Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Bí eṣú bá jẹ oko tán eṣú á lọ, a ku alátanpopo. | 1 |
Ẹrú lẹgbẹ, iwọfà lómiye, Ọmọ-Oșú lọbàkan. | 1 |
Alekapobíi-igi-ńlá sòroó yájú sí. | 1 |
Àgbà mẹ́ta kì í ṣi èkùlù pè; bí ọkán bá ni ‘‘ekulu,’’ èkejì a ní ‘‘ekùlù,’’ ẹ̀kẹta a ní ‘‘èkùlù.’’ | 1 |
Adigunjalẹ̀ kolu sójà ní Òndó. | 0 |
Ohun tó ń dá gbogbo èyí sílẹ̀ kò ju bí wọn ò ṣe tí ì yanjú ètò ìdìbò. | 0 |
Bílíònú mẹ́fà ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti yòó ná lórí Àmọ̀tẹ́kùn. | 0 |
Ó sọ wí pé iṣẹ́ náà wà ní Ìtaọlá, ó sì ní kí wọ́n wá sí Èkó. | 0 |
Àń bẹrú alájá; ajá șe b'óun là n bẹrú. | 1 |
Orí kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ iléèwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ méje yọ lọ́wọ́ ikú òjijì. | 0 |
Ẹní níhun-ún se kì í rẹdùn oro. | 1 |
Bùtù-bútú ọ̀nà Ìjèṣà lọmọdé fi ń ṣeré; bí kò kọ́mọ ní rírìn ẹsẹ̀, a kọ́mọ ní yíyan. | 1 |
Aya-n-ò-rọmọ-ri tí í tanná wo'yún lọgànjọ. | 1 |
Elenurírí ló l'àmù ìyá rẹ. | 1 |
Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá ti tẹ àwọn afurasí méjì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí. | 0 |
Abíọ́lá tí ń ba agbẹjọ́rọ̀ rẹ̀ sọ́rọ̀. | 0 |
Gbèsè ò sí, ẹsín ò sí. | 1 |
A kì í gbé'lé gbọfà láirogun. | 1 |
Báráyé 'ò bá sayéere, làá rántí èrò-ọrun. | 1 |
Aje-tuúlẹ ni tìrèké. | 1 |
Àdúgbò ti wọn kó àwọn tí ogun lé kúrò sí ló ti wa dàbí ìboju òkú pẹ̀lú bí ibẹ̀ ṣe pa lọ́lọ́. | 0 |
B'ẹrú bá pé jọmọ, ká fi ș'ọmọ. | 1 |
KA ki í feran ikún gbọn eran àgbọnrín nú. | 1 |
Àparò, aṣọ-ọ̀ rẹ́ ṣe pọ́n báyìí? O ní ìgbà wo ni aṣọ òun ò níí pọ́n? sán jíjẹ, òru sísùn, oúnjẹ ò ṣéé fi sílẹ̀ lọ́sàn-án; orun ò ṣéé fi sílẹ̀ lóru. | 1 |
Àwáyó fara ẹ̀ gbodì. | 1 |
Àwọn agbébọn ti di àwátì nígbà tí àwọn agbófinró yóò fi ya dé ibẹ̀. | 0 |
Ọlábísí rọ gbogbo olùgbé ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun kí wọ́n ṣe ara wọn ní ojú ni alákàn fi ń ṣọ́rí. | 0 |
Àṣìṣè nínú èsì àyẹ̀wò léwu púpọ̀. | 0 |
Ẹran (eni) níí múni jedin. | 1 |
Ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá tó wà ní Ìbarà kò jìnnà púpọ̀ sí ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún ti wáyé. | 0 |
Abínúẹni kò s ọ̀ràn deni. | 1 |
Wọ́n kí Dámilọ́lá káàbọ̀ sí àárín àwọn tí Òkìkíọlá ti tú yẹ̀rì wọn níta gbangba. | 0 |
Àwọn aṣọ́bodè gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ wọn bí iṣẹ́ bí a bá fẹ́ ní àlàáfíà. | 0 |
Eléérú ní ń ṣọkọ alátà; wọ́n bímọ wọ́n sọ ọ́ ní Òwó-ṣọ̀kan. | 1 |
Lára ẹ̀sùn míì tí wọ́n fi kàn án ni pé ó lu alámùúlégbè rẹ̀. | 0 |
Àwọn òṣìṣẹ́ ẹ̀ka ìrìnnà òfurufú lórílẹ̀-èdè Nàìjìríà bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ méjì. | 0 |
Àbáyòmí àti Dolápọ̀ ṣì wà lẹ́nu iṣẹ́ ọlọ́pàá. | 0 |
Àáyán ò leè kún kọjá ọjọ tó gbẹṣin. Odò Ògún 'ò lẹè kún kọjá ọjọ tó gbọtọ̀ọ̀tọ èèyan; tó gbọtọ̀ọ̀tọ èèyàn; tó fọmọ Asẹyìn fódò-Ògùn gbé. | 1 |
Àparò ń gba ikú oníkú kú, áḿbọ̀ǹtorí ikú ara-a rẹ̀. | 1 |
A ṣàlàpà lọṣọ̀ọ́ kò fẹ, a ṣe ohun gbogbo fún igi; ó yẹgi. | 1 |
Ariwo tí àwọn aládùúgbò mi ń pa ló jí mi láàárín òru. | 0 |
Àrùn ní ń múni jẹun ọ̀tá. | 1 |
Eso pele la fi n jija oyè. | 1 |
‘‘Ọjọ́ tí mo ti ń bọ̀ n kò rírú ẹ̀ rí’’: olúwa rẹ̀ mọ ìwọ̀n ara rẹ̀ ni. | 1 |
Didá là á kọo dà; kí a tó rò bí ẹmu. | 1 |
Mo ní ṣèbí nígbà tó bá ráyè jáde kúrò nínú ilé ọ̀hún lálàáfíà ni. | 0 |
Àgbàká lẹsẹ̀ ń gba ọ̀nà. | 1 |
Ẹní burú gọ; ó gbé. | 1 |
Ẹ má jẹ́ kí àwọn ọlọ̀tẹ̀ pín Nàìjíríà yẹ́lẹ-yẹ̀lẹ. | 0 |
Aláiforọlonilọnìyàn l'awo ìlú wèrè. | 1 |
Mi ò fẹ́ kí obìnrin náà la igi ọwọ́ rẹ̀ mọ́ mi lórí. | 0 |
Bí a bá ńyọ́lẹ̀ dà, ohun abẹ́nú a máa yọ́ni ṣe. | 1 |
Eerin jogun ọlá ni wọ́n kì wọ́n nílé e wọn. | 0 |
Ẹ̀fẹ́-ẹ́ dẹ̀fẹ̀ iyán; a paláwẹ́ ẹ̀kọ baálé ilé ní ẹ̀ ń pèun bí? | 1 |
B'ásínkùrọ bá ní òun ò mọye èkùrọ tí òun ti sín, òkúta to fi ń sín in mọye èkùrọ t'óun ti sín. | 1 |
Àjọ tó ń mójú tó ètò ìdìbò ń retí ìdáhùn àwọn ènìyàn ìbéèrè yẹn. | 0 |
Bí ojú bá mó, olówò a gbówò; ọ̀rànwú a gbé kẹ́kẹ́ ; ajagun a gbé apata; àgbẹ̀ a jí tòun tòrúkọ́; ọmọ ọdẹ a jí tapó tọrán; ajíwẹṣẹ a bá odò omi lọ. | 1 |
Ìròyìn ọ̀hún tún jẹ́ kí ilé iṣẹ́ náà pàdánù ètò ẹ̀yáwó láti ilẹ̀ òkèèrè. | 0 |
Eso, eso lelépo ń rìn bile bá n yọ, bí kò bá fẹ se ara re lófo (epo). | 1 |
Bojo bá se díẹ a dàná. | 1 |
Ẹni a fẹ sá bá, òun tun ń sá lọ. | 1 |
Kì í kù díẹ kí á pa á; kí ó wọgbó. | 1 |
Àtiwáyé ò dàbí àtirọ̀run. | 1 |
‘‘Gbà mu’’ ò tán ibà. | 1 |
Atètèṣágbẹ́ kì í mọ ọgbẹ́-ẹ́ ṣá bí aṣánisan. | 1 |
Àwọn olólùfẹ́ wọn ní ìbọ̀wọ̀ fún wọn. | 0 |
Adébíyìí jẹ́ elégbèlẹ́yìn ẹgbé wa. | 0 |
A-ṣọ̀tún-ṣòsì-má-ba-ibìkan-jẹ́, irọ́ la ó bàá níbẹ̀. | 1 |
Ààrẹ ti bá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yọ àyájọ́ ọdún tuntun. | 0 |
Àmọ̀pé àti àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ ri dájú pé àwọn mọ ohun tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ fún nígbà gbogbo. | 0 |
Àbúrò mi ra ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn. | 0 |
Arábìnrin sọ wí pé òun fi ara mọ́ ọn pé kí ìbáṣepọ̀ àwọn túká. | 0 |
Bí ìjì ti ń jà lóko bẹ́ẹ̀ náà lo ń jà nílé, koda ó hú igi òhun gbòǹgbò rẹ̀. | 0 |
Awọ́ni ní ń fìdí ara-a rẹ̀ lànà fún ẹni tí ń wọ́ lọ. | 1 |
Àdàbà ò wá oúnjẹ sẹ́nu òrofó; oníkálukú ní ń wá oúnjẹ sẹ́nu ara-a rẹ̀. | 1 |
Bí eegbọ́n bá so mọ́ ajá lẹ́nu, akátá là ń ní kó já a? | 1 |
Wọ́n ti fi ọkàn ẹlẹ́dẹ̀ rọ́pò ọkàn àwọn ènìyàn méjì ṣáájú ṣùgbọ́n tí ó padà já sí ikú. | 0 |
Adétibà pàṣẹ pé kí Adégbémilé máa san owó oúnjẹ ọmọ rẹ̀. | 0 |
A kì í sọrọ ìkọ̀kọ̀ lójú olófòófó. | 1 |
Bí wọ́n bá ti gba ẹyin méjèèjì ni ẹnìkan yóò wá gbé oyún náà. | 0 |
Wọ́n gbé akẹ́kọ̀ọ́ tó ṣèṣe lọ sí ilé ìwòsàn ìjọba tó wà lágbègbè ìṣẹ̀lẹ̀ náà. | 0 |
Kò sì sí ẹ̀rí kankan láti fi hàn bóyá wọ́n halẹ̀ mọ́ ọn. | 0 |
Agbèfọ́ba rọ ilé-ẹjọ́ láti sọ àwọn afurasi méjèèjì sí àtìmọ́lé títí ìwádìí yóò fi parí. | 0 |
Àwítẹ́lẹ̀ ní ń jẹ́ ọmọ́ gbẹ́nà; ọmọ kì í gbẹ́nà lásán. | 1 |
·Biyán ò pọ, iyán ò le | 1 |
A kì í m'órín, kí a múlù. | 1 |
Àwọn gómìnà lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú kan ti darapọ̀ mọ́ mìíràn. | 0 |
Ètè-òkè, ètè-ìsàlę la jùmọ fi í șe 'hàà' 'hòòo'. | 1 |
Agbódegbà sọ wí pé òun kò jẹ̀bi ẹ̀sùn. | 0 |
Bí eégún ẹní bá jóore, orí a yáni. | 1 |
A kì í fúnni ľ'ẹmu k'á má fi há sí i (lé é). | 1 |
A kì í há ẹran kí òroòró má gba tiẹ níbẹ. | 1 |
Bó jẹ́ ìkà ló bá wù ọ́, máa ṣe é lọ. | 0 |
Ọdún kan ti kéré jù láti ṣàgbéyẹ̀wò sáà ìjọba Ààrẹ Tinúbú. | 0 |
Àwọn agbófinró sì ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìwádìí wọn lórí rẹ̀. | 0 |
Àwọn kan ní olórí ẹgbẹ́ onígbàálẹ̀ kò nífẹ̀ẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó. | 0 |
Mákindé sọ pé Tọ́pẹ́ kì í fẹ́ kí àwọn ènìyàn máa jókòó sórí tébùrù pọ̀nmọ́ rẹ̀. | 0 |
Ebi òjòjò àgbà, ò-pàgbà-fọwọ- mẹkę. | 1 |
Àtigùn làá kọ ọmọdé, a kì í kọ o látisọ. | 1 |
Atọpárá ní í fikuú seré. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.