Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Bóòlù lu așọ tán, kọrọo yàrá ní í gbé.
1
Àwọm ọmọ ìta lu enìkan pa ní ìpínlẹ Ọ̀ṣun.
0
Àwọn ọmọ Yorùbá míràn ò mọ̀ pé èèwọ̀ ni kí obìnrin wọ igbó orò.
0
Etí kan 'ò yẹrí (yẹ orí), ẹsẹ kan 'ò yẹnà. (yẹ ọnà).
1
Àgbàká labiyamọ ń gbàjá mọ́ ọmọ-ọ rẹ̀.
1
Bí ẹni ẹní bá kú lókèèrè, à pẹta-a rẹ̀ wálé.
1
A ní Tanlúkú ò mọ̀-ọ́ jó, Tàǹlukú wá gbè é lẹ́sẹ̀.
1
·Eyìn l'àbámọ ń gbé.
1
Gbogbo ohun tó ń dán kọ ni wùrà.
1
Àgbákò fẹ́ kí wọ́n yanjú ọ̀rọ̀ ètò ìdìbò ṣíwájú kí ìjọba tuntun tó wọlé.
0
Bí iyán ti ńfún lóko ẹgàn, bẹ́ẹ̀ náà ní ńfún ní ti etílé.
1
Bí ẹnlá ti mọ ló ń jó mọ.
1
Àjòjì ò mọ pé ará-ilé ò fẹràn ará wọn.
1
Abíọ́lá sọ wí pé ó dájú pé àbòsí kan ń lọ lórí ọ̀rọ̀ àìlera Bọ́lá.
0
Àgbàlagbà ńfìrọ́jú rọ̀run, a ní kó kílé kó kọ́nà; ojú rere ló fi ńlọ?
1
Ìgbìyànjú ti bẹ̀rẹ̀ ní ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn fún ìpèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu.
0
Àìná ṣèlérí pé òun yóò mú àwọn agbófinró dé ọ̀dọ̀ tí òun ra ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀.
0
A kì í pe ìyàwó kó kan alárẹnà.
1
Dòsùnmú ní iṣẹ́ abẹ náà kò bá òdì lọ lára igbákejí.
0
Apani kì í jẹ́ ká mú idà kọjá nípàkọ́ òun.
1
Èeyàn lọlá.
1
Àgbà tí kò yáni lẹ́gbàá ìkọ̀kọ̀, bó bá dáṣẹ́ ilé sílẹ̀ a kì í lọ.
1
Àgbà kán ṣe bẹ́ẹ̀ lÓgùn; Yemaja ló gbé e lọ.
1
Ẹní tí kó fun ni níwọ, a kì í fún un lẹbòótòró.
1
“Bí kò gbà kó má gbà” ni adámú yóò șe fi aásà san oodegbeta.
1
Yálà ó wù ẹ́ tàbí kò wù ẹ́, dandan ni láti gbá bọ́ọ̀lù fún ilé-ìwé yẹn.
0
Kò sí nǹkan tó wáyé tó lè ṣokùnfà irú ikú òjijì bẹ́ẹ̀.
0
A kì í fi ejò sórí òrùlé sùn.
1
Afẹlẹ-gbowó-olówó òun afipá-gbà-á okanhùn.
1
Bí ó ti wù kí Olúkọ̀tún gbójú tó, Ajagùnnà ni bàbá-a rẹ̀.
1
Bọ́sẹ̀ bú sí ẹkun ayọ̀ lẹ́yin tí ó parí ìwádìí.
0
Àkọ́bí ẹlẹ́ran kì í já mọ́ wọn lọ́wọ́.
1
Ọlọ́pàá kan pàdé ikú òjijì níbi ìjà àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ọlọ́kadà nílùú Èkó.
0
Kò dára tó bí a kò bá yọjú sí àwọn agbaṣẹ́ṣe tí a gbé iṣẹ́ fún.
0
Jagunjagun sọ wí pé iṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ni àwọn ṣe.
0
Àwọn agbègbè mìíràn tí Lọ́ńdọ̀ọ̀nù yóò tún móoru jùlọ ní Nassau.
0
Ajenífẹni orẹ șòròo ní; kò pani tì.
1
Ajewẹre ló ń jẹ t'Érin; ajęwàdùwàdú níí ję'ję Ẹlírí.
1
Anìkànrìn ejò là ń fàdá pa.
1
Bí gbogbo ayé bá jẹ Olóòsà, ta ni yóò ké “Héèèpa!”?
1
Eyẹ tí ó ń sọ ikù kì í ri í jẹ, torí síso rẹ ọdún mẹta, wíwọbo rẹọdún mẹta, kí ó tó jẹrà ọdún mẹta gbáko.
1
Aláàfin tó wàjà fi Àyìndé jẹ oyè Máyégún ti ilẹ̀ Yorùbá.
0
A mọ aláré, a mọ eléki; aláṣìsọ ló kù.
1
Èké ò pe ara-a rẹ̀ lórúkọ; ìkà ò pe ara-a rẹ̀ níkà.
1
Àbá nlkán ń dá, lkán 'ò le mu òkúta.
1
Ẹ̀bi alábaun kì í gbèé dẹ̀bi àna-a rẹ̀.
1
Eyín funfun kì í s'ọkàn funfun.
1
Gege l'ó se; gbèsè Abíjo.
1
Kòkòrò kékeré ni ó máa ń ṣokùnfà àrùn
0
Dàda ò leè jà, ṣùgbọ́n ó lábùúrò tó gbójú.
1
Wọ́n ti ṣe àfikún sí owó oṣù àwọn òṣìṣẹ́ lórí iṣẹ́ wọn.
0
Ẹní ní ni l'óògùn ló ń rọni. (Ẹní sọni l'óògùn ló n fún ni lẹrọ ẹ.)
1
Àgbà tọmọde ri tí kò kí, iwàa wọn ló m'ọmọdé fojú pa wọn rẹ.
1
Èèmọ̀ ní Ìmọ̀: Onímọ̀-ọ́ sòpá, ayaa rẹ̀-ẹ́ dégbò.
1
Gbogbo aráilé Ọkánlàá ń sunkún rẹ, Ọkánlàwọn alára wà nínúigbó tó ń serée géle bí Obọ.
1
Àwọn ìdọ̀tí ojú ọ̀nà àti gọ́tà máa ń fa omíyalé.
0
Àjọ tó ń gbógun ti ìwà àjẹ́bánu fi ẹ̀sùn kan Yẹmí pé ó ń kó owó pamọ́ sókè òkun.
0
Àṣírí òṣìṣẹ́ tó ń jí dúkìá Iléeṣẹ́ wa kó padà tú sí ọ̀gá Iléeṣẹ́ lọ́wọ́.
0
A kì í bí ni ní mọrọ; k'ára má rọni.
1
Ó bà mí lẹ́rù pé obìnrin yẹn kú bẹ́ẹ̀.
0
Bí a bá s'akin,akì í fọhùn bí ojo, bí a bá ș'ojo; a kì í fọhùn bíi akin.
1
Àgàlámàsà rìn kọí kọí (pẹ ògiri).
1
Enu àimenu,ètè àimétè ló ń koràn bereke.
1
Alábahun Ìjàpà níjọ tóun ti jágbọn-ọn 'Hòo' lọrùn ò ti wọ òun mo.
1
Akínjọbí Adéjùmọ̀ ti fi ìgbà kan gbé ìlú òyìnbó rí.
0
A kì í toríi gbígbó k'á pa'já. A kì í toríi kikàn k'á pàgbò. A kì ítoríi wérewère pòbúko.
1
Ìjọba kéde pé kí a ṣọ́ra fún gbígbé ìròyìn búburú.
0
Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé gíga kan ṣekú pa ara rẹ̀ ní ọjọh Ẹtì.
0
Òkìkíọlá sì tún máa pàtẹ àwọn ìyàwó rẹ̀ sórí afẹ́fẹ́ lọ.
0
Àròyé ò kún àjọ.
1
Ìjọba sọ wí pé kò tí ì sí àìsàn kankan nínú ìlú yìí.
0
Àwọn ṣọ́jà gba ìpè pàjáwìrì láti ọ̀dọ̀ àwọn aláṣẹ ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
0
Mi ò mọ̀dí tó fi ní kí n kẹ́rù mi lọ́sàn-án kan òru kan.
0
Bí ọ̀rán bá pẹ́ nílẹ̀, gbígbọ́n ní ń gbọ́n.
1
A kì í du orí olórí kí àwòdì gbé tẹni lọ.
1
Ìwà ìbàjẹ́ nínú ìdánwò jẹ́ ohun tí a gbọ́dọ̀ fi òpin sí.
0
Adìẹ funfun lààyò adìẹ.
1
Bí ayé bá ń yẹni, ìwà ìbàj là ń hù.
1
Gbamgba lÀșá ń ta. Àsá kì í ta níkọrọ
1
Àwọn ológun ìlú Òṣogbo tí ń gbé ìgbésẹ̀ láti rí Ọ̀gbéni Àlàní.
0
Àwòdì, olójú-iná.
1
Adarí ilé aṣojúṣòfin ni Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà.
0
Ẹ̀gbọ́n mi bí ọmọkùnrin kan mọ́jú òní.
0
” Eera l'óun ràntí kékeré òun. lgbà wo lèèrà dàgbà?
1
Ẹni tí ò bá mọ okùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn awakọ̀ kò ní lè sọ sí ọ̀rọ̀ náà.
0
Erìgì àlọ níí s'ọlá fákápò awo.
1
Èèyàn kékeré sànsẹ adiẹ, a máa báni sọrọ bí àgbà.
1
Wọ́n pe èèyàn méjì láti wá sọ ohun tí wọ́n mọ̀ nípa ikú ọkùnrin ọlọ́dẹ ọ̀hún.
0
Láàárọ̀ kùtùkùtù ni ọ̀rẹ́kùnrin yìí fi Ọláyínká sílẹ̀ nínú yàrá.
0
Èlò ni irun tó rẹ́wà yìí bádé?
0
Ète lẹgbọn, èrò làbílé, ọgbọn-inú làbídákun wọn.
1
Èèyàn márùn-ún la kì í dá lẹkun má-se. Ẹkún alára ní í da ara rę fún wọn. A kì í pé kí ękúwárápá (alátọsí) ó ma yowó ilá. A kì í pe kónígege má fokùn danrùn wò. A ki í pe kásòpá ma mùú oko nídìí ọpẹ. A kì í pé kóníjàkùtẹ má rìn nínúú ègiyàn eèrùn. A kì í pé kogbóogbọ ìyàwó kó má renú eèkan lọfúnsáárí.
1
Ẹlòmíràn tún fi ara pa yàtọ̀ sí ẹni tí wọ́n jí gbé lọ.
0
Eyín t'ájá fi ń b'ọmọ e seré ló fi n ge é jẹ.
1
Àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ búrẹ́dì nílùú Ìlọrin lu ọ̀gá wọn ní jìbìtì owó.
0
Ẹlòmìíràn ti ń gbaradì fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù nínú wọn.
0
Oníbàárà ilé ìfowópamọ́ ni àwọn oníṣẹ́ láabi ọ̀hún.
0
Bí a 'ò bá b'Ọfún; kí a b'Ọlọkànran, ayéOlúfe a bàje.
1
Àwòdì ń rà, inú aládì bàjẹ́ .
1
Fágá, fàgá, fágá, ohun tó șeé fágá làá fií fágá. A kì í fi, 'Níwòyíàná, mo ti na iyáà mú fágá', fágá.
1