Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Àtẹ́lẹwọ́ finú ṣọ̀kan; àtàm̀pàkó ṣe tiẹ̀ lọ́tọ̀.
1
Ìyapa òbí máa ń nípa tí kò dára lára àwọn ọmọ wọn.
0
Àwọn Iléeṣẹ́ ìròyìn gan-an ni a ò bá sọ pé wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ kiri.
0
Ajìnfìn, má ta ojú ilé; ọ̀pọ̀lọ̀ jìnfìn má ta ojú àtijáde.
1
Ayé àtijọ́ ni àwọn èèyàn ń tẹ̀lé àṣà àti ìṣe kò rí bẹ́ẹ̀ mọ ní ìsinyìí
0
Owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jù lọ fa ìbínú àwọn òṣìṣẹ́.
0
Àkíyèsí yìí fi hàn pé àwọn ènìyàn kan ni wọ́n pa ọlọ́dẹ náà.
0
B'éèyàn ò bá ti f'ojú sun omi níwájú, kì í tęse bere leyin.
1
Ó ṣòro láti mú kí ènìyàn mìíràn yí ìpinnu wọn padà.
0
Àșẹẹẹ-tọ-ọtí-wò, okùn bàǹtẹ já, bí a bá wa mu ún yó ń kọ?
1
Bí a j'oyin pẹ pẹ pẹ; tí a jàdò jìn dòdò; kí a mná sàsùnpiyè péjọkan ń bọ wá jọkan tẹni ó sùn, tẹni 'ò ní jí s'áyé mọ.
1
Àwọn oṣiṣẹ pàjáwìrì kan náà wá sí ibi ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí wọ́n n yọ Bím̀bọ́ jáde lábẹ́ pátákó náà.
0
Wọ́n kéde Tówojú gẹ́gẹ́ bí igbá-kejì adarí.
0
Bámúbámú ni omi mu oko ọ̀sìn adìẹ Tóyìn Akíngbọlá.
0
B'ẹja-ńlá bá sọ lódò, ojú-omi a parę.
1
Eni tó mùkùn l'ódò tó lọ jí ogede jẹ; b'ó bá yá, èèpò rẹ yóóléf'òó téńté s'ójú-omi.
1
Alákàrà kì í fẹ́ kí ẹnìkejì gbé agbada.
1
Eni tí kò ní sáré-a-rè, tí kò ní 'Tètè-dé'; ló ń gbé ségbè.
1
Afẹká l'ayéé fẹná, àrànká l'oòòrún ń ràn.
1
Àwọn olùgbé orílè-èdè Nàìjíríà lásìkò yìí nílò láti ní ohun ìdánimọ̀.
0
Àdéhùn tó wà láàárín àwọn méjéèjì ni pé wọn ò ní dalẹ̀.
0
Bí bàtá bá ń dún bíi mólo, k'Ónímọgbà ó fura.
1
Bí ọmọdé bá lówó, ìgbéraga ní ń dà lójú àgbà.
1
Ó ní òun sọ fún un lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ tí òun rí i pé kí ó gba òun láàyè láti bá a lò pọ̀.
0
Aboyún bí, ìhá tù ú.
1
Àwọn ènìyàn gbé ẹ̀bùn wá fún mi lọ́jọ́ ìgbéyàwó mi.
0
Àwọn aṣòfin tún pàṣẹ pé kí àwọn olórí ẹ̀ka kan kó àwọn ìwé kan wá.
0
Ẹlẹ́dẹ̀ ò mẹ̀yẹ.
1
Ẹ̀kọ́ máa ń sodo sínú àwọn ojúlówó fíìmù èdè Yorùbá.
0
Aṣiwèrè èèyàn ní ń kọṣẹ́ àbọ̀ ọjà.
1
Akásọlérí mọbi òun ń rè.
1
Eni tó mọdí orọ tele níí bu àbùjá èké.
1
Èèyàn mẹ́fà, nínú èyí tí ọmọọwọ́ kan wà jáde láyé látàrí ìjàmbá ọkọ̀.
0
Arákùnrin kan sọ ìdí tí òun fi fi ipá bá ọmọ ọdún méje lòpọ̀.
0
Ewé ló ń sin obì.
1
Ẹgbẹ́ tí Ọ̀gbẹ́ni Àjùwọ̀n àti àwọn ènìyàn rẹ̀ dá sílẹ̀ máa ń lọ káàkiri àdúgbò láti lọ ṣe àyẹ̀wò
0
Orísúnmbáre ni àwọn oníṣẹ́ láabi pọ̀ sí.
0
A kì í fi adię-odò b'orí ęnì.
1
Àwọn àkàndá ẹ̀dá ò tí ì fún ìjọba lésì kan pàtó.
0
Ẹ máṣe bú Ọlọ́run torí ọrọ̀ ajé tí kò dára àti òṣì tó gbalẹ̀ ní Nàíjíríà.
0
A hán ìkokò lọ́wọ́ ọ̀tún, a hán ìkokò lẹ́sẹ̀ òsì; ó ku ẹni tí yóò kò ó lójú.
1
Daada ló wà nínú.A,B.D.
1
Ajé tún ọmọ bí.
1
A kì í kélèé ṣẹṣọ
1
Adérọ́pò sọ̀rọ̀ lórí ohun tí Ààrẹ lè ṣe láti dẹ́kun ìpànìyàn ní Ọ̀tà.
0
Àwọn dẹrandẹran tún sọná sun ṣọ́ọ̀bù ní Ojú-òóré.
0
Ẹgbẹ́ kan wà tí a mọ̀ sí ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ fásitì ní Nàìjìríà.
0
A kì í peni lólè ká máa gbé ọmọ ẹran jó.
1
Àwọn agbébọn pa ènìyàn mẹ́tàlá ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun
0
Túndé Babalọlá ló kọ fíìmù àgbéléwò àwọn ayálégbé.
0
·èyitía pa ko làn tù èyí ti àn tù wà nínú igbo.
1
Alágbe ò ń kú lOyọo.
1
Wọ́n ké sí àwọn ará ìlú ní kété tí àwọn ọmọ ogun gúnlẹ̀.
0
Ení b'áyé mulẹ, á b'áyé moje.
1
Àlùsì ẹsẹ̀ tí ń fa koríko wọ̀lú.
1
Olórí ìlú tó bá ń wá àlàáfíà fún ìlú rẹ̀ kò ní ṣe bẹ́ẹ̀.
0
Ọlọ́pàá fẹ́ kí àwọn ará ìlú nígbàgbọ́ pé àwọn kò ní figbá kan bọ ọ̀kan nínú.
0
Awọn èèyàn ńláńlá ló wá sí ibi ayẹyẹ náà.
0
Gbà yí, sò yí, kì í tán lọrọ alántakùn.
1
Bá ò kú ìṣe ò tán, bẹ́dàá bá ṣì wà láyé ìrètí ń bẹ.
0
Èmi ni olùdíje tó fẹ́ lọ ṣojú ẹgbẹ́ wa nínú ètò ìdìbò tó ń bọ̀ lọ́nà.
0
A gbọ́ ìròyìn tuntun nípa Alàgbà Ajéìgbé.
0
A kì í yàgò fún ẹlẹ́ṣin àná.
1
Àwọn ajínigbé ti kàn sí ìyàwó Páítọ̀ lórí aago.
0
Àwọn agbébọn kọlù àgọ́ ọlọ́pàá márùn-ún lásìkò ìwọ́de.
0
Àkókò tí ètò ìdìbò máa ń wáyé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ètò ìdìbò Ààrẹ yìí wáyé.
0
Ẹgbẹ́ epo pẹtiróò tí aládàáni wà káàkiri ní Nàìjíríà.
0
Ení l'áya méji, kó pèkan lóorun.
1
Babaláwo tó nífá òun kì í roko, kì í kọpẹ, kò ní sài b'óșì dìgbàró
1
Àwọn ènìyàn máa ń pe Adépọ̀jù ní bàbá Ìjẹ̀bú.
0
Arẹ́gbẹ́ṣọlá ń ràn mí lọ́wọ́ lórí ìtọ́jú àwọn opó.
0
Èèyàn ló dáso fẹkọ, èèyàn náà ló rin ẹkọ ní ìhòòhò.
1
Àwọn ẹranko pàápàá nílò omi fún ìwàláàyè wọn.
0
Àwọn òbí sọ wí pé àwọn alákòóso ilé-ẹ̀kọ́ kò ṣe ohun tó yẹ lórí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ àwọn.
0
Nítorí kí nǹkan ba lè dára láàárín ìlú ni a ṣe gbọ́dọ̀ ṣe bí ó ti yẹ.
0
Eni tí ò mọrọo sọ níkọkọ, kò leè mọ ọ wí ní gbamgba.
1
Obìnrin kan sọ pé òun ti ń ṣètò àti sá lọ.
0
Kọmíṣọ́nà fọ́rọ̀ àwọn obìnrin sọ pé ó ti pẹ́ tí àwọn ti ń wá Ajíṣafẹ́.
0
Bí a bá lọ, bí a bá bọ (dé) kí a má gbàgbé eni a pé a ó so lókùn leekan.
1
‘‘Bá mi na ọmọ-ọ́ mi’’ ò dénú ọlọ́mọ.
1
Ọláńrewájú tún sọ wí pé àwọn ti fi ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣekúpani náà tó àwọn agbófinró létí.
0
Àbá ní ń di òtítọ́; ojo ni kì í jẹ́ ká da.
1
Bí a bá ń ṣẹ́ gègé ìjà, ká mú ti ológbò kúrò; ọba lọba ń jé .
1
Àwọn àgbẹ̀ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ kò tó ìdá méjì àwọn tí àwọn ọ̀daràn ń pa.
0
Èyí ni ó ṣe àfihàn rẹ̀ wí pé epo rọ̀bì wà ní ìpínlẹ̀ Bodè, Gáà, Bójúrí àti Najúro.
0
Diméjì Ajíkòbí ti di olóògbé ní báyìí.
0
B'ẹmìí gùn, bá ò kú, ire gbogbo ló ń șojú ẹni.
1
Àșegbé 'ò sí, àșepamọ ló wà.
1
Bí àrígiṣẹ́gi-í bá ṣẹ́gi, orí ara-a rẹ̀ ní ń fií rù ú.
1
Wọ́n kéde nígbẹ̀yìn pé Bọ́lá ló jáwé olúborí.
0
Màá bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti ṣe àtúnṣe àwọn kùdìẹ̀kudiẹ mi.
0
Atannáwẹbí Èsúó; ó ní Èkùlù ló bí ìyá òun.
1
Bí a kò bá lè mú ọkọ, a kì í na obìnrin-in rẹ̀.
1
Adájọ́ àgbà ti padà sọ pé òun kò jẹ̀bi ẹ̀sùn tí ìjọba fi kan òun.
0
Bí oṣù-ú bá lé, gbogbo ojú ní ń rí i.
1
Àwọn ẹgbẹ́ ẹlẹ́yinjú àánú ti ń pín oúnjẹ fún àwọn ènìyàn.
0
Àwọn olórin nílò àròjinlẹ̀ kí wọ́n tò kọrin.
0
Àwọn ìdílé yìí ló lè fi agídí bá iléèṣẹ́ ológun sọ̀rọ̀ lásìkò ètò ìdìbò.
0
Bí iná kò bá tán láṣọ, ẹ̀jẹ̀ kì í tán léèékánná.
1
Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn olórí ìlú ni ó jẹ́ kí mímú àwọn awakùsà ṣeéṣe.
0