Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àlejò kì í pìtàn ìlú fónílé. | 1 |
A kì í fi gbogbo ọnà ẹbùrú han àlejò, torí ọjọ kan ìjà. | 1 |
Ení wo Gelede dópin ìran. | 1 |
Ó sì tún sọ pé wọ́n máa kó ìwé ìrìnnà wá nírọ̀lẹ́. | 0 |
Olówóòkéré ló ṣe fíìmù náà jáde. | 0 |
Àwọn jàǹdùkú gba báàgì kan tí owó, káàdì ìfowó pamọ́ àti dúkìá mìíràn lọ́wọ́ Bímpé. | 0 |
Ináọlájí sọ pé ìdí rèé tí wọn kì í fi í sọ fún ẹnikẹ́ni. | 0 |
Ẹ wo bí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré ṣe ṣe àyájọ́ Ọjọ́ | 0 |
Àfín kì í wọjà kí a má mọ. | 1 |
Àwọn òṣèré àti òǹkọ̀wé ní Nàìjíríà ti yanṣẹ́lódí. | 0 |
Ọ̀kan ṣoṣo nínú àwọn ìyàwó méjì tí Àjàdí ní ni ó wà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ ní Àgbádárègè. | 0 |
Bí ìdí ìkokò kò bá dá a lójú, kì í gbé egungun mì. | 1 |
Bí a bá jà níta, ojú ní í ti ni. | 1 |
Àìgbọn ló p'Ògbojà. Wọn ľ'Ógbòojà, iyáà rẹ kú'. | 1 |
Òjíṣẹ́ Ọlọ́run ti padà sí Èkó lẹ́yìn tí ó ti parí ohun tí ó lọ ṣe. | 0 |
Ẹní fẹ olè níyàwó, ó gbé tie. | 1 |
Ẹni tó wọ àgbọn, làgbọn-ọn bọ fún. | 1 |
Ẹní tó feni làá á fę, èèyàn ti o fẹmi; àá jinà sì ì ni. | 1 |
Alááyan ní ń jẹun ogun. | 1 |
Yàtọ̀ sí ikọ́, àwọn àìlera mìíràn wà pẹ̀lú àjàkálẹ̀-àrùn. | 0 |
Ilé ìwòsàn tuntun tó wà ní agbègbè Ìkọ̀tún mọ ìtọ́jú àwọn aboyún ṣe púpọ̀. | 0 |
Ẹ̀tọ́ Nàìjíríà ni láti bèèrè fún ẹ̀yáwó lọ́wọ́ àjọ ayánilówó àgbáyé. | 0 |
Bámijókòó làbíkú ń jẹ́ ; ẹni tí ò bímọ rí ò gbọdọ̀ sọ Ọmọ́láriwo. | 1 |
Ayídóborí tafà sókè: ojú Olúwaá tó wọn. | 1 |
Àgọ́ ọlọ́pàá tí ọmọbìnrin ọ̀hún ti lọ fi ẹjọ́ sùn kò jìnà sí ilé wọn. | 0 |
Bí arákùnrin náà ṣe máa ń tọ́jú aya àti ẹbí rẹ̀ kò bójúmu tó. | 0 |
Àdìó ń jẹ́ ẹjọ́ ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án. | 0 |
Bí a kò bá tó ìyà-á ká tí à ń kọ̀ ọ́, àjẹkún ìyà là ń jẹ. | 1 |
Gbogbo 'kò-sí-ijo-ijo-o-kun' kọ lawọn obi wọn rókòó mùkọ. | 1 |
Ẹsẹ oníbú làá wò ó s'oògùn. Bí ó bá subú délẹ, a à ní: 'llẹ ni Beèke n yè sí'. Bí ó bá ta gíẹgíẹ, tí ó bá ró o, a á ní: “Àtatu ni ti gbegi.” | 1 |
A sebẹ̀ fún Fádípẹ̀, Fájẹbẹ̀-ẹ́ fá a lá; ọlọ́bẹ̀ ló lábẹ̀. | 1 |
Àwọn ọmọ ogun yóò wọlé sí inú ìlú ní ọ̀gànjọ́ òru. | 0 |
Eni ará rọ ló ń rọra. | 1 |
Atiku ní òun kò faramọ́ láti gbé iṣẹ́ fún àwọn ilé iṣẹ tí ó fẹ́ ṣe ọ̀nà yìí. | 0 |
Ìwádìí fi hàn pé Fákẹ́yẹ ta ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ olóògbé náà fún ẹnìkan. | 0 |
Màríà ní òun rí i pé òun ti lóyún nínú igbó àwọn ajínigbé ọ̀hún. | 0 |
B'áyé bá se gbà, là á se é gbé e. | 1 |
Èpè ẹpà kì í mú lkún. | 1 |
A tẹ́ní bẹẹrẹ kò sí oǹdá; a pàjùbà bẹẹrẹ kò sí oǹkọ. | 1 |
Awuyewuye tí ń jáde lórí ọ̀nà tí ìjọba àpapọ̀ fẹ́ ṣe ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | 0 |
Bẹẹ r'ọmo elòmíràn lórí eșin, gbèsè ló fi ń seso r òde. | 1 |
Ìpinnu ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ni èyí, ìjọba kò sì ní yí ìpinnu rẹ̀ padà. | 0 |
Olóyè Adéòtí ṣe ayẹyẹ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ọlọ́dọọdún ní gbọ̀ngán Afẹ́ Babalọlá. | 0 |
Ikú Ìdòwú ń ya àwọn aráàlú lẹ́nu gidi púpọ̀. | 0 |
Èèyàn kì í lẹ kó ma leè dánúbí, ìjà nì kò ní lè jà. | 1 |
Arábìnrin Atinúkẹ́ pariwo síta pé kí àwọn èèyàn ṣàánú òun. | 0 |
Akíntóyè mọ̀ pé ọwọ́ àwọn ma tẹ àwọn onínàbì ìlú tí ń gbá àwọn ènìyàn. | 0 |
Baba kì í tęàjà fún ọmọ gùn. | 1 |
Èèyàn 'ò ní gb'édè bí Òfé k'ó má maraá re bíi Odídẹ. | 1 |
Ẹdá e má rẹdá pìn, èèyàn ẹ má se ro ènìyàn pín. | 1 |
Bọ́lá ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn máa dìbò fún. | 0 |
Ẹní sòkò lù àgbọnrín s'aájò ọbẹ,eranló s'era abitetegboingbonin. | 1 |
Màríà ní òun kàn fẹ́ máa bá ìgbé ayé òun lọ ni. | 0 |
B'éèyàn 'ò s'ọmọ nù; kò leè rí i he. | 1 |
A kì í j'ojú meję. | 1 |
Ọdún méje sẹ́yìn ni mo bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ nípa ṣíṣe àkàrà òyìnbó. | 0 |
Wọ́n sọ pé gbogbo ọ̀nà tí àwọn mọ̀ ni àwọn yóò fi ran ìwádìí àwọn ọlọ́pàá lọ́wọ́. | 0 |
Àṣírí tú lọ́dún tó kọjá pé ìyàwó Aláàfin àti Òkìkíọlá ń ṣe wọlé-wọ̀de. | 0 |
Kò pọn dandan kí àwọn ìbejì láti inú ìyá kan rí bákan náà. | 0 |
Awofelę bomí kó je a ríkùn asebi. | 1 |
Ẹ̀là ìlẹ̀kẹ̀ ò lójú àtokùnbọ̀; alágbẹ̀dẹ ò rójú ará. | 1 |
Bí wọ́n bá fi lè gba béèlì rẹ̀, ẹjọ́ lè dàrú. | 0 |
B'Ọba titun bá gb'adé, iránsẹ èșí a d'ẹni ìgbàgbé lọgán. | 1 |
Dé e re, gẹ ée re, ìpénpéjú lààla fì là. | 1 |
Ẹ ju àdáá lẹ', 'ẹ kì í mọlẹ', ẹràn bii oòre kọ. | 1 |
Àìgbọ́n ni yó pa Iṣikan; a ní ìyáa rẹ̀-ẹ́ kú, ó ní nígbà tí òún gbọ́, ṣe ni òun ń dárò; bíyàá ẹní bá kú àárò là ń dá? | 1 |
Bí ijó bá di ijó àgbà, ìlù a yípadà. | 1 |
Ìjìyà tó yẹ yóò wà fún gbogbo ìwà àjẹbánu pátápátá. | 0 |
Ayé kòi bàjẹ bàlùmọ k'ékùuté máa l'Ólógìnní pajẹ. | 1 |
Wọ́n jí ọ̀gágun ológun gbé sá lọ káwọn ọmọọṣẹ́ rẹ̀ má ba gbé e sá lọ. | 0 |
Àwọn ọmọ ìlú Ìbàdàn máa ń sẹ ìrànwọ́ fún àwọn amúlùúdùn. | 0 |
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn àgbẹ̀ ló ní ìbọn lọ́wọ́. | 0 |
Àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni wọ́n máa ń sun àtìmọ́lé. | 0 |
Ààrẹ ṣe ìfilọ́lẹ̀ wíwa epo rọ̀bì ní ọjọ́ ìṣẹ́gun. | 0 |
Ìjọba fún àwọn èèyàn láyè láti máa ṣe ọrọ̀ ajé wọn bíi ti tẹ́lẹ̀. | 0 |
B'ọmọ 'ò jọ șòkòtò a á jọ tòbí. | 1 |
Gbogbo Ọtọnkùlú péjọ; wọn 'ò róògùn àbámo se. | 1 |
Àjànàkú ò tu lójú alájá; o-nígba-ajá ò gbọdọ̀ tọ́pa erin. T | 1 |
Olórí aṣòfin sọ wí pé òun ti ra gbogbo ohun èlò tí ayẹyẹ náà nílò. | 0 |
Ẹ-kòì-f -mi-kù, tó ta ajá-a rẹ̀ lókòó. | 1 |
Aláṣọ-kan kì í ná ànárẹ. | 1 |
Èpo orógbó ló ń b'àșírí orógbó. Èpo obì ló ń b'àsírí obì. Èpo ataare l'ó ń b'àșírí ataare. | 1 |
B'ẹsin bá jẹ káhún yó, a lóun ó sòkè dilẹ. | 1 |
Oríṣiríṣi ọ̀nà ni ènìyàn lè gbà láti wá ojútùú sí ìṣòro. | 0 |
Ẹ̀sùn ìjínigbé, ìṣekúpani àti ìdigunjalè wà lára ẹ̀sùn tí wọ́n kà sí Lánrewájú lẹ́sẹ̀. | 0 |
Gbogbo àwọn Mùsùlùmí àgbáyé ń retí bóyá àwọn yóò rí oṣù láti lè bẹ̀rẹ̀ àwẹ̀. | 0 |
Ìjọba yóò wá ojútùú sí ìṣòro tó ń kojú àjọ tó ń ṣe àmójútó ibùdókọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. | 0 |
"Ẹ fà á wọlé" ló yẹ ẹlẹ́ṣin. | 1 |
A-tọrọ-ohun-gbogbo-lọ́wọ́-Ọlọ́run kì í kánjú. | 1 |
Àwọn àjọ tó ń mójútó ètò ìdìbò gbé ìdìbò náà kalẹ̀ lánàá. | 0 |
Eni oro8ò kan ló ń dúndùn-ún òkété a ní: 'N 'ò gbo fín-in fin-in:·Eni tá 'ò fẹ nilé e ń jìn. | 1 |
Gígo lo gọ, tó o se bí o gbọn. | 1 |
A léṣu sílẹ̀ páńdọ̀rọ̀-ọ́ já lù ú; èlé m bénì? | 1 |
Àifenipeni, àifèèyàn-pènìyàn lará-oko fi ń sán bàntẹ wọlú, a ní:“Ta ni ń bẹ níbẹ̀?” | 1 |
Àgbà ló tó Orò-ó lọ̀; ọba ló tó ehín erin-ín fun. | 1 |
Eni ara rẹ wù ní í tanná alẹ sílé. | 1 |
Afẹ́fẹ́ káràkátà tuntun tó fẹ́ wọ ìpínlẹ̀ yìí rọrùn kí a má sọ ìdàkejì. | 0 |
Bọ́lá yóò kádìí ìrìn-àjò rẹ̀ sí ìlú Lárúbáwá. | 0 |
Adùn ní ń gbẹ̀hìn ewúro. | 1 |
Bí ẹrú yó bàá jẹ ìfun, ibi ẹ̀dọ̀ ní-í tí ń bẹ̀rẹ̀. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.