Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Ọ̀rọ̀ obìnrin kan tó ń gbé lẹ́yìn ilé bàbá onílé Mákindé ló sọ ọ́ di èrò àhámọ́.
0
Ayáraròhìn, aya ọdẹ, ó ní ọkọ òun-ún pa èkínní, ó pa ẹ̀kẹfà.
1
Ògúnléndé ni alága gbogbogbòò.
0
‘‘Ò báà rí, o ò gbọdọ̀ wí’’ ní ń pa akọni.
1
Àwọn ajínigbé tún ṣoró ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lóṣù tó kọjá.
0
Àyọ̀-yó ni bàtá à-jó-fẹ-ehín.
1
Àwòdì jẹun èpè sanra.
1
Ẹní a ò bá fàdàmọ gbé relé-ọkọ, òru ló fi sálo.
1
Bó ku ọwọ kan, àdán yóò fi rọ.
1
Ẹ̀já kì í já kó pé.
1
Eégún tí ń jẹ orí ẹṣin, orí àgbò ò lè kò ó láyà.
1
Àwọn kan ò mọ ohun tí wọ́n fẹ́.
0
B'óbìnrin 'ò bá tẹ, ọkùnrin ò leè s'ọkọ rẹ.
1
A kì í saájú ẹlẹ́ẹ̀ẹ́dẹ pè é.Bẹ́ẹ̀ẹ́dẹgbẹta ló fẹ pè ni,bẹ́ẹ̀ẹ́dẹgbẹrintà ni, a 'ò mọ.
1
Ayọ̀ ń rò mí lẹ́jọ́.
0
Babaláwo tó sàsàję-ewé làá pàgbòó dúpẹ fún.
1
Ẹdá tá ò leè mú, Ọlọrun Ọba làá fún-ún mú.
1
Bí ó ba di ìlọ, à á kì í ni.
1
Àgbàrá òjò-ó bánijà, ó bá ojúde ẹni lọ.
1
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun mọ rírì gbogbo ìgbésẹ̀ tí àwọn ọmọ-bíbí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà gbé nípa fásitì náà.
0
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin ti ń ṣe gudugudu méje àti yààyà mẹ́fà nínú àwọn ẹ̀kọ́ wọn.
0
Àń bá oníkúrúnà jẹwọ (seré) ó ní inú òun 'ò da, ẹní rí ara rẹpàá ti mọ.
1
Ení bá rí akebo-ikórita-mẹta je, kí ó fi oore se é. Ìpọnjú níi múnii jebo oríta-meta.
1
Ináọlájí sọ̀rọ̀ lórí ohun tí orílẹ̀-èdè nílò.
0
Kò dìgbà tí a bá ra aṣọ tuntun kí a tó ṣọdún.
0
Bí sammọnyan bá ń jó, àláárì má ń gbè é lẹsẹ ni.
1
Ẹ̀ka ìròyìn ayélujára Tìrìbúúnù náà tún fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn agbébọn yìí múlẹ̀.
0
À ń kì í, à ń sà á, ó ní òun ò mọ ẹni tó kú; ó ń gbọ́, ‘‘Ikú mẹ́rù, pàgá, a-biṣu-ú-ta-bí-òdòdó, a-lábà-ọkà, a-roko-f yẹ-jẹ’’; ó ní, ‘‘Àgbẹ̀ ló kú, tàbí ọ̀nájà?’’
1
Gómìnà tuntun ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun kéde pé kí gbogbo nǹkan dáwọ́ dúró nígbà tí ó dé.
0
Ọba Owólabí yóò ṣe ayẹyẹ ọdún kan lórí oyè lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀.
0
Ẹrú-ọkọ l'àsiyèle àgbe.
1
Àwọn aláṣẹ ṣèlérí pé iṣẹ́ ń lọ lábẹ́nú.
0
Ẹlòmíràn yóò sọ máa ohun tí kò ṣẹlẹ̀ rárá.
0
Ọ̀pọ̀ oṣù ni Bọ́lá fi kópa nínú ètò ìpolongo ìbò àti ìdìbò tó wáyé kọjá.
0
Ení eni 'ò sehun, èèyàn ẹní 'ò sènìyàn; a 'ò ní (lè) fi wé aláàáròlásán.
1
Wọ́n ti pín àwọn ohun ìlera fún àwọn ènìyàn.
0
Múìbí sọ pé òun kò fi ipá mú àwọn ọmọ náà nígbà tí àwọn ọlọ́pàá báwọn sọ̀rọ̀.
0
Adàgbàkọlà, ríré níí ré.
1
A fún ọ lọ́bẹ̀ o tami si; o gbọ́n ju ọlọ́bẹ̀ lọ.
1
B'éèyàn bá su s'éwée kókò, tí ó jáwé gbúre nùdí, olú-ọbe ní ímú irúu wọn.
1
Òru ni àwọn oníṣẹ́-ibi náà ń fi òru bojú jí ohun-ìní àwọn ará ìlú.
0
Àgbọnrín ní: “Ìrin onà jínjìn fitan ẹni pa orún-dín-ọjo.”
1
Adájọ́ ilé ẹjọ́ ti dá ẹjọ́ pé kí Adéyanjú máa lọ sílé.
0
Ẹjẹ á fẹ e bẹệ bẹệ'; ọmọ béè béè níí bí fún ni.
1
Ẹni tí ìbọn bà ṣubú lójú-ẹsẹ̀, ó sì kú pátápátá.
0
Abiyamọ ló mọwọ́ ọ̀já.
1
Àwọn afọbajẹ ìlú Ọ̀yọ́ sọ pé Gómìnà Ọ̀yọ́ kò gbọdọ̀ yẹ àwọn lọ́wọ́ wò.
0
Abilékọ máa ń ti irú ọmọ bẹ́ẹ̀ mọ́ ọkọ rẹ̀ lọ́rùn nínú ilé.
0
Àgbàrá gbé ọmọ ọdún mẹ́tàlá lọ ni Àkúrẹ́.
0
Àwọn ikọ̀ ológun kò rí ẹnì kankan mú nínú àwọn jàǹdùkú tó dá wọn lọ́nà.
0
Gbogbo èèyàn ló m'ẹkùn èèyàn mélòó l'ẹkùnún mọ.
1
Bí a ó yan àlè; Ònkó (oògùn tó kápáa mágùn) làá tọjú.
1
Kò sí ìdáríjì bí ọwọ́ bá fi bà nínú àwọn tí wọ́n ń jà.
0
Àfikún owó iná kò rọrùn fún èèyàn láti san.
0
Lórí ẹ̀sùn kejì, ó ní kí wọ́n lọ fi ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́ta-mẹ́ta gbára.
0
Òkìkíọlá sọ wí pé òun yóò fi ẹjọ́ ẹnikẹ́ni tó bá ṣẹ òun sun ọlọ́pàá ni.
0
Ààbò tó mẹ́hẹ kò fún àwọn ará ìlú ní ìfọkànbalẹ̀.
0
Adarí fún ọ̀rọ̀ òkèèrè ilẹ̀ Nàìjíríà tẹpẹlẹ mọ́ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ náà.
0
Ọkùnrin oníwà tútù náà ti di olóògbé.
0
Eni moni lójú ki a dúpe lowo e, èèyàn ni ò wobi a wà
1
A gbọ́ pé Àlàní lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú ọkùnrin kan láti gbé egbòogi olóró.
0
Àṣà dída ẹran níbikíbi di èèwọ̀.
0
Aládùúgbò ẹni ni ọmọ ìyá ẹni.
1
Gbogbo èèyàn ló ń bá Ọbùn sòwò.
1
“Bí a bá mìn ín à á pọ ọ” Ọnà-ọfun ẹni ní í ya.
1
Alábahun ń ràjò, ó sí ọpọn-lfá 'ẹ rẹ dérí.
1
B'o bá já màá so o'kò ní șài ní kókó.
1
Ẹgbẹ́ òṣèlú Alágbàdo sọ pé kò sí ọ̀rọ̀ nínú ohun tí Làmídì sọ.
0
Àlémú ò yẹ àgbà; àgbà kì í ṣe ohun àlémú.
1
Bàbá Àjàyí sọ wí pé ọ̀rọ̀ tó jáde lẹ́nu dókítà kò dùn mọ́ òun nínú.
0
Adelé alága l'Ékòó ní àdéhùn wà láàrín ààrẹ àti Tinubu.
0
Adẹ́rìn-ín-pòṣónú méjìlá ló wà níbi ayẹyẹ òpin ọdún tí ìjọba Èkó gbé kalẹ̀.
0
Olórí ojúbọ òrìṣà ìlú Ọ̀ṣun sọ̀rọ̀ ní Òṣogbo.
0
Ìlanilọ́yẹ̀ yóò bẹ̀rẹ̀ fún àwọn ènìyàn lórí ewu tó wà fún dídá egbòogi lò
0
Adélànà sọ pé kí ìjọba àpapọ̀ ṣe àfikún àwọn ẹ̀ṣọ́ elétò àbò ní ìpínlẹ̀ Kwárà.
0
Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá orílẹ̀-èdè yìí ti lé àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ mẹ́ta dànù.
0
‘‘Baálé pè mí n kò wá,’’ ọ̀hànhàn ní ń pa wọ́n.
1
Gbà soko ni, gbá sílę.
1
Baba enikan 'ò gbin yárin, fúnra yánrin níí so lóko.
1
Bí a bá sọ pé ẹyẹ ni yó jẹ ojú ẹni, bí a rí tí-ń-tín, a ó máa sá lọ.
1
Bí orí kan-án bá sunwọ̀n á ran igba.
1
Bí a bá ṣí ìdí ẹni sókè, ọmọ aráyé á rọ omi gbígbóná sí i.
1
Àyìndé ti padà sá kúrò nílé.
0
Àwọn ènìyàn kò tètè fi ọ̀rọ̀ tó àwọn ọlọ́pàá létí.
0
Adébọ́lá sọ pé òun fẹ́ kí ọmọ náà wà ní ìkáwọ́ òun fún ìtọ́jú tó péye.
0
Àwọn ọ̀dọ́ mìíràn fẹ́ràn láti máa ṣe ohun ìtìjú.
0
Bí a bá yọ Jigá, àá yọ Olú ẹ ni.
1
Ẹ̀ka ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ wa wà ní agbègbè Eléwé-ẹran.
0
Àyìnlá sọ ẹni tó dá orin Fújì sílẹ̀ gan an ní Nàiìjíríà.
0
Enú tó fínjú ló ń b'olówó e je awúje.
1
Àwọn jà̀ǹdùkú lọ sí agbègbè kan ní ìlú Ìbàdàn tí wọ́n sì lé àwọn olùgbé ibẹ̀ kúrò.
0
À ń báni mú adìẹ à ń forúnkún bó; bówó bá ba òkókó, a ò ní fún aládìẹ?
1
Adùn ló ń gbeyìn ewúro.
1
Àwọn agbófinró sọ wí pé níṣe ni àwọn ọ̀daràn túbọ̀ ń pọ̀ sí i.
0
Adájọ́ ní kí afurasí yìí kó ìwé ìrìnà òkè-òkun rẹ̀ sílẹ̀.
0
Ayọ̀ mu ọti yó ní àyeye ìsọmọlórúkọ lánàá.
0
Gẹge ńlá níí gbàkọ-òwú.
1
Eégún tó rorò, l'aráà 'Wóó tọ.
1
Àì-kúkú-joyè, ó sàn ju, ‘‘Ẹnu mi ò ká ìlú’’ lọ.
1
Arọ́basá ò ṣojo.
1