Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Bá a bá ń bẹ láyé ẹ jẹ́ á ṣe ara wa lóore, bí a bá wà láayè ẹ jẹ́ á da ọ̀rọ̀ ara wa rò.
0
Mò ń fi àsìkò yìí rọ àwọn akẹgbẹ́ mi yòókù láti jẹ́ ká fi ìmọ̀ Aṣọ̀kan.
0
Ìjọba ti gbé ìgbésẹ̀ ńlá láti gba òbítíbitì owó táwọn wọ̀bìà ẹ̀dá kan kó jẹ padà.
0
B'óbìnrin ò bá l'órogún, bó ti ń ș'Ọbà, ni yóó máa Osun loode-Oko.
1
Ìjọba Èkó ti dá àwọn ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tó ń hùwà kò tọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó padà sílé.
0
Nígbà tí dẹ́rẹ́bà ọkọ̀ náà kíyèsí pé òun kò rí ọkọ̀ òun mọ́.
0
Ó ní òun ra adìẹ náà láti lè pa á fi ṣe àjọyọ̀ ọdún ni.
0
Ẹni eégún ń lé lọ kó máa rọjú, bó se ń rẹ ará-ayé, ló n rẹ èrò-orun.
1
Ní kété tí àwọn màlúù tó jẹ májèlé kú làwọn alápatà ti ń sọ ọ̀bẹ sí wọn lọ́rùn.
0
Àwọn àwòrán kan fi ojú àwọn apànìyàn mẹ́ta hàn lórí ẹ̀rọ ayélujára.
0
Bábá bo bábá; bàbà bo bàbà; ewé ọ̀pọ̀tọ́ bo ewé òrom̀bó.
1
B'íná báràn;kò s'ọmọ tí yóo tọwọ bọ eérú.
1
Olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú nílùú Ìbàdàn ni arákùnrin náà.
0
Bí ẹni ńlá ò bá tán, ọ̀ràn ńlá ò lè pani.
1
Ẹni Òjò pa, tí Șàngó ò pa; kó pa'bi b'ọrí ló tọ.
1
Ìlú tí wọ́n kó àwọn èèyàn náà lọ jẹ́ èyí tí àwọn ọmọ gànfé pọ̀ sí púpọ̀.
0
B'éèyàn 'ò b'ánitan; kò gbọdọ j'ogún ẹni.
1
Gb'ọmọ foyàn, gbọyàn fọmọ, k'ọyàn șá ti dẹnu ọmọ ni.
1
Àáké kan wọ'gbó, òkìkí ẹ kàn ká'gbó gbogbo.
1
Ẹní Òyìnbó fẹrán; lÒyìnbó ń bẹ níșę.
1
A kì í ríwà oníwà ká fọwọ́ jurí.
1
Ilé ẹjọ́ ti da ẹjọ́ tí wọ́n pè ta ko gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nù.
0
Àwo ìjálá náà wà fún ìgbádùn ọdún iléyá tí ó ń bọ̀ yìí.
0
Ó ní òun kàn fẹ́ sinmi díẹ̀ kí òun náà tó máa lọ ni.
0
Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá ro ju ti àwọn adigunjalè ọ̀hún lọ.
0
Abilékọ kan ṣàlàyé lórí ìdí tó fi gb'oyún láti ìta wá sọ́ọ̀dẹ̀ ọkọ.
0
Àwọn ọ̀rẹ́ náà jọ ara wọn bí ìmumu.
0
Mínísítà fọ́rọ̀ àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti gbé olórí aṣòfin tó fẹ́ fi àwọn obìnrin lọ́kọ.
0
Àwọn asòfin máa ń pe ìjọba padà lórí àwọn ìgbésẹ̀ wọn.
0
Á ṣe kaye àwọn èèyàn tó wà lẹ́wọ̀n ni a fi ri pé ó ti pọ̀ si lọdún yìí.
0
Níwọ̀n ìgbà tí obìnrin náà ti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé àlàáfíà lòun wà.
0
Wọ́n ti gbé òkú Ògúnrónbí pamọ́ sí ilé ìwòsàn.
0
Àwọn ìjọba kàn ń ṣe àwọn aráàlú bó ti wùn wọ́n.
0
Àdásílẹ̀ níí yóó dàá oko eéran lára.
1
A ní kí ohun tó wuni wá, ohun tó dára-á bọ́ sílẹ̀; bó dára tí kò wuni ńkọ́?
1
Ajá kì í jobì.
1
Babalágọ 'ò gọ, ẹrù ló pọ.
1
Ayé ò ṣé-é bá lérí; wọ́n lè ṣeni léṣe.
1
Akékeé ta ọmọ náà níbi ó gbé sùn.
0
Ajá òyìnbó dára, ó ku àtiṣọdẹ.
1
Àmọ̀pé gba àpá lọ́wọ́ ẹni tí ó ṣe ní èṣe lánàá.
0
Aláṣọ àlà kì í jókòó sísọ̀ elépo.
1
À ń bẹ̀rù alájá, ajá ṣebí òun là ń bẹ̀rù.
1
Àìgbọràn ló mú ki àwọn ọmọ iléèwé ijọ́sí fi ikú ṣe ìfàjẹ.
0
Wọ́n ti yan Oyèkànmí gẹ́gẹ́ bí akápò bákan náà fún fásitì Iléṣà.
0
A ó máa wò ó; ti ljàpá fi tiná bọié.
1
Àwọn aládùúgbò gbìyànjú láti parí ìjà láàárín àwọn méjèèjì.
0
Àwọn òṣìṣẹ́ mẹ́ta tí àṣírí wọn tú wà ní ẹ̀ka ìṣirò owó.
0
Aláṣejù ajá ní ń lépa ẹkùn.
1
B'áwo ba ké 'Eríwo yàà', ogbẹrì 'ò gbodọ ní:'Àyà gbó, àyà tọ,' bí 'ò bá fẹ dárán-an mọríwo; àti mọrẹrẹ.
1
Adìẹ da ẹtù nù ó mú un jẹ, b'ó ba ṣàparò yóò bàá iyán oko lọ.
1
A ó tì sorí ọmọ tó tóbi?
1
Bíọ́dún tí ó ṣiṣẹ́ agbégilére gbẹ́ ère ààrẹ orílẹ̀-èdè yìí.
0
Mi ò lérò pé a lè máa sọ̀rọ̀ nípa ìgbésí ayé Ọlákúnmi ní àsìkò tí a wà yìí.
0
Ẹni lè na ni lè gbèjà eni.
1
Kòkòrò àìfojúrí kan ló fa àjàkálẹ̀-àrùn ní ilẹ̀ aláwọ̀ funfun.
0
Dẹ̀hìndé sọ pé àwọn ọlọ́pàá ṣígun padà sí agbègbè ìṣẹ̀lẹ̀ náà lẹ́yìn tí wọ́n ti kọ́kọ́ lọ.
0
Bí a bá sọ̀kò sí àárín ọjà, ará ilé ẹni ní ń bà.
1
Bí ẹnìkán ṣe ohun tí ẹnìkan ò ṣe rí, ojú-u rẹ̀ á rí ohun tí ẹnìkan ò rí rí.
1
Ẹlẹ́bí ò run orín gbọọrọ.
1
Àjànàkú jẹ́ ẹranko tó tóbi jù lórí lẹ̀.
0
Àdìó ni bàbá ìsàlẹ̀ fún àwọn ọ̀daràn.
0
Àtèké, àtikà,b'ọn láwọn n b'áni kedùn; wọn a yòónú. Sàsàèèyàn níí báni dárò tí 'ò yọni. (leyìn)
1
Bí a 'ò ș'ọdę rí; a mẹsẹę kò lọ.
1
Dín-dín-dín là ń bólú; dín-dín-dín là ń báwọ̀; dín-dín-dín là ń bá olóòṣà tòun tèkó orí-i rẹ̀.
1
Àwọn ọ̀rẹ́ àti ara ti dé láti ìgbà tí ìnáwó ti ku ọ̀sẹ̀ méjì fún ti oyè ọba Owólabí.
0
Àtíkù ní Nàìjíríà wà lásán láìsí ẹni tó ń tukọ̀ rẹ̀.
0
Èyí sì ti mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn fi ara pa yánnayànna.
0
Afurasí ọ̀daràn náà sọ nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé ọ̀gá akọrin ilé ìjọsìn lòun.
0
Àtè pẹyẹ mẹ́yẹ kú.
1
Abẹrẹ bọ l'owọ adẹtẹ ó dète.
1
Bí Ajóbíewé Àrẹ̀mú ṣe jẹ́ gbajúgbajà tó, ìyàwó kan ṣoṣo ló ni.
0
Dàda 'ò lè jà, ó lábùúrò tó gbójú.
1
Òṣìṣẹ́ tí ó bá ń wá ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́ gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́ takuntakun ni.
0
Èèyàn gígùn ò ṣé-é bọ òrìṣà méjì.
1
Bàbá alápatà di èrò àhámọ́ lẹ́yìn tí àwọn ọlọ́pàá fi páńpẹ́ òfin gbé e.
0
Dídi òṣèré olókìkí kọjá mímọ̀ọ́ṣe.
0
Àkàṣù ò níbií rè lágbọ̀n.
1
Wọ́n ti rí ọkọ̀ tí àwọn ajínigbé gbà lọ́wọ́ Olúfóyè.
0
Ẹ̀hìn àjànàkú là ń yọ ogbó; ta ní jẹ́ yọ agada lójú erin?
1
A ì í gbọ́ wuyewuye nílé-àgbà lẹ́ẹ̀mejì.
1
Bẹ́ màrìwò, bẹ́ ọ̀gẹ̀dẹ̀, ọjọ́ kan-náà ni wọ́n ń yọ.
1
Láàárin ọjọ́ díẹ̀ ni ẹ̀mí àwọn ènìyàn tí wọ́n lùgbàdì àrùn fi ń bọ́.
0
Ilé ẹjọ́ yóò gba gbogbo owó tí àwọn arúfin pa níbi igbó gbíngbìn.
0
Ẹ wá wọkọ̀ ojú-irin ọ̀fẹ́ láti Èkó lọ sí Ìbàdàn.
0
Àdóòsí loògùn ọrọ.
1
A tún máa ń rí àyájọ́, ọfọ̀ àti èpè nínú orin Àyìnlá nígbà mìíràn.
0
A kì í mẹyẹ so, k'á múu lóhùn so.
1
Bí iwájú ò bá ṣeé lọ sí, ẹ̀hìn a ṣeé padà sí.
1
Òfin àtọwọ́dọ́wọ́ lásán ni ọ̀rọ̀ pínpín ipò gómìnà sí ẹlẹ́kùn-jẹkùn.
0
Fẹmọfẹyàá; bí a bá bi í; yóó rìí wí.
1
Bí a bá jẹkọ, à dàrí jewé.
1
A kì í fàì j'oyin f'ọwọ oyin bájú.
1
B'óbìnrin 'ò j'owú, ọbẹ 'ò lè dùn.
1
Àwọn mìíràn sáré dojú bolẹ̀ nítorí ìró ìbọn tí wọ́n gbọ́.
0
Amúniṣẹ̀sín ẹ̀tẹ̀ tí ń múni lọ́gangan imú.
1
Bí ọ̀lẹ́ bá lẹ, ìgbòrò-o rẹ̀ á gbójú.
1
Àwọn agbófinró ni wọ́n mú Lánrewájú láti ọjọ́ tí àwọn ènìyàn rẹ̀ ti ń wá a.
0
Ata-á kéré; ìjá jù ú.
1
Àgbàrá kọ́ ni yó gbèé omi lọ.
1