Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
A-lèjà-má-lè-jà-pẹ́: ẹlẹgb ojo. | 1 |
Àwọn ọlọ́pàá pẹ̀lú àwọn ẹbí Olorunfemi gbé òkú rẹ̀ lọ sí ilé ìgbókùúpamọ́sí. | 0 |
A ní ká rọ́jú jẹ̀kọ ọ̀bùn, ó ń dá ẹ̀kọ rẹ̀ kéré. | 1 |
‘‘N ò níí fẹ́, n ò níí gbà’’: ibi tó sùn sí lánàá, kò níí sùn síbẹ̀ lónìí. | 1 |
Ọláyínká jẹ́ oníbàárà ilé ìtura wọn tí wọ́n ti mọ̀ tipẹ́. | 0 |
Àpòtí ajé ń bẹ lọ́wọ́ ìyáàyá mi. | 0 |
Dákun-dábọ̀ fiyèdénú lórí àṣìṣe tí àwọn ọmọ rẹ ṣe. | 0 |
Ọ̀nà àrà ni àwọn ènìyàn mẹ́rin fi bọ́ lọ́wọ́ àwọn jàǹdùkú. | 0 |
Èpè díẹdíẹ ló n pòkúùgbé. | 1 |
Dẹ́rẹ́bà sọ wí pé Èkó ni òun ń lọ. | 0 |
Adébimpé gba omijé lójú Adédiméjì. | 0 |
Bàbá àgbàlagbà sá kúrò nílé lẹ́yìn tí ìyàwó rẹ̀ lóyún ìbẹta. | 0 |
A kolé kótópó fÒrișà kó gbé, b'Óòșà bá ní kòtóòun,kí òun alára ki àdá mole l'óòrùn gangan, ki ó wo'gbó lo pa eke, kió pa ts | 1 |
Àjàó parọ́ fún àwọn kan pé òun yóò bá wọn tań àṣìṣe tí ó wà lórí nọ́ḿbà ìdánimọ̀ wọn. | 0 |
Àwọn arìnrìn-àjò Mùsùlùmí ti ń gbéra lọ sí ilẹ̀ mímọ́. | 0 |
A kò ní sinmi bí a kò bá rí nǹkan tí à ń fẹ́. | 0 |
Bọlá ń tà a wù wọn.BỌlá dojúdé, a sú wọn. Àkeyinsi-ọlá 'ò tiẹsunàn rárá. | 1 |
Àgbàká nigbà ń gba ọ̀pẹ. | 1 |
Adítí ajá ò șeé mu règbé-ode. | 1 |
Ìwà àgàbàgebè àwọn ọba kò jẹ́ kí ẹ̀sìn àbáláyé rí ojú rere ìjọba. | 0 |
Ẹ̀ṣọ́ ilé ìfowópamọ́ ló fi tó aláṣẹ létí. | 0 |
Ààrẹ ní àwọn ọ̀dọ́ yóò gbádùn àtìlẹyìn òun lọ́dún tuntun. | 0 |
A kì í ṣe ọ̀rẹ́ èrò ká yọ̀; èrò yó relé bó dọ̀la. | 1 |
Ìmọ̀ràn máa ń wà nínú àwọn orin Àyìnlá Ọmọwúrà. | 0 |
A kì í rán ọ̀lẹ wo ojú ọjọ́ àárọ̀. | 1 |
Ègún 'ò lódó, esan kì í sùn. | 1 |
A kì í j'ojú mẹran. | 1 |
‘‘Kítìjú pa mí’’: ààrẹ èpè ni. | 1 |
Ìjọba kéde orúkọ oníṣòwò kan àti àwọn mẹ́rìnlá mìíràn. | 0 |
Àwọn ọ̀dọ́ ìsẹ̀yín náà ń gbọ́ orin Àyìndé. | 0 |
Bí ebí bá ń pa ọ̀lẹ, à jẹ́ kó kú. | 1 |
Adẹ́tẹ̀- rí wèrè, ó kán lùgbẹ́ . | 1 |
Bí a ri ogbọn mọlẹ, á á hù jáde. | 1 |
Bí a bá ti ríra ẹni pẹ, a kì í pè 'ó tójọ mẹta' “Báwo lo se dà?” làábèèrè. | 1 |
A ò lóbìnrin à ń dá oóyọ́ sí; bí a bá dá oóyọ́ sí ewúrẹ́ ni yó jẹ . | 1 |
Bí iṣu ẹní bá funfun, à fọwọ́ bò ó jẹ. | 1 |
Arákùnrin kan tó jíǹde ní mọ́ṣúárì nígbà kan rí padà wá kú. | 0 |
Ẹnu-isà là bájá, ohun tó lé e débẹ la ò mọ. | 1 |
B'éèyàn l'àgbára tẹfọn, kò pé kó là'wo (la iwo) lórí sarasara. | 1 |
Àràbà ni bàbá; ẹni a bá lábà ni baba. | 1 |
Àwọn ọ̀dọ́ dìde láti wá ojútùú sí ìwà ìjínigbé. | 0 |
Yóò ya èèyàn lẹ́nu pé ẹni tí wọ́n ń pè ní ọmọlúwàbí ni wọn yóò bá nídìí ìwà burúkú. | 0 |
Alágbàfọ kì í p'óun 'ò f'așọ tó rírí (dọti) | 1 |
Bí a ò șu tán, kí a tọ tán, ojú ẹni kì í rọ. | 1 |
Àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn lágbàáyé ń kó ẹ̀sìn tiwọn mọ́ra. | 0 |
Gbogbo ohun tó bá ti da'șọ borí, ti ní k'ọn sá fóun. | 1 |
Ayekòótọ́ kó olówó rẹ̀ yọ lọ́wọ́ ikú gbígbóná. | 0 |
Ọláfisóyè tún ṣàlàyé pé òun rí ọmọkùnrin kan tó sáré jáde nínú ọkọ̀ rẹ̀. | 0 |
Bí pákọkọ ò tiẹ dàrán, kò sọ ọ derú Babalágo. | 1 |
Alukoro ọlọ́pàá ṣàlàyé wí pé aago mẹ́wàá ni ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún wáyé. | 0 |
Bójúrí ti jẹ́wọ́ fún àwọn agbófinró pé lóòótọ́ lòun máa ń lu àwọn èèyàn ní jìbìtì. | 0 |
Àwọn ìran eré-ìdárayá máa ń dùn ń wò. | 0 |
Ibẹ̀ lèmi àti obìnrin náà ti bẹ̀rẹ̀ sí í jà. | 0 |
Àṣírí òṣìṣẹ́ mẹ́ta tú lásìkò ìwádìí. | 0 |
Agbọ́n ń sẹ́; oyin ń sẹ́; ojú ọmọ olóko ló wú yìí. | 1 |
Gbogbo ọpẹ kọ l'onígbà ń gùn. | 1 |
Obìnrin kan bímọ nínú igbó yẹn tó sì kú síbẹ̀. | 0 |
Alukoro iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èkó sọ pé wọ́n tún ṣe ọlọ́pàá mìíràn léṣe. | 0 |
Bínú re ti rí tèmi o rí béè; iba rí bée, à bá tí jà láéláé. | 1 |
Ẹni tó kó háhá, ó yá ẹrú, ẹni pòòyì abà, ìyen yá ìwọfà, kí níalágbàdo yóo yá? | 1 |
Ení pé kí lÀjànà ń se l'órò, kò ní kìyáwo òun jáde wá wòran Orò. | 1 |
Bí a bá dúró ni déèdé; gbogbo rẹ ni yóò jọraa wọn. | 1 |
Àgbò t'ó tàdímẹyìn, 'ò șojo agbára l'ó lọ mú wá. | 1 |
Báyìí ni nǹkan ṣé ń lọ nílé Ìgbòho lónìí. | 0 |
Balógun ní àwọn ìbátan tí ó tó méjìlá. | 0 |
Àwọn ẹgbẹ́ awakọ̀ ìpínlẹ̀ Èkó sọ wí pé àwọn kò ní tẹ̀lé ohun tí àwọn adarí àwọn sọ. | 0 |
Bí ìkọlù Ifẹ̀ sí Ilésà ṣe ń tẹ̀síwájú lójoojúmọ́ ni ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ fún àwọn ènìyàn láti kúrò níbẹ̀. | 0 |
Báa ti șe là á wí, ẹnìkan kì í yan àná ẹ lódì. | 1 |
Àgbò méjì kì í mumi nínú-u koto kan. | 1 |
Ayé 'ò nípekun. | 1 |
Eni ńlá lò sehun ńlá, Ìyàlódé-Ìbàdàn gbéàká mì, ó f'ọmọrí-odótayín. | 1 |
Èké ìbídùn tó ń kí Eégún kú àtijọ. Níbo ni Ìbidùn ti mọ ará-orun? | 1 |
Kò tí ì sí ìwòsàn fún àrùn kògbóògùn. | 0 |
Bí ojú kò bá ti Ẹ̀hìn Ìgbẹ̀tì, ojú ò níí ti Èkó. | 1 |
Kì í ṣe ìgbà àkọ́kọ́ tí irú nǹkan báyìí yóò ṣẹlẹ̀ ní Ayédáadé. | 0 |
Ẹ ṣọ́ra fún gbígba ayédèrú ìwé ẹ̀rí àyẹ̀wò ààrùn àjàkáyé. | 0 |
Àṣẹ̀ṣẹ̀-bẹ̀rẹ̀ òșì (òtòși) bí Ọlọ́rọ̀ ní í rí. Ojúlówó așọ níí máa fi wo geere lọ́jọ́ gbogbo. | 1 |
Bí ọmọdé bá ṣubú a wo iwájú; bí àgbá bá ṣubú a wo ẹ̀hìn. | 1 |
Ó ní wọn kò sì tún sọ̀rọ̀ nípa ibi tí Bọ́lá wà rárá. | 0 |
Alukoro iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn ni Abímbọ́lá Oyèyẹmí. | 0 |
Asákòkó pẹlú ẹ ló ń gbẹ. | 1 |
Mo kí Tọ́pẹ́ láàrọ̀ ọjọ́ kejì tí mo rí i. | 0 |
”Ebi ki í rálejò sójú. | 1 |
Bí bàtá bá ró àrójù, yíya ní ń ya. | 1 |
Àwọn àgbẹ̀ tí ẹgbẹ́ wọn ń jẹ́ Ayétòrò ló dá ikọ̀ àgbẹ̀ sílẹ̀. | 0 |
Èèyàn kì í yànkọ (yan ẹkọ) níbi ọwọ ẹni 'ò ti tágbọn. (tó agbọn) | 1 |
Àlàyé rèé lórí bí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe ń yan ààrẹ ní Ọ̀yọ́. | 0 |
Àmọjù ló b'ẹkùn Șàárẹ jẹ. Ó ló fín páta, ó fín pàta, ó wá ń káláje. | 1 |
Kò sí bí a ṣe lè gbọ́ ìdájọ́ àwọn ènìyàn wa láti àríwá lásìkò tí a wà yìí. | 0 |
Ó sọ wí pé ìdí tí òun fi kó wọn lọ ìlú Kánò ni láti lè bá wọn ṣètò ìrìnàjò wọn. | 0 |
Àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó ò ṣé bá ẹ̀dá kankan sọ | 0 |
Àwa náà ni àwọn mọ̀lẹ́bí tiwa tí à ń tọ́jú. | 0 |
Ariwo ni wọ́n máa ń fi orin pa ní àdúgbò tí mò ń gbé. | 0 |
Àwọn agbẹjọ́rò tí wọ́n ṣẹ̀ wọ iṣẹ́ ni adájọ́ àgbà ṣe ìbúra fún. | 0 |
Bí a bá bẹlẹpọn wí, kí a bẹlẹpọn náà wí. | 1 |
Ó ní bí ẹni tí wọ́n bá fẹ́ tọ́jú bá ṣe pẹ́ sí lọ́dọ̀ wọn ni wọn yóò ṣe bu owó àìsàn. | 0 |
Àjọ elétò ìlera fọkàn ará ìlú balẹ̀ pé kòsí ewu. | 0 |
Àwọn Wòlíì méjì míràn ti kéde wàhálà ìwọ́de sáájú. | 0 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìlú Òmìnira ní ìlú Súnmọ́mi béèrè fún ìrànlọ́wọ́. | 0 |
Èsúrú ẹni ló ń tọwọ ẹni bepo. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.