Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
A kì í lé aká (adẹtẹ) sígbó kí a tún máa gba towọ ẹ. B'orí ẹ òbìni, Eledàá rẹ yóó bèèrè.
1
Adájọ́ sọ pé ohun tí àwọn Ọ̀yọ́mèsì ṣe kù-díẹ̀-káàtó.
0
Aró t'ó bá dé l'ó yę kí á rę.
1
Aláṣọ-kan kì í ṣeré òjò.
1
Àdìó fi kun pé ìtòsí ẹ̀ka ilé iṣẹ́ wọn ni àwọn tó ń lu jìbìtì náà ṣí ọ́fíìsì wọn sí.
0
A kì í sehun tó wuyì lójú odì ẹni.
1
Bí ọmọdé bá mọ ayò, ẹyọ la ó fi pa á.
1
Alájọbí ò sí mọ́, alájọgbé ló kù.
1
Ọwọ́ ba olè ají-ẹran-gbé kan ní ìsọ̀ àwọn alápatà ní kárà.
0
Àti òwúrọ̀ ọjọ́ ni ìjọba burúkú ti wà.
0
Bí a ò hùwà itùfù (etùfù) a kì í kíyèsí eyìnkùnlẹ (ìpàko).
1
Àti ìgbà tí ìyanṣẹ́lódì yìí ti bẹ̀rẹ̀, ayé kò rọrùn.
0
Atenilárà bí Ajé 'ò sí.
1
Àjò tí kò wunií rè n làá dífá sí.
1
Adérántí ni ẹni tí àìsàn kíndìnrín ń bá fínra kó tó di pé ó ṣe iṣẹ́ abẹ.
0
Bẹ e bá jepà tán e má dèèpo e lé wa lórí.
1
Àgbákò sọ pé ọ̀rọ̀ ìmọ̀ nípa òfin pọ́nńbélé ni èyí.
0
Aṣíwájú ni ẹ máa jẹ́, kìí ṣèrò ẹ̀yìn èyí ni àdúrà àwọn òbí.
0
” Eégún eleégún kì í gbeni. Òòsà olóòșà kì í gbèniyàn.
1
Àwọn dókítà rẹ̀ fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé kò nílò àyẹ̀wò kíndìnrín mọ́.
0
Àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n, ọ̀mọ̀wé bí i mẹ́wàá ni àwọn tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ àwọn olùkọ́ fásitì.
0
Àwọn méjèèjì ni ọlọ́pàá ti gbé jàǹtò lọ sí àgọ wọn.
0
Àwọn oníròyìn ò tí ì mọ iye ènìyàn tó ti bá ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì lọ.
0
Ẹ k'ọmọ lófèé, nítorí àjòji tó ń bo.
1
B'ajá bá ń sáábà ẹkùn, kẹkùn náà máa sáábę ajá ló yę (to).
1
A kì í ní ọ̀kánjúwà ká mọ̀; ará ilé ẹni ní ń sọ fúnni.
1
Àwọn òǹtajà màlúù lọ fi àwọn màlúù wọn jẹko láti inú ọjà Oníwàrà.
0
Bọ́lá Tinúubú ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó.
0
Ìjà yìí ti mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí lọ ní ìlú Káraóle.
0
Borokinní àsejù, oko-Olówó ló ń múnií lọ.
1
Bí wọ́n ti ń ja ìjà ẹ̀sìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ló wà nílùú Àgànyìn.
0
Ọ̀dọ́mọkùnrin kan tó fipá bá ọmọbìnrin kékeré kan nílùú Abẹ́òkúta ti kábàámọ̀.
0
Àwòmọ́jú kì í pọ̀tá; mọ́jú-mọ́jú lọrùn ń dùn.
1
Àwọn Ọba alayé ń gbé ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá ga dípò ẹ̀sìn ìbílẹ̀.
0
Àlejò tó b'ómi ísanwo bá ońje.
1
B'ọtùn-ún bá kúnì, a f'òsì bẹra.
1
Ẹjọ́ ti dé ọ̀dọ̀ baálẹ̀ ìlú, kò sì sí ẹ́ni tó lè tú ìgbìmọ̀.
0
Àwọn lọ́balọ́ba ní Fáyẹmí kójú òṣùnwọ̀n láti jẹ ààrẹ Nàìjíríà.
0
Agbẹjọ́rò náà rọ ilé ẹjọ́ láti pàṣẹ pé kí wọ́n fi pásítọ̀ náà pamọ́ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n.
0
Egbẹ igi nigi ń gbá lójú.
1
‘‘Gba àkàṣù’’ ní àbọjà ni ‘‘Gba iṣu bọ̀ọ̀kù’’ ní àmọ́dún.
1
Àkèré ní kàkà k'óun má dunbẹ; tapá titan òun á á re (tán) sí.
1
Gbogbo nǹkan yóò padà bọ̀ sípò lẹ́yìn èyí.
0
Afẹ́fẹ́ kì í fẹ́ kí omi inú àgbọn dànù.
1
Alukoro sọ wí pé àwọn ará ìlú ló ta àwọn lólobó.
0
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde àfikún sí owó ẹ̀kọ́.
0
Edá ló ń wojú, Olúwa Ló ń wo okàn.
1
‘‘Ta á sí i’’ kì í báni wá ọfà.
1
Àlùkẹrẹsẹ ò mọ̀ pé olóko-ó ládàá.
1
Àwọn agbófinró yóò fi ọwọ́ òfin mú àwọn jàǹdùkú náà ní kíákíá.
0
Ẹni tí ò tó gèlètè kì í lé geru.
1
Ẹ̀tọ́ tí a fẹ́ gbà ni èyí tí wọ́n fi èrú gbà níbi ìdìbò sípò ààrẹ.
0
Afàkàràjẹ̀kọ, ó ní òun gbé ata mì.
1
Ìjọba kò fẹ́ ìpéjọ tàbí ìpàdé àdúrà kankan ní mọ́ṣáláṣí gbogbogbòò.
0
A kì í dé ìgbàro èṣí ká fẹ́ ohun okòó kù.
1
Ẹní ní dòjé ló ń pa bẹrę.
1
Ó máa tó oṣù kan gbáko tí wọn yóò fi ṣe ìdánwò náà.
0
Orí kó Màríà yọ kúrò ní ibùdó àwọn ajínigbé láti ọdún kan tó ti wà níbẹ̀.
0
Àwọn àgbẹ̀ tún ń lo àwọn irinṣẹ́ wọ̀nyẹn láti ṣàwárí ẹni tí ìrìn rẹ̀ kò bá mọ́ lọ́wọ́ alẹ́.
0
Enì Olúwa ke, ise Ló rán an.
1
A kì í gbójú-u fífò lé adìẹ àgàgà; a kì í gbójú-u yíyan lé alágẹmọ.
1
Gbogbo ọmọ ni Jagun lọjú ìyá ẹ.
1
Arọmọrán-ánșẹ ò lọgàá.
1
Ààfáà bọ̀rọ̀kìnní: bí Ọlọ́run ò bá ṣeni lágbà, a kì í fìyànjú ṣe bí àgbà.
1
Àwọn ànfààní tó wà nínú ìbálọ̀pọ̀ fún ọkàn àti ara.
0
Fákẹ́yẹ sọ wí pé òun gbà pé ohun aburú gbáà lòun ṣe.
0
‘‘À ń jùwọ́n’’ ò ṣéé wí lẹ́jọ́; ìjà ìlara ò tán bọ̀rọ̀.
1
Ilé dàwó bí àwọn ènìyàn ti ń gbìyànjú àtisálọ.
0
Òkú Ọláyínká ni wọ́n bá lórí ibùsùn níbẹ̀.
0
Àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ sọ pé gbogbo àwọn ọ̀daràn yóò káwọ́ pọ̀nyìn rọjọ́ níwájú adájọ́.
0
Fìjà f'Ọl'ọrún ja, k'ó o f'ọwọ lẹrán.
1
A-ti-kékeré-ṣẹrú ò mọyì ọmọlúwàbí.
1
Gbogboogbo lowo ń yo jorí. Gbogboogbọ ni màrìwò opee yo jope.
1
Ẹní ní ni lóògùn ló ń rọ ni.
1
Àwọn aṣòfin Èkó pàṣẹ fún olórí òṣìṣẹ́ ọba láti yọjú sí àwọn.
0
Aṣooregbèṣù: baba àdánù.
1
A fárí igún, a yọ tàkàlàmàgbò lẹsẹ, nígbà tí ó kan àtíòro wọn lábẹ kú, bẹẹ àtíòro ló labẹ.
1
Wọ́n ti ń fún àwọn ènìyàn tó fara gbọgbẹ́ nínú ìjàmbá ọkọ̀ ní ìtọ́jú pàjáwìrì.
0
Àwọn darandaran ba oko àwọn àgbẹ̀ jẹ́, wọ́n sì ń pa àwọn ènìyàn ibẹ̀.
0
A kì í pa igún jẹ ká sẹ́; kì í ṣe ẹyẹ baba ẹnìkan.
1
Wọ́n ní ojoojúmọ́ ni àrà máa ń wáyé nínú ilé Òkìkíọlá.
0
Eépín ni kànnkàn obùn.
1
Adìẹ ò lè ti ìwòyí sunkún ehín.
1
Aṣọ tái tíì rán kì í ṣoni.
1
Àyìndé ti làgboro já láti ọjọ́ pípẹ́.
0
Ọba tuntun kò lè jẹ bí àwọn ohun èlò oyè jíjẹ ò bá pé.
0
Ẹ̀bùn ìmọ̀ọ́ṣe rẹ̀ jẹ́ ká wò ó pé lóòótọ́, àkàndà ènìyàn ni.
0
Àwọn afẹ́nifẹ́re ló pín ẹran ọdún délé mi nítorí ìfẹ́ wọ́n ní sí mi.
0
B'Áyékòótọ bá jẹ ká yó tán, kótokòto ni yóó máa tò.
1
Enmọ lukutupẹbẹ adìẹ lóyún ó bàję.
1
Ẹ̀bìtì ò peèrà tó ṣe pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ ; ẹnu ẹni ní ń pani.
1
Àwọn ọlọ́pàá ti rí dúkìá tí àwọn Sùmọ́nù àti àwọn ará ìyókù rẹ̀ jí.
0
Àmọ́ ẹni tí wọ́n lọ bá sọ pé kí òun fara balẹ̀.
0
Àfáà ń wáàsù kí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ má gba abẹ́rẹ́ àjẹ́sára.
0
Ẹni tó pèèbù-ikà orí ọmọ rẹ ni yóó hù lé.
1
Àtijẹun, ọ̀tọ̀tọ̀ ọ̀ràn.
1
Àgùntàn ò ìtíì kú à ń wì í níná; bóbá wá kú ńkọ́?
1
Ọláyínká jẹ́ gbajúgbajà obìnrin oníṣòwò kòkó.
0
Àwọn aláṣẹ ṣèlérí ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí ìjàmbá ilẹ̀ rírì ṣe.
0
Àràbà ńlá fojú di àáké.
1