Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Àwàsẹyìn akàn kì í pakàn.
1
Àwọn ọlọ́pàá ti yọ̀ǹda òkú olóògbé fáwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀.
0
Alukoro àjọ ọ̀hún sọ pé inú àpò ìrẹsì ni àwọn afurasí náà kó igbó pamọ́ sí.
0
Èké tan-ni síjà ẹkùn, ó fi ọrán ṣíṣ sápó ẹni.
1
Àwọn èèyàn la ìjà wa, wọ́n sì bá wa dá sí i.
0
Òní ni àyájọ́ ọjọ́ ìbí ọ̀gá mi ní ibiṣẹ́.
0
Ìjọba àpapọ̀ ti buwọ́lu àwọn ètò tuntun mọ́kànlélógún.
0
Àwọn ọlọ́pàá tó ń tẹ̀lé gómìnà Ìpínlẹ̀ Kogí ti palẹ̀ ẹrù wọn mọ́ nílé gómìnà.
0
Àwọn aṣọ tí mo sá ò gbẹ, òjò tún pa á mọ́ ibi tí mo sá a ṣí.
0
Àwọn fìrí-nídìí-ọ̀kẹ́, alọ-kólóhun-kígbe ẹ̀da kan ti palẹ̀ kẹ̀kẹ́ mẹ́ta ní ilé iṣẹ́ ibi tí wọn ti ń tà á.
0
Bí ò sí t'Odù Ìwòrì tó ní k'álágbẹdę ìmògún ó dú lójú, m'ẹnu nì,kó se àgbọn isàle woriworì, gbogbo irin n iì bá ti jóná tán mágbede.
1
Fún'ra eni làá sọ pé a wà níbìkan.
1
Aláàárẹ̀ náà gbé ẹ̀mi mì sí iléèwòsàn náà.
0
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìyanu kan ṣẹlẹ̀ ní òkè odò lówùúrọ̀ òní.
0
Àfi kí Ọlọ́run dùn ún nínú.
0
Ayo níí lé àlejò lóko.
1
Fásitì Ifẹ̀ ti gbé ìgbìmọ̀ kan kalẹ̀ láti wádìí ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé ní ọgbà àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
0
Ẹrù ọmọ Ọjeję, bíbà ló ń bani, kò leè pani.
1
Akéèrà kì í roko ìrà kó sanwó.
1
Ìjọba àpapọ̀ yóò bẹ̀rẹ̀ ètò ìkànìyàn láìpẹ́ yìí.
0
Owó pọ́ọ́kú ni Àlàbí máa ń ta àwọn ẹran tí ó jí gbé.
0
Afọgbọ́n ọlọ́gbọ́n ṣ'ọgbọ́n ó gbọn ju'Fá lọ.
1
Àjọ aṣọ́nà ní ọ̀kànlélúgba èèyàn ló dèrò ọ̀run nínú ìjàmbá ọkọ̀.
0
Báwo ni òkú ṣe máa sọnù ní ilé-ìgbókupamọ́́ sí?
0
Lára àwọn tí wọ́n kéde orúkọ wọn jẹ́ oníṣòwò owó ilẹ̀ òkèèrè.
0
ọpọ awọn ọmọ orilẹede miran, ninu eyi ti Naijiria wa, lo ṣi ha si Sudan bayii ti wọn si n ke gbajare si ijọba orilẹede koowa wọn pe inu ewu nla lawọn wa.
0
Ayé ò fẹ́ni fọ́rọ̀, àfi orí ẹni.
1
Àwọn Iléeṣẹ́ ìròyìn lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan jẹ̀bi ẹ̀sùn yìí.
0
Atipo ò mọ erèé; ó ní, ‘‘Bàbá, mo réwé funfun lóko.’’
1
Èèyàn márùn-ún farapa, ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá àti ilé sì jóná.
0
Àwọn alátakò lè lúgọ de àwọn ọmọ ogun ní àsìkò ogun.
0
Eeṣin ń kun gbogbo ilé torí òórùn náà.
0
Àyẹ̀wò àrùn ọpọlọ ni yóò jẹ́ kí ìjọba mọ̀ bóyá awakọ̀ kò ní ìpèníjà ọpọlọ.
0
Abánikú ọ̀rẹ́ ṣọ̀wọ́n; abánikú, ogun ní ń bani lọ.
1
Agbẹnusọ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Oǹdó sọ wí pé wọ́n ṣá Ọláolúwa ní àdá.
0
B'ọmọdé hun agbọn, kò leè hun yibiyibi.
1
Gúdúgúdú 'ò fìgbàkan túraá le.
1
Akeúgbagóòdì ní àpẹẹrẹ wèrè díẹ̀díẹ̀.
0
Àgbà tó ń yọlệệ dà, ohun burúkú a máa yọ o șe.
1
Àwọn adigun jalè kọlu ilé àwọn olóṣèlú kan ni Èkó.
0
Àwọn àgbẹ̀ ẹgbẹ́ tí wọ́n ń pè ní Ọbalàgbẹ̀ ni wọ́n dá ẹgbẹ́ náà sílẹ̀.
0
Àdàbí jà ó jèpè.
1
Àfòmọ́ ń ṣe ara-a rẹ̀, ó ní òun ń ṣe igi.
1
Dúró dè mí; àlè, lò ń mú wọn-ọn lèkísà-așọ.
1
Bí a ò gùn, tá ò ga, kò pé kí a ma mẹni a bá ș'ọgba; kò pé k'ámá m'ẹni a gbọnrè. (jù lọ)
1
Àwọn nǹkan tó ṣe kókó nípa àwọn olùdíje fún adárí ẹgbẹ́ ló sọ.
0
Agbe l'olóhùn eré, Àlùkò l'olóhùn orò,Ọbàràwonrínl'olóhùn-un mà sọrọ, mà sọrọ.
1
Àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Òǹdó ṣì ń tẹ̀síwájú nínú ìwádìí wọn.
0
À-rí-ìgbọdọ̀-wí, ẹran ilé tí ń fojú dọdẹ.
1
A kì í jẹ aládùn méjì pọ̀.
1
Ààbọ ọrọ làá sọ fọmọlúàbí, bó bá dénú e a di odidi.
1
Ẹni wọn rò pé kò leè ká'lá, ó ń pọrá (ọrúnlá)
1
Ẹlẹdẹ tó ń padię jẹ, a kì í tà á sílé.
1
A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ó bá wa torí ìwà àwọn èèyàn.
0
Àbàtá ta kété bí ẹnipé kò bá odò tan.
1
Ginniginni Iólógìnni n yo májęlójúonílé. (méku).
1
A-rìn-fàà-lójú-ak gàn, a-yan-kàṣà-lójú-abúni, abúni ò lówó nílé ju ẹnu-u rẹ̀ lọ.
1
Gómìnà Ayédatiwa jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdíje fún ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó.
0
Ó yẹ kí àbájáde ìpàdé lórí ìgbésẹ̀ yíyan Aláàfin tuntun tẹ ìjọba lọ́wọ́
0
Bí 'ò síkú-ilé, t'òde 'ò leè pani.
1
Àwọn orílẹ̀-èdè ní ẹkùn ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Yúróòpù ń gbóná jọjọ.
0
Títí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ pa lè báni dẹ́kun àjàkálẹ̀-àrùn.
0
Mi ò ṣe irú nǹkan báyìí rí láyé mi.
0
Bí ọmọdé bá pa eku, a dá a jẹ, bó bá pa ẹyẹ, a dá a jẹ, ṣùgbọ́n ọjọ́ tó bá dáràn gòdògbà, a fà á wá sọ́dọ̀ ọ bàbá-a rẹ̀.
1
Àtàrí àjànàkú kì í ṣẹrù ọmọdé.
1
Ẹyìn Ahun; kì í ș'ẹní àtẹsùn.
1
Bí ayá bá gbọ́ tọkọ, wàhálàá tán.
1
Àwọn èrò tó wà nínú ọkọ̀ kò ráyè jáde títí tí wọ́n fi deérú.
0
Ìrọ̀rùn ni gbogbo nǹkan máa ń jẹ́ bí àsìkò rẹ̀ bá tó.
0
B'árá iwájú 'ò bá sìnà, èrò-ẹyìn ò ní sùngbẹ.
1
A ò mọ iṣu tí yóò kẹ̀ẹ́hìn ọgbà.
1
Baba-ìsìnkú ò fọmọ-ọ rẹ̀ sọfà; alábàáṣe ń fọmọ-ọ rẹ̀ kówó.
1
Wọ́n ní kí ló tún kù fún èèyàn tó ti kọ́kọ́ fi ẹgbẹ́ bàbá bàbá ẹ̀ ṣe ọkọ.
0
A kì í lápá-a bàbá ká má nìí ti ìyá.
1
Àwọn oníṣẹ́ okòwò náà kò ní wàhálà kankan pẹ̀lú rẹ̀.
0
Bó jẹ́ ire ló bá wù ọ́, máa ṣe é lọ.
0
Bí ọ̀bùn ò mọ èrè, a mọ ojú owó.
1
Àgbàdo kì í ṣe èèyàn; ta ní ń rí ọmọ lẹ́hìn eèsún.
1
B'á'ò rẹni gb'ọkàn lè; a tẹpá (tẹra) mọșę ęni.
1
Alàgbára má mèrò baba olę.
1
Òṣìṣẹ́ tó bá ṣiṣẹ́ takuntakun jùlọ yóò máa gba ẹ̀bùn owó.
0
Adénúgà tẹpa mọ́ṣẹ́ láti ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀.
0
A kò lè dá àrùn yìí mọ̀ lára ẹni tí ó bá kó o.
0
Àyẹ̀wò ìbátan wáyé lórí ọmọ yìí.
0
A kì í gbọ́n tó Báyìí-ni-n-ó-ṣe-nǹkan-àn- mi.
1
‘‘Mo ṣe é tán’’ ló níyì; a kì í dúpẹ́ aláṣekù.
1
Akòrọ̀yìn Nàìjíríà ko ìròyìn òkèèrè lórí ìjínigbé akẹ́kọ̀ọ́bìnrin.
0
Àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ò mọ̀ pé ó ti fi oògùn oorun sínú oúnjẹ wọn.
0
Àșẹ-Òjé làá pa ní bòńkẹlẹ.
1
Ẹní s'ọkò lu Àgbọnrín sàájò ọbeę, eran ló ya eran abitete gbọningbonin.
1
Àwọn tó ń lé awakọ̀ náà kò jẹ́ kó sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n rí i mú.
0
Wọ́n ní ìròyìn yìí ti ba ilé iṣẹ́ àwọn lórúkọ jẹ́ jìnà.
0
Àparò tó dúró lórí ebè; ó dúrò tìfura tìfura.
1
Àjọ ìdìbò yóò rí i dájú pé kò sí ìwà màgò-mágó ní ìgbà ìdìbò.
0
A ò mọ ibi orí ń bá ẹsẹ̀-ẹ́ rè.
1
Ìdí ni pé gbogbo àgbáyé ló ń wárí fún orúkọ náà.
0
Abíọ́dún ní òun kò tilẹ̀ rántí ọ̀rọ̀ náà.
0
Àwọn òbí fajúro sí ipò tí àwọn ọmọ wọn wà.
0
A kọ́lé bíríkótó, a ní kí òrìṣà gbà á; bí kò bá gbà á, kó lọ sígbẹ̀ẹ́ kó lọ ṣá ẹkẹ́, kó lọ sọ́dàn lọ họ okùn, kó mọ bí agara-á ti ń dáni.
1
Ẹ̀là lọ̀rọ̀; bóbìnrín bá jókòó a laṣọ bòbò.
1