raw_text
stringlengths
2
128k
sikiru kayode adetona ọba sikiru kayode adetona tí a bí ní ọjọ́ kẹwa oṣù karun ọdún 1934 ni awujale ti ìjẹ̀bú wọ́n fi jẹ ọba ní ọdún 1960 èyí ló mú kí adetona jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọba tí o tí pẹ́ lórí àléfà ní ilẹ̀ naijiria baba rẹ ni ọmọ ọba rufai adetona tí ìyá rẹ si jẹ alaja wolemotu ajibabi adetona nee onasile gẹ́gẹ...
àṣà ìsìnkú ìgbà tá a kú là á dère ènìyàn kò sunwọ̀n láàyèbẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ọ̀rọ́ ìsìnkú ní ilẹ̀ káàárọ̀ o o jíireadìyẹ ṣe pàtàkì nínú ètò ìsìnkú àgbà
eré ọmọdé eré ọmọdé gbogbo ọmọdé ní orílẹ̀-ayé ni o fẹran eré ṣíṣe nínú ilénínú ọgbà ní àdúgbò àti ní ìgbro ọmọdé a maa ba gbogbo ènìyàn ṣiré tàbí ki o jáde láti bá ẹlẹgbẹ rẹ̀ ṣiré ni àdúgbò kan naa inú dídùn àti ẹ̀rín jẹ́ àmì eré ṣiṣe laarin ọmọdé àti àgbà akọ́mọlédè ìjìnlẹ̀ yorùbá vol 1
efunroye tinubu abí arábìnrin efúnpòróyè ọ̀suntínúbu olúmọ̀sà ní odún 1810 arábìnrin yii jẹ gbajúgbajà onísòwò nípa òwò erú o jẹ ẹni tí o gbajúmò ni ìlú èkó nígbàtí ọba adéníji àdèlé olúwolé akíntóyè àti dòsúmú wa lórí oyè nìgbà náà abí akínkanjú obínrin yii ní agbẹ̀gbẹ̀ ojókòró ní ìlú ẹ̀gbá ti orúko bàbá re a sì maa j...
gambo sawaba hajia gambo sawaba tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kejì ọdún 1933 tí ó sìn ṣaláìsí lóṣù kẹwàá ọdún 2001 15 february 1933 october 2001 jẹ́ ajìjàǹgbara ẹ̀tọ́ obìnrin afowóṣàánú àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni igbákejì alága ẹgbẹ́ òṣèlú great nigeria people's party tí wọ́n sìn tún yàn án gẹ́gẹ́ bí...
judy sheindlin judith susan sheindlin née blum ni abí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1942 ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà amòfin àti akọ̀wé sheindlin ti gba àmì-ẹ̀yẹ ìdáni lọ́lólá ti day-time emmy award ní ọdún 1996
aṣọ àdìrẹ aṣọ àdìrẹ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn aṣọ ìbílẹ̀ ilẹ̀ yorùbá tọmọdé tàgbà ni ó ń wọ aṣọ àdìrẹ tí wọ́n ṣiṣẹ́ ọnà oríṣríṣi sí lára nílànà ìbílẹ̀ tí ó sì wà ní àwọ̀ oríṣríṣi sí
hilda dokubo nigerian film actress and youth advocate hilda dokubo tí a tún mọ̀ sí hilda dokubo mrakpor jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn ọ̀dọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti fìgbà kan jẹ́ olùgbaninímọ̀ràn pàtàkì lórí ọ̀rọ̀ ọ̀dọ́ fún gómìnà àná ìpínlẹ̀ rivers peter odili ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ...
agidigbo
emeka ike emeka ikejẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà
ògógóró ògógóró jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́n pọn láti ara ẹmu igi ọ̀pẹ tàbí agbe ó jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́n máa ń mú káàkiri ìwọ̀-oòrùn áfíríkà pàápàá jùlọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà lóde òní ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń ka ethanol sí ògógóró ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ rárá kẹ́míkà ni ethanol ṣùgbọ́n ògógóró jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́...
àtòjọ àwọn gbajúmọ̀ òṣèlú-bìnrin ọmọ yorùbá list of yoruba women in politics from enwp source categoryyoruba women in politics in the english-language wikipedia names in red do not have a page in the yoruba wikipedia each of these women has a page in the english-language wikipedia they are found in that category and ca...
òkè olúmọ òkè olúmọ ni òkè kan tí nó wà ní ilẹ̀ ẹ̀gbá ìlú abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ ògùn ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà òkè olúmọ jẹ́ ibìsálà fún àwọn ará abẹ́òkúta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí wọ́n sì ń bọọ́ pẹ̀lú oríṣríṣi ẹbọ àbẹ̀wò sí òkè olúmọ òkè olúm...
niji akanni
anthonia kehinde fatunsin anthonia kehinde fatunsin jẹ́ awalẹ̀pìtàn ọmọ nàìjíríà èyí tí àwọn onímọ̀ gẹ̀ẹ́sì mọ̀ sí archaeologist wọ́n kà á sí obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìṣẹ̀ǹbáyé ní nàìjíríà àti obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ olórí ilé mùsíọ́mù orílẹ̀-èdè ìbàdàn iṣẹ́ ìṣe ààyè rẹ̀ ti dojúkọ púpọ̀ jùlọ lórí amọ̀ mímọ ...
nicole scherzinger nicole scherzinger /ʃ ɜːr z ɪ n ər / bi nicole prescovia elikolani valiente june 29 1978 jẹ́ akọrin oníjó òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti gbajúmọ̀ olóòtú tẹlifíṣàn ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ wọ́n bí i ní ìlú honolulu ní ìpínlẹ̀ hawaii ó gbé louisville kentucky dàgbà ó kẹ...
abisoye ajayi akinfolarin nigerian women's activist abísóyè àjàyí akínfọlárìn tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù karùn ún ọdún 1985 19 may 1985 ní ìpínlẹ̀ òndó jẹ́ oníṣẹ́ àdáni àti olù polongo ìkẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ìyá tí kò ní ànfàní láti kẹ́kọ̀ọ́ oùn ni olùdásílẹ̀ àjọ 'pearls africa youth foundation...
padita agu padita agu tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹwàá ọdún 1980 13th october 1980 jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti kópa lóríṣiríṣi nínú àwọn sinimá-àgbéléwò èdè gẹ̀ẹ́ṣì ṣùgbọ́n ipa tó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń the last three digits lọ́dún 2015 lo sọ ọ́ di gbajúmọ̀ òṣèré...
aminu bayero aminu bayero jẹ́ emir ìlú kánò tí ó wà ní orí ìtẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ wọ́n fi í jẹ emir ìlú kano lẹ́yìn tí ìjọba ìpínlẹ̀ kánò lábẹ́ ìṣàkóso gómìnà abdullahi umar ganduje rọ̀ emir àná sanusi lamido sanusi lóyè nítorí ẹ̀sùn ìkówójẹ
sanusi lamido sanusi muhammadu sanusi ii tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí sanusi lamido sanusi tí wọ́n bí ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù keje ọdún 1961 31 july 1961 jẹ́ emir àná ti ìlú kánò tí ìjọba ìpínlẹ̀ kano lábẹ́ ìṣàkóso gómìnà abdullahi umar ganduje rọ̀ lóyè lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹta ọdún 2020 lọ́jọ́ yìí kan náà ni ìjọba ìpínlẹ̀...
abdullahi umar ganduje abdullahi umar ganduje ofr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1945 25 december 1945 jẹ́ olóṣèlú àti gómìnà ìpínlẹ̀ kánò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015 kí ó tó di gómìnà òun ni igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ kano lọ́dún 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015
ìgbéyàwó ìṣẹ̀ǹbáyé láàárín àwọn ẹ̀yà ìgbò ìgbéyàwó ìṣẹ̀ǹbáyé ni wọ́n ń pè ní igba ukwu ní ilẹ̀ ìgbò ní apá ìlà oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ìgbéyàwó kìí ṣe ìsopọ̀ láàárín ọ̀dọ́bìnrin àti ọ̀dọ́mọkùnrin tó fẹ́ di ọkọ àti aya níkan ṣùgbọ́n ojúṣe àwọn òbí àwọn ẹbí àti àwọn ará àdúgbò ìdí nìyí tí ìkọ̀sílẹ̀ fi ṣọ̀wọ́n láàárín wọnlẹ́y...
àkójọ àwọn yoruba women in politics
yoruba gege bi ede akokunteni of in eto eko ede abinibi lo fa eko ede akokunteni ede akokunteni ni ki a ko ede miiran ti ki i se ti awujo ti a bi ni si kun eyi ti a mo teletele eyi ni pe ki a ko ede ti a ko gbo teletele ri mo ti abinibi eni awon wo ni o le je akekoo ko si eni ti ko le ko ede kun tire omode n ko o agba ...
àkàyé àkàyé èyí ni kíkà àpilẹ̀kọ kan ní àlàyé yálà fún ìdánwò bí ó bá jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tàbí fún ìgbádùn ara ẹni ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ní ìṣòro ma ń dojúkọ àwọn olùkó láti kọ́ àwọn ọmọ ní àkàyé lára irú àwọn ìṣòro tí ó ma ń wáyé nínú ìwé kíkà ní wi pé ọ̀pọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ lè dá ìró mọ̀ yàtọ̀ sí ara wọn ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni ó tún jẹ́ w...
jones arogbofa jones ọladẹhinde arọgbọfa tí a bí ní ọjọ́ kẹwa oṣù kọkanla ọdún 1952 10 oṣù kejì 2024 wá láti ìjọba ìbílẹ̀ akòko tí ó wà ní guusu ìwọ oorun ní ipinle ondo arọgbọfa jẹ́ ọ̀gágun tí ó ti fẹ̀hìntì nínú iṣẹ́ ológun ẹ̀kọ́ arogbofa gba oyè diploma nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ ẹ̀rọ rochester instit...
akaye
tolu odebiyi tolulope odebiyi tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kọkànlá ọdún1963 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè naijiria tí ó wá láti ìpínlẹ̀ ògùn odebiyi ni wọn dìbò yàn sí ilé ìgbìmọ̀ aṣojú àgbà láti jẹ́ aṣojú fún ìwọ oorun ti ìpínlẹ̀ ògùn ní ọdún 2019 ó ti kọ́kọ́ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú gomina ibikule amosu ti ìpínlẹ̀ ògùn gẹ́gẹ́ bí olór...
aminu ado bayero aminu ado bayero b ọdun 1961 ni ami- ọba 15th ti kano lati idile sullubawa fulani o gun ori itẹ ni 9 oṣu kẹta ọjọ 2020 ni atẹle idogo ti muhammad sanusi ii nipasẹ gomina ti ipinle kano abdullahi ganduje igbesi aye ati eto-eko bayero ni lati kano state ati ki o jẹ keji ọmọ ado bayero awọn 13th emir ti k...
bí covid-19 ṣe rápálá wọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà bí covid-19 ṣe rápálá wọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà kò ṣẹ̀yìn àrè kan láti ìlú milan lórílẹ̀-èdè italy tí ó wá sí orílẹ̀-èdè nàìjíríà lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2020 ìròyìn sọ wípé àrè náà ti wọn kò dárúkọ rẹ̀ rìnrìn àjò wá láti orílẹ̀-èdè italy sí ilé-iṣẹ́ lafarge tí ó ń ...
ìbọ̀sẹ̀ ìbọ̀sẹ̀ ni aṣọ pélébé kan tí a rán ní dédé ìwọ̀n tí ẹsẹ̀ lè gbà tí kò sì gùn ju dédé kókósẹ̀ lọ s ma ń eọ ìbọ̀sẹ̀ sí ẹsẹ̀ nígbà tí a bá wọ irúfẹ́ àwọn bàtà kan kí ó lè jẹ́ kí ìrìn ẹni ó lè já geere ní ayé àtijọ́ awọ ẹran ni wọ́n ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìbọ̀sẹ̀ ìwúlò ìbọ̀sẹ̀ ìbọ̀sẹ̀ wúlò púpọ̀ nítorí bí ó ṣe ...
ìtọ̀ liquid by-product of metabolism in the bodies of many animals including humans ìtọ̀ ni omi kan tí ó ń sun láti gbogbo oríkéríké ara tí ó sì gba inú kídìnrín lọ sínú àpò ìtọ̀ tàbí ilé ìtọ̀ èyí ma ń wáyé nínú ara gbogbo ẹranko elégungun jíjáde tàbí sísun omi ara tí kò wúlò fún àgọ́ ara mọ́ yí ni ó parapọ̀ tí ó di ìt...
frankfurt
ukréìn
dangote group ilé-iṣẹ́ alájọni dangote ni orúkọ àkójọpọ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ tí àkójọpọ̀ oníṣòwò àti ẹni tí ó lówó jùlọ nílẹ̀ áfíríkà alhaji aliko dangote dá sílẹ̀ káàkiri àgbáyé àti lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ìgbìmọ̀ ìjọba tó tóbi jùlọ ní ìwọ̀-oòrùn áfíríkà àti ọ̀kan nínú àwọn tó tóbi jùlọ ní ilẹ̀ áfíríkà ẹgbẹ́ náà ń gba òṣ...
abel oluwafemi dosumu abel oluwafemi dosumu tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ mega99 ni wọ́n bí sí oshòdi ìlú ńlá ní ìpínlẹ̀ èkó ìpín ìsàkóso ti nàìjíríà ó gba oyè ìmọ̀ sáyẹ́ńsì bsc nínú ìmọ̀ ìṣirò-owó láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ọlábísí onàbánjọ ní ọdún 1994 ó dá ẹgbẹ́ olórin kan sílè tí wọ́n pè ní abel dosunmu àti mega 9'9 band ...
ìjọba ìbílẹ̀ oṣòdì-ìsọlọ̀ local government area within lagos state nigeria oṣòdì-ìsọ̀lọ̀ jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ lga kan láàrín ìpínlẹ̀ èkó ìjọba ìbílẹ̀ yí jẹ́ dídá sílẹ̀ lábẹ́ ìṣẹ̀jọba gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní ìpínlẹ̀ èkó alhaji lateef káyọ̀dé jákàndè tí gbogbo ènìyàn tún mọ̀ sí bàbá kékeré ẹni tí ó kọ́kọ́ jẹ́ alága àti o...
ngozi ezeonu ngozi ezeonu tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ ngozi ikpelue ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1965 may 23rd 1965 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òníròyìn tẹ́lẹ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ìlúmọ̀ọ́kà nípa ṣíṣe ẹ̀dá-ìtàn ìyá nínú sinimá àgbéléwò lédè g...
angélique kidjo angélique kpasseloko hinto hounsinou kandjo manta zogbin kidjo known as angélique kidjo born july 14 1960 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ajìjàǹgbara ọmọbìnrin láti orílẹ̀-èdè olómìnira benin beninese tí ó tún míràn orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ olórin-bìnrin nípa ìṣẹ̀wọ́ kọrin àti fídí...
isah misau isah misau tí a bí ní ọdún 1970 ní bauchi orílẹ̀ èdè naijiria jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ naijiria lọ́wọ́lọ́wọ́ oun ni alága ìgbìmọ̀ ti o nri sí ọ̀rọ̀ nípa àwọn ọmọ ogun orí omi ní ilé asojú àgbà ti ilẹ̀ naijiria ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ní naijiria tí ó n ṣojú aringbungbun tí ìpínlẹ̀...
kíndìnrín kíndìnrín jẹ́ àwọn ẹ̀yà ara inú méjì tí ìrísí wọn dà bí ẹ̀wà tí a lè ṣalábàápàdé rẹ̀ ní árá gbógbó ẹranko élégúngún àwọn kíndìrín yí wà ní apá ọ̀tún àti apá òsí ní ìsàlẹ̀ àyà àwọn kíndìnrín wọ̀nyí ma ń gba ẹ̀jẹ̀ sára láti ara iṣan tí ó só pọ̀ mọ́ ọkàn tí wọ́n ń pè ní renal arteriee kíndìnrín kọ̀ọ̀kan ni ó tún...
iṣan iṣan ni okùn ara tí ó rọ̀ jùlọ tí a lè rí ní ara púpọ̀ nínú ẹranko nínú iṣan kọ̀ọ̀kan ni a ti rí protein actin àtimyosin tí wọ́n gba orín ara wọn kọjá nínú iṣan lọ́hùn ún àwọn èròjà wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ kí iṣan le rọ̀ tábí kí ó wà láàrin méjì gẹ́gẹ́ bí ipò tí ara bá wà lásìkò kan iṣẹ́ iṣan láamra iṣẹ́ àwọn iṣan in...
ẹ̀wà ẹ̀wà ni ìkan lára àwọn igi eléso tí ó ń so ohun jíjẹ ẹlẹ́yọ tí ènìyàn tàbí ẹranko lè jẹ gẹ́gẹ́ bí óúnjẹ oríṣi ọ̀nà tí a lè gbà jẹ ẹ̀wà ọ̀nà tí a lè gbà láti sè tàbí jẹ ẹ̀wà pọ̀ jántì-rẹrẹ lára rẹ̀ ni gbígbìn àti kíkórè ẹ̀wà yàtọ̀ sí àwọn óuńjẹ akẹgbẹ́ ẹ̀wà tókù ẹ̀wà ní tirẹ̀ jẹ́ ohun eléso tí ó nílò ooru tàbí oòru...
dígí object that reflects light dígí tàbí díngí ìwògbè ni ohun èlò kan tí a ń lò láti fi wo àwòrán ara ẹni tí yóò sì gbé àwòrán náà wá fúni gẹ́gẹ́ a ti rí oríṣi dígí tí ó wà lára àwọn dígí tí ó wọ́pọ̀ tí a má ń rí tàbí lò jùlọ ni panragandan plain mirror èkejì ni dígí ẹlẹ́bùú cirved mirror wọ́n ma ń lo dígí yìí láti fi...
ìrẹsì cereal grain and seed of different oryza zizania and zizania species ìrẹsì jẹ́ èso irúgbìn ohun ọ̀gbìn tí gbogbo ènìyàn ma ń jẹ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé pàá paa jùlọ ní ilẹ̀ asia ohun ọ̀gbìn yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ohun ọ̀gbìn óúnjẹ tí wọ́n pèsè jùlọ ní àgbáye ní iye 7415 mílíọ́nù tọ́ọ̀nù ní ọdún 2014 lẹ́yìn ìrèk...
ìrèké group of cultivated plants ìrèké jẹ́ igi tẹ́rẹ́ gíga tí ó ma dùn mìnsìn-mìnsìn nígbà tí a bá ge sẹ́nu ó sábà ma ń hù jùlọ níbi tí ilẹ̀ omi rẹ̀ bá wà ní ìwọ̀ntún-wọ̀nsì òun sì ni wọ́n fi ń ṣe ṣúgà jíjẹ ìrísí rẹ̀ ìrèké ma ń ga níwọ̀nn bàtà mẹ́fà sí ogún óma ń ní kókó ní ìpelel ìpele tí adùn rẹ̀ sì ma ń dá lórí ìpel...
eewo orisa to je mo iwa mimo èèwò ni ohun àìgbodò se ìyen ìwà èérí tí òrìsà kórìíra àpeere òrìsà òrìsà obàtálá obàtálá lòdì sí ìdòtí tàbí nnkan ègbin ìwà eke ìwà àìsòdodo àti òdàlè òrìsà sàngó sàngó kórìíra ìwà olè àrá ni ó n sán pa olètí yóò sì gbé ohun tó bá jí le ní àyà òrìsà ògún ògún lòdì sí ìwà iró-pípa èké-síse ...
owo sise ise de omo alaseje owo de omo alasela owo sise ti a tun mo si kara-kata je okan pataki ni ara ise aje awon yoruba erongba ontaja ni lati jere nitori 'ere ni omo oloja n je' eni ti o ta oja lai jere tabi pa oju owo 'sowo sooti ni' pataki owo sise ni ile yoruba owo sise je awon yoruba logun nitori awon idi wonyi...
pópù fransisi i
babatunji olowofoyeku
ẹ́gíptì
sandra achums sandra achums jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti afowó-ṣàánú ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà
hantavirus hantavirus tàbí orthohantavirus jẹ́ kòkòrò ẹ̀ràn àìfojúrí tí ó máa ń jẹyọ lára eku ó jẹ́ ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí tí ó máa ṣẹ̀yọ lára eku ṣùgbọ́n kìí ṣe wọ́n ní ìjàmbá kankan ènìyàn lè kó ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí hantavirus láti ara ìtọ̀ irọ́ tàbí imìgbẹ́ eku èyí lè fà àìsàn ìbà tí wọ́n ń pè ní hantavirus hemorrha...
remi sonaiya
segun odegbami
isu
iru
abà small clustered human settlement smaller than a town abà tàbí abúlé ni ìletò kan tí a kọ́ ilé oríṣríṣi sí tí àwọn ènìyàn dá sílẹ̀ fún gbígbé abà tàbí abúlé ma ń fẹ̀ tóbi tí ó sì ma ń ní èrò púpọ̀ ju ahéré lọ lọ́pọ̀ ìgbà abúlé ló sábà ma ń dàgbà sókè di ìlú ńlá nípa bí àwọn ènìyàn bá ṣe ń pọ̀ si kí á tó lè pe ibì ka...
alákàn alákàn tàbí akàn tí wọ́n ń dà pè ní decapod ní èdè gẹ̀ẹ́sì jẹ́ ẹranko tí ó lè gbé lórí ilẹ̀ àti inú omí gíríkì = short / = tail ẹranko yí ma ń gbé nínú pàlà pálá ihò ilẹ̀ tàbí abẹ́ àwọn ewéko ní etí omi bákan náà ni kò sí ibi tí wọn kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé pátá ìrísí rẹ̀ alákàn jẹ́ ẹranko tí gbogbo egungun ara rẹ...
àjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020 àjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020 tàbí àjàkáyé-àrùn covid-19 ni àjàkáyé-àrùn tí ó ṣẹlẹ̀ ní ààrin ọdún 2019 àti 2020 tí ò ń tàn káàkiri orílẹ̀ èdè gbogbo àgbáyé lọ́wọ́lọ́wọ́ kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kòrónà tí ó ń ṣàkóbá fún èémí ọ̀wọ́ kejì sars-cov-2 ló ṣokùnfà àjàkálẹ̀ àrùn ...
èràn kòrónà
pataki oruko ninu ede yoruba pataki oruko ninu ede yoruba awon yoruba ka oruko si pupopupo eranje l' o je fun won lati maa ro itumo oruko ti won ba gbo tabi ti won ba n lo oruko ti eniyan tabi oja tabi ilu tabi adugbo ba n je kun fun itumo pataki ti awon eniyan maa n ranti nigbakuugba ti isedale awon yoruba la n wi yi ...
àrún èrànkòrónà ọdún 2019 ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa àrún náà fún kòkòrò èràn tó ún fàá ẹ wo sars-cov-2 àrùn èrànkòrónà ọdún 2019 tàbí ní èdè gẹ̀ẹ́sì bíi coronavirus disease 2019 covid-19 jẹ́ àrún àkóràn kan tí èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró èràn kòrónà irú 2 sars-cov-2 ń mú wá àrùn náà kọ́kọ́ jẹ́ dídámọ̀ ní decembe...
coronavirus disease 2019
201920 coronavirus pandemic
covid-19
eré wúrà eré wúrà ti ọ̀gbéni gabriel afoláyan ko wúrà yíì jẹ́ ohun tí gbogbo ènìyàn fẹ́ jogún àwọn alówò funfun wa láti òkè òkun láti wa wúrà yíì ẹ̀re yíì bakan náà lójẹ́ ki a mò iye owó ti wúrà yi gbẹ́wòn ti o je 1billion us dollar enìkan ni ìdílé kookan ni o létò láti mo ibi tí wúrà yíì wa nínú eré yíì bakan náà arák...
gold statue
hadja saran daraba kaba hadja saran daraba kaba tí a bí ní ọdún 1945 jẹ alápon obínrin tí ìlú guinea àkọ̀wé àkọ́kọ́ tí olùdarí gbogbogbò tí mano river union àti olúdíje alákòso 2010 ní ìdìbò gbogbogbò guinea ní ọdún 2010 ìgbésìayé hadja saran daraba kaba ní a bí ní 1945 ní coyah guinea o ṣe ìkẹ́kọ̀ bí ilè elẹ́gbogi ní ...
islam bibi islam bibi pashtó ni ọdun 1974 - 4 oṣu karun ọdun 2013 jẹ ọlọpa obinrin kan ni afiganisitani ati pe o tun jẹ aṣáájú-ọnà ninu ija fun abo o jẹ arabinrin ọlọpa ti o ga julọ ni akoko iku rẹ ni afiganisitani o si ṣe awọn iṣiṣẹ si awọn talibans o gba awọn irokeke ikuwo si pa on ni oṣu keje ijo merin 2013 igbesi a...
lučka kajfež bogataj lučka kajfež bogataj tí a bí ní ọdún 1957 jẹ́ onímọ̀-jìnlẹ̀ ara ìlú slovenia àti olúdíje olúborí jojú nobel ní 2007 ìgbésì ayé a bí bogataj noi ọdún 1957 o parí ní ọdún 1980 láti àti gbà ìwé-èkọ́ dókítà láti olùkọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ isé ràle o jẹ́ awadi ati alámọ̀dájú ní unifásítì of ljubljana bogataj jẹ́ ...
nelsa cardoso nelsa cardoso ti a bi ni ọdun 1970 jẹ alamọdaju ara ilu brazil ati olukọ itan igbesiaye ti a bi ni ọdun 1970 ni ilu brazil o ni imo ni sciences lati ile eko universiti ni ilu brazil
àjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020
àsà ìgbéyàwó ní ilè yorùbá ìgbéyàwó jẹ́ ìsopọ̀ láàrin okùnrin àti obìnrin lati di eyokan láti jọ máà gbẹ́ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí oko àti aya àsà ìgbèyawó ní ilè yorùbá se kókó àwon babańlá wábọ̀ wọ́n ní “ìyàwó dùn ùn gbé omo dùn ùn ko jade” ìgbèyawó je àsà to se pataki ju omo bibi lo paapaa jùlo láyé óde òní eni ti o bà ti to l...
ọ̀fun ọ̀fun tí a tún mọ̀ sí ònfà óúnjẹ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà ara inú tí ó dàbí okùn oníhò tí ó ń ṣíṣẹ́ gbígbé óúnjẹ láti ẹnu lọ sí inú ikùn tí ó wà ní ara gbogbo ohun abẹ̀mi tí ó bá ti ń jẹ tàbí mu ohun kóhun fibromuscular ọ̀fun yí dà bí ahòho tí ó gùn ní ìwọ̀n mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n lára àgbàlagba ènìyàn tí ó rọra gba ...
àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 ní ilẹ̀ nàìjíríà ongoing covid-19 viral pandemic in nigeria ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2020 ni wọ́n kọ́kọ́ kéde láti fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ àkọ́kọ́ nípa àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 múlẹ̀ ní ilẹ̀ nàìjíríà nígbà tí wọ́n ṣe àyẹ̀wò fún ọmọ orílẹ̀-dè italy kan ni ìlú èkó tí àyẹ̀wò si fi hàn wípé ó ní àrùn...
gògóńgò gògóńgò ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹ́yà ara ìfọ̀ tí ó wà ní iwájú ọrùn gbogbo ẹranko elégungun iṣẹ́ rẹ̀ gògóńgò ni ó ń ṣàkóso bí ohun jíjẹ àti mímu kò ṣe ní gba òdì nípa ṣíṣètò ìyàtọ̀ láàrin ònfà ọ̀fun ohùn àti tááná tí ó gbé èémí jáde nígbà tí a bá ń jẹun lọ́wọ́ gògóńgò tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yí náà ni ó tún gbé ọ̀pá ẹ̀jẹ...
ẹranko elégungun ẹranko elégungun ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí subphylum ẹranko elégungun ma ń sábà ní chordates egungun ẹ̀yìn ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumchordata tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje 69963 níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn lála àwọn àkójọpọ̀ àwọ...
naira marley nigerian singer and songwriter naira marley tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gangan ń jẹ́ azeez fáṣọlá tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1994 9th may 1994 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin àti oǹpilẹ̀kọ̀wé-orin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ní ààrẹ ẹgbẹ́ olólùfẹ́ àgàbàgebè rẹ̀ tí wọ́n ń pè ní marlians ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ ...
billy dee williams william december billy dee williams jr ojoibi april 6 1937 je osere osere gbohungbohun ati oniseona ara amerika
shettima mustapha shettima mustafa ofr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1939 - 2022 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi mínísítà fún ètò ọ̀gbìn laarin ọdún 1990 sí ọdún 1992 ní ọdún 2007 wọ́n yan shettima gẹ́gẹ́ bi mínísítà fún àbò sínú ètò ìṣàkóso ti umaru yar'adua lẹh...
àsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbá aṣa oge ṣíṣe ní ilẹ yorùbá oge ṣíṣe jẹ́ ọ̀kan nínú àsà ilè yorùbá tí ó níse pẹ̀lú bí a tí se ń tún ara wà se àti bí a se mú ẹwà ara wà jáde àì mò ànfàní àti iyì tí o wà níbi oge ṣíṣe àti ṣíṣe ẹwà ní ilè yorùbá ni ìsọ̀rí ohun ti àwa ọ̀dọ́ ìwòyí ko fi pàtàkì oge ṣíṣe ní ayé òde òní tí a bá rí ...
2020 coronavirus pandemic ni ile naijiria
ayo fasanmi ayọrinde fasanmi tí a bí ní ọdún 1925-2020 jẹ́ onímọ̀ nípa òògùn àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé a bí ayọrinde fasanmi ní ọdún 1925 ní ìye èkìtì agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ ekiti ní guusu ìwọ-òòrùn nàìjíríà ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀kóbẹ̀rẹ̀ ti saint paul tí ó wà ní ebute mẹta àti ilé-...
tolu olukayode odugbemi
ambrose campbell ambrose campbell tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ ọládipúpọ̀ adékọ̀yà campbell tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1919 ó sìn kú lọ́jọ́ méjìlélógún oṣù kẹfà ọdún 2006 19 august 1919 22 june 2006 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin àti adarí orin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni wọ́n gbà pé ó jẹ́ olùd...
àsà ilà kíkọ ní ilé yorùbá àsà ilà kíkọ ní ilè yorùbá ilà kíkọ jẹ́ n kan pàtàkì tí àwọn ọmọ yorùbá fi ń dára wón mò ní ayé ojó òwe yorùbá kan so pe títa ríro ni a n kò ilà sùgbọ́n bí o bá jiná tán a di oge ní ìgbà àtijọ́ àsà ilà kíkọ jẹ ohun àmúyangàn àti ara oge ṣíṣe fún tọkùnrin-tobìnrin ní ilẹ̀ yorùbá bí a bá wo ojú...
ògbójú ọdẹ nínú igbó olódùmarè
ògbójú ọdẹ nínú igbó irúnmalẹ̀
ruth kadiri ruth kádírì jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé olùkọ fọ́rán àwòkà eré ìtàgé àti olùgbéré jáde ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ruth ní ọjọ́ kẹrìlélógún oṣù kẹta ọdun 1988 ní ìlú benin tí ó jẹ́ olú-ìlú fún ìpínlẹ̀ ẹdó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti yábàá tí ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa business ad...
ẹgbẹ́ olóṣèlúaráìlú àwọn aráàlù nàìjíríà
seni sulyman tahir omoseni seni sulyman bi ni ọdun 1985 jẹ otaja orilẹ-ede naijiria kan ati igbakeji alakoso ni andela imọ-ẹrọ agbaye bi iṣẹ iṣowo o bẹrẹ ni oludari awọn iṣẹ fun andela ni nigeria ati lẹhinna di alakoso orilẹ-ede ti ilu mẹfa ni oṣu mẹfa lẹhin naa sulyman tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti igbimọ awọn oludari ni fate fo...
cacovid cacovid jẹ́ àjọ tí àwọn oníṣòwò àti ilé-iṣẹ́ aládàáni dá sílẹ̀ láti ṣègbè fún ìgbógun tí àjàkálẹ̀ àrùn ẹ̀ràn kòrónà lórílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn pàràkòyí oníṣòwò bíi àlíkò dàńgótè fẹ̀mi ọ̀tẹ́dọlá ọ̀pọ̀ àwọn olówó mìíràn àti àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá-ńlá ní wọ́n gbìmọ̀pọ̀ dá àjọ yìí sílẹ̀ láti ṣe ìkówójọ fún àjọ ìjọba àpap...
ẹnu nínú ìmọ̀ ẹ̀yà ara ènìyàn ẹnu ni ẹ̀yà ara àkọ́kọ́ tí ó kángun sí ona ọ̀fun tí ohun jíjẹ àti ohun mímu ń gbà kọjá tí ó sì pèsè itọ́ fún ìrọ̀rùn ahọ́n kí ọ̀rọ̀ ó lè já geere gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara ìfọ̀ ẹnu ní agbára lati pèsè àti láti gba itọ́ dúró pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ epithelium tí ó wà nínú ẹnu lára iṣẹ́ rẹ̀ láti ẹnu ni iṣ...
ẹ̀yà ara ìfọ̀ ẹ̀yà ara ìfọ̀ tàbí ibùsọ̀rọ̀ ni àwọn ẹ̀ya ara kan tí ó dá wà fún ọ̀rọ̀ sísọ́ tàbí kí á lò wọ́n fún àgbékalẹ̀ èdè láti ẹnu àwọn èyà ara ìfọ̀ náà ni àwọn ìṣesí ẹ̀yà ara ìfọ̀ ìṣesí méjì ló wà fún àwọn ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó wà ìṣesí alkọ̀ọ́kọ́ ni
ètè ètè ni èyà ara tí ó jẹ́ àbáwọlé sí ẹnu ọmọnìyàn àti ẹranko tí fara hàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó mú kí orí ó pé níye ètè tún jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà ara tí ó ma ń lọ sókè sílẹ̀ sọ́tùn ún àti ósì yálṣ nígbà tí a bá ń jẹun mumi tàbí tàbí sọ̀rọ̀
ahọ́n muscular organ in the mouth of most vertebrates ahọ́n jẹ́ ẹ̀yà ara ìfọ̀ tí ó jẹ́ iṣan tí ó wà ní inú ẹnu ènìyàn tàbí ẹranko tí ó jẹ́ eléegun lẹ́yìn iṣẹ́ tí ahọ́n ń ṣe ahọ́n ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ya ara tí ọmọ ènìyàn ń lò fún ìbánisọ̀rọ̀ jíjẹ óúnjẹ tí gbogbo ẹranko tókù sì ń lò ní ìlànà kan náà yàtọ̀ sí ìbásisọ̀rọ̀ ...
itọ́ itọ́ ni omi ara tí ó ń sun láti ibùsun kan nínú ẹnu yálà lára ènìyàn tàbí ẹranko lára ènìyàn itọ́ tí ó ń sun tó ìdá 995 omi pẹ̀lú electrolytes kẹ̀lẹ̀bẹ̀ ẹ̀jẹ̀ funfun epithelial cells níbi tí dna ti ma ń sun jáde iṣẹ́ tí itọ́ ń ṣe itọ́ ma ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìbomirin ẹnu rínrin óúnjẹ ó sì tún ma ń ṣiṣẹ́ ìgbémì tí ó s...
stephanie mills stephanie dorthea mills ojoibi march 22 1957 je akorin akoro-orin ati osere ara amerika mills gbajumo nigba to kopa ninu ere oritage the wiz gege bi dorothy lati odun 1975 titi de 1977 orin re home lati inu ere na di onipo kinni ni amerika fun chart rb ati ikan ninu awon orin re to gbajumo julo mills gb...
cissy houston american singer emily cissy houston oruko idile drinkard ojoibi september 30 1933 je akorin soul ati gospel ara amerika houston gba ebun grammy ni emeji fun awon orin re houston ni mama akorin whitney houston iya-iya fun bobbi kristina brown aunti fun awon akorin dionne ati dee dee warwick ati ibatan akor...