Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Kò sí ọ̀nà àbáyọ fún ẹni tí ó há sínú ilé.
0
Mọ̀lẹ́bí Táyé sọ pé wọ́n pa á tì sí ọgbà ẹ̀wọ̀n tó wà ní Òkè-kúrá.
0
Àdìó ni ó máa ń gba owó ìtúsílẹ̀ fún àwọn ajínigbé.
0
Àwòdì n rà bàbà; inú aládìę bàję.
1
A gbọ́ pé Táyé gbekuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra lẹ́yìn tí ó ti wà látìmọ́lé ọgbà ẹ̀wọ̀n Òkè-kúrá.
0
Gbogbo igi ló ń wowe, irókò ń wọ, àtiwowé opę dọrun.
1
Ẹsẹ-kan-ọlà kì í pẹ l'ójúde àpọn.
1
Àlàbí ní ibi tí àwọn nǹkan ọ̀sìn náà bá pọ̀ sí lòun sáábà máa ń lọ.
0
Dámilọ́lá máa ń kọ ọ̀rọ̀ oríṣiríṣi sí àwòrán Òkìkíọlá tí ó bá gbé síta.
0
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn adarí àjọ elétò ààbò.
0
Dámilọ́lá bí ọmọ ọkùnrin làǹtìlanti ní ọ̀sẹ̀ tó lọ.
0
Àìtètèmólè, olèé mólóko.
1
Ìjọba fẹ́ mọ ibi tí epo rọ̀bì tún pẹ̀ka dé.
0
Àwọn ọlọ́pàá ti fi ọwọ́ òfin mú Fọlọ́runṣọ́ lọ ságọ̀ọ́.
0
Bí a bá ń rìn láwùjo kí a máa b'ojúwęyìn.
1
Iṣẹ́ àkànṣe àṣekágbá ilé-ẹ̀kọ́ gíga ló ń dá akẹ́kọ̀ọ́ náà dúró sí ilé ẹ̀kọ́.
0
Eyo níí s'oníko igbọnsę.
1
Àwọn alọ-kólóhun-kígbe ẹ̀dá ọ̀hún ráyè láti kó àwọn ènìyàn náà lẹ́rù.
0
inú Màríà kò dùn sí bí ó ṣe lóyún rárá.
0
À ń sunkún Awúgbó, Awúgbó ò sunkún ara-a ẹ̀.
1
·Eni tán ko (rán) níkà tó gbà, òun alàra níkà nínú ni.
1
Akówó-ẹbọ 'ò mọ ọ lólè.
1
A kò ní ṣe ìwádìí kankan lórí òṣìṣẹ́ tó para ẹ̀.
0
‘‘Mo yó lánàá’’ ò kan tebi.
1
Akíkanjú wọgbó, o ṣòwò igba èèyàn.
1
Adájọ́ Wálé sọ pé nǹkan ọ̀sìn ọ̀hún ń da gbogbo àdúgbò láàmú.
0
Wọ́n bá bàbá àti màmá nínú àgbàrá ẹ̀jẹ̀ bí wọ́n ti wọlé.
0
Inú lè ṣi ènìyàn bí nígbà mìíràn.
0
Ọmọ wọn obìnrin tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí wáyé níṣojú rẹ̀ ló lọ fi ẹjọ́ bàbá rẹ̀ sùn ní àgọ́ ọlọ́pàá
0
Dà bí mo șe dà' afọjú ń ș'eré-òkò.
1
Àkúrẹ́ ni wọ́n ti ṣe àṣeyẹ náà.
0
Bí Lánmbe bá fe te'fá Ìnàkí á bọko.
1
Àwọn ajínigbé ní tábìlì kan tí wọ́n ti ń dúnbú àwọn ènìyàn.
0
Ìgbìyànjú iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ti so èso rere níbi ìwádìí ti wọ́n ṣe.
0
Gúnnugún ba lórùlé, ojú tólé; ojú tóko.
1
Àgbà kì í wà lọ́jà kórí ọmọ titun wọ́.
1
A kì í dá ọwọ́ lé ohun tí a ò lè gbé.
1
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn yóò ṣojú ìpínlẹ̀ Ògùn níbi ìdíje àwọn ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
0
A kì í tọrọ ilé gbé, kí a tọrọ ilé kú sí.
1
Ẹni máa gbàdúrà fún wèrè kì í dijú.
1
Èèpo-egúsí tó ó dihun aìíjírí, leyín tí a tí fọmọ-inú ę jàmọlà,jiyán tán.
1
B'álásínwín bá ń másínwín èé so, k'óníwèrè náà mú wèrè 'ẹ dè.
1
Àwòdi-òkè 'ò ríșe f'ẹfọn níjù.
1
B'óní gbàjámo bá n farí fín ni, a kì í fowotorí kò nípa á wò,t fábikan kú.
1
Gbogbo ìgbésẹ̀ tí yóò máa mú kí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun gòkè ni àwọn aṣòfin yóò máa ṣe.
0
Mi ò fọwọ́ kan obìnrin náà nígbà tí ó ń bá mi jà.
0
Bí a bá ń sunkún, à máa ríran.
1
Àwọn jàndùkú ń dánà de àwọn ọkọ̀ lójú pópó.
0
Àwọn ògùn tí ara mi máa fi yá kíákíá.
0
Báyìí là ń șe nílée wa, èèwọ ibò míràn.
1
Ệèkàn l'ọmọdéé sín táa kì í.
1
Ajá tó rí mọ́tò tó dúró fi ara-a rẹ̀ bọ Ògún.
1
Àgbà tí kò nítìjú, ojú kan ni ìbá ní; ojú kan náà a wà lọ́gangan iwájú-u rẹ̀.
1
Àwọn ìgbìmọ̀ aláṣẹ níláti jókòó láti tẹ̀lé ìgbésẹ̀ tó yẹ.
0
Àsírí Olọrun Bò, baba ta ló lee tú u.
1
Màlúù tó lé lógójì kú nílùú Ìlọrin látàrí májèlé tí wọ́n jẹ.
0
Lára ìgbésẹ̀ tí Adélékè ṣe àtúnṣe sí ni yíyí orúkọ ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun padà.
0
Àwọn èèyàn ṣe ìdájọ́ lọ́wọ́ ara wọn.
0
Ẹ̀bùn orin kíkọ ni Ọlọ́run fún mi.
0
Eré b'Ẹdun nílẹ, Ẹdun 'ò meréé sá.
1
A kì í gbé ẹran erin lérí ká máa fẹsẹ̀ wa ihò ìrẹ̀.
1
Arábìnrin Ajímọ̀bí ní ọgbọ́n ẹ̀wẹ̀ ni ọkọ òun fi mú òun mọ́lẹ̀.
0
A kì í ď'ójú-ogun wẹfọn.
1
Èké lojú ó tì bó dọ̀la.
1
Bàbá Àmọ̀ó ní bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun ti gbà fún Ọlọ́run síbẹ̀ ikú rẹ̀ ṣì dá ọgbẹ́ sí òun lọ́kàn.
0
Bí a bá bu ìrẹ̀ jẹ, ká bu ìrẹ̀ sápò.
1
Àwọn tébi ń pa nì kò jẹ kákàrà Ọjà ó kùtà.
1
B'éèyàn bá dáa ládajù, igi-oko la fi í wé; wọn a ní: 'Lámorín dáa bí ère.'
1
Àìrọ-Òjò kì í kádún.
1
Alákàntànpó ojú ò leè ta eran pa.
1
Èébì kì í gbéni l'ójú ebi òjòjò àgbà.
1
Ìlú òdì-kejì Oko-ìrèsé ni àwọn ọlọ́pàá ti mú àwọn ọ̀daràn náà.
0
Àgbàdo ní ohun ̀gbìn tó pọ̀ níta ní báyìí nítorí àsìkò rẹ̀ ni a wà.
0
Mi ò mọ̀ pé ìṣesí mi bí àwọn ènìyàn nínú lọ́pọ̀lọpọ̀.
0
Bí ó ti wuni là ń ṣe ìmàle ẹni; bó wu Lèmámù a fẹlẹ́dẹ̀ jẹ sààrì.
1
Àwọn ojúlùmọ̀ àti àwọn afẹ̀nifẹ́re náà ń kí Bíọ́lá pẹ̀lú.
0
Àwọn ayédèrú ìròyìn tó gbà'gboro kan lásìkò ìwọ́de kò dára.
0
Gbé erù re wá kí á jo gbé e, aájò kí a bà jọ je e kọ; kó má baàyí dà yí yepe ni.
1
Àìgbọ́ràn máa ń kóbá ọmọ ẹlòmíràn ó sàn láti máa gbọ́ràn.
0
Èèyàn kì í p'ọmnọ ọlọmọ l'ẹkún kí tiẹ rẹrìn-ín.
1
Gbogbo àwọn aṣòfin ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ló fọwọ́ sí àbá tí wọ́n kà.
0
Kò sí ìyàtọ̀ kankan rárá nínú ìwòsàn tí a bá wá pẹ̀lú adúrú owó tí wọ́n ń gbà.
0
Ìbànújẹ́ tí ìyẹn máa ń mú wá máa ń pọ̀ ju ti ẹni tí àwọn èèyàn máa ń tàn lọ.
0
Bájo 'ò bá tojú ọmọdé tú rí, àkogbẹyìn ni yóó fẹe máa kó.
1
A kì í yin ọmọdé lójú ara rẹ̀; ìfàsẹ́hìn ní ń kángun ẹ̀.
1
Bóșùká bá pọ j'orí lọ; ọrùn ní í wọni.
1
Àpèjúwe lalágbẹ̀dẹ ń rọ.
1
Bí inú ẹnìkan ò bàjẹ́, inú ẹnìkan kì í dùn.
1
lgbe Owó làparò ńí ké ká'ko. (kiri oko)
1
Alágbára níí jagun, èèyàn rùsẹrùsẹ níí ș'àgbẹ, èèyàn pẹlẹpẹlẹ níí ṣe Babaláwo.
1
Ayéfẹ́lẹ́ gba àwọn ọ̀dọ́ níyànjú.
0
A ṣe ohun gbogbo tán; ti ẹlẹ́nu ló kù.
1
Akátá jẹyìn ó ṣu ihá; ohun a bá jẹ là ń ṣu.
1
Àì-roko, àì-rodò tí ń ṣápẹ́ fún eégún jó.
1
Gbogbo orin laránmún ò le gbè, bii ti sán-salùbo ko.
1
Awo kan ò sí nínú awo ẹ̀wà.
1
Wọ́n sọ wí pé ariwo adìẹ yìí máa ń dí gbogbo àwọn ará àdúgbò lọ́wọ́.
0
À̀àrẹ wá gbàdúrà pé kí Ọlọ́run tẹ́ olóògbé náà sí afẹ́fẹ́ ire.
0
Ẹ má bínú pé mo pẹ́ dé èrò pọ̀ lọ́jà lónìí ni torí ọjà ọdún tí wọn ń rà.
0
Àgbàlagbàá ṣenú kẹrẹndẹn; èyí tó máa ṣe ń bẹ níkùn-un rẹ̀.
1