Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àwọn aláàánú kan gbìyànjú láti gbé àwọn tó fara pa lọ sí ilé ìwòsàn. | 0 |
B'áhọn báife te,alóun fé kan imú. | 1 |
Bógbó ba dé ara a d'ara àgbà. | 1 |
E yékèéé se, èké ló ń pani. | 1 |
·Eni a bá bá mu aásà kó yo, eyín ló fi n pọn ni. | 1 |
Baálé àlejò ni baba àlejò. | 1 |
Eni dúró dé relùwé, ọrun ló ń lo. | 1 |
Àjọ ni tìlú; ọba ló lagbo. | 1 |
Ehoro tó jẹṣu, tó dùn mọ, a tún padà wá. | 1 |
B'éégún bá ń sẹnu jẹjẹ mutí, àfi kó șe jẹję bí kò bá fẹ wọgbàle teje teje. | 1 |
Bí a bá ń sùn láhéré, títọ lopọlọo tọ ọ lu ni. | 1 |
Mo sáré di ewéédú sí kéékèèké bá a ṣe máa ń dì í. | 0 |
Ẹpọn 'ò r'ára fi pamọ fún bàntẹ. | 1 |
Lálónpé ni ẹ̀gbọ́n fún Odùọlá. | 0 |
Adítí Ajá; 'ò seé dęgbę. | 1 |
Ọ̀túnba pín owó fún gbogbo àwọn aláàwẹ̀. | 0 |
Bíre bá wọlé, kí á na sùúrù síi, torí bínú bá le í wogbólálejù ire ni. | 1 |
Ajemábun-ara-ję iyàwó sòróó fę. | 1 |
Wọ́n ti fi ètò ìtẹ́ ẹ̀yẹ òkú sí ọjọ́ Ẹtì tó ń bọ̀. | 0 |
Àdúrà, a fí ń dun ara wa nínú ni. | 1 |
Òkìkíọlá sọ pé Dámilọ́lá kò lóyún débi tí yóò bímọ rárá. | 0 |
Àtalákọrí, àtalákọra, kò séyìí tó ó seé pè lọmọ ẹni. | 1 |
Àṣírí àwọn egbòogi tí àwọn arúfin kan kó wọ̀lú ti tú síta.. | 0 |
Àwọ́n kan ń fẹnu wa ìwàkuwà. | 0 |
Bí ojú owó ẹni ò yóni, ènì ò lè yóni. | 1 |
Àtúnṣe ti dé bá iṣẹ́ ọ̀gbìn ni gbogbo orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | 0 |
Ògúnrónbí fi ọ̀bẹ gún ọlọ́pàá lórí. | 0 |
Bí ojúmọ́ mọ́ lékèélékèé a yalé ẹlẹ́fun, agbe a yalé aláró, àlùkò a yalé olósùn. | 1 |
Àìdé ikú làá so àjà mọrùn, bíkú bá dé, àjà a sọnù, a á gbé alájà lọ ráúráú. | 1 |
Akitiyan àwọn agbófinró so èso rere. | 0 |
A gbé gàárì ọmọ ewúrẹ ń rojú; kì í ṣe ẹrù àgùntàn. | 1 |
B'á a r'Ádàn-án, à sì f'Òòbè sẹbọ. | 1 |
Àwòdì ò náání à ń kùngbẹ́; igí wó ẹyẹ́ fò lọ. | 1 |
Àgbàlagbà kì í ṣòbééré. | 1 |
Ẹni tó níka lòrùká yẹ. | 1 |
Bí ọgbọ́n bá tán nínú, a tún òmíràn dá. | 1 |
Ayé le; bí o bá a o pa á; bí o ò bá a o bù ú lẹ́sẹ̀. | 1 |
Ràúfù àti Fáyẹmí ni wọ́n dá ìfaǹfà ogun abẹ́lé sílẹ̀. | 0 |
B'ọmọ bá délée baba rẹ, a dọmọ gidì. | 1 |
Elege l'ọmọ (ni) títọ. | 1 |
Àgbàlagbà tó b'ọmọdé tayò, a á jòbu (jẹ òbu.) | 1 |
Èèyàn méjì míì farapa nínú ìjà ọlọ́pàá àti ọmọ ìta ni Ayetoro | 0 |
Bí ó ti wù kí ọmọdé tètè jí tó, ọ̀nà ni yó bàá kùkùté. | 1 |
Bí a kò bá tí ì lè kọ́lé àgọ́ là ń pa. | 1 |
Aláṣejù tí ń pọkọ ní baba. | 1 |
A kì í sin àlè kọjá odò; ohun tí ń ṣe ọṣẹ́ ò tó nǹkan. | 1 |
À kì í fójú olòjú sòwò kí á jèrè. | 1 |
Bí a bá pàtọ pọ, kùșù níí hó. | 1 |
B'owo eku șe mọ ló se fi ń bọjú (nujú). | 1 |
Bí a bá ní ogún ẹrú, tí a ní ìwọ̀fà ọgbọ̀n; ọmọ lèrè ẹni. | 1 |
Àwọn agbófinró ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ran àwọn akẹgbẹ́ wọn lọ sí Èkó láti gba ọkọ̀ náà. | 0 |
A kì í bímọ sílẹ tán kí a șẹsẹ máa jiyàn pé yóo jèẹ akọ tàbí abo. | 1 |
Níbi gbọ̀ngàn àpérò àwọn aṣòfin ni wọ́n ti pàṣẹ yìí. | 0 |
A kì í sá fún àjíà ká dìgbò lu eégún. | 1 |
Bí ìwà ọ̀daràn kò bá lọlẹ̀ nílùú Ọ̀yọ́ ìjọba kò ní jáwọ́ lórí ọ̀rọ̀ náà. | 0 |
Awo aláwo la kì í dá lẹ́ẹ̀mejì. | 1 |
A kì í fi owó du oyè-e alágbára. | 1 |
Onídàájọ́ gbé ìdájọ́ rẹ̀ kalẹ̀ lórí ẹ̀sùn ìbanilórúkọjẹ́ | 0 |
‘‘Mo kò ó’’ kì í ṣe àìní àpèjúwe. | 1 |
Wọ́n fẹ́ kí gbogbo ọmọ Ìbò jákèjádò wá sílé bí àkókò ìkànìyàn bá tó. | 0 |
‘‘A ò mọ eyí tí Ọlọ́run ó ṣe’’ ò j á bínú kú. | 1 |
A kì í jayé ọba ká ṣu sára. | 1 |
Eni tó mọ o, kì í wó o. | 1 |
Arúgbó tó ń jẹ gbèsè ni, èwo ni yóó dúró san níbẹ! | 1 |
Babaláwo ń sunkún efọrí, ekún-un kí laláisàn ó sun? (kí ni káláisàn ó se). | 1 |
Fúlàní șe bí òkùnrùn wọlú, alágbára se bí ọlẹ wàjo. (wọ àjọ) | 1 |
Àwọn aláṣẹ sọ wí pé wọ́n fẹ́ da ẹgbẹ́ àwọn rú. | 0 |
B'ónílé bá ní kí a jẹ é tán, àlejò a ní kí a jẹ ẹ kù. | 1 |
Eégún p lóde, ó fètè òkè dáhùn; wọ́n ní, ‘‘Baba kú àbọ̀,’’ ó ní, ‘‘Hì ì ì.’’ | 1 |
Ẹni a torí ẹ padię, iwe ló ń ję. | 1 |
Àwọn sọ́jà kọ̀ọ̀kan wà ní Èkó tí wọ́n tí ń lo bí ọdún mẹ́sàn-án nídìí iṣẹ́. | 0 |
Adéríbigbé ní gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ló ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn mọ̀lẹ́bí tó farapa. | 0 |
Bí a bá ń wo gege níran yóò yìí orùn ká. | 1 |
Àwọn iṣẹ́ abẹ fífi kíndìnrín ẹlẹ́dẹ̀ rọ́pò ti èèyàn ti lulẹ̀ tẹ́lẹ̀rí. | 0 |
Apajájẹ- ní ẹ̀rù adìẹ ḿba òun. | 1 |
Wọ́n ti dárúkọ àwọn ọ̀daràn tó kọlu Orísúnmbáre. | 0 |
Bí wọn ti ń mọ níran okinni, l'okinni mọ; kì í se péírin tán níbi tíwọn tí ń rọ o. (ń se é) | 1 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rawó ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba kó dá àwọn olùkọ́ lóhùn. | 0 |
Ó yẹ kí àsọyé wà láàárín ìpínlẹ̀ méjèèjì kí irú ìgbésẹ̀ náà tó wáyé. | 0 |
Lẹ́yìn tí wọ́n bá ti yẹ ọ̀nà wò ni wọ́n tó lè kó àwọn ènìyàn kúrò. | 0 |
Bí a kò fẹ́ ẹni nílùú, a kì í tó abẹ́rẹ́. | 1 |
Ebi kì í pa'gún dalę. | 1 |
Dókítà iléèwòsàn Dárasími ni Adédoyin Dòsùnmú. | 0 |
A kì í wí síbẹ kí á kú síbẹ. | 1 |
Ẹni tí kò ì ráàyè à-ń-ș'ahun, kì í șèșe Ọmọbọ. | 1 |
Funfun niyì eyin, ẹgùn gàngàniyì ọrùn. | 1 |
Àbúrò fajúro sí ẹ̀gbọ́n rẹ̀. | 0 |
Bí a bá f ràn ọ̀rẹ́ ẹni láfẹ̀ẹ́jù, bó bá forígbún, ìjà níńdà. | 1 |
Bí ènìyàn bá mọ nǹkan tọ́jú, kí ó rántí ẹni tí ó mọ̀ ọ́n wá. | 0 |
Ayálégbé tó fojú ba ilé ẹjọ́ gbọ́dọ̀ san owó ìtanràn. | 0 |
Àgbà tó bú èwe lèwe ń bú. | 1 |
À ní kí a pàșẹ pọ, kí á jùmọ jẹ' yán oko, ẹníkan lóun àgbà-iyà. | 1 |
Bilę bá n gbe òsìkà, kínú oloore má se bàje. Bó pẹ ikà à ka oníkà, ire á bólóore. | 1 |
Àwọn àgbàlagbà ń fẹ́ kí àwọn ọmọdé rí bí ayé ṣe rí. | 0 |
Ìkọlù wáyé láàárín àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn méjì ní ìpínlẹ̀ Èkìtì. | 0 |
Afatarẹ́nilójú, alè-e baále. | 1 |
A kì í fi osùn ẹní șe àlọkúnná. | 1 |
Bí o finú ṣìkà tí o fòde ṣòótọ́, ọba séríkí á rín ọ rín ọ. | 1 |
Yíyan àwọn alákòóso tuntun fún Fásitì Iléṣà jẹ́ èyí tí kò bófin mu. | 0 |
Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ àwọn ènìyàn ni wọ́n ti lùgbàdi àrùn. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.