Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Bí eégún ó bàá wọlẹ̀, orò ní ń ṣe.
1
Àjíún ń ṣe nǹkan oṣù lásìkò tí Bámgbọ́lá fipá bá a sùn.
0
Arugudu òjò tí ń ṣú laàrin òru.
1
Àgbàlagbà kì í méku dání kó di amùnrín.
1
Àwọn ọlọ́pàá mú ọgbọn àwọn oníjìbìtì ní Abẹ́òkúta.
0
Èékánná owọ ni 'ò jękun șọde.
1
Aráyé,abojú pete.
1
Àwọn agbébọn tó ṣe ìkọlù naa, lo ọkọ méjì lati fi ṣe ikọlu ọjọ́ náà.
0
Ọwọ́ ba àwọn amòòkùnṣèkà ẹ̀dá mẹ́ta ní ilé ijó.
0
B'ójú-àànú bá fọ; tìkà níí kù.
1
Aponjú-abẹ-lá 'ò tójúu idàá pọnlá.
1
Àtòrì l'ayé, b'ó bá lò swájú, á tún lò seyìn.
1
B'Ákàlà jojú tán; a a ha onà-ọfun kerẹ kere.
1
Bí a bá ń j'oyin lọ títí, tí à ń jàdò lọ sàà; ó yẹ kí a máa díjọ níran iye eni t'on f'ojo gbogbo ję jogbo.
1
Àkọ́bí ni ti ẹlẹ́ran.
1
Abímitán ò da nǹkan; ara la fi ń ré.
1
Eégún wá bùrà bó ò dégbó rí, Orò wá búra bó ò dégbàlei alábàjà wá búra bí o ò bá bÁláàfin tan!
1
Eșinșin tí ò lẹgbę, l'ọgbà ló ń kú sínú otí.
1
Díẹ̀ ló kù kí dókítà kan àti nọ́ọ̀sì mẹ́ta padà ẹ̀mí wọn sọ́wọ́ àwọn olùfẹ̀hónúhàn náà.
0
Àárín àwókù ọkọ̀ tó rún jégé ni wọ́n ti rí òkú àwọn èèyàn méjì yọ.
0
A ti rí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ tí Ìdòwú sọnù sọ́jà ní ìsọ̀ eléèlò.
0
Alárìnjó tí yó jòó, kó ti ìwòyí mú ẹsẹ̀ kó le kó kó kó.
1
Gìrì lọgàn-án toríí jìn.
1
Àwọn àgùnbánirọ̀ yóò ṣe ìkéde ìfẹ̀hónúhàn nípa ewu tó wà níbi ìwà ìbàjẹ́.
0
Ó kan ilẹ̀kùn ṣùgbọ́n kò rí ẹnì dá a lóhùn.
0
‘‘Bí mo lè kú ma kú’’ lọmọkùrín fi ń lágbára; ‘‘N ò lè wáá kú’’ lọmọkùnrín fi ń lẹ.
1
Agbẹjọ́rò ní kí adájọ́ jẹ́ kí ó sanwó ìtanràn dípò kí ó lọ sẹ́wọ̀n.
0
Epo nìrojú obe.
1
Ilé ẹjọ́ yóò ṣe ìdájọ́ olóyè Ìkẹ́ àti ìyàwó rẹ̀ ní oṣù karùn-ún.
0
Àgbìgbò gorí Ìrókó tigbe ìráhùn bọnu kan kan kan.
1
Bí eégún ò bá ṣe ohun tó tóbi, atọ́kùn-un rẹ̀ kì í tú u wò.
1
Bóomọ́ yọ láàrin bàbà.
1
Ìyá mi wà lábúlé wa ní Oko Àwo.
0
Ìjọba ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan láti fòpin sí gbígbé ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ kiri.
0
Ọláwálé gbóríyìn fún gbogbo àwọn ọmọ-bíbí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà fún adúrótì wọn.
0
Ẹlẹ 'ò níyì l'Ájàșẹ, Baálẹ ibẹ idọ ló ńn ro.
1
Àwọn aráàlú ń dunnú pé gbogbo ìgbìnyànjú wọn ò pòfo.
0
Ìjọba ń ṣètò láti san owó gbà má à bínú fún àwọn tí ọ̀nà kíkọ́ náà ṣàkóbá fún ilé ìgbé wọn.
0
Mákindé sọ wí pé níṣe ni Tọ́pẹ́ fọ́ òun létí láti ẹ̀yìn.
0
Asọ̀ baba ìjà.
1
Ìlú Kánò ni àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin ọ̀hún tó lajú lẹ́yìn tí wọ́n jẹun tán.
0
Wọ́n ní kí ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún Gómìnà Ọ̀yọ́ láti fara mọ́ ẹni tí àwọn bá fà kalẹ̀.
0
Akọ ajá lọ́lá; àgùàlà niyì oṣù.
1
Àdàbà ò jẹ̀pà; kanna-kánná ò jẹ sèsé.
1
Ìjọba buwọ́lu kíkọ́ ibùdó káàkiri ìlú Àbújá.
0
A bímọ lÓwu, wọ́n ní ‘‘akọ mbábo?’’ Èwo ni yó ṣọmọ níbẹ̀?
1
A rí àkọsílẹ̀ kan lórí ẹ̀rọ ayélujára lọ́jọ díẹ̀ sẹ́yìn.
0
Gẹge ìyàwó ń bọ wá dẹtẹ.
1
Bí o máa ṣe aya Olúgbọ́n ṣe aya Olúgbọ́n; bí o máa ṣe aya Arẹsà ṣe aya Arẹsà, kí o yéé pákọ̀kọ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ògiri; ẹni tí yó ṣe aya Olúfẹ̀ a kógbá wálé.
1
Afúnijẹ kì í fún nií tà.
1
A-búni-lọ́lẹ ò mọ ohun tí ń ṣeni.
1
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ onímọ́tò ti bẹ̀rẹ̀ ìjà ní ìlú Èkó.
0
Eni jeyán sùn a á só lóru, ệní mùkọ sùn áá to yàyà
1
B'ẹran bá șe tó làkunbọ ẹran ma ń mo.
1
Àwọn ikọ̀ tí ń ṣe iṣẹ́ yìí kò gbowó, bẹ́ẹ̀ ni wọn kìí gbé ìbọn lẹ́nu iṣẹ́.
0
Àìtètè-fẹyàwó, ọrẹ làá tọjú.
1
Èwo ni kéèyàn máa fi tipátipá ti ara rẹ̀ mọ́ àwọn tí wọ́n láwọn kò fẹ́ ẹ lọ́rùn.
0
Ata tí wọ́n lọ̀ ò kúná rárá ìdí tí mo fi dá a padà nìyìí.
0
Aláṣedànù tí ń fajá ṣọdẹ ẹja.
1
Àwọn ènìyàn gbọ́dọ̀ yàgò fún ìwà ṣíṣe ìdájọ́ lọ́wọ́ ara wọn.
0
Eégún kì í wọlé kó má da nnkan, ohun tí ó dà la ò mọ.
1
Ìjà láàárin àwọn elédè méjì ni olóṣèlú fẹ́ parí.
0
Bí a kò bá pa ìjí han ìjí, ẹ̀rù kì í ba ìjí.
1
Ẹni mọ gígùn ệwù ló ń wọ ọ.
1
Bí ọmọdé bá dárí sọ apá, apá á pá; bó bá dárí sọ ìrókò, ìrókò a kò ó lọ́nà.
1
Tébùrù pọ̀nmọ́ obìnrin kan díjà sílẹ̀ láàárín àwọn alájọgbélé mẹ́ta ní ìpínlẹ̀ Ògùn.
0
Ijọba orilẹede Naijiria ni awọn yoo bẹrẹ si nii ko awọn ọmọ Naijiria kuro ni Sudan lọjọ Iṣẹgun, ọjọ Karundinlọgbọn osu kẹrin ọdun tó kọjá.
0
Lọ́gán ni àwọn ọlọ́pàá ṣíná sọ́kọ̀ tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í tọpasẹ̀ wọn.
0
A ó bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ tiwa bí gbogbo ètò ìfinijoyè bá bẹ̀rẹ̀.
0
Ó sọ wí pé àsìkò kan wà tí òun kó àrùn ìbálòpọ̀ láti ara obìnrin náà.
0
Akọ́kọ́dájọ́ lọ̀tá ẹlẹ́jọ́.
1
Ọ̀rẹ́ mi tún sọ pé àti wí pé ọmọ Yorùbá bí Yẹmí bá wà ní ìjọba.
0
Ebọ a'á dà, Òògùn á jẹ, òótó-inù ló máa lékè.
1
Akógilápá, teyìn ló jù.
1
Aróòótọmáso òun afọrọsábẹahọnsọ ọkanńùnkanhùn tó ń ru kánún.
1
Egbògi olóró gbígbé jẹ́ ìwà ọ̀daràn.
0
Ilé oúnjẹ ìgbàlódé tí wọ́n ti ń ta èso kò ní ọjà mọ́ nígbá.
0
Àsá ò leè débi ldì ń rè.
1
A kì í ṣíwájú ẹlẹ́ẹ̀ẹ́dẹ́.
1
Bí nǹkan ṣe rí ní Nàìjíríà ló rí ní Amẹ́ríkà.
0
Ayọ̀délé ní ọwọ́ pálábá Àlàbí yóò ségi lọ́dún tuntun.
0
Àdìgún ṣe ìgbéyàwó alárédè pẹ̀lú ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀.
0
Eni tó kigbe níwon ló mewon igbe-kiké.
1
Bàtà la fi ń ṣagbára láàrin ẹ̀gún.
1
Abẹ́rẹ́ jádìí, àkísà ń yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀; ó rò pé òyìnbó ò gún mọ́.
1
Ọwọ́ àjọ tó ń gbógun ti lílò àti gbígbé oògùn olóró ti ba àwọn ọ̀rẹ́ méjì.
0
Adénúgà jẹ́ àkàndá ẹ̀dá tó gbajúgbajà.
0
Ipa tí àwọn ọ̀daràn yìí ń ní lórí ètò ọrọ̀ ajé kò kéré rárá.
0
Bọ́lá ní ohun tó ń ṣẹlẹ̀ báyìí fihàn pé Ààrẹ nílò àyẹ̀wò ọpọlọ.
0
Ìgbà tí àwọn ọlọ́pàá téṣàn Láfẹ́nwá wá yanjú ọ̀rọ̀ náà ni àlàáfíà tó jọba.
0
Àṣẹ̀ṣẹ̀yọ màrìwò, ó ní òun ó kan ọ̀run; àwọn aṣáájúu rẹ̀-ẹ́ ṣe bẹ́ẹ̀ rí?
1
Àwọn olólùfẹ́ Ronkẹ́ Ìdídowó ti ń fọnmú lórí èsì àyẹ̀wò.
0
Mo di obìnrin náà lọ́wọ́ mú kí ó má la igi mọ́ bàbá mi.
0
B'íná bá ń jóni; tó jó ọmọ eni, ť'ara ẹni làá kọkọ gbọn.
1
A kì í p'Òrò sóde kí a má leè lọ o.
1
Báwo ni ẹ ṣe ń ta ọjà yín?
0
A kì í múlé móko kọ́kan má yẹ̀.
1
Àkùkọ ńlá ò j kí kékeré ó kọ.
1
Bí ìgbà tí èèyàn fi ìyà àìmọ̀dí jẹ aráàlú ni bí kò bá sí Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún wọn.
0
Bàtà ló ń b'àșírí aká.
1