Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àwọn oníṣẹ́ ìwòsàn náà ń wá ọ̀nà àbáyọ sí àjàkálẹ̀-àrùn. | 0 |
Àkọ́bí Bàbá Ìjẹ̀bú ṣe ìgbéyàwó alárinrin lópin ọ̀sẹ̀ tó kọjá. | 0 |
"Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìlú Òmìnira ní ìlú Súnmọ́mi sọ̀rọ̀ sókè! | 0 |
Àwọn tó ń jà ti ṣèlérí láti má ṣe jà mọ́. | 0 |
Ilé ìwòsàn Ìdẹ̀ra ni wọ́n kó òkú àwọn èèyàn méjì tó kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ sí. | 0 |
Lójú ẹsẹ̀ tí adigunjalè yìí bẹ́ bọ́ọ́lẹ̀ ni ó kú fin-ín fin-ín. | 0 |
A kì í sùn jẹ́rìí ìdí. | 1 |
Àwọn nkan tó gbajúmọ̀ nípa ìlú Ìbàdàn ni a máa mẹ́nu bà. | 0 |
Àwọn agbẹnusọ rẹ̀ sọ pé bàbá lọ fún ara nísinmi ni. | 0 |
Bí a 'ò bá pa kóóko bo ilé-Òòșà, a kì í já t'ara rẹ | 1 |
Àwọn agbófinró ya lu ibùba àwọn agbésùmọ̀mí. | 0 |
Ìròyìn sọ wí pé wọ́n pa ogúnlọ́gọ̀ àwọn ènìyàn. | 0 |
Mi ò mọ̀ bóyá ìyá mi ti gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi yìí. | 0 |
Àgbà tó bú ọmọdé fi èébú-u rẹ̀ tọrọ. | 1 |
Adájọ́ ti pàṣẹ pé kí wọ́n gbé afurasí náà. | 0 |
Àwọn ológun yóò já lu àwọn ọlọ̀tẹ̀ lójijì. | 0 |
A kì í gbọ́n tó ‘‘Èmi-lóni-í.’’ | 1 |
Adásínilọ́rùn, obìnrin ọ̀dọ̀gọ: ẹlẹ́rú ń wá ẹrú ẹ̀, ó ní kí wọ́n j kí ọkọ òun ti oko dé ná. | 1 |
Àyà ọmọ náà máa ń tètè já tọrí náà má pariwo mọ́ ọ. | 0 |
B'ónígbèsè 'ò bá ij ì tí ì l'ówó lọwo, ó yẹ kò sì lọro rere lenu. | 1 |
Ámbọ̀dé tó tún jẹ́ olóṣèlú kàgbákò ikú òjijì lọ́nà oko | 0 |
Ayọ̀mídé ń gbọ́ fèrè àwọn ọlọ́pàá nígbà tó wà nínú ọkọ̀ àwọn ajínigbé. | 0 |
A kì í mú ìbọn tetere. | 1 |
Àwọn èèyàn pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàmbá ọkọ ní Èkó. | 0 |
Àjẹ́ lápo, ojúu rẹ̀-ẹ́ rọ̀. | 1 |
A kì í s'òògùn ewà. | 1 |
Eyìn funfun leso erín, iwà rere lẹso ènìyàn. | 1 |
A-ti-ara-ẹni-roni, ajá ọdẹ. | 1 |
Eré tájá sá kú, apẹrẹ ni wọn ó fi wá kó elędę níbẹ. | 1 |
Ajédéjẹ kì í jẹ ọ̀kan mọ. | 1 |
Abẹ̀òkuta wà ní ẹkùn ìwọ̀ oòrùn gúúsù Nàìjìríà. | 0 |
Ẹni a lè mú làá lẹdíímọ, agánrán le lẹdí m'ágbàdo. | 1 |
Obìnrin onípọ̀nmọ́ fẹ̀sùn kan Mákindé pé ó fi ìkúùkù gbá òun níkùn lásìkò ìjà. | 0 |
A kì í gbélé mọ ẹni ogún pa. | 1 |
Ìlúfẹ́milóyè ń béèrè lọ́wọ́ àwọn aráàlú àwọn ohun tí wọ́n fẹ́ lára ọba wọn. | 0 |
Biyàá 'ò bá tòșì, ọmọ inúu rẹ ò leè ráre. | 1 |
Àgbà tó gba gbàdù, ó gba ìtùnú. | 1 |
Àwọn tí wọ́n pàdánù ilẹ̀ wọn kẹ́dùn. | 0 |
Àpá kì í jọ̀lọ̀ kó dà bí ara ẹni; ká jà ká rẹ́ ò dà bí rẹ́ ìpilẹ̀ṣẹ̀. | 1 |
A kì í fi ẹ̀tẹ̀ sílẹ̀ pa làpálàpá. | 1 |
Àtigbó, àtọdàn ni wọn ń gbáríjọ tọn ń gbọnwú àràbà. | 1 |
Ajá tí ò létí ò ṣéé dẹ̀gbẹ́ . | 1 |
Àwọn dókítà ní Adérántí yóò jẹ́ àpẹẹrẹ ìrètí fún àwọn tó ń fi kíndìnrín parọ́ lágbàáyé. | 0 |
Àwọn ẹgbẹ́ a-jà-fẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn ṣe ìwọ́de ní Agáka. | 0 |
Àwọn àgbàgbà rọ àwọn ìyàwó ilé láti rọra ṣe pẹ̀lú àwọn ọkọ wọn. | 0 |
Biná bà koni (jani) àkótán ni. Omí kó ni (jani) àkókù. | 1 |
Ẹ wo bí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré ṣe ṣe àyájọ́ Ọjọ́ | 0 |
Ọ̀rọ̀ ẹjọ́ tó wà ní kóòtù nípa ètò ìdìbò tó wáyé kọjá ni wọ́n gbájú mọ́. | 0 |
Bí kò sí tọ̀mọ̀, kí là ń wá ní fùrọ̀ onífùrọ̀. | 1 |
·Bó bá remi ká wi, èwo ni kí a máa gbóndò ki a máa fito rawo. | 1 |
Gbogbo adiẹ ló n dùdú lókùnkùn. | 1 |
Elékòó ń jó wọ ààfin Ìgà Ìdúgànràn. | 0 |
Ẹ máṣe bú Ọlọ́run torí ọrọ̀ ajé tí kò dára. | 0 |
Adìẹ́ ń jẹkà, ó ń mumi, ó ń gbé òkúta pẹ́-pẹ̀-pẹ́ mì, ó ní òun ò léhín; ìdérègbè tó léhín ń gbé irin mì bí? | 1 |
Gbogbo ohun tó wà ní ìkáwọ́ mi ni mo fi ń ṣe ìtọ́jú rẹ̀. | 0 |
Àlùbami ni Ṣégun máa ń lu ìyàwó rẹ̀. | 0 |
Ilé ni àwọn agbófinró ti fi páńpẹ́ òfin gbé pásítọ̀ lórí ikú Tóyìn. | 0 |
Àjànàkú ló nìgbẹ́; irọ́ ni gbogbo ẹranko ńpa. | 1 |
Àkó ajá kì í pẹ lóde. (Ajá olomo) | 1 |
Ó sọ èyí látàrí bí ooru inú ọkọ̀ ṣe pa àwọn ọmọdé mẹ́ta. | 0 |
Bí ọkọ̀ ṣe wọ́n ni yóò sọ iye tí wọn yóò ta ọjà kọ̀ọ̀kan. | 0 |
Bí alẹ́ bá lẹ́ , bọnnọ-bọ́nnọ́ a rẹ̀wẹ̀sì. | 1 |
Àlàbá jẹ́ aṣáájú ikọ̀ ti wọ́n fa ara wọn kalẹ̀ láti máa ṣọ́ àdúgbò Ìfẹ́sowápọ̀. | 0 |
Àtọlé ló ń șí ľ'ára așọ, àhunmọ kì í șí. | 1 |
Bí a bá fi tòlótòló ș'òògùn-àtè; irú ẹyẹ wo la ó fi mú? | 1 |
Ệluúlú tó ń pe òjò, șé baba rẹ kọlée páànù sóko? | 1 |
Gbígbé egbòogi olóró yóò túbọ̀ pọ̀ sí i ní orílẹ̀-èdè wa yìí bí Bọ́lá bá fi di ààrẹ. | 0 |
Àgbẹ̀ gbin ohun gbogbo má gbin iyọ̀. | 1 |
Àì sọkùnrin l'Obìnrin-ín j'ogún àdá. | 1 |
B'éèyàn 'ò nírú așọ kì í fașọ ya. | 1 |
Adigunjalè ọ̀hún ni ilé ẹjọ́ mú lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ìwádìí. | 0 |
Èpè werewẹrẹ ló ń pakọ Ìgalà. | 1 |
‘‘Gbà sókè’’ ni ‘‘Gbà sọ́kọ̀’’; ohun tá a bá sọ síwájú là ń bá. | 1 |
Adìẹ ìbá lọ́kọ́, ìbá fi ààtàn ṣe nǹkan. | 1 |
Adélébọ tó ń firó ẹ há abíyá, olórí oníșe ni. | 1 |
Ìyanṣẹ́lódì tí àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga gùn lé yóò wá sí òpin láìpẹ́. | 0 |
Èwo lèwo nínúu 'ọmọo mi ò jẹ Ọganga mọ,ògòngò ló hi | 1 |
Alákùkọ lẹ́bàá ẹnubodè ìpínlẹ̀ Ògùn ló ti wáyé. | 0 |
Ẹ jẹ́ kí a máa rántí pé àwọn ènìyàn kan ti ṣe ìgbìyànjú ṣáájú wa. | 0 |
Ìgbésẹ̀ kejì: Ṣíṣe é ní awo òru láì ní jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀. | 0 |
Agbada tó bá wọn jó àgbàdo ò rí rún; Ọkọ tó bá wọn roko kò ríṣu je. | 1 |
Olúṣọlá kó sí páńpẹ́ òfin ní Ìbàdàn. | 0 |
Àgbàlagbà kì í yọ ayọ̀-ọ kí-ló-báyìí-wá? | 1 |
Bísó baba 'ò rùn, ọmọ a fi tiẹ kún un. | 1 |
Aṣápẹ́ fún wèrè jó, òun àti wèrè ẹgbẹ́ra. | 1 |
Àwọn kan sọ pé ẹjọ́ àwọn agbébọn yìí lọwọ́ nínú. | 0 |
Bọ́lá ní òun máa ka ẹ̀kọ́ ìṣirò owó ní fásitì. | 0 |
B'a ò gbólù ará Oyo láàáro, taletale a ó gbòrin wọn. | 1 |
Àjọ woléwolé ní àwọn ti gbàṣẹ láti gbé ẹsẹ̀ lé àwọn dúkìá bí ilẹ̀ àti ilé. | 0 |
Bàbá Lọlá sọ fún BBC Yorùbá pé òun fẹ́ ìdájọ́. | 0 |
B'éèyàn l'óyún-ọrọ bí 'ò bá ì bí i, ara kì í rọ ọ. | 1 |
Bàbá Ìfẹ́ mu lọ kọ́ṣẹ́ títún mọ́tò ṣe. | 0 |
Bí wọ́n bá pe ọmọ ọkọ ní ọmọ àlè, ilé ti dàrú. | 0 |
Àgbà lẹ́tù; àlàárì lọba aṣọ. | 1 |
Ayé kì í fenì láti àáro dale. | 1 |
Àwọn ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lójú-ẹsẹ̀ láti lè mú àwọn ajínigbé ọ̀hún. | 0 |
Àjọ aṣọ́nà kìlọ̀ f'áwọn awakọ̀ tó máa tẹ fóònù lórí ìrin ní Èkó. | 0 |
Ẹlẹ́wọ̀n tí àwọn wọ́dà ń gbé lọ ti sá àsálà bá àwọn agbébọn lọ. | 0 |
Ajóbíewé Àrẹ̀mú kì í ṣe òògùn ìsọ̀yè. | 0 |
Àwọn agbébọn tí ń ṣekú pa àwọn ènìyàn ní agbègbè Àjá ní ìpínlẹ̀ Èkó. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.