránṣẹ́ sí Akérédolú pé kó mú àwọn ìlérí rẹ̀ ṣẹ. | 0 |
Ọmọwúrà tún kọrin bú ni àwọn onínàbì obìnrin. | 0 |
Àkókò tó lò làti fi sáré yanilẹ́nu. | 0 |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn ti bu ẹnu àtẹ́ lu ìgbésẹ̀ tí Gómìnà Adélékè gbé. | 0 |
Ìjọba kò ní fojú sílẹ̀ fún ìwà búburú lásìkò yìí. | 0 |
Gege nirùu esin ń kora won. | 1 |
Bíbí ire ò ṣé-é fowó rà. | 1 |
Bí kọlọkọlọ bá kú, adìẹ ò l'ẹkún-ún sun. Adiẹ kú inú aáyán ádùn,dùn dùn. | 1 |
Agídí páálí òun ìyọnu; akùrẹtẹ̀ òun ìyà. | 1 |
Mi ò mọ̀ pé ẹ̀mí burúkú ti ń wọnú mi nígbà náà. | 0 |
Àyìnlá Ọmọwúrà máa ń fi orúkọ ìyá rẹ̀ ki ara rẹ̀. | 0 |
Adéoríọ̀kín sọ wí pé òun ti ń gbaradì fún ìgbàlejò àwọn ènìyàn láti ilẹ̀ òkèèrè. | 0 |
Abẹ ní ń bẹ orí; oníṣẹ́ àtẹ́lẹsẹ̀ ní ń bẹ ọ̀nà; bèbè ìdí ní ń bẹ kíjìpá; bí a dáwọ́-ọ bíbẹni, a tán nínú ẹni. | 1 |
Ẹgbẹ̀rún ibalùwẹ̀ ò lè tó sánmà. | 1 |
Ẹni bá f'ojú d'Orò, Orò a á gbé | 1 |
Àwọn èwe fẹ́ràn eréepá jù. | 0 |
Àrùn tí ń jẹ́ nárun ò sí; ebi ní ń mú ara-á yi. | 1 |
Adásínilọrùn obìnrin Ọdọgọ, ẹlẹrú ń wẹrú, ẹlẹ́rù ń wẹrù, ó ní kíwọn jẹ k'ọkọ òun ó dé. | 1 |
Àwo orin Yínká Ayéfẹ́lẹ́ tuntun máa jáde láìpẹ́ yìí. | 0 |
Ẹni tí kó fifá tanni; a kì í fọpẹlẹ tàn án. | 1 |
Àjọ ayánilówó ti fi owó ṣèrànwọ́ fún àwọn àgbẹ̀. | 0 |
Àfẹjọ-ẹni-sùn, kò mọ pé a ó ríhun rò lọdọ Ọba. | 1 |
Àwọn adigunjalè gbà ọ̀kadà lọ́wọ Jẹ́nyọ̀ lọ́jọ́ kẹrìndínlógún, oṣù kejì ọdún tí a wà yìí. | 0 |
Àkèekèé ò ṣé-é dì níbò. | 1 |
Àdóìṣí loògùn ọrọ̀. | 1 |
Ohun tó mú káwọn ọlọ́pàá mú Bámgbọ́lá ni pé ó fipá bá ọmọbìnrin kan sùn. | 0 |
Amukòkò kì í gbàgbé iṣáná. | 1 |
Adelé Gómìnà ṣàpèjúwe ìwà ọba alayé gẹ́gẹ́ bí ìwà àfojúdi. | 0 |
Ẹgbẹ́ iṣu kọ́ niyán. | 1 |
B'ọlogbọn méjì ba'jùmọ ń jefọ láwo kan; bí wọn ò bá sọra,omitoro ni wọn ó fi jeun keyìn. | 1 |
Àdúrà, a fi ń dun ara wa nínú ni. | 1 |
Alága àdúgbò Mosáfẹ́jọ́ ti gba àwọn ọlọ́dẹ àdúgbò tuntun méjì. | 0 |
Arákùnrin kan mú ọ̀rọ̀ nípa ìjà ilẹ̀ lọ sí àgọ́ ọlọ́pàá. | 0 |
A kì í dá tuntun sórò. | 1 |
Àwọn ọ̀daràn ń gbìyànjú láti lọ ta ọkọ̀ náà sílùú òdì kẹ́ta. | 0 |
A-mọ̀ràn-mòwe ní ń làdí ọ̀rọ̀. | 1 |
Ọ̀pálọla sọ wí pé ló jẹ́ kí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí di mímọ̀ fún àwọn agbófinró. | 0 |
Érò tètè jí, èrò jẹ'lẹ ó gbọn, tèrò là ń wí férò. | 1 |
Èkúté ilé ò fibi àjà han ara wọn. | 1 |
Bí a bá pe Sàkọtún tí kò ję; kí á pe Sàkòsì. | 1 |
Àìsí èèyàn lóko là ń bá ajá sọ̀rọ̀. | 1 |
Bí iṣú bá tán lóko, obìnrin a di àwòdì; a ní rírà lòún tún ń rà jẹ kiri òo. | 1 |
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fojú alága ẹgbẹ́ awakọ̀ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀ hàn síta. | 0 |
Ọlọ́kadà méjì jí oògùn kó níbi ìpamọ́. | 0 |
Tànmọ́ọ̀ Oyinlọlá já nígbà tí ọmọ rẹ̀ sọ fún un pé kò ṣeé ṣe kí òun dúró bí lọ́yà rẹ̀. | 0 |
Bàntẹ 'ò lókùn lẹyìn, ó lówó nínú. | 1 |
A kì í kéré k'á má leè dá bínú, (dánú bí) ìyà la ò ni lè kọ. | 1 |
Ẹnìkan ni wọn ń file fún dà. | 1 |
Adìẹ funfun ò mọ ara ẹ lágbá. | 1 |
Àáyá n tiro, Ògúngbè ń bẹrẹ | 1 |
B'éèyàn fọlẹ ni sọmẹlẹdàgbẹ, kò pé ó torí ẹ pàjùbà. | 1 |
Àwọn eléré orí ìtàgé ṣe fídíò kan. | 0 |
Àwọn ajínigbé lè lọ sí ààfin ọba láti jí ọba gbé. | 0 |
Eyín kan ni gbèsè ni; bí a bá ti ká eyín kan náà, àbùșebùșe. | 1 |
Àwọn ẹgbẹ́ kan ní kí ìjọba dá wọn lohùn lórí owó oṣù. | 0 |
Àdá lẹnu tálákà; igbó la ó fi ṣán. | 1 |
Àwọn ọ̀daràn kan pa dẹ́rẹ́bà kan wọ́n sì jí ọkùnrin mẹ́ta gbé lọ lánàá. | 0 |
Àteníisùn ni tàgbędę. | 1 |
Àwọn ènìyàn kan tí Bámiṣé kò dárúkọ ń gbèrò láti da ìdìbò náà rú. | 0 |
Àlàní fi ipá bá Àríkẹ́ lòpọ̀ lánàá. | 0 |
Àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin mẹ́rin tí Adébísí fi oògùn sínú oúnjẹ fún sùn lọ fọnfọn. | 0 |
Ẹni tí kò nírú ẹni, kì í mọyì eni. | 1 |
Àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè Afíríkà ń múra fún ètò ìdìbò gbogbogbò tí yóò wáyé nínú oṣù yìí. | 0 |
Eégún fẹjaá jẹ, Àbàlá ò fódòó gbọn. | 1 |
Ẹní pàgbín jẹ níí mọgbín lẹrọ. | 1 |
Àìtètèjí inú ọ̀tá ń dùn, a jí tán inú ń bí wọn. | 1 |
A rí fídíò ẹ̀rọ ayàwòrán pápá ìṣeré náà. | 0 |
Àgùàlà ń b'óșùú rìn, wọn șe b'ájá ẹ ní se. | 1 |
Ẹní lórí Ìgunnu 'ò gún tó, kó gbé àkàșọ lọ tún un se. | 1 |
Ẹni tí kò rẹni wá a, kì í sọnù. | 1 |
Àìgbọ́dọ̀máṣe ni ìwẹ́ gbọ́dọ̀ jẹ́ fún gbogbo ẹ̀dá èèyàn. | 0 |
Àgbàlagbà kì í sun oorun àsùnlọlá; bí kò bá fẹ ľ'álę l'ojọ-alę. | 1 |
Akínwọlé rà á ní ọgọ́sàn-án náírà ní àná. | 0 |
Lẹ́yìn ọjọ́ márùn-ún ni a tó rí owó | 0 |
Afínjúu Ààre; ó fi àkísà dí orùbà; ó ń wá ẹniire-é bá sú epo. | 1 |
Èròńgbà ìjọba lórí ilé tí wọ́n ń kọ́ láti lè dín ìṣòro àìrílégbé tó ń kojú àwọn èèyàn. | 0 |
A kì í mọ́ egbò fúnra ẹni ká sunkún. | 1 |
Ìjọba buwọ́lu iṣẹ́ àgbàṣe fún àtúnṣe ojú ọ̀nà nílùú Àbújá. | 0 |
Àwọn òǹtajà mìíràn ti lọ ilé wọn kí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó wáyé. | 0 |
Àwọn ẹgbẹ́ yìí máa ń lọ káàkiri láti fọ̀rọ̀ wá àwọn tí wọ́n bá pẹ́ níta lẹ́nu wò. | 0 |
Adelé Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó sọ pé wọn kò ní ṣàìfi ìjìyà tó tọ́ jẹ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. | 0 |
B'ọgbọn-inú ẹni ò bá to nií d'ẹwù, á tónií dáso. | 1 |
A kò ní gba èsì kankan mọ́ bí ilẹ̀ òní bá fi ṣú. | 0 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fìdí rẹmi nínú ìdánwò àṣewọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga. | 0 |
Àwọn ológun ń ṣe ìgbáradì láti rí i pé ohun gbogbo dúró déédéé. | 0 |
Ajá ilé ò mọdẹ ṣe. | 1 |
Àwọn tá a gb'órúko wọn lánàá, a ò gbọ orúkọ omọ wọn lónìí.Àwọn tí àń gbọ orúkọ wọn lónìi; a 'ò ní gbọ orúkọ omọ wọn lola. | 1 |
Ejo ki í sejọ ẹni kí a má mọdá e. | 1 |
A ti wọ inú oṣù kẹfà èyí tó jẹ́ ìdajì ọdún yìí. | 0 |
Ikú àwọn ènìyàn mẹ́ta dá wàhálà sílẹ̀. | 0 |
Aró tó bá dé, òun ló yę k'á rę. | 1 |
Gúnnugún torí abe rárí. | 1 |
Kí ni ìtumọ̀ irúfẹ́ ohun tí kò dára bí èyí nínú àwùjọ wa? | 0 |
Ebi ò mọ pé oókan ò sí nilé, b'ójúmọ bá ti mọ lebi ń pani. | 1 |
Asárétete ní ń kọjá ilé; arìngbẹ̀rẹ̀ ni yó rìí oyè jẹ. | 1 |
Bí a kò bá dáṣọ lé aṣọ, a kì í pe ọ̀kan lákìísà. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.