Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Așo-ibora kì í lápò.
1
A kì í fi iná sórí òrùlé sùn.
1
Àdàbà ń p'ògèdè bí ẹní pẹyẹlẹ 'ò gbọ, ẹyẹlę gbọ, títiri ló n tìr.
1
Èkejì nínú wọn sì yọ dágà.
0
B'álágbede bá fejú eni kù ọyà ọtọ ni yóò mù-ún. (se)
1
Àkàìkàtán ni àwọn oore Ọlọ́run láyé ẹni kọ̀ọ̀kan wa.
0
Onírúurú eré ló wà tí ènìyàn lè ṣe gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́.
0
Babalọlá Fálémi fi àwọn káàdì báǹkì náà gba owó lẹ́nu ẹ̀rọ ìgbowó.
0
Arábìnrin Atinúkẹ́ Ṣóbọ́lá ni ìyá Lọlá.
0
Bàbá mi rọ ìyá mi pé kí ó tẹ̀lé òun lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn adarí ètò ìjọba.
0
Búni-búni abèébú wontiwonti lára.
1
Àgbà tí kò mú iṣu wá sábà ò níí jẹ iyán alẹ́.
1
Babaláwo kì í firo pelú Opele. Èyí tó bá firo pẹlú Opele; ara re ní í tàn jẹ.
1
B'ébi bá ń p'ọlẹ e jọle ó kú. Kíkú tàikú ọlẹ 'ò wúlò.
1
Àwọn Ọba aládé mẹ́ta ni yóò rìnrìn-àjò pẹ̀lú ààrẹ orílẹ̀-èdè yìí.
0
Ẹ má bá mi lé ìyàwó mi lọ torí èmi ni mo san owó orí ẹ̀.
0
Apá èkúté-ilé ò ká awùsá; kìkìi yíyíkiri ló mọ.
1
A-fàtẹ́lẹwọ́-fanná kì í dúró.
1
‘‘Ó ṣe mí rí’’; ògbó adìẹ rí àwòdì sá.
1
Ayé 'ò jẹ ń rójú, ó sàn ju ayé gbàgbéè mi.
1
Abẹ̀wẹ̀ ń wá ọ̀tá fúnra ẹ̀.
1
Wọ́n gún akẹ́kọ̀ọ́ Fásitì Àkùngbà lọ́bẹ pa ní ìrọ̀lẹ́ Ọjọ́bọ.
0
Ẹlẹ́mùn-ún ò mú eégún.
1
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ.
1
Gbèsè nikú, kò s'eni tí kò ní san.
1
Gbèsè Ológìnní, à-san-n-santán.
1
Akíọdé sọ wí pé kò sí ẹnikẹ́ni tó sun inú ilé ìgbé náà lọ́jọ́ náà.
0
A ṣe àlapà lọ́ṣọ̀ọ́ kò yẹ; a ṣe ohun gbogbo fúngi, o yẹ igi.
1
Bara sùn, Bara 'ò jí, bó bá yà,ohun tí yóó jìíBara ò ní sài j Bara.
1
Àjojẹ 'ò dùn b'énìkan 'ò ní; ọjọ a bá ní làá pè'de àjọję.
1
A kì í gbèé d'oníle lÓkun.
1
Àìbìkítà àwọn ará àdúgbò náà ń kóbá àwọn ọmọdé wọ̀nyí.
0
Bá mi mú ẹlẹ́rìndòdò kọ̀ọ̀kan wá fún àwọn àlejò.
0
Ajá ní ńlá omi lẹ́bàá-lẹ́bàá; eṣinṣin ò kún àtẹ ìlẹ̀kẹ̀; ọmọrí igbá ò fìdí kalẹ̀ kó gún rẹ́gí-rẹ́gí.
1
‘‘Kò pa ẹtu kò j kí ẹtu jẹ̀,’’ tí ń faṣọ funfun ṣọdẹ.
1
Àdábá nìjà; ẹni tí ìjà ò bá ní ń pera-a rẹ̀ lọ́kùnrin.
1
A pàkàșù, Baálé ní 'òóò'. Wọn ní: 'Baba a ò báa yín wì'. ó níbó s'omitoro lásán òun óó fi jẹ e'.Ta ni ò mọ pebi ló ń pa Baálé!
1
Wọ́n dojú ìbọn kọ àwọn ọlọ́pàá bí wọ́n rí wọn.
0
Àwọn ọmọ olókùú sukún ní ọjọ́ òkú bàbá wọn.
0
Afurasí ọ̀daràn máa jìyà ẹṣẹ rẹ̀ tí ó bá jẹ̀bi.
0
Alábùkù bí ọkọo 'pà ẹè' tó kérò mẹta tó lóun ti kún.
1
Ìgbìmọ̀ àwọn afọbajẹ ìlú Ọ̀yọ́ sọ pé ẹjọ́ tó dá gómìnà Ọ̀yọ́ láre kò tẹ́ àwọn lọ́rùn.
0
Bí ìyá ò sí, ta ní j ṣe ọmọ ọlọ́mọ lóore?
1
B'ẹrù bá pọ lọrùn ogẹdẹ, a fẹfẹ bíntín níí bì í wó o.
1
Èèmọ̀ lukutupẹ́bẹ́; ìyàwó lóyún tán ọ̀na ò gba ọkọ.
1
Agbègbè Àánú-ni-mo-rígbà ni Ọládipúpọ̀ ti gba ọkọ̀ náà lọ́hùn-ún.
0
Àwọn eré ìdárayá wà fún àwọn aláboyún.
0
Alákòóso ilé ìfowópamọ́ rọ àwọn ènìyàn láti dá owó padà.
0
Ọwọ́ tún ti tẹ afurasí agbingbó mẹ́ta.
0
Eran tí a kì í jẹ,a kì í f'eyín pín in.
1
Edá tó bá ní sùúrù 'ò ní jẹka.
1
Báróo wa jáde, baba ta ló le re e?Bí a pèlù tá ò jó, baba ta lóle jò?
1
A kì í nìkan gbé agán kẹ́sẹ̀-ẹ rẹ̀ má wọ̀ọ́lẹ̀.
1
Bílé bá dá, adẹtẹ à á yan fanda.
1
Ẹmú, báàlẹ lágbẹdẹ.
1
Bí ọtí bá kún inú, ọtí á pọmọ; bí oòrùn-ún bá pọ̀ lápọ̀jù a sọ ọmọ di wèrè; bí a bá lọ́ba lánìíjù a sínni níwín; tẹ̀tẹ̀ ẹ̀gún pọ̀ lódò o di olú eri.
1
Ìjọba ti rọ gbogbo àwọn aráàlú pé kí wọ́n má ṣe fòyà rárá.
0
‘‘ Ọ̀ràn yí ò dùn mí’’: ẹ̀ẹ̀kanṣoṣo là ń wí i.
1
Àgbinsínú l'egbin ń gbin.
1
A-báni-gbé kì í yáná; a-bọ̀rìṣà kì í sun òtútù; ẹyin gẹ́gẹ́ kì í gbé àwùjọ; ilé kannáà ni wọ́n kọ́ fún àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta.
1
Ó ní inú igbó ni àwọn ti bára àwọn nígbà tí àwọn jí,
0
Nígbà tí ọkùnrin náà ráàyè já ọ̀bẹ gbà lọ́wọ́ ìyàwó rẹ̀ ni àwọn ọlọ́pàá wọlé.
0
Diẹ l'ọmọ nínú oun tí a wá se láyé.
1
Ẹ̀hìn ológbò kì í balẹ̀.
1
"Gbogbo yín, e dà gọrọrọ wá, ẹ wá jẹun”. Ońjẹ tí 'ò tóniíjẹ, a kì íp'eni lọkànkàn.
1
Ewìrì ní í fẹnu ara rẹ rojọ fún iná.
1
Etí l'àgbà ń fẹrẹ, àgbà kì í fẹrẹ ẹnu.
1
Așòwòòjèrè, la fi í dàbí ẹni tí 'ò mọjàá ná.
1
A-gbẹ́jọ́-ẹnìkan-dájọ́, òṣìkà èèyàn.
1
Ó tún jẹ́ ọdẹ ní ilé epo kan yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ ọ̀gá akọrin.
0
Bí òkété bá dàgbà, ọmú ọmọ-ọ rẹ̀ ní ń mu.
1
B'Okèété bá fẹ șe mọyìn, a á rÁse.
1
Abanilóríjẹ́: ilé-e rẹ̀ ní ń tií mú abẹ wá.
1
Adébóyè kìlọ̀ pé kò yẹ kí àwọn èèyàn máa sọ̀rọ̀ lòdì sí Ọlọ́run.
0
A mọ rírí rẹ̀ torí náà ni a ṣe ń jó tí à ń yọ̀.
0
Aboyún kì í gbọn kílẹ má jẹ lára ẹ.
1
Àwọn ọlọ́pàá pè fún ìrànlọ́wọ́ àwọn ènìyàn.
0
Àjọ àláàbò sọ pé àjàkálẹ̀-àrùn yóò di ohun ìgbàgbé.
0
Owó àwọn méjèèjì jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba ọ̀kẹ́.
0
Ẹni bú Oșòdì ti bú Kòsọkọ Ọba.
1
Ajá tí yóó sọnù, kì í gbọ fèrè Ọlọde.
1
Arọtęsá 'ò șojo.
1
Àwọn ọlọ́jà ti pàdánù ọ̀kẹ́ àìmọye dúkìá wọn.
0
Aṣòfin ilẹ̀ wa há sí ìlú òyìnbó lórí ẹ̀sùn ṣíṣòwò lórí ẹ̀yà ara èèyàn.
0
Bí ìgbín ńfà, ìkaraun a tẹ̀lé e.
1
Àwọn olórí ìjọba tí aje ìwà ìjẹkújẹ bá ṣí mọ́ lórí kò ní fara ire lọ.
0
B'Álántakùn ó ó báni ja; a ta káni kárí ara.
1
Èyí kì í ṣe nítorí pé wọ́n fẹ́ràn àwọn ará Ọ̀ṣun tàbí wọ́n fẹ́ràn gómìnà fúnrarẹ̀.
0
Àyìnlá Ọmọwúrà ti ìpasẹ̀ orin kíkọ mú ìdàgbàsókè bá èdè Yorùbá.
0
Bí igún ti ní ìlasa, bẹ́ẹ̀ ni àwòdí sì ní bòbo.
1
·Enitl'o bimo lesin-in 'o pon dooro (igbá tí a firn fami kan nga)
1
Gbogbo eyẹ ló ń selé, a ò mọlée Labalábá.
1
B'éèyàn 'ò lÓlú aso lokèélokèé, kì í fàlàárì fọn'kun àmódi.
1
Ẹgbẹ́ epo pẹtiró tí aládàáni máa ń ṣe ìpàdé lóòrèkóòrè.
0
Ẹni tí 'ò gbọn l'ààwee gbò.
1
Ẹlẹ́nu-ú tóó rí sá.
1
Àjàkálẹ̀-àrùn túbọ̀ ń pọ̀ sí i káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.
0
Aponri-kéré kò gbọn tó asowomá-rà. Ajé-á-wogbá,'ò gbọn tóÌyáà-mi-'ò-ràn-mí-lękọ.
1
Apàjùbà-má-dèébẹmọ, ò ní sài ṣ'àgbẹ̀ iṣu bó dàmọ́dún.
1
Bọrọ 'ò bá pọlọrọ kò leè pa aláfòoòfojúrí.
1