Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Adájọ́ sọ pé ẹ̀ṣẹ̀ tí Àlàní ṣẹ̀ yìí tako òfin. | 0 |
Àwínná owó 'ò yẹni; àgbàbọo sòkòtò ò ye ọmọ ènìyàn, bí kò báfún ni lẹsẹ, a ṣoni lórúnkún. Ohun ẹni regí ní í bánií mu. | 1 |
Àkọsẹ̀bá, èyí tí ń jẹ́ ìfà. | 1 |
B'Eyá bá d'Ẹkùn, eran níí paá ję. | 1 |
Bí a bá kórìírá ęlęjo eni, ębi làá ję. | 1 |
Àwọn ọmọ igun tó ń jà kò ní ìpalẹ̀mọ́ kankan fún ogun. | 0 |
À-jẹ-tán, à-jẹ-ì-mọra, ká fi ọwọ́ mẹ́wẹ̀ẹ̀wá jẹun ò yẹ ọmọ èèyàn. | 1 |
Ẹlẹ́dẹ̀ tó kú légbodò ló ní ká fòun jẹyán. | 1 |
‘‘Má bàá mi jẹ ìdùn,’’ ẹran ní ń lé lọ. | 1 |
Ẹ wo ìgbà mẹ́rin tí Ààrẹ ti tàpá sí ìlànà òfin orílẹ̀-èdè Nàíjíríà. | 0 |
Ariwo orúkọ Mákindé tí obìnrin onípọ̀nmọ́ pa ló mú kí ọkọ rẹ̀ ké sí àwọn ọlọ́pàá. | 0 |
Ẹ má jẹ́ kí ìyà yìí ó jẹ mí gbé. | 0 |
Àwọn ìjàm̀bá kan lè wáyé níbi tí wọ́n ti ń ya eré. | 0 |
Àkàsù baba ekọ. | 1 |
Aṣọ tó kuni kù ní ń jẹ́ gọgọwú. | 1 |
Àwọn aráàdúgbò ló lọ pe ọlọ́pàá wá láti wá mú mi. | 0 |
Àyìndé ní àṣẹ ààrẹ lórí pípa ẹni tó bá jí ìbò gbé tako òfin. | 0 |
Àwọn ọlọ́pàá ti dé sí ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé. | 0 |
Ahùwà-ìbàjẹ́ sẹ bí tòun là ń wí; aṣeburúkú o kú ara fífun. | 1 |
B'ómi bá balę omi a nípa. | 1 |
Bí ìbí bá tẹ̀, bí ìbí bá wọ́, oníkálukú a máa ṣe baba nílé ara-a rẹ̀. | 1 |
Ẹni tí a ò pè láwọ, a kì í rán an láwo. | 1 |
B'ọn yí mi sébẹ, ma yí wọn sí poro-oko. | 1 |
Adájọ́ rán bàbá tó fi ipá bá ọmọ ọdún mẹ́rin lò pọ̀ lẹ́wọ̀n gbére. | 0 |
Tolúlọpẹ́ kó sí páńpẹ́ àwọn ọlọ́pàá ní Ìlú Èkó. | 0 |
Ìjọba kò ní fojúure wo ìwà àjẹbánu mọ́ láti àsìkò yìí mọ́. | 0 |
Àkànní tun fẹyin Túndé gbolẹ̀ nínú àtúnkà ìbò tó wáyé ní Ọ̀tà. | 0 |
Denge tutù l'ẹyìn ó gbóná nínú. | 1 |
Eré àsápajúdé ló máa ń dá ẹ̀mí àwọn èrò ọkọ̀ légbodò. | 0 |
Afàkàrà-jiyán 'ò lọrọo're lẹnu. | 1 |
Arìngbẹ̀rẹ̀ ni yó mùú oyè délé; asárétete ò róyè jẹ. | 1 |
Àjà kì í jìn mọ́ ológbò lẹ́sẹ̀. | 1 |
Bíșin bá là lálàjù; ọdọmọdé là á bẹé ká. | 1 |
Kí ènìyàn ṣe é lọ́nà tó dára bí a bá fẹ́ fi ẹ̀hónú wa hàn. | 0 |
Eèrà ò fẹ́ pòpóòrò dénú; kí-ń-kín-ní layé ń fẹni mọ. | 1 |
Àwọn awakọ̀ máa ń mọ̀-ọ́n-mọ̀ wa ọkọ̀ dúró sójú pópó lọ́pọ̀ ìgbà. | 0 |
Ẹtọ ni kẹdàá m'ẹmín l'ẹmin, kó m'ẹmìn lẹmì. | 1 |
Bí a bá ti fàgbò féégún, àá jòo okùn e ni. | 1 |
A kì í mú oko mú ẹjọ́ kí ọ̀kan má yẹ̀. | 1 |
Wọ́n gba àwọn ènìyàn ní ìmọ̀ràn lórí ààbò. | 0 |
Òfin yàtọ̀ ní ti ọ̀rọ̀ àwọn ẹranko inú igbó tí wọ́n lè pààyàn lára. | 0 |
Babalọlá ni wọ́n gbé lọ sí ilé-ẹjọ́. | 0 |
Bàbá Ìjẹ̀bú kọ́ ilé tuntun sí Òṣogbo. | 0 |
Àlùkò ò ní ohùn méjì; ‘‘Ó dilé’’ lagbe ń ké. | 1 |
Obìnrin onípọ̀nmọ́ ọ̀hún mú igi àpólà dání lọ́wọ́. | 0 |
Adìẹ ò l'órúnkún ẹjọ. | 1 |
‘‘Mo bí, mo bí’’ kì í ṣe ọmọ rere. | 1 |
Àwòràn kan lójú òpó ìròyìn ilẹ̀ Nàìjíríà fi díẹ̀ lára ìjàm̀bá náà hàn. | 0 |
Àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn ti mú òṣìṣẹ́ ilé-ìgbókúpamọ́ sí méjì kan. | 0 |
Àṣá ò lè balẹ̀ kó gbéwúrẹ́. | 1 |
Àṣírí jìbìtì bẹ́ẹ̀ kò ní tú lọ́jọ́ iwájú. | 0 |
Ọ̀gá ọlọ́pàá bá àwọn mọ̀lẹ́bí olóògbé kẹ́dùn ikú èèyàn wọn. | 0 |
Bí olóde ò kú, òdee rẹ̀ kì í hu gbẹ́gi. | 1 |
A-wọ̀lú-má-tẹ̀ẹ́ , ìwọ̀n ara-a rẹ̀ ló mọ̀. | 1 |
Àkẹ̀hìnsí ọlá ò sunwọ̀n. | 1 |
Àgbà tó fi ara-a rẹ̀ féwe lèwe ń bú. | 1 |
Kò sí bí àwọn ọlọ́pàá ṣe lè mọ̀ bóyá òótọ́ ni pé wọ́n fipá mú un. | 0 |
Mo nírètí pé ìgbésẹ̀ tí a gbé lórí ọ̀rọ̀ tó wà nílẹ̀ yìí ni ó tọ̀nà. | 0 |
Ajé sọ ọmọ nù bí òkò. | 1 |
Adáhunșe Ògù kì í rèlú Ọyọ lọ gbẹbí, bẹe'oọdo ni tOyọ ò gb rÒgù lọ gbẹbí ọmọ. | 1 |
Ajá ti erée rẹ̀ẹ́ bá dánilójú là ńdẹ sí ehoro. | 1 |
Ewé t'ólóori ní l'ó fi ń gbekọ. | 1 |
Wọ́n fi orúkọ bo ọ̀rẹ́kùnrin Ọláyínká yìí láṣìírí. | 0 |
Alágbàfọ̀ kì í bá odò ṣọ̀tá. | 1 |
Adé ń bẹ ľ'Ákẹ, àṣẹ ń bẹ lỌgbẹ. | 1 |
A ní kíhun t'ó wuni ó wá, ohun tó dára bọ síbẹ; b'ó bá dára bí'ồo bá wuni ń kọ? | 1 |
Èèwọ̀ ni tọwọ̀; a kì í figi ọwọ̀ dáná. | 1 |
Àtẹ́lẹsẹ̀ àwẹ̀nù tó dojú ara-a rẹ̀ délẹ̀. | 1 |
Ẹnu 'ò sunàn, ẹlẹnuú pọn ọn lá. | 1 |
Gúdúgúdú kì íș'ojúgbà dùndún. | 1 |
Ẹni fẹni làá fimọràn lọ. | 1 |
Ènìyàn ló k'ẹsin l'óró, ẹșin 'ò níkà nínú. | 1 |
Èèyàn nilé. | 1 |
Àgbà tí kò mọ ìwọn ara rẹ l'odòó gbé lọ. | 1 |
Bàbá' l'Onígbàjámọ ń jẹ; bó ti wù ó kéré mọ. | 1 |
Iṣẹ́ oko ríro ni iṣẹ́ tí àwọn ènìyàn mìíràn máa ń yàn láàyò. | 0 |
Bàbá Sùwé lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀sẹ̀ ní àhámọ́. | 0 |
Àfáà Kàrímù ń wáàsù kí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ má gba abẹ́rẹ́ àjẹ́sára. | 0 |
Ara ò ni ìwọ̀fà bí onígbọ̀wọ́; a-bánikówó lara ń ni. | 1 |
Àwọn ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà. | 0 |
Àkùkọ adiẹ kan ló ń ba oògùn ọmọdé je - Bí won bá ní, yoo ra obì ifin, obi ipà, ọkọ-ataare, a ní apá òun ká a. Bí babaláwo bání: “Àti àkùkọ adìę kan' ọmọdé a ní: “Níbo ni ki ń ti rowó rà á?' | 1 |
A gbọ́dọ̀ ní àfojúsùn láti gba ẹ̀tọ́ wa tí àwọn kan já gbà. | 0 |
A kì í mu tábá kí a la Àkesán já. | 1 |
Dídùn là á bá'lé Olúkoyin. | 1 |
Eégbọn di mo Ayìnrìn lenu, wọn ní k'Adię lọ yàn án, adię tikáonje. | 1 |
Ọ̀gbẹ́ni Ògúndípẹ̀ ni yóò di alámòójútó ìwé àti àkọsílẹ̀ fún fásitì Iléṣà. | 0 |
Ọjọ́ kẹ́ta tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀ ni wọ́n tó rí ọ̀kadà náà níbi tí òjò wọ́ ọ lọ. | 0 |
Ọgbọ́n àrekérekè ni àwọn agbófinró fi mú àwọn ajínigbé. | 0 |
Ẹni tí yóò wòran àgbà méjì, kò ní sài rúbọ àyalù. | 1 |
Wọ́n fi ẹ̀sùn ṣíṣòwò ẹ̀yà ara kan aṣòfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | 0 |
Olúgbadé ni ẹ̀gbọ́n fún àwọn ìbejì ọ̀gárá ọlọ́ṣà tí ọwọ́ tẹ̀. | 0 |
Wọ́n rí àwọn ènìyàn mìíràn tí wọ́n lùgbàdi àjàkálẹ̀-àrùn nínú ọjà. | 0 |
Àṣá ni baba ẹyẹ. | 1 |
‘‘Ṣe mí níṣu’’ ní ń ṣíwájú ‘‘ẹ kúuṣẹ́’’ bí? | 1 |
A kì í fi ọ̀rọ̀ sílẹ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀. | 1 |
Tàbí kí àwọn afurasí san ọ̀kẹ́ àìmọye owó gẹ́gẹ́ bí owó ìtanràn. | 0 |
Àwọn agbébọn kiná bọ ọkọ̀ àti dúkìá àwọn aráàlú. | 0 |
Àlàáfíà baba ẹ̀ṣọ́; ojúrírí baba ara líle. | 1 |
Gbà, mo bùn ó 'N 'ò fẹ ș'àgbàe. | 1 |
Ìṣòro tí ọ̀pọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ ní níbi ẹ̀kọ́ ni ìṣòro àìfọkànsí. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.