Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Bí a kò bá láyà-a rìndọ̀rìndọ̀, a kì í jẹ aáyán.
1
Àwọn agbébọn wọ ìbòjú lásìkò tí wọ́n kọ lu ọkọ̀ àwọn ẹlẹ́wọ̀n.
0
Afínjú pónm̀póla, Oge tí i k'osùn láìwẹ
1
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ.
1
Àwọn ọ̀dọ́bìnrin tí wọ́n jẹ́ olùdíje fún ipò ayabá pọ̀ ní ọdún yìí.
0
Ará Ìwó ní í rẹrùú wòran, èrò Ìbàdàn a sọ tiẹ kale.
1
Àgbàlagbà kìí sòbééré.
1
Alukoro Fásitì Ifẹ̀ sọ wí pé ìbànújẹ́ ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà jẹ́ fún ọ̀gá àgbà ilé-ẹ̀kọ́ náà.
0
Ìró ìbọn tí àwọn èèyàn ibẹ̀ gbọ́ kó jìnnìjìnnì bá wọn.
0
A kì í kọ ọmọ bí ká sọ ọ́ ní Èwolódé?
1
Àì- náání orí-isu ló mú èbù rà.
1
A ì í bániígbé kí a farahẹ.
1
A kì í rí i ká tún sọ pé a ò ri mọ́.
1
Bí àjẹ́ bá mupo, ojú-u rẹ̀ a rọ̀.
1
Gbe e ni kóndó ń jẹ gbẹ ẹ ní kóndó. Gbę ę ní kùmọ ń jẹ gbę e ní kùmọ, ẹwo ni máa gbẹ ẹ nìsó - kùmo Arííriì.
1
Abíọ́lá sọ fún àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ láti retí ọ̀rọ̀ lórí bí wọ́n ṣe bá a gbé oyún.
0
A kì í binú aládun ká jàtẹ.
1
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń béèrè fún ìrànlọ́wọ́ láti kúrò ní agbègbè ogun.
0
B'éèyàn gb'ówó Keyìndé lọ, èpè ńlá ni Táyéwò yóò máa sę.
1
Àìkú ẹ̀kìrì, a kì í fi awọ-ọ rẹ̀ se gbẹ̀du.
1
Ẹnu t'áyéfi ń se. "pẹlẹ Olówó, n'ọn fi ń se 'pẹlẹ Òtòsì. Àmọ'pẹlẹ Olówó' ó yá ju, 'pẹlẹ Òtòșì'
1
B'ónkà bá ń kà á, kí'mọràn máa sẹ gègé 'ẹ s'ọwọ, k'ọlọgbọn máa finú rán an.
1
Afifilàperin ijo kan niyì ę mọ; bó bá dijọ keji ó d'olóogún.
1
Ẹ̀ má ṣe bí ewúré, ẹran aláìgbọràn.
0
Èèyàn bí òkété là á fọrọèkùro lo.
1
Abíọdún gbàwìn àmọlà (ẹba) lọwọ elẹhàá, elehàá kì í jáde osán, Abíọdún kì í jáde òru!
1
Ìbáṣepọ̀ láàárín Aláàfin àná àti Gómìnà ló fà á tí yíyan ọba kò fi yá.
0
Bí a kò bá rígún, à fàkàlà ṣẹbọ.
1
Aṣòfin yanjú aáwọ̀ ọjọ́ pípẹ́.
0
Ó dà bíi pé ọkùnrin náà àti ìyàwó rẹ̀ níjà.
0
Ẹní tí kò ì tíì rári-àpọn kì í yẹnà.
1
Àwọn ọ̀rẹ́ mẹ́ta fa ayélujára ya torí ọ̀rọ̀ wọn níle aṣòfin Èkó.
0
Èèyàn ńlá ma ń ju Òrìșà ńlá lọ nígbà mííràn.
1
Ènìyàn mẹ́ta kú níbi tí wọ́n ti fẹ́ yọ ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ wọn tó jábọ́ sí ṣáláńgá.
0
Bí iná bá jóni, tó jó ọmọ ẹni, tara ẹni làá kọo gbọn.
1
Aláyà ló lè gbélé-ńlá
1
Ariwo àjìjà ní ń dọ́run.
1
Bí a kò bá ní èsè ẹ̀fà, a kì í kó iṣu òje.
1
B'ólówó bá tę, ó yaláșeșá ni.
1
Àṣá ń tà, àwòdì ń rà; àwòdì tí ń gbé adìẹ lọ́sàn-án ò sanra to igún; bỌ́lọ́run ò pa igún, ohun tí igún bá rí a máa jẹ.
1
Ako ológbò ló ń m'ówó rá.
1
Àwọn agbófinró àti ẹ̀ṣọ́ aláàbò ti ń yanjú ìṣòro tó ń kojú ààbò ní díẹ̀ díẹ̀.
0
Ajóbíewé Àrẹ̀mù sọ ìtàn ayé rẹ̀ fún ìwé-ìròyìn Aláròyé
0
Apani kì í fẹ kí wọn mùdà kọjá nípàkọ òun.
1
Àwọn òbí gbọdọ̀ kọ́ àwọn ọmọ wọn ní Kíkóra ẹni níjánu.
0
Àwọn òṣìṣẹ́ ẹ̀ka ìrìnnà òfurufú ní Èkó ṣe bẹbẹ.
0
Mo fi Olúwa bẹ̀ ọ́ láti má ṣe tú àṣírí tí mo fi lé ọ lọ́wọ́ yìí síta.
0
Ẹbọ ẹnìkan là ń fi ẹnìkan rú.
1
Bí agbọ́n bá máa ṣorò, a kìdí bọlẹ̀; bí idà-á bá máa ṣorò, a ki ẹ̀kù bọ àkọ̀.
1
Eni wọn ń tàn kì í tún tan ààtàn.
1
Ìjà láàárín àwọn aláṣẹ ẹ̀ka ìjọba kan ń ṣe àkóbá fún iṣẹ́ ìdàgbàsókè.
0
Àgbìgbò, rọra fò, ọdẹ́ ti dé sóko; àgbìgbò tí ò bá rọra fò á bọ́ sápò ọdẹ.
1
Babalọlá Fálémi pàrọ̀ píìnì àwọn káàdì báǹkì mẹ́ẹ̀dógún náà.
0
Tẹkún-tomijé làwọn òǹtajà kan tí wọ́n ń ta màlúù nílùú Ìlọrin wà.
0
A kì í fi ìyá ẹní dákú ṣeré.
1
Ilé ẹjọ́ fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé lóòótọ́ ni ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún wáyé láago mẹ́ta ọ̀sán.
0
Àìdábùro ò yàgbà; àìní tòbí ò yobìnrin.
1
Ààrẹ bá wọn kẹ́dùn lórí ìkọlù àti òfò ẹ̀mí tó ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ náà.
0
Àdán òun Òòbe ẹgbẹra.
1
Ọkàn ìyá mi kò balẹ̀ nígbà tí ó gbọ́ nípa ìjàmbá tí bàbá mi ní.
0
Eleran kì í sùn, k'óníjànjá tanná mọrí.
1
Abólú jiyàn ló ń pẹ láàfin.
1
Agbẹjọ́rò fún ìjọba àpapọ̀ ṣàlàyé pé, ọ̀rọ̀ ààbò jẹ ojúṣe ìjọba àpapọ̀.
0
B'ẹdàá rọ l'árọjù, ìyà kì í gbài ję wọn, ẹgbin kì í sài ta lé wọn.
1
Ẹyìn lọgbọn kù sí.
1
Ara kì í kọ'lẹ kó kọ orí-ẹní
1
Ệèmejì ni onílé ń gbọrọ.
1
Àgbà ní ń jẹ orí àdán; ọmọdé ní ń jẹ orí ẹyẹkẹ́yẹ.
1
Ewé-odán se jù bẹe lọ, eran ló fi je.
1
Ìgbẹ́ gbuuru lè jẹ́ látàrí jẹ̀díjẹ̀dí tàbí àrùn mìíràn.
0
Akitiyan àwọn agbófinró láti bá a sọ̀rọ̀ já sí pàbo.
0
Ọwọ́ alẹ́ ni mo máa ń padà sílé lẹ́yìn iṣẹ́.
0
Ẹ tètè wá ọgbọ́n dá sí ìrìnàjò òfurufú yòówù tí ẹ bá fẹ́ rìn.
0
Bí a bá ká okó mọ́ obìnrin nídìí á ní kùkú ni.
1
Ó kéré ní ìgbà tí a lè rí òkodoro ọ̀rọ̀ ní ibi ìṣẹ̀lẹ̀ kan.
0
Àwọn akọ̀ròyìn sọ pé ìjọba ò ṣe òtítọ́.
0
Ba mi namọo mi', ò dénú ọlọmo.
1
Orin Àyìnlá Ọmọwúrà máa ń kún fún àwọn ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ Yorùbá.
0
Bí ẹjá bá sùn, ẹja á fi ẹja jẹ.
1
Bí o máa ra ilá ra ilá, bí o máa gba ènì gba ènì; ọmọdé kì í wá sọ́jà Agbó-mẹ́kùn kó wá mú eku.
1
Gbengbelekú; kì í rẹnií bá kú.
1
Àwọn èèyàn sọ pé Gbọ́láhàn kò ṣe ìwádìí.
0
Àwọn mọ̀lẹ́bí kò fẹ́ ìròyìn náà ní ìta gbangba.
0
Eni gbọ bí ẹni, a kì í tàn án.
1
Àwọn ọ̀dọ́kùnrìn tó fẹ́ sọ ilé ìjọba di ilé ọtí ni a máa lé dànù.
0
· Èniyàn ni ò je. Olorun 'Ò d'enikan kó má niilári.
1
Bile bá ń gbòsìkà, oore a máa súnií se.
1
Adarí àjọ elétò ìlera ni Kọ́láwọlé Ọláwuyì.
0
Gúnnugún bu awo-ayé șe, Àkàlà bu awo-ọrun mọ.
1
Àfọ̀pa ni Bọ́sẹ̀ máa ń fo aṣọ ẹ̀gbọ́ ìyá rẹ̀
0
Awo ibẹrẹ làá kọkọ kọ kí a tó kọ awo Ìgunnu.
1
Bí pẹ́pẹ́yẹ bá jẹ òkúta, omi ni yóò fi ṣu.
1
Alùwàlá ológbò ọgbọ́n àti kẹ́ran jẹ ni.
0
Àpáàdì ní ń ṣíwájú ọ̀fọ̀nná.
1
Aláìnítìjú lọ kú sílé àna-a rẹ̀.
1
Ọwọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ba ọ̀daràn kìíní ní ìpínlẹ̀ Òndó.
0
Ìjà náà kò parí títí di ẹnu ọjọ́ mẹ́ta yìí.
0
Awuye-wuye kan wáyé pé Sọjí ló pa ìyàwó rẹ̀.
0
B'éèyàn 'ò lóògùn irìndọ (ìrìnyà) kì í jẹ aáyán.
1
Àwọn ọlọ́pàá ló gba àwọn òbí awakọ̀ sílẹ̀ nígbà tí ènìyàn ya bò wọ́n.
0