Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
‘‘Wo ọmọ-ọ̀ mi dè mí’’: ó ń lo kíjìpá mẹ́ta gbó; mélòó ni ọlọ́mọ-ọ́ máa lò gbó? | 1 |
Àkùkọ-ọ́ kọ, ọ̀lẹ́ pòṣé. | 1 |
Enu-àimẹnu, ètè-àimétè ló ń k'ọràn bẹrẹkẹ. | 1 |
Bí ọjọ́ tí a bíni ṣe jẹ́ pàtàkì ni ọjọ́ ikú náà ti ṣe pàtàkì. | 0 |
Díndín-in-dín ọbẹ l'áàyò fi ń dìrújú ọkọ wọn. | 1 |
Bí kò bá sí owó, baba ẹnìkan ò ju baba ẹnìkan lọ. | 1 |
‘‘Máa lọ, àlejò’’ kì í ti ẹnu onílé wá. | 1 |
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ní àfi tí ìjoͅba bá san owó oṣù àwọn lásìkò. | 0 |
Bí obìnrín bá wọgbó Orò, a ò lè rí àbọ̀-ọ ẹ̀ mọ́. | 1 |
Àwọn méjì yòókù nínú ọmọ mẹ́ta tí bàbá yìí bí jẹ́ tọ́ọ̀gì. | 0 |
Àwọn ọmọdé mẹ́rin kan kú sí inú ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́. | 0 |
Àpèmọ́ra là ń pe Tèmídire. | 1 |
Àwọn olóṣèlú burúkú pọ̀ ju gidi lọ ní orílẹ̀-èdè yìí. | 0 |
Àwo ò mọ̀ pé òun ó jata. | 1 |
Wọn kò tí ì mọ bí ẹnì kẹrin wọn ṣe rìn. | 0 |
Aṣíwájú ló san owó ilé-ìwé mi lọ́pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn. | 0 |
Àwọn kọ̀ọ̀kan farapa ní pasẹ̀ àwọn jàǹdùkú kọ̀ọ̀kan ní ìlú Ìbàdàn ní ọjọ́ Aje tó kọjá yìí. | 0 |
Èkó ni wọ́n bí mi sí, tí mo dàgbà sí. | 0 |
Àwọn èèyàn náà sọ pé kò dẹrùn láti ṣègbọ̀nsẹ̀ tàbí túra. | 0 |
A kì í pàgbà kó dáhùn, kó tún wá sọ p'óun ò sí nílé. | 1 |
Ìfẹ́olúwa sọ pé níṣe ni afurasí ọ̀hún máa ń tọ́ bọ́rọ́. | 0 |
Asọ-funfun 'ò bá àbàwọn rẹ. | 1 |
Kì í ṣe gbogbo ènìyàn ló kúndùn oúnjẹ àárọ̀ ní jíjẹ. | 0 |
Àìjẹunsùn ẹkùn, a ò lè fi wé ti ajá. | 1 |
Àfowọ́rá ò kí ń ṣe nǹkan tó da. | 0 |
Àwọn agbébọn ṣíná ìbọn bo ọkọ̀ kan ní agbègbè olómi ní ìlú Ìbàdàn. | 0 |
‘‘Ọ̀gá ń bọ̀, Ọ̀gá ń bọ̀!’’ ni yó pa ọmọṣẹ́ . | 1 |
Àìmọ̀ọ́jó là ń tàkìtì; ijó-ò mí ju àńtọ bọ́. | 1 |
Àgbà lẹtù; ẹyẹ oko kì í párí lásán. | 1 |
Ará bàjẹ, Olùkù kọ ọ. | 1 |
Àwọn alátìlẹ́hìn gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó ń ka oríṣiríṣi ẹ̀sùn síra wọn lẹ́sẹ̀ lójoojúmọ́. | 0 |
Olówólafẹ́ bẹ ìjọba láti bá àwọn wá nǹkan ṣe sí ọ̀rọ̀ àwọn agbébọn. | 0 |
Àwọn agbófinró mú Fákẹ́yẹ nígbà tí Ẹ̀mílójù mú wọn dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. | 0 |
Àjọ àláàbò ìlú gbé ẹsẹ̀ lé oko igbó méjì. | 0 |
Ayé lòkun, èèyàn lọ̀sà; a kì í mọ̀-ọ́ wẹ̀ ká káyéjá. | 1 |
Abuké ló ru ẹrù òrìṣà má sọ̀. | 1 |
Ayọ̀mídé ní ìwé ìbọn tí ó ní àti ìwé ìrìnnà, tó fi mọ́ oògùn ìwé rẹ àti ìwé ìrìnnà. | 0 |
Ajóbíewé gbìyànjú oríṣìíríṣìí nígbà kékeré rẹ̀. | 0 |
Ajíbọ́lá ni ọmọ gbajúgbajà agbábọ́ọ̀lù yìí nígbà kan sẹ́yìn. | 0 |
B'éèyàn ti j'àmọlà tó ni yóò fi wọ lanku tó. | 1 |
Àwọn mẹ́fà kú nínú àwọn sójà tí ó lọ jà fún ìlú. | 0 |
Asínwín Ìká, aṣiwèrè Ìlúká, wọ́n dáríjọ, wọ́ ní àwọn ń ṣọ̀rẹ́ . | 1 |
Bígií bá sídìítán, ilẹpa rẹ a tọ o. | 1 |
Àjọ elépo rọ̀bì ní epo rọ̀bì ti fẹ́ ṣe àwárí epo rọ̀bì. | 0 |
Aago kan kọjá ọgbọ̀n ìṣẹ́jú ló lù báyìí, ṣé o ti fẹ́ máa lọ ní? | 0 |
Bí a ó bàá ș'òjóró là á pe irun kan 'ò junrun kan lọ; bẹẹ irun ìpénpéjú sàgbàa irùngbọn. | 1 |
Bá 'ò kú, a ó jeran tó térin. | 1 |
Ọ̀gá ọlọ́pàá sọ pé ìjìyà tó tọ́ làwọn yóò fi jẹ Fọlọ́runṣọ́ bí ó bá jẹ̀bi ẹ̀sùn náà | 0 |
Bí 'ò bá lọwọ ayé nínú, ọmọ ọdún mẹta 'ò gbọdọ sínwín. | 1 |
Àròyé niṣẹ́ ìbakà; kí niṣẹ́ ẹyẹ lóko? | 1 |
Bí wọn bá ló ď'ọwọ Ìmàle, Ìmàle á ní ó ďọwọ Ọlọrun. | 1 |
Balógun sọ wí pé àbá tí ó bá dára jùlọ ni àwọn yóò mú lò. | 0 |
Fíìmù náà ń sọ̀rọ̀ nípa àpéjọ àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé. | 0 |
Àáfà tó níyàn yóó mùú, ọmọ rẹ ò ni jẹ tírà. | 1 |
Ẹlòmíràn tún ṣàlàyé pé àwọn pe àwọn ọlọ́pàá nígbà tí àwọn olè náà dé | 0 |
Àlọ ti alábaun; àbọ̀ ti àna-a rẹ̀. | 1 |
Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣàfihàn àwọn olè àti àwọn afipá-báni-lòpọ̀ mẹ́ẹ̀dógún mìíràn. | 0 |
Òkú Ràúfù tí wọ́n gbé kúrò bí ọ̀pọ̀ àwọn alákatakítí nínú. | 0 |
Àrùn níí sakọni dọle | 1 |
B'íná bá n jó l'óko; màjàlà á délé wáá rò. | 1 |
Onílé wa pè mí nígbà tí mo ti ibiṣẹ́ dé lálẹ́. | 0 |
Bí olósùn-ún bá lọ osùn, ara-a rẹ̀ ní ń fi dánwò. | 1 |
‘‘Pẹ̀lẹ́’’ lákọ, ó lábo. | 1 |
Ẹ̀gún ò gún ọmọ lẹ́sẹ̀ ká yọ ọ́ lẹ́sẹ̀ ẹrú. | 1 |
Bi pepeyebámiòkúta; omi ní ó fi su. | 1 |
Bí a bá bi àgbà tó kúrú mọ́lẹ̀, yóò rí wí. | 1 |
Àti ibùdó tí ó ti ń ṣiṣẹ́ ni ó ti dèrò Teste-de-Buch ní Faransé. | 0 |
Fọlọ́runṣọ́ sọ wí pé wọ́n gbé owó ńlá kalẹ̀ bí òun bá lè ṣe é. | 0 |
B'éèyàn dára, bí 'ò bá mọ, yóó rẹni wí fún un. | 1 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n jẹ àǹfààní ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ ti lọ sí ìrìnàjò. | 0 |
Bí olókùnrùn yó bàá kú, kó má purọ́ mọ́ àlapà; omitooro kì í korò. | 1 |
Bí Ògún ẹní bá dánilójú,àfigbárí. | 1 |
Eekan l'atannife n tanniife mo. | 1 |
À ń wá ẹni tí a ó fọmọ fún, olòṣì ń yọjú. | 1 |
Àjẹsílẹ̀-ẹ gbèsè tí ò j kí ẹgbẹ̀fà tóó ná. | 1 |
·Ete ló h wá: Babalóòsà ti ó n bèbi edo-igbin. Asipa tó ń wá ito emo yóo kan àbùkù. | 1 |
Báyií là n se nilée wa; èèwọ ibòmíràn. | 1 |
Bọ́lá ní ó wu òun kí òun dá ilé-ìfowopamọ́ sílẹ̀. | 0 |
Ayé di lẹhẹ-n-hẹ: ẹyin adì tòkè wá fọ́ ìpọn. | 1 |
Àwọn olùkọ́ fásitì ò ṣiṣẹ́ fún oṣù méje. | 0 |
Ìjà láàárin ikọ̀ méjì tó ń lọ lọ́wọ́ ní ìlú Súnmọ́mi ṣì ń tẹ̀ síwájú. | 0 |
Àwọn ajínigbé wọ́ Ayọ̀mídé sínú ọkọ̀ tí wọ́n gbé wá. | 0 |
Wọ́n béèrè fún ohun tí wọ́n lè jẹ tí wọ́n sì lè mu nígbà tí ebi pa wọ́n. | 0 |
Ìgbésẹ̀ kí-onílé-gbé-ilé rẹ̀ wà lára àwọn ọ̀nà láti dẹ́kun àjàkáyé-àrùn. | 0 |
Àkẹ̀hìnsí onígẹ̀gẹ́, bí ẹni tí ń kébòsí. | 1 |
Àmọ̀ó ẹni ọdún mọ́kànlélógún fi ara gba ìbọn lásìkò tó ń ṣọ́ àwọn èèyàn ìlú rẹ̀. | 0 |
Àwọn kan ń jí àwọn ọba gbé láìbẹ̀rù. | 0 |
Àmàlà déLùúgùn ó doyin-mọmọ. | 1 |
Gbamgba gbàmgbà làá d'ífá ilú. | 1 |
Akínjídé ni ẹnìkan tí Ọlọ́run kó yọ nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà. | 0 |
Agbègbè Orísúnmbáre ni wọ́n ti mú ọ̀kan lára àwọn afurasi náà. | 0 |
B'ísó iyá 'ò rùn, ť'ọmọ a ki pọn pọn. | 1 |
Fákẹ́yẹ fipá bá ọmọbìnrin tó kọnu ìfẹ́ sí lò pọ̀ nílùú Jóbíewé. | 0 |
Èkìtì dẹ́kun sísan owó ìfẹ̀yìntì fáwọ̀n Gọ́mìnà àná àti igbákejì . | 0 |
Àwọn àkàndá ẹ̀dá ní ìjọba kò ka àwọn kún. | 0 |
Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ń fi ọ̀rọ̀ wá ṣọ́jà náà lẹ́nu lọ́wọ́. | 0 |
A kì í gb'eyin l'érí pàntèté. | 1 |
Ará ọ̀run ò ṣ tí aṣọ. | 1 |
Bí ò bá seé kó pọ, yóo seé kó lọtọọtọ. | 1 |
A-sáré-ṣá-ṣá-nínú-ẹ̀gún ò sá lásán; bí kò lé nǹkan, nǹkan ńlé e. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.