Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Eran esin, abikúnnilenu-tete. | 1 |
Àwọn aráàlú ò lè lọ ibi-iṣẹ́ lóri ọ̀rọ̀ ọ̀wọ́n epo. | 0 |
Bọ̀rọ̀kìnní òun ọlọ́rọ̀ ẹgbẹ́ra; ọ̀bùn òun aṣiwèrè ọ̀kan-ùn; ọ̀kánjúà òun olè déédé ni wọ́n já sí. | 1 |
Ẹléwọ̀n kan yọ̀ bọ́rọ́ mọ́ àwọn ọ̀gá wọ́dà mẹ́jì lọ́wọ́ ní ìlú Èkìtì. | 0 |
Àpàkòmọ̀rà, tí ń gẹṣin lórí àpáta. | 1 |
Bí Ọlọ́run ń ṣe rere, à ní Ó ń ṣe ibi. | 1 |
Afínjú ní ń jẹ iwọ; ọ̀mọ̀ràn ní ń jẹ obì; màrí-màjẹ ní ń jẹ awùsá. | 1 |
Eni kò i kúkòmọkú tí yóó pa òun. | 1 |
Dábírì sọ wí pé ọkàn àwọn wà pẹ̀lú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè àwọn. | 0 |
A-rọ́jú-fúnni-lóhun-ún sàn ju a-rọ́jú gbà-á lọ. | 1 |
Fàáafa làá bú baba Olófòófó. | 1 |
A gbọ́ pé wọ́n dọ́gbọ́n mú ọ̀dọ́mọdékùnrin kan lọ sí òkè òkun. | 0 |
B'ọwọ bá dí, ojú kì í dí. | 1 |
Àlááfíà ni a fẹ́ kí ó jọba ní orílẹ̀-èdè wa. | 0 |
Àwọn ọlọ́jà Èkó ń pariwo lórí ọ̀wọ́n-gógó owó ọkọ̀. | 0 |
Baba ẹnìkan ò gbin yánrin; baba ẹnìkan ò gbin tẹ̀tẹ̀, fúnra-a rẹ̀ ní ń hù. | 1 |
À-jókòó-àì-dìde, à-sọ̀rọ̀-àì-gbèsì, ká sinni títí ká má padà sílé: àì-sunwọ̀n ní ń gbẹ̀hìn-in rẹ̀. | 1 |
Kò yẹ kí ìrántí ẹnikẹ́ni jẹ́ baálé ṣá-àdá-ṣá-àdá tàbí ìwà ìpáǹle. | 0 |
Agbédè bí Òfé, amaraáre bí Odíde. | 1 |
Akẹ́kọ̀ọ́ kan dágbere fáyé ní ilé-ẹ̀kọ́ kan. | 0 |
B'éèyàn 'ò bá lẹni nígbìmọ, bó rojọ àreẹ,ębi ló máa já sí. | 1 |
Àdùnní gbìnyànjú láti sá kúrò níbẹ̀ ṣùgbọ́n ó há sí àárín ọkọ̀ méjì. | 0 |
A kì í ṣ'awo f'ọlọgbẹrì mọ. | 1 |
Ààyè ìfọpo rọ̀bì lè fọ epo tí orílẹ̀-èdè púpọ̀ lè lò. | 0 |
Àwọn ọ̀dọ́ ti fọ́n sí ìgboro láti fẹ̀hónú hàn tako ìṣẹ̀lẹ̀ yìí. | 0 |
Èèyàn búburú pọ̀ ó jùgbẹ́; ẹni reré wọ́n ju ojú lọ. | 1 |
Ẹrú lèrò, b'ó ba ti sálọ, kì í seé mú mọ. | 1 |
Bí a kò ṣe ọdẹ rí, a kò lè mọ ẹsẹ̀-ẹ kò-lọ-ibẹ̀un. | 1 |
Awọgbẹ ò si èrè, owó ló tarí e wọgbẹ. | 1 |
Lórí fọ́nrán oníṣẹ̀ẹ́jú díẹ̀ kan ni a ti rí ìwà burúkú tí obìnrin náà hù. | 0 |
Èèyàn-án ní òun ó bà ọ́ jẹ́ o ní kò tó bẹ́ẹ̀; bí ó bá ní o ò nùdí, ẹni mélòó lo máa fẹ fùrọ̀ hàn? | 1 |
Àwọn ajínigbé gbé Ayọ̀mídé padà sílùú Oǹdó láti Ọ̀rẹ̀ lọ́jọ́ Ọjọ́bọ. | 0 |
Àwọn ọ̀dọ́ ti ti ilẹ̀ òkèèrè dé. | 0 |
Àwọn oníròyìn kò sọ bí ọ̀rọ̀ ọ̀hún ti rí. | 0 |
Bí àkíyèsí bá tó, a ó mọ pé pìpọn epo yàto sí teje. | 1 |
Àwọn agbófinró agbègbè Àánú-ni-mo-rígbà tọpasẹ̀ ọkọ̀ náà dé ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. | 0 |
Ààrẹ Bùhárí lo àsìkò ayẹyẹ náà láti fi gbàdúrà fún tọkọ-taya. | 0 |
Ebi kì í wọnú, k'ọrọ mìíràn ó wọ ọ. | 1 |
Èmi ò rí nǹkan tó jọ mọ́ pé wọ́n ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó nínú eré ṣíṣe. | 0 |
pé kí ló rí níbẹ, ó ní; òun rí ìkòkóolomí,òun ropa, àmno o kolokọlọ (kilọkìlọ) ló pọ níbẹ. | 1 |
Àwọn kòkòrò tí jẹ gbogbo irè oko tí mo kó pamọ́ sóko. | 0 |
B'ókùn ba máparò, a sọ o d'ęgbę eyękęyę. | 1 |
Adìẹ-odò ò ṣéé bọ ìpọ̀nrí. | 1 |
Àpẹẹrẹ èyí tún ń wáyé tí a bá wo bí àwo orin tó gbé jáde láìpẹ́. | 0 |
Wọ́n ní káwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí wọn kò tí ì ní káàdì máa lọ forúkọ sílẹ̀ ní kíákíá. | 0 |
Bí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣe ṣe àṣeyọrí lórí ààrùn rọmọ lápá-rọmọ lẹ́sẹ̀. | 0 |
Bí a bá káșo rere kalę (sílę) a kò gbọdọ fọnná síi. | 1 |
Ààrẹ kò fààyè gba kí ẹnikẹ́ni lo àwọn ọlọ́pàá láti fi ṣẹrú ìbò. | 0 |
Bí aáṣẹ́ bá ti ń fò, bẹ́ẹ̀ la ti ń sọ̀kò sí i. | 1 |
À ń dáhùn sí gbèsè; góńgó orí ẹ̀ la kì í kán. | 1 |
Èèyàn kì í ș'oògùn ewà. | 1 |
Bí alágbára-á bá jẹ ọ́ níyà, fẹ̀rín sí i. | 1 |
Àbẹmọlẹ eèkàn níí sojú regúnregún. | 1 |
Lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó tún ṣe dáadáa púpọ̀ ní sáà ẹ̀kọ́ tó kọjá ni Adéróunmú. | 0 |
Bí ẹni tó ní òun ń lọ p'ẹja kábọ bá ń kisán; ó tọ kí ominú kọ ni. | 1 |
A lè rí àwọn iṣẹ́ Ajóbíewé káàkiri ilé-ìtajà rẹ́kọ́ọ̀dù. | 0 |
Wọ́n ti ka àbá tuntun náà nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. | 0 |
B'éèyàn 'ò dùn l'áwo, kò leè dùn nímùlẹ. | 1 |
A sé ẹtu, a ò sé ẹtu, ọparún gbá a nídìí; ọ̀ràn ẹtu ni bí? | 1 |
Àwọn ìjọba kọ́ ní wọ́n ni owó ìlú. | 0 |
Àwòdì tí ń re Ìbarà, ẹ̀fúùfù-ú gba nídìí, ó ní iṣẹ́ kúkú yá. | 1 |
Bí Onílé bá ń jẹ eésan, àlejò ò gbọdọ' l'óun fẹ jẹ èkùrọ. | 1 |
Ó dùn mí pé obìnrin náà kú lẹ́yìn ìjà wa. | 0 |
Àrẹ̀mú mú ẹ̀sùn wá sí iléeṣẹ́ ọlọ́pàá. | 0 |
Bífá 'ò sẹ l'ójú awo, ẹrù ò ní bologberi. | 1 |
Àgbà tó gbin èbù ìkà, orí ọmọ-ọ rẹ̀ ni yó hù sí. | 1 |
Alájá ló ń lọ l'óde là ń gbóhùn odu, Olóòșà ló n lọ l'óde là n gbóhùn àjà. | 1 |
Ẹlęwù kan 'ò jíjó-ęgbę. | 1 |
Ìròyìn ìgbéyàwó láàárín Ọdúnm̀bákú àti Ìfẹ́lọlá kò ní tán lẹ́nu àwọn ènìyàn fún ìgbà pípẹ́. | 0 |
Àìkú ẹkìrì ta ló jẹ fawọ ẹ se gbẹdu. | 1 |
Adébímpé wà ní bèbè ẹ̀wọ̀n ba tí ń sọ̀rọ̀ yìí. | 0 |
Ẹkàn gbarigidí wọlẹ̀; ọ̀gbágárá wọlé ó ku àtiyọ. | 1 |
Bàbá Ayọ̀ọlá sọ pé ọmọ òun ń gbìyànjú láti dá ààbò bo ara rẹ̀ ni. | 0 |
Àwọn kan bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ nípa ohun tó ń jẹ́ wọn níyà ní ìpínlẹ̀ wọn. | 0 |
Ẹ má náání ọkùnrin yìí jàre, eré ló ń ṣe. | 0 |
Bí a bá ń jiyàn sípàá, à ṣí aṣọ kúrò. | 1 |
Bí ọlọgbọ́n bá ń fi wèrè se iṣu, ọ̀mọ̀ràn a máa fi gègé yàn án. | 1 |
Ìdí ni pé kí igun tó ń jà má lọ jí ẹnikẹ́ni nínú wọn gbé. | 0 |
Ẹ̀mejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn ọlọ́ṣà ọ̀hún ti ṣọsẹ́ ládùúgbò náà nínú ọ̀sẹ̀ kan. | 0 |
Wọ́n ti kọ́kọ́ gbé òkú Ràúfù kúrò ní itẹ́ òkú. | 0 |
Arítẹnimọ̀ọ́wí, ó fi àpáàdì ràbàtà bo tirẹ̀ mọ́lẹ̀. | 1 |
Sáà méjì ni Ọládélé fi jẹ gómìnà lásìkò ìjọba alágbádá. | 0 |
B'órí pẹ níè, a 'á dire. | 1 |
Inú mi yóò dùn láti pín ìrírí mi pẹ̀lú àwọn tí wọ́n wojú Ọlọ́run fún ọmọ. | 0 |
Ajé ní ń ba ojú ọ̀rẹ́ jẹ́. | 1 |
Wàhálà ti pọ̀jù lọ́rùn mi lásìkò yìí. | 0 |
Àáké tó ń gégi nígbó kò sẹ, gbẹnàgbẹnà ń bu ẹtù sarí. | 1 |
Ẹ kà nípa ìgbésí-ayé olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ọ̀kín. | 0 |
Ní ọjọ́ Ẹtì ni a gbọ́ pé wọ́n gbé Táyé dìgbàdìgbà. | 0 |
Àgbà ò sí ìlú bàjẹ́ ; baálé ilé kú ilé dahoro. | 1 |
Àwọn ènìyàn kan sọ pé ilé ìwòsàn ni ó kú sí lẹ́yìn tí wọ́n gbé e dé ibẹ̀. | 0 |
Àwọn kan ti ń pariwo kiri pé Bọ́lá nìkan ló lè ṣé. | 0 |
Àwọn ìbejì tí a bí nígbà kan náà kì í sáábà hùwà bákan náà. | 0 |
Aláǹgbá tó fojú di erè, ikùn ejò ni yó bàá ara-a ẹ̀. | 1 |
Adùn l'ó ń gbẹyìn ewúro. | 1 |
Àgúnbàjẹ́ ni tolódó. | 1 |
Àwọn tó kú lọdún yìí pọ̀ gidi gan-an. | 0 |
Akin Adéṣínà ti jẹwọ́ pé ọmọ bíbí ilẹ̀ yorùbá gidi ni òun. | 0 |
A gbọ́ pé inú igbó ńlá kan ni wọ́n kó gbogbo àwọn ọmọ náà gbà. | 0 |
Ajewere ló ń je ť'Érin; ajęwàdùwàdú níí ję'jẹ Ẹlírí. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.