raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
jídé ògúnsànyà jídé ògúnsànyà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin jẹ́ oníṣòwò ìlú bá ní tajà aláṣe àti olùdarí búlọ́ọ́gì ògbóngẹ́ ti orí ẹ̀rọ alátagbà níb i tí ó ti ń dá àwọn ènì😨 nípà bí a ṣe lè lówó-jèrè |
gozel green gozel green jẹ́ ilé iṣẹ́ ìránṣọ ti àwọn obìnrin ìgbàlódé tí àwọn ìbejì tí orúkọ wọn ń jẹ́ sylvia enekwe àti olivia okoji dá sílẹ̀ ní ọdún 2012 ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránṣọ ti ìgbàládé yí pẹ̀lú ìwúrí ará ọ̀tun láti ọ̀dọ̀ ìyá tó bí wọn lọ́mọ tí òun náà jẹ́ aránṣọ jẹun pupọ̀ nínú aṣọ tí àwọn ... |
rose odika rose odika jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ delta lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1988 ó ti tó ọgbọ̀n 30 tí ó ti ń ṣiṣẹ́ sinimá-àgbéléwò lédè yorùbá òun ni gómìnà ẹgbẹ́ tíátà tí wọ́n ń pè ní theater... |
waaris waaris tí ìtumò rẹ̀ lédè yorùbá jẹ́ àrólé ni eré sinimá onípele aládùn lédè hindu láti orílẹ̀ èdè indian tí wọ́n gbé jáde lọ́dún 2016 tí wọ́n máa ń ṣe àfihàn rẹ̀ lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn àwọn olórin nooran sisters ti kọrin nípa àkọ́lé eré yìí gẹ́gẹ́ bí ìṣe àwọn bacha posh olú-ẹ̀dá ìtàn eré yìí arti singh àti sania to... |
fúrá fúrá jẹ́ ónjẹ́ tí a fi ọkà bàbà àti àwọn èròjà míràn ṣe tí ọ́ wọ́pọ̀ láàrín àwọn ẹ̀yà fúlàní àti hausa ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti niger àwọn fúlàní ni wọ́n ni ẹ̀yà ónjẹ ìbílẹ̀ yí wọ́n sì ma ń ṣe fúrá dà nunù pẹ̀lú lílọ àgbàdo tàbí ọkà bàbà tí wọn yóò sì fi wa ra tí wọ́ fún láti ara màlúù pòó pọ̀ fún mi mu |
lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀ lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀ ni irúfẹ́ lẹ́tà tí a ma ń ká sí àwọn ará ẹbí ọ̀rẹ́ àti iyèkan ẹni ìdí tí wọ́n fi pe lẹ́tà yí ní gbẹ̀fẹ̀ ni wípé àyè gbà wá gidi-gidi láti dá àpárá ṣẹ̀fẹ̀ ṣòfófó àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ nítorí ẹni tí a ń ke lẹ́tà náà sí jẹ́ a mọ̀ tẹ́lẹ̀ tí a sì ma ń bá ṣàwàdà àwọn ohun tí ó ṣe kókó nínú lẹ́tà yí o... |
lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ̀ lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ̀ ni oríṣi lẹ́tà kejì tí a ma ń kọ sí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ àdáni tàbí ti ìjọba yálà nígbà tí a bá ń wáṣẹ́ tàbí fẹ́ gba ohun kan tàbí òmíràn ní ọwọ́ irúfẹ́ ènìyàn bẹ́ẹ̀ ó fi han wípé irúfẹ́ ènìyàn yí kò ní ra ye láti ma ka ìtàn tàbí ka yẹ̀yẹ́ tàbí àwàdà èyíkéyí nítorí iṣẹ... |
sílábọ́ọ́sì sílábọ́ọ́sì jẹ́ ìlapa-èrò iṣẹ́ tàbí àkóónú kókó iṣẹ́ inú ètò ẹ̀kọ́ kan tí a fẹ́ fi kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kéré àti jẹ́ kí olùkọ ó ní ìkápá lórí ohun tí ó fẹ́ kọ́ kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà ó sìn lè gbaradi fún kókó ẹ̀kọ́ tó kan kí won lè ṣe àṣeyege kẹ́yìn ẹ̀kọ́ náà |
kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù educational plan ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ curriculum vitae nínú ètò ẹ̀kọ́ kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ni ó túmọ̀ sí pààpin kókó ètò-ẹ̀kọ́ nínú ìlànà ikọ́ni ó tún lè jẹ́ àgbékalẹ̀ pàtó tí ó dá lé ìrírí àti òye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ìkọ́ni tààrà kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ma ń kó kókó iṣẹ́ ohun èlò ìkẹ́kọ́ àti ọ̀nà ìṣe ìgbéléwọ̀n fún ... |
àgbékalẹ̀ ẹ̀kọ́ àgbékalẹ̀ ẹ̀kọ́ ni ó dá lè ìfọ́sí wẹ́wẹ́ ìlapa èrò olùkọ tí ol ùkọ́ ti pèsè kalẹ̀ ní kíkùn lórí ìgbékalẹ̀ bí ẹ̀kọ́ yóò ṣe ye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nínú iyàrá ìkẹ́kọ́ ẹ̀wẹ̀ ojojúmọ́ ni olùkọọ́ gbọdọ̀ ma kọ ìlapa èrò ẹ̀kọ́ fún àsìkò ìkẹ́kọ́ kọ̀ọ̀kan ṣáájú kí ó tó wọ iyàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ èyí yóò mú kí ẹ̀kọ́ ó ye àwọn ... |
orin-ìyìn orílẹ̀-èdè nàìjíríà lédè yorùbá ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀ wọ́n gba orin-ìyìn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ arise o compatriots tí ìtumọ̀ lédè yorùbá jẹ́ ẹ dìde ẹ̀yin ará wọlé gẹ́gẹ́ bí orin-ìyìn orílẹ̀ èdè náà lọ́dún 1978 tí wọ́n sìn fi í rọ́pò orin ìyìn àtijọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ nigeria we hail thee tí ìtumò ... |
àjọ̀dún fanti ní ìpínlẹ̀ èkó àjọ̀dún fanti ní ìpínlẹ̀ èkó tí wọ́n tún máa ń pè ní àjọ̀dún kàrétà èkó tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí lagos carnival lédè gẹ̀ẹ́sì jẹ́ àjọ̀dún tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ìwọ oòrùn afíríkà àjọ̀dún yìí máa ń wáyé nígbà àjọ̀dún lagos black heritage festival èyí ni àjọ̀dún alárinrin agbáṣà àti ìṣe ìbílẹ̀ ga t... |
allwell adémọ́lá allwell adémọ́lá tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọjọ́ kẹ̀sán-án oṣù kẹjọ ọdún 1983 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin olùdarí oǹkọ̀tàn akọrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ-ọmọbìnrin adájọ́-àgbà jùlọ àkọ́kọ́ ní nàìjíríà adájọ́-àgbà olóògbé adétòkunbọ̀ adémọ́lá ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìg... |
ìkẹ́kọ́ òkèrè ìkẹ́kọ̀ọ́ òkèrè ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí wà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ọ̀nà wọn jìn tí wọ́n sì kò sì ní ànfàní láti dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn nílé ẹ̀kọ́ ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí ma ń dá lé fífi àwọn àkóónú kókó àti àwọn àtúpalẹ̀ ẹ̀kọ́ gan an ránṣẹ́ sí akẹ́kọ̀ọ́ ní ibi kíbi tí ó bá wà lórílẹ̀ àgbáyé nípa lílo àpò ìfìwé... |
aliyu mai-bornu mallam aliyu mai-bornu tí wọ́n bí ní ọdún 1919 tí ó sì ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 1919 - 23 february 1970 jẹ́ òkúná-gbòǹgbò onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àkọ́kọ́ tó jẹ́ gómìnà ilé ìfowópamọ́-àgbà tí nàìjíríà |
clement nyong isong clement nyong isong cfr tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1920 ó sìn kú ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2000 20 april 1920 29 may 2000 o jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti onímọ̀ ilé-ìfowópamọ́ tí ó jẹ́ gómìnà ilé ìfowópamọ́-àgbà tí nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1975 nígbà ìṣèjọba ológun ọ̀gágun yakub... |
babagana umara zulum ọ̀jọ̀gbọ́n babagana umara zulum tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1969 august 26th 1969 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ borno lórílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni gómìnà ìpínlẹ̀ born lọ́wọ́lọ́wọ́ wọ́n dìbò yàn án lọ́dún 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú apc ìgbà èwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti... |
ìjọba ìbílẹ̀ lowest tier of administration within a sovereign state ìjọba ìbílẹ̀ jẹ́ ìṣèjọba tí ó kéré jùlọ tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìpín ágbègbè kọ̀ọ̀kan láti jẹ́ kí ètò ìṣèjọba pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́ẹ́ sún mọ́ àwọn ará ìlú ó jẹ́ ìpín ìṣèjọba tó kéré sí ìjọba ìpínlẹ̀ àti ìjọba àpapọ̀ pàápàá pàápàá jùlọ lorílẹ̀-èdè nàìjíríà lábẹ́ èt... |
ìgbìmọ̀ òpútà ìgbìmọ́ òpútà ni ìgbìmọ̀ tí ó túmọ̀ sí ìgbìmọ̀ tí ó ń rí sí ìwádí ìlòdì sí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn jẹ́ ìgbìmọ̀ tí ọ̀gágun àti ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí olúṣẹ́gun ọbásanjọ́ fu lọ́lẹ̀ lẹ́yìn ìṣubú ìjọba ológun tí ó ti jẹ gàba ní orí orílẹ̀-èdè nàìjíríà títí di ọdún 1998 in terms of reconciliation the commission also worked tow... |
kẹ̀kẹ́ alùpùpù kẹ̀kẹ́ alùpùpù ni kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ méjì tí ó ń lo ẹngìnì àti epo bẹntiróò láti fi rìn ní ojú pópó wọ́n fún kẹ̀kẹ́ alùpùpù yí ní orúkọ ìbílẹ̀ rẹ̀ ọ̀kadà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní àfijọ ọkọ̀ òfurufú kan okada air tí ó wà ní àrọko ìpínlẹ̀ benin amọ́ tí kò sí mọ́ kẹ̀kẹ́ alùpùpù ni ó wọ́pọ̀ jùlọ ní apá ìwọ̀ oòr... |
epo rọ̀bì bẹntiróò /pəˈtroʊliəm/ jẹ́ ọ̀kan lára ohun àlùmọ́nì kan tí ó ní àwọ̀ méjì àwọ̀ dúdú àti omi ará yẹ́lò tí wọ́n ma ń wà jáde lábẹ́ ilẹ̀ wọ́n ma ń fe ohun àlùmọ́nì yí sí oríṣiríṣi ọ̀nà ní èyí tí a ti rí epo bẹntiróò àti àwọn mìíràn wọ́n ma ń ṣàdáyanrí oríṣiríṣi epo sọ́tọ̀ láti ara bẹtiróò nípa lílo ohun tí eọ́n ... |
epo bẹntiróò |
àgbékalẹ̀ ẹ̀kọ́ lesson note |
àtòjọ àwọn ààrẹ orílẹ̀-èdè cameron èyí ni àtòjọ àwọn ààrẹ orílẹ̀-èdè cameron láti ìgbà tí wọ́n ti gba òmìnira lọ́wọ́ orílẹ̀-èdè faransé lọ́dún 1960 títí di òní yìí ènìyàn méjì péré ló ti jẹ ààrẹ orílẹ̀-èdè cameron lẹ́yìn òmìnira wọn ààrẹ tó wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́ ni paul biya ó ti wà lórí oyè láti ọjọ́ kẹfà oṣù kọ... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn azerbaijan àtòjọ́ àwọn ìwé ìròyìn azerbaijan jẹ́ àwọn ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ tí ó ń jáde ní àti orílẹ̀-èdè azerbaijan wọ́n ń gbe àwọn ìwé ìròyìn yí tí ó tó 3500 jáde ni èdè azerbaijani tí wọ́n sì ń gbé ọgọ́rún àti ọgbọ̀n 130 jáde ní èdè russian tí wọ́n ń gbé àádọ́rin 70 ní èdè gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n sì ń... |
eyín fún ìtumọ́ míràn ẹ wo eyín ìṣojútùú eyín jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí ó le koko tí kìí rọ̀ tí ó ma ń hù jáde láti inú erìgì nínú ẹnu tí a ma ń lò láti jẹun tàbí fọ́ egungun gbogbo eranko tí ó ní egungun lẹ́yìn tí wọ́n sì ma ń rún ónjẹ lẹ́nu ni wọ́n ma ní eyín nígbà tí pupọ̀ nínú wọn ma ń fi eyin ṣọdẹ tàbí dáàbò bo ara wọn ... |
àtòjọ àwọn ìwé-ìròyìn lórílẹ̀-èdè amẹ́ríkà wikimedia list article èyí ni àtòjọ àwọn ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde tí wọ́n sìn ń tà lórílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ítí di 2014 update iye ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n wà lórílẹ̀ èdè amẹ́ríkà jẹ́ 1331 mẹ́wàá tó gbajúmọ̀ káàkiri jùlọ nínú àwọn ìwé-ìròyìn amẹ́ríkà àwọn wọ̀nyí ni mẹ́wàá... |
lúwòó gbàgídà lúwòó gbàgídà jẹ́ ọba obìnrin àti ọọ̀ni akọ́kọ́ fún ìlú ilé-ifẹ̀ tí ó jẹ́ orírun gbogbo ọmọ kóòtù-oòjíire ìtàn rẹ̀ lúwòó jẹ́ ẹni abiyì arẹwà onímọ́-tótó àti akínkankú obìnrin gẹ́gẹ́ bí àjogúnbá àṣà àti ìṣe àwọn yorùbá gbà wípé ọmọ ọkùnrin níyì wọ́n sì tọ́ nípò àṣà ju obìnrin lọ nítorí wípé ọmọ obìnrin yóò... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ alabama èyí ni àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ alabama wọ́n ṣẹ̀dá àkọ́kọ́ lọ́dún 1811 ṣùgbọ́n kí ó tó di ọdún 1850 ìpínlẹ̀ alabama tí ní ìwé-ìròyìn tó tó éjìlélọ́gọ́rin 82 tí mẹ́rin nínú wọn jẹ ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ àwọn ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ àti àwọn tí kìí ṣe ojoojúmọ... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ alaska <includeonly> èyí ni àwọn ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n ṣì ń tẹ̀ jáde ní ìpínlẹ̀ alaska lorílẹ̀-èdè amẹ́ríkà </includeonly> àwọn ìwé-ìròyìn ọ̀sẹ̀-ọ̀sẹ̀ tí wọ́n ṣì ń tẹ̀ jáde báyìí èyí ni àwọn ìwé-ìròyìn ọ̀sẹ̀-ọ̀sẹ̀ tí wọ́n ṣì ń tẹ̀ jáde ní ìpínlẹ̀ alaska lorílẹ̀-èdè amẹ́r... |
àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ manufactured piece of hard-wearing material awo àlẹ̀mọ́lẹ̀ni ohun tí wọ́n fi àwọn èlò bí sẹ̀rámíìkì òkúta láti ara àpáta irin amọ̀ tàbí díígí ṣe lílò rẹ̀ wọ́n ma ń lo àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ fún ṣíse ilẹ̀ ara ilé tàbí òrùlé ṣe lọ́jọ̀ ìrísí rẹ̀ àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ ma ní igun mẹ́rin mẹ́ta tàbí kí ó rí róbótó nígbà tí wọ... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ arizona <includeonly> àwọn wọ̀nyí ni ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n ń tẹ̀ jáde lowo ní ìpínlẹ̀ arizona lórílẹ̀ èdè amẹ́ríkà fún iwé ìròyìn olọ́sẹ̀ọ̀sẹ̀ wò àtòjọ ìwé ìròyìn ní ìpínlẹ̀ arizona</includeonly> arizona business daily - lórí ìkànnì ayélujára ní azbusinessdailycom |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ arkansas <noinclude> èyí ni àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ arkansas lórílẹ̀ èdè usa àwọn àpilẹ̀kọ ìtọ́kasí 1884 catalogue of periodical publications arkansas history and present condition of the newspaper and periodical press of the united states washington dc govern... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ california california newspapers túndarí síbí yìí fún a history of newspapers in california ẹ wo history of newspapers in california èyí ni àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ california lójoojúmọ́ àti ọ̀sẹ̀-ọ̀sẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ààtò ìlú tí wọ́n ti ń tẹ̀ wọ́n jáde ìwé-ìr... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ní ìpínlẹ̀ colorado <includeonly> èyí ni àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn amẹ́ríkà ojoojúmọ́ tí wọ́n ń tẹ̀ jáde ní ìpínlẹ̀ colorado fún tí ọlọ́sẹ̀ọ̀sẹ̀ ẹ wo àwọn àtòjọ ìwé-ìròyìn ní colorado</includeonly> <noinclude> |
ìpínlẹ̀ titun mẹ́ksíkò |
ìpínlẹ̀ new york |
ìpínlẹ̀ washington |
àtòjọ àwọn ìlú ńlá lórílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àwọn àpilẹ̀kọ yìí kún fún àtòjọ àwọn ìlú ńlá lórílẹ̀ èdè amẹ́ríkà |
àtòjọ àwọn ìlú ǹlá tí àwọn ènìyàn tí pọ̀jù lórílẹ̀-èdè amẹ́ríkà èyí ni àtòjọ àwọn àtòjọ àwọn ìlú ńlá ìlú àti àwọn abúlé lórílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ní àtò ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan àgbègbè tàbí àgbègbè àwọn ará colombia |
àtòjọ àwọn àgbègbè tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn ní ìpínlẹ̀ alabama àwọn ibi ìyàsọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn jẹ́ àwọn àgbègbè tí ìjọba kò ì tí ì mú mọ́ra tí wọ́n kò sìn ní asojú adìbòyàn àti àlà lábẹ́ òfin àpapọ̀ àwọn census-ibi ìyà sọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn ní ìpínlẹ̀ alabama jẹ́ énìdínlógúnlélọ́gọ́rùn ún 118 semmes- mo... |
àtòjọ àwọn ìlú àti ìlú-ńlá ní ìpínlẹ̀ alabama àtòjọ àwọn ìlú àti ìlú-ńlá ní ìpínlẹ̀ alabama county seat state capital and county seat |
àtòjọ àwọn ìlú àti ìlú ńlá ní ìpínlẹ̀ alabama |
àtòjọ àwọn ìlú àti ìlú-ńlá ní ìpínlẹ̀ alabama |
àtòjọ àwọn ìlú ńlá lórílẹ̀-èdè amẹ́ríkà nípa àgbègbè wọn wikimedia list article àtòjọ yìí jẹ́ ti àádọ́jọ àwọn ìlú-ńlá nípa ilẹ̀ àgbègbè wọn àwọn ibi tí omi wà wà nínú àpapọ̀ ìlẹ̀ àgbègbè yìí ṣùgbọ́n bí a bá tò wọ́n nípa àpapọ̀ àgbègbè àwọn ìlú-ńlá tí wọ́n wà létí omi yóò tóbi ju àwọn ìlú-ńlá tó kù lọ lọ́nà tó kọjá òṣùw... |
ọkọ̀ ojú-omi akérò ọkọ̀ ojú-omi akérò jẹ́ àgbàyanu ọkọ̀ akérò akẹ́rù tí ó lé rin irin-àjò káàkiri àgbáyé lórí alagbalúgbú omi ọkọ̀ ojú-omi akérò tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ohun ìrìnsẹ̀ tí ó ń ṣe ọmọnìyàn ní ànfàní pupọ̀ yálà fún iṣẹ́okòwò tàbí ìṣèwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ |
bùkọ̀lá awóyẹmí bùkọ́lá àwoyẹmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí arugbá tí wọ́n bí lọ́dún 1988 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ kwara lórílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ìyàwó gbajúmọ̀ òṣèré mìíràn tí ó ń jẹ́ dàmọ́lá ọlátúnjíó gba orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ arugbá látàrí ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí ògbóǹtarìgì òní-sinimá tú... |
arugbá arugbá jẹ́ gbankọgbì sinimá àgbéléwò kan tí gbajúmọ̀ olóòtú àti olùdarí túndé kèlání gbé jáde lọ́dún 2008 sinimá yìí dá lórí àṣà arugbá tí ó máa ń wáyé nínú ọdún ìbílẹ̀ kan tí wọ́n máa ń ṣe ní ìlú òṣogbo ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ọ̀ṣun òṣogbo gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin bùkọ́lá awóyẹmí tí ó fẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré dàmọ́lá ọlátúnji n... |
dàmọ́lá ọlátúnjí dàmọ́lá ọlátúnjí tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kejì february 2nd jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè nàìjíríà dàmọ́lá ní ọkọ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin bùkọ́lá awóyẹmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí arugbá kí dàmọ́lá tó fẹ́ arugbá ìyàwó àkọ́fẹ́ rẹ̀ ni raliat abíọ́dún wọ́n ... |
àtòjọ àwọn olú-ìlú àwọn orílẹ̀-èdè ní àgbáyé èyí ni àtòjọ àtòjọ àwọn olú-ìlú àwọn orílẹ̀-èdè ní àgbáyé nínú rẹ̀ a lè rí tí àwọn olú-ìlú àwọn orílẹ̀-èdè olómìnira àwọn orílẹ̀ èdè tí kò ì tí ì dá dúró tàbí àwọn tí ó ṣì ń jìjà àlà-ilẹ̀ tàbí ibodè àwọn olú-ìlú àwọn orílẹ̀-èdè lágbáyé tí wọ́n wà nínú àtòjọ yìí ni àwọn orílẹ... |
michael bloomberg michael rubens bloomberg tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1942 february 14 1942 jẹ́ pàràkòyí olóṣèlú oníṣòwò àti oǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà òun ni aláṣẹ àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ bloomberg lp bloomberg ni alákòóso ìlú-ńlá new york láti ọdún 2002 sí 2013 lọ́wọ́ báyìí òun ní adíje dùpò ààrẹ... |
délé mọ́mọ́dù chief délé mọ́mọ́dù èyí ti orúkọ àpèjá àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ ayòbámidélé àbáyọ̀mí ojútẹlẹ́gàn àjàní mọ́mọ́dù tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1960 16th may 1960jẹ́ gbajúmọ̀ akọrọ̀yìn oníṣòwò àti asọ̀rọ̀ṣínilọ́yẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni olórí àti olùdásílẹ̀ ìwé-ìròyìn olóṣooṣù àwọn aláfẹ... |
agége agége jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní ìpínlẹ̀ èkó tí ó sì tún jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan tí wọ́n ṣe àfàyọ rẹ̀ láti ara ìjọba ìbílẹ̀ ìkẹjà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìtàn agége agége jẹ́ ìlú kan tí ó ti wà tipẹ́ wọ́n ọ ìlú náà ní orúkọ nígbà ti iná òwò òwò obì ṣe ń jo gerege níléẹ̀ nàìjíríà àwọn tí wọ́n ta ìlú yí do ni àwọn ènìyàn à... |
laide bakare laide bakare tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹwàá ọdún 1980 7th october 1980 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olóòtú àti oníṣòwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú láídé bákàrè jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní nàìjíríà lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ gírámà rẹ̀ ó kàwé g... |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ agege |
2shortz nigerian former rapper photographer and filmmaker william orioha tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí 2shortz ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1979 3 march 1979 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà olùkọ orin àti ọ̀kọrin ráápù tẹ́lẹ̀ àmọ́ tí ó ti di ayàwòrán àti olùgbéré ìtàgé jáde ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà báyí ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún... |
beverly osu nigerian actress and model ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ beverly naya beverly ada mary osu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀ oṣù kẹjọ ọdún 1992 september 271992 jẹ́ alájótà oníhòhò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di ìlú mọ̀ọ́ká lórí àwọn ipa rẹ̀ ní oríṣiríṣi sinimá àti ipa tí oko ní inú big brother africa ẹlẹ́kẹjọ irú ... |
ìlú muṣin ìlú muṣin agbègbè àti ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ èkó ìlú yí wà ní àdojúkọ òpópó tó lọ sí ìlú ìkẹjà muṣin jẹ́ ìlú kan tí ilé àt èrò pọ̀ sí gidi tí ètò ìmọ́ tótó sì mẹ́hẹ ní àárín èkó gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbe níbẹ̀ tó 633009 níye |
charles olúmọ charles olúmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí àgbákò ṣùgbọ́n tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ abudul salam sànyàolú jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀ èdè nàìjíríà nínú sinimá àgbéléwò èdè yorùbá tí ó jẹ́ abala nollywood ni ó ti gbajúmọ̀ iṣẹ́ tíátà rẹ̀ àgbákò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíá... |
túndé àlàbí-hùndéyín túndé àlàbí-hùndéyín tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ dúdú tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 1953 6th june 1953 jẹ́ gbajúmọ̀ a yàwòrán olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú àgbádárìgì|badagry ní ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ túndé àlàbí-hùndéyín jẹ́ gbajúgbajà ... |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mushin |
akinbami oluseyi macaulay |
mọsún fìlání nigerian film and voice actress mọsún fìlání jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ olóòtú ètò orí rédíò ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbà-èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ wọ́n bí ní ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ṣùgbọ́n ìpínlẹ̀ èkìtì ni àwọn òbí rẹ̀ tí ṣẹ̀ wá ó... |
bídèmí kòsọ́kọ́ bídèmí kòsọ́kọ́ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1988 21st october 1988 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọba jídé kòsọ́kọ́ ẹbí wọn ní à bá má pè ní ẹbí sinimá àgbéléwò lórílẹ̀ è... |
táíwò oyèbọ́lá agbóná táíwò oyèbọ́lá agbóná jẹ́ ọ̀dọ́mọbìnrin ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógún tí ó jọba nípò adelé ní ìlú ààyè ní ìpínlẹ̀ oǹdó lorílẹ̀-èdè nàìjíríà ó wà lọ́mọ ọdún méjìlélógún ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga ifáfitì achievers university ní ìlú ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ oǹdó tí ó ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣègùn òyìnbó lọ́dún 2017 tí ifá fi yàn... |
bídèmí kòsọ́kọ́ |
achievers university private university in owo nigeria achievers university jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ifáfitì tí wọ́n tẹ̀dó sí ìlú ọ̀wọ̀ ní ìpínlẹ̀ oǹdó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ ifáfitì aládàání tí wọ́n dá sílẹ̀ lọ́dún 2017 tí ìjọba àpapọ̀ sìn fọwọ́ sí ó gúnwà sí àgbègbè ìdásẹ̀n ní ìlú ọ̀wọ̀ ifáfitì achievers university jẹ́... |
àtòjọ àwọn ifáfitì aládàání lórílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn ifáfitì aládàání tí national university commission nuc tí ìjọba àpapọ̀ fún láṣẹ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà a ṣe àtòjọ yìí nípa àtò álúfábẹ́ẹ̀tì |
àtòjọ àwọn ifáfitì ìjọba lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ifáfitì ìjọba pín sí ọ̀nà méjì gbòógì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìjọba àpapọ̀ àti ìjọba ìpínlẹ̀ ní wọ́n ní ẹ̀tọ́ àti àṣẹ láti ọwọ́ national university commission àjọ ìjọba àpapọ̀ tí ó ń darí mójútó ìdásílẹ̀ ifáfitì lórílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ṣe ìdásílẹ̀ ifáfitì |
ikọ́ ikọ́ jẹ́ ọ̀nà gbígbé atẹ́gùn jáde pẹ̀lú agbára láti ọ̀nà ọ̀fun kí a lè fọ ọ̀nà ọ̀fun náà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìdọ̀tí tí ó sá pamọ́ síbẹ̀ ikọ́ wíwú lè jẹ́ lẹ́ẹ̀kan tàbí léra-léra tí yóò sì mú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ dání wíwúkọ́ léra-léra lè túmọ̀ sí wípé àìsàn tàbí àrùn kan wà ní àgọ́ ara nítorí wípé púpọ̀ lára àwọn àrùn àgọ́ ara ni... |
kuforiji olubi |
èdè àbèsàbèsì àbèsàbèsì tàbí akpes jẹ́ èdè ní nàìjíríà ní àwọn ìpínlẹ̀ òndó see also wiktionary dialect comparison àbèsàbèsì dialects and èdè yorùbá |
àtòjọ àwọn ifáfitì ìjọba lórílẹ̀-èdè nàìjíríà |
àtòjọ àwọn ifáfitì aládàání lórílẹ̀ èdè nàìjíríà |
èdè àhàn àhàn jẹ́ èdè ní nàìjíríà ní àwọn ìpínlẹ̀ òndó see also wiktionary vocabulary comparison èdè àhàn èdè ayere èdè yorùbá |
èdè ọ̀kọ́ ọ̀kọ́ jẹ́ èdè ní nàìjíríà ní àwọn ìpínlẹ̀ kogí see also wiktionary vocabulary èdè ọ̀kọ́ èdè yorùbá |
ìwé ìrìnà ìwé ìrìnà ni àkójọ pọ̀ ìwé ìdánimọ̀ tí ìjọba orílẹ̀-èdè kan sì fi òntẹ̀ lù fún ìrìn-àjò ọmọ orílẹ̀-èdè bẹ́ẹ̀ àmọ́ èyí kìí ṣi ìwé àṣẹ ìgbélùú rárá ìwé yí wà fún ìrìn-àjò lọ sí orílẹ̀-èdè mìíràn àwọn ohun tí ó ṣe kókó jùlọ ni orúkọ ẹni tí ó ni ìwé ìrìnà náà ibi tí wọ́n ti bíi ọjọ́ ìbí àwòrán ìdánimọ̀ pélébé ìbu... |
ilà kíkọ nílẹ̀ yorùbá ilà kíkọ nílẹ̀ yorùbá jẹ́ kíkọ tàbí fífa ìlà sí ojú orí apá tàbí itan gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan pàtàkì tí àwọn yorùbá ń gbà láti ṣe ọ̀ṣọ́ dá ara wọn mọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ bí àṣà àti ìṣe ìwúlò ilà kókó ilà kíkọ nílẹ̀ yorùbá ni kí wọ́n lè mọ ènìyàn mọ́ ìdílé rẹ̀ ní gbogbo ibi tí ó bá lọ ilà yí lè j... |
ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tí a lè ṣe ìkékúrú rẹ̀ sí tsp jẹ́ ilé iṣẹ́ tí ó eà ní ọ̀nà bí a ṣe lè rí ara ẹni bá sọ̀rọ́ yálà nípa lílo ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́ tàbí ìtàkùn ayélujára ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tàbi tsps ni ó jẹ́ wípé nígbà kan rí ìjọba oríl... |
ìlà ìpè integrated circuit card for a mobile device ìlà ìpè ni a lè pè ní àmì ìdánimọ̀ fún oníbàárà subscriber identity module tí gbogbo ènìyàn ń pè ní sim card jẹ́ àmúpamọ́ circuit kan tí ó wà fún títọ́jú orúkọ àti àwọn àmì ìdánimọ̀ gbogbo tí oníbàárà bá fi sílẹ̀ lásìkò tí ó fẹ́ gba ìlà ìpè rẹ̀ àwọn ohun tí oníbàárà f... |
bright chimezie bright chimezie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960 1st october 1960 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ìgbà kan ọmọ bíbí ìgbò lórílẹ̀-èdè nàìjíríà |
monalisa chinda nigerian actor film producer and tv personality monalisa chinda tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 13th september 1974 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣàn àti gbajúmọ̀ olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
oga chameleon |
jiopolima geopolymers jiopólímà geopolymers jiopólímà jẹ́ ohun èlò àtọwọ́dá gẹ́gẹ́ bi seramiki àwọn ohun tí ógùn tí ó sopọ̀ pẹ̀lú covalent àwọn nẹ́tíwọkì tí kòní gantán amorphous àjẹkù obsidian gílásì folti jẹ́ pāti diẹ nínú àwọn ohun èlò fún jiopólímà jiopólímà le jẹ́ ohun ìwúlò fún ìs’ẹ̀dá ǹkan tí ó rí ara gba iná tí... |
eṣinṣin ilé eṣinṣin ilé tí wọ́n ń dà pè ní musca domestica jẹ́ ohun tí ó ń fò tí ó sì jẹ́ ọ̀ksn lára ẹbí cyclorrhapha wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eṣinṣin yí wá láti ayé cenozoic kí ó tó na fọ́n ká sí orílẹ̀ àgbáyé ó jẹ́ ọ̀kan lára kòkòrò tí ó wọ́pọ̀ nínú ilé ìrísí rẹ̀ eṣinṣin ilé tí ó bá ti dàgbà ma ń ní àwọn olómi eérú s... |
ilé ilé tí a tún ńndà pè ní ibùgbé jẹ́ ibi tàbí àyè tí a lè ma sùn tàbí gbé pẹ̀lú àwọn ẹbí wa ohun èlò ìkọ́lé ilé lọ́pọ̀ ma ń jẹ́ ohun tí wọ́n ms ńa fi igi àti ikí kọ́bláyé àtijọ́ irúfẹ́ ilé báyí ni wọ́n ń ń pè ní abà àmọ́ láyé òde òní oríṣríṣi ohun èlò ni wọ́n fi ń kọ́lé àwọn ohun èlò bí iyẹ̀pẹ̀ sìmẹ́ntì òkúta páànù ì... |
esinsin |
eṣinsin ilé |
hanks anuku nigerian actor hanks anuku tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1960 27 august 1960 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò èdè gẹ̀ẹ́sì àti ìgbò as of 2017 anuku was naturalized and became a ghanaian ìgbà èwe rẹ̀ anuku lọ sí ilé-ìwé loy... |
osita iheme osita iheme mfr tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù kejì ọdún 1982 february 20 1982 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí pawpaw látàrí ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn pawpaw nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń aki na ukwa pẹ̀lú chine... |
chinedu ikedieze chinedu ikedieze mfr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 1977 12 december 1977 ní ìlú bende ní ìpínlẹ̀ abia lórílẹ̀ èdè nàìjíríà jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ̀ nípa ipa tí ó máa ń kó pẹ̀lú osita iheme nínú àwọn sinimá àgbéléwò pàápàá jùlọ sinimá àgbéléwò ... |
clem ohameze clem ohameze jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ti ń ṣeré fún nǹkan bí ogún ọdún sẹ́yìn clem ohameze bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 1995 ṣùgbọ́n ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ ní kété tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ end time ó ti kópa nínú sinimá àgbé... |
blessed stars football academy blessed stars football academy ile-ẹkọ ijinlẹ ere idaraya ti o da ni ipinle akwa ibom nigeria ile-ẹkọ giga naa da ni 2002 o si fi aṣẹ nipasẹ gomina ti tẹlẹ ti ipinle akwa ibom akpan isemin ile-ijinlẹ yii da pẹlu ero-iṣe iṣere ati idagbasoke awọn elere idaraya ni nigeria ile-ijinlẹ wa ni a... |
lafiaji okuneye bilikis láfíàjí okùnẹ́yẹ bilikis jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìlera ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó a bí bilikis ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdún 1972 ní erékùṣù ìlú èkó ó jẹ́ gíwá ilé ẹ̀kọ́ olùkọ́ni àgbà ti adéníran ògúnsànyà college of education |
àsálà àsálà ni èso igi èyíkéyí nínú àwọn ẹ̀yà igi tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pè ní juglans àsálà jẹ́ ọ̀kan lára èso jíjẹ nígbà tí ó bá ti gbó ànfàní èso àsálà èso àsálà dára fún wíwo àìsàn ìtọ̀ ṣúgà ó dára fún kí ọpọlọ ó pé ìrísí rẹ̀ èso àsálà rí roboto èpo rẹ̀ dúdú mìnì àmọ́ tí a bá fọ tàbí làá inú rẹ̀ funfun báláú tí ohun kan... |
àgbo àgbo jẹ́ ohun mímu àti ọ̀kan pàtàkì nínú ohun tí a lè fi ṣe ìwòsàn àgọ́ ara nípa kíkó egbògi ewé àti èpo ìbílẹ̀ pa pọ̀ láti lè fi tọ́jú àìsàn àrùn àti ooríṣríṣi ohun tí ó lè fa àìlera sí ara ẹ̀dá tàbí ẹranko ànfàní àgbo lára àwọn ànfàní àgbo ni |
andrew fielding andrew fielding jẹ́ ọmọ bíbí ìlú hampstead ní ìlú london ní orílẹ̀-èdè england a bi nínú oṣù belu ó si kú ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù èbìbì ọdún 2012 ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ìwádí òun pẹ̀lú alan àti john carew lórí ìmọ̀ oògùn ìwádí rẹ̀ dálé ìmọ̀ iṣan ara àti pataki lori ìbáṣepọ̀ iṣan nínú ara ó jẹ́ ààrẹ fún àwọn... |
mahdi aliyu gusau mahdi aliyu gusau igbakeji gomina lọwọlọwọ ti ipinle zamfara o jẹ ọkan ninu igbakeji alabojuto ti abikẹhin lati dibo ni ọjọ-ori rẹ lati ọjọ kẹrin ti orilẹ-ede naijiria o jẹ ọmọ si gbogbogbo aliyu mohammed gusau minisita fun aabo aabo aliyu muhammad gusau |
apoti àpọ́tí jẹ́ ohun ìjókòó tí ó ní orí pẹrẹsẹ tí a fi igi tàbí pákó ṣe ẹnìkan ṣoṣo péré ni àpótí lè gbà lórí ìjókòó kan bákan náà ni kò ní igun tí a lè gbé ọwọ́ lé lọ́tún tàbí lósì ó ma ń ní ẹsẹ̀ méjì mẹ́ta tàbí mẹ́rin èyí dá lórí agbègbè tí a bá ti ríi a kò lè sọ wípé àga ni àpótí nítorí àì ní apá tàbí igun tí a lè ... |
ọ̀rọ̀ ìṣe ọ̀rọ̀ ìṣe ni ọ̀rọ̀ tí ó ń fi ohun tí a ń ṣe lọ́wọ́ tí a ti ṣe kọjá tàbí ohun tí a óò ma ṣe lọ́jọ́ iwájú hàn nínú gbólóhùn èyí ni kókó inú gbólóhùn èdè yorùbá òhun ni ó wà láàrin olúwa àti àbọ̀ ó lè ṣíwájú ólùwa ó sì lè síwájú àbọ̀ òpómúléró inú gbólóhùn ni ọ̀rọ̀ ìṣe jẹ́ |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.