Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Àwọn alákòóso ilé epo ti sọ wí pé àwọn ti dáwọ́ epo títà dúró.
0
·cèlè 'ò dùn bí ki á món qn wé, ká mon-qn wé kò dàbí kó yení.
1
Àwọn ọlọ́pàá ti mú ẹni tí ó jẹ̀bi ẹ̀sùn lọ sí àgọ́ wọn.
0
Kò sí ohun tí ènìyàn kò lè rò mọ́ alátakò ẹni lẹ́sẹ̀ bí ó bá di ọ̀rọ̀ òṣèlú.
0
Emọ n sálọ, àfè n sálọ, ení kí wọn ó díhò pinpin. Kí ló tún kùnínú ihò tí e ń dí?
1
Ààsẹ Ọyọ 'ò ń ró 'gbà' àfi 'mú wá'.
1
B'owẹ (Bẹbẹ) kí o rỌkèsẹ, sàgbe kí o ráhun.
1
Àwọn láńlọọ̀dù àdúgbò ti kọ lẹ́tà sí àwọn ọlọ́pàá nípa àwọn tó ń ta igbó.
0
Àkùkọ tí yóò kọ ni, àṣá kò níi gbé e.
0
Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ti dojú ìjà kọ àwọn agbésùnmọ̀mí.
0
Ìtìjú kò jẹ́ kí ọmọ àgbẹ̀ lè fi bàbá rẹ̀ hàn lójú agbo.
0
“Dúró dè mí” “mò ń bọ” àwọn méjéèjì ọkùnrin ni.
1
Àwọn agbésùmọ̀mí kọlu ilé ìjọsìn Àgùdà.
0
Ọkùnrin náà sọ pé àwọn ẹrù ilé-iṣẹ́ kan tòun kó ló wà nínú ọkọ̀ náà.
0
Àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ń béèrè fún ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ ìjọba àpapọ̀.
0
Aláṣẹ pàsẹ láti mú àwọn adarí agbègbè lọ sí ibi ìpéjọpọ̀ kan
0
Aago mẹ́rin ni mo ti máa ń jí láti ṣe ìgbaradì.
0
Ó sọ wí pé wọ́n ń fìyà jẹ àwọn nínú igbó.
0
Àjàpá ní bí òún bá jẹ, tí òun mu, tí òun yó, ara òun a yá; ṣùgbọ́n ìgbà tí òún bá rántí irán ìdí òun, òun a bú s kún pẹ̀rẹ̀.
1
A kì í dùbúlẹ̀ ṣubú.
1
Ẹni tí kò jẹ kí tàgbà sẹ ni olóko ń gbé ajáa rẹ.
1
Ìgbà tí wọ́n dé Èkó, Àlàó sọ fún ọ̀rẹ́ rè pé ọkàn òun kò fibẹ́ẹ̀ fẹ́ràn ibi tí wọ́n wà.
0
Àwọn tó gba àmì ẹ̀yẹ ni ìjọba ń fi ìyà jẹ jù lọ.
0
Àparò fò, aṣọ ẹ tán
1
Bí o kò bá ṣe oríire, gbìyànjú rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan si.
0
Arúgbó ṣoge rí; àkísà-á lògbà rí.
1
Lásìkò tí ìyá mi lóyún, mo máa ń tẹ̀le bàbá mi lọ sí ọjà, láti lọ ra nǹkan.
0
A pa ẹmọ́ lóko ilá, a jù ú sí ọ̀kẹ́ ìlasa; ilé ẹmọ́ lẹmọ́ lọ.
1
Adìyẹ bàbá ba dàmí lóògùn nù .
0
Alágbára níí jagun, ẹni ọrọ dùn níí ṣàgbẹ, kíkọ-ifá dọwọ Oníyè-nínú.
1
Adìẹ bá lókùn, ara ò ròkún ara ò rọ adìẹ.
1
Ajóbíewé Àrẹ̀mù pé ẹni ọgọ́rùn-ún ọdún láyé.
0
Apàjùbà 'ò mọ'lẹ ọrọ.
1
Bí ehoro ò lè sáré bí ìgalà, bíi ká fi wé ti ìjàpá kọ́.
1
Àlàbí Ògúndépò pinnu láti ṣe ẹ̀yẹ ìkeyìn fún Ọba Adéyẹmí.
0
Nígbà tí ó pa á tán ni ó wọ́ òkú obìnrin náà sí ẹ̀gbẹ́ títì.
0
Àgbéré-e ṣìgìdì tó ní ká gbé òun sójò: bí apá ti ń ya nitan ń ya; kidiri orí ò lè dá dúró.
1
Ayé àgbẹ̀ bí àjẹrọ̀run.
1
Àwọn afurasí wa ọkọ̀ náà gún sí ẹ̀gbẹ́ títì.
0
Àjẹgbé nigún ń jẹbọ.
1
Ayẹ̀wé owó wò kan àti ẹni tó ń tún ọ̀pá omi ṣe wà lára wọn.
0
‘‘Ọmọ yìí ṣe gbọ́n báyìí?’’ Ó ní baba nísàlẹ̀ ni.
1
Abebẹ níí bẹkú. Abẹbẹ ní í bàrùn; b'óoru bá mú abẹbẹ níí bęệ.
1
Àwọn ènìyàn Gáà àti Bodè yóò ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn aláṣẹ.
0
Aṣọ kan-án kángun sára eégún ju ọ̀kan lọ.
1
Òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bí ọmọ ọkùnrin làǹtìlanti.
0
A kì í kọ'fá wọ'gbódù k'á má róbì tó gbó káká jẹ.
1
Arọ ni ìdènà òrìṣà.
1
Ọtí tí Ògúnrónbí mu ti pa á, kò sì jẹ́ kí ó rí nǹkan rò.
0
Ẹni tá 'ò fẹ nílé 'ẹ ń jìn.
1
Ìjọba sọ wí pé àwọn àìṣedéédé àwọn yóò yàtọ̀.
0
Àròkàn ní ń mú à-sun-ùn-dá wá; ẹlẹ́kún sunkún ẹ̀ ó lọ.
1
Àwọn ọlọ́pàá rí àwọn ọmọdé kangbà sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn agbénipa.
0
Amí ni wọ́n fi mú agbódegbà ọ̀hún.
0
Abiyamọ, kàgbo wàrà; ọjọ́ ń lọ.
1
Wọ́n fẹ̀sùn kan Àjàká pé ó mọ̀-ọ́n-mọ̀ fèsì ìdìbò agbègbè rẹ̀ pamọ́.
0
Ọ̀kan nínú àwọn tọ́ọ̀gì méjèèjì yọ ọ̀bẹ alásóóró.
0
Àwọn òbí awakọ̀ náà kò sí nínú ọkọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ lásìkò tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí wáyé.
0
Ìwà yìí lè sọ ojúṣe àwọn aṣòfin di yẹpẹrẹ bí àṣà yìí bá ń lọ bẹ́ẹ̀.
0
Gbogbo ìgbà ni ìlọsíwájú ń bá Iléeṣẹ́ ìtẹ̀wé tí Ọlágòkè dá sílẹ̀.
0
Bí owó bá ti mọ ni oògùn ń mọ.
1
Bí abẹrę, bí abẹrẹ làá sèké; bí ó bá tó okóó rọ ni wọn fì ń sin nì
1
Ó ní wọ́n tún kìlọ̀ fún òun láti má ṣe janpata rárá.
0
A kì í sọ pé kíkà ṣe é k'á wò ó.
1
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn adigunjalè ló fi ara kó ìbọn nígbà tí àwọn agbófinró kojú wọn.
0
Wọ́n ti fi ọwọ́ òsì júwe ilé fún Làmídì.
0
Àwọn ọdún ìbílẹ̀ mìíràn kì í ṣẹ̀yìn Adénúgà.
0
Ọlájídé fẹ́ kí àwọn jàǹdùkú káwọ́ pọ̀nyìn rojọ́ lórí ìdí tí wọ́n fi lu akẹgbẹ́ wọn pa.
0
Olóyè Ìkẹ́ àti ìyàwó rẹ̀ ni wọ́n jọ ń jẹ́jọ́ ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn náà.
0
Ìjọba Èkó ti ṣàwárí abẹ́ afárá tuntun nílùú Èkó tí àwọn èèyàn ń gbé.
0
Àtẹ̀jáde náà wà lórí ìyanṣẹ́lódì àwọn òṣìṣẹ́ ẹ̀ka òfurufú.
0
Eegun (Eyín) làá kọkọ fi í sàlejò kí a tó fi ẹran se é.
1
Àwọn akẹgbẹ́ Adéọlá ń fìyà jẹ ẹ́ ní ìgbà tí wọ́n wà nínú ilé ẹ̀kọ́.
0
Àìsí-ńlé ẹkùn, ajá ń gbó.
1
Ní àṣálẹ́ lẹ́yìn tí àwọn òǹtajà kan ti ń palẹ̀mọ́ ni àwọn jàǹdùkú ya bò wọ́n.
0
Ẹgbẹ́ erin ò wọ́n lÁlọ̀.
1
Aṣọ tó kángun ṣéégún làá pè ni jẹpẹ.
1
Awọn jàǹdùkú yin ìbọn fún àwọn èèyàn inú ọkọ̀ tí à ń wí nítorí owó.
0
Aṣọ tuntun ní ń ṣe olúwa-a rẹ̀ tòde-tòde.
1
Ẹni tí ó bá ṣe ìfẹ́ akọ sí akọ yóò fi ẹ̀wọ̀n jura.
0
Epo òyìnpbó 'ò dín àkàrà.
1
Àwọn tí ń bọ̀ lẹ́yìn ń fi Olúayé ṣe àwòkọ́ṣe.
0
Ẹni a kó patię bò, ní i wá sìgàsigà.
1
A kì í r'óko l'óko-ikún kí á gbin ẹpà síbẹ.
1
Agẹmọ ò ṣé-é jẹ lẹ́nu.
1
Bí àgbàlagbà kò bá ríbi jókòó, gbédìígbédìí a gbé ọmọdé.
1
Ẹní da eèrú leérú tọ.
1
Àṣírí ohun tí ọ̀pọ̀ ènìyàn kò mọ̀ ni pé alákíkanjú ẹ̀dá nìkan ló lè la ìṣòro bí èyí.
0
Ẹdá 'ò l'áròpin, Gàmbàrí ń ra mọtò ní Sábó.
1
Àtijẹ awùsá kò tó àtimumi.
1
Alákatam̀pò-ó bojú wòkè.
1
Alágbára méjì kì í múlé tira àijà.
1
Àrùn ẹ̀dọ̀foró àti ìnira èémí jẹ́ àpẹẹrẹ àrùn lára ènìyàn.
0
Abiyamọ s'ọwọ kòtò namọ ę.
1
Bí a bá f'ẹsẹ ta òkú òșìkà nílẹ, ìkà óó di méjì.
1
Ìjọba fẹ́ kí ọba alayé ṣètò bí àlàáfíà yóò ṣe jọba ní gbogbo tìbú-tòóró ìlú.
0
Ààbo ìlẹ̀kẹ̀ ò dára níbàdí; etí kan ò dára lágbárí.
1
B'éégúnbá ju eégún lo,àwọn leégún n fe e wòran ara wọn.
1
Àjòjì tó bú baálẹ̀-ẹ́ di ẹrù tan.
1
Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ yí orúkọ rẹ̀ padà kí ó kàn sí wa.
0