Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Àwọn ènìyàn náà ni wọ́n halẹ̀ mọ́ òun pé kí òun gbà kí ajá bá òun láṣepọ̀.
0
A kò lè dárúkọ àwọn obìnrin méjì náà.
0
Ìwádìí tó ń lọ lọ́wọ́ lórí ẹ̀sùn ìwà ìbàjẹ́ ni yóò mú kí àwọn agbófinró di èrò àhámọ́.
0
Èyí tó burú ni kí ènìyàn kan jókòó síbì kan kí ó sì máa tan ara rẹ̀.
0
Ajànàkú ò l'éèkàn, atẹgùn ò ní'bùso.
1
Gàgàló șubú owọ tẹ ọparun.
1
Bí a bá perí ajá, ká perí ìkòkò tí a ó fi sè é.
1
Ààrẹ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ti fi àìdùnnú wọn hàn lórí bí ìgbé ayé àwọn òṣìṣẹ́ kò ṣe rọrùn.
0
Ẹni tífá rẹ kì í jẹ'ja, ó tọ kí ó gbèèwọ omi mímu pẹlú e.
1
Àwọn ọlọ́tẹ̀ ló ń gbìyànjú láti dá ọ̀tá sílẹ̀ láàrin wa.
0
B'ọrọ tó wuni bá ń tẹnu ẹni jáde, k'étí ẹni máa retí kòbákùngbéoro.
1
Àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò ará ìlú rí ọta ìbọn mẹ́ta nínú igbó.
0
Foyèkẹ́ fi ìdùnnú rẹ̀ hàn sí Adélékè ní ti ìnáwó àti ìnára rẹ̀.
0
Ẹni tí a ò tó gígàn là á gàn án.
1
Èèyàn púpọ̀ ti fara gbọgbẹ́ lóríṣiríṣi látàrí ìjàmbá ọkọ̀ akẹ́rù gbọ̀gbọ̀rọ̀ tó wáyé.
0
Àwọn ọ̀dọ́ méjì pinnu láti kọ̀wé fi iṣẹ́ sílẹ̀.
0
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ni ìyà ìyanṣẹlódì náà ń jẹ jù.
0
Àwọn oníṣẹ́ ìwádìí ìjìnlẹ̀ ń wá ojútùú sí àjàkálẹ̀-àrùn.
0
Ṣíṣe ẹ̀ṣà ìrìnàjò lè dẹ́kun ìtànká àjàkálẹ̀-àrùn.
0
À-gbàbọ̀-ọ ṣòkòtò, bí kò fúnni lẹ́sẹ̀ a ṣoni; rẹ́múrẹ́mú ni ohun ẹni ń bani mu.
1
Akíntúndé ní àjọ tó ń rí sí ìforúkọ sílẹ̀ àwọn ilé iṣẹ́ wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
0
A si n gbadura pe Ọlọrun yoo fi ọrun kẹ ẹ.
0
Àpáǹtètè ń bẹ láyé; kò sí lọ́nà ọ̀run.
1
B'áyé bá yẹ wọn tán, ìwà ibàję ni wọn ń hù; ló dá fún Àwúrèbe tó ń s'ọde agííińtí.
1
Akọ ológbò-ó mú owó rá.
1
Bọ̀rọ̀kìnní ju ọlọ́rọ̀ lọ.
1
Ẹni tí ó ra ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ olóògbé jẹ́wọ́ pé Fákẹ́yẹ ló tà á fún òun.
0
Arákùnrin tó ń múra bí obìnrin fẹ́ràn gbajúgbajà olórin.
0
Àbíkẹ́hìn-in gbẹ̀gẹ tí ń yọ olóko lẹ́nu.
1
Bí ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani.
1
Balogun máa ń dẹ́rù ba àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Erínfọlámí.
0
Ajá jẹmí kò kú, adìẹ gbé ekòló mì kò tutọ. Ìgbín jẹ yẹpẹ kò ha kẹlẹbẹ. Wọn bèèrè pé kì ló dé? Wọn ní ohun tí a bá jẹ síkùn ení tí kò pani òun ni oògùn-ebi.
1
Ẹkọ dí kókó; kì í sẹjo alágbàdo.
1
Àwọn olùdíje ń wá ìbò lọ́dọ̀ àwọn alátìlẹ́hìn àti ọmọ ẹgbẹ́.
0
Ikú ọlọ́dẹ yìí dá ìbẹ̀rùbojo sílẹ̀ ní àdúgbò Dálímore.
0
‘‘Ata-à mi dandan, iyọ̀-ọ̀ mi dandan,’’ olórí èpè.
1
B'árùn se wá kọ ló ń lọ.
1
Ẹgbẹ́ òṣèlú Onígbàálẹ̀ sọ wí pé ìgbésẹ̀ tí gómìnà náà gbé kò bójú mu rárá.
0
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ èrò ṣíná ìbọn níbi ìpolongo ìbò tí ó wáyé.
0
Ènìyàn gbàgbé Ọlọrun Rántí.
1
Mo fẹ́ kí a jọ máa ní àsọyépọ̀ ní gbogbo ìgbà.
0
Igun Làmídì sọ wí pé ẹgbẹ́ òṣèlú Alágbàdo ń ṣiṣẹ́ tako ìdájọ́ ilé ẹjọ́.
0
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ máa ń fẹ́ ọmọ Balogun nínú ẹgbẹ́ wọn .
0
Eléérú ló ń sungì.
1
A gbọ́ wí pé ó ti tó ọdún mẹ́ta tí àwọn ará Òkè-odò ti ní iná-ọba gbẹ̀yìn.
0
Gbẹrẹ 'ò ran ebi; àkàsù-ẹkọ l'oògun ẹ.
1
Ẹjọ́ a-f ni-lóbìnrin là ń wí; a kì í wíjọ́ a-f ni-lómọ.
1
Àì-lè-jà ni à ń sọ pé, ‘‘Ojúde baba-à mi ò dé ìhín.’’
1
B'álágbede bá ń lu'rin ľ'ójú kan, ibę l'ápeerę ni.
1
Egbòó kẹ, iná kẹ, ohn ọmọ èèyán náà kẹ.
1
Ẹdá tó mọ yááyì l'ayé ń fẹ.
1
Akì í pé kíkà ẹdá se é kọ wò ó (ká rí i).
1
·cbogbo ohun tí a bá ní se, kì a fàsejù kún un, kó lè baà tó waáje.Gbingbìnnikin ló ń wiwo.
1
Àwọn ènìyàn Oǹdó ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ìjọba.
0
À ń jù wọn ò ṣéé wí lẹjọ; ìjà ilara ò tán bọrọ.
1
Apata-á ríkú kẹ̀hìn si í; apata ní ń gbani lógun.
1
Alukoro ẹgbẹ́ àwọn ọmọ Ìbò, Ẹ̀míọlá ló sọ èyí di mímọ̀ láìpẹ́ yìí.
0
Ayé ò fẹ́ ká ru ẹrù ká sọ̀; orí ẹni ní ń sọni.
1
Àṣẹ̀ṣẹ̀wọ́n ológbò ní ń jìyà; bó bá pẹ́ títí a tó eku-ú pa.
1
Ệèkan nìjẹbú ń sí lọ nílé ẹni.
1
Àyà-níní tóògun lọtọ.
1
Ànàmú ni tọgà.
1
Èèyàn mẹfà mu ọ,o ní ò n ba wọn-ọn lọ. Ò ń bá wọn lọ, àbítuláàsì?
1
Tọ́pẹ́ sọ pé mo gbá òun ní ẹ̀ṣẹ́ níkùn nígbà tí à ń jà.
0
À ń gba òròmọ adìẹ lọ́wọ́ ikú, ó ní wọn ò jẹ́ kí òun jẹ̀ láàtàn.
1
A ti bẹ̀rẹ̀ sí ní máa san àwọn owó tí wọn jẹ àwọn òsìsẹ́ fẹ̀yìntì fún ìgbà pípẹ́ báyìí.
0
Ìwà ẹlẹ́yàmẹ̀yà tí wọ́n ti kásẹ̀ rẹ̀ nílẹ̀ láti ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn wà lára àwọn okùnfà ìwà ipá.
0
A-dọ́gbọ́n-pàgùntàn-jẹ Ìlárá, ó ní ojú ẹ̀ ń ba òun lẹ́rù.
1
Àjànàkú fojú ìṣ wọ̀bọ, ọ̀bọ ò tọrọ jẹ.
1
Ewúro kórò tewé tewé, egbęsì koró tegbò-tegbò.
1
A kì í rí a-rẹ́-má-jà; a kì í rí a-jà-má rèẹ́ .
1
Ẹ̀fọn náà lágbára ju àwọn òògùn apa ẹ̀fọn lọ.
0
Bó o bàá jẹ nnkan; ìmọràn ni kí o gbà.
1
Bẹ́ẹ̀ sì ni kì í fara hàn lára ẹlòmíràn.
0
Wọ́n sọ fún àwọn agbófinró ní ilé ìwòsàn pé Àìná ti dákẹ́.
0
Asárélówó ń bẹ lọ́nà ogun; Apọ̀ṣẹ̀ṣẹ̀ ḿbẹ lọ́nà èrò; Bó-pẹ́-títí-n-ó-là ń bẹ lábà, ó ń jẹ ẹ̀sun iṣu.
1
Ọ̀yọ́mèsì tún rọ Gómìnà láti má ṣe yan ìgbìmọ̀ afọbajẹ mìíràn.
0
A kì í toríi fòrò dákọ; a kì í torí adándó ręgì.
1
Èròńgbà wà pé wọn yóò kọ́ ilé iṣẹ́ ìfọpo rọ̀bì sí agbègbè náà láti máa fọ epo.
0
Àwọn olóde ìyàwó pa agbo ọ̀tọ̀ fún ijó jíjó.
0
Hilàhílo kì í tán ľọrọ isọwo abímọ-mátọo.
1
Epo 'ò yọ bí òrí, òrí 'ò yọ bí àdín eyan (àgbọn/yánkò)
1
Bó se ń se ọ, ló ń se mí, àlè-ikòkò.
1
A kì í fi 'mo dàgbá' mọ Akínmoorìn.
1
B'ọjà bá tú, a ku pàtę-pàte.
1
Ìdíje bọ́ọ̀lù ọlọ́rẹ̀ẹ́-sọ́rẹ̀ẹ́ yóò wáyé láàárín orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Ṣáínà.
0
Báyìí ni o ṣe lè di ọmọ onílùú pẹ̀lú òfin tuntun orílẹ́èdè.
0
Kò ju ìṣẹ́jú díẹ̀ lẹ́yìn náà ni wọ́n sọ fún mi pé obìnrin náà ti kú..
0
Àyìnkẹ́ fi ẹ̀rí hàn pé àwọn ayédèrú ènìyàn ti wà ní ojú òpó ayélujára.
0
Àṣẹ iléẹjọ́ ní kí wọ́n wọlé padà.
0
Bí nnkan 'ò bá ì ì bàję, kì í tò.
1
Àti wà lókè téńté nínú iṣẹ́ tí mo yàn láàyò nílò owó.
0
Àṣá wo ahun títí; àwòdí wo ahun títí; idì baba àṣá, kí ló lè fi ahun ṣe?
1
Ọmọ onílùú kan ló gún akẹ́kọ̀ọ́ Fásitì Àkùngbà lọ́bẹ pa.
0
Ẹgbé òṣèlú wa kò se ìpàdé pẹ̀lú ẹgbẹ kankan o.
0
Durí (dura) kí o tó duyè.
1
Ẹnu ìjà èmi àti obìnrin onípọ̀nmọ́ náà ni bàbá mi ti bá wa.
0
Mo bẹ gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ràn mí lọ́wọ́.
0
Àtẹ̀jáde kan fi ohun tí Àtíkù kọ sí orí ìkànnì rẹ̀.
0
Àgùntàn 'ò pașọ èșí dà.
1