raw_text
stringlengths
2
128k
steve ayorinde steve olúṣẹ̀yí ayọ̀rìndé tí wọ́n bí lọ́dún 1970 jẹ́ kọmíṣọ́nnà-àná fún ètò ìrìn-afẹ́ iṣẹ́-ọ̀nà àti àṣà tí ìpínlẹ̀-èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣáájú àkókò yìí ó jẹ́ kọmíṣọ́nnà nípa ìròyìn àti ọgbọ́n-ọnnú nígbà ìṣèjọba gómìnà-àná tí ìpínlẹ̀ náà akinwunmi ambode lọ́dún 2015 bákan náà ó ti fìgbà kan jẹ́ ọ̀gá-àg...
hannah ojo ajakaye hannah ojo ajakaiye jẹ́ akòròyìn orílé èdè nàìjíríà wọ́n yan-an gege bí print science journalist fún ọdún 201 láti gbà àmi ẹ̀yẹ nigeria academy of science èyí tí ó sì gbà àmi ẹ̀yẹ náà ìgbé ayé ojo ko gbọyè láti ilẹ ìwé fásitì tí ọbáfẹ́mi awólowó tí ilé -ifè ní orílé èdè nàìjíríà ní ọdún 2016 ojo gbà ...
national mirror nigeria daily newspaper national mirror jẹ́ ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ lórílẹ̀-èdè nigeria ọmọba emeka obasi ní ó dá ìwé-ìròyìn national mirror sílẹ̀ lọ́dún 2006 lára àwọn abala ìwé-ìròyìn náà ni daily mirror saturday mirror àti sunday mirror nígbà tí ó di ọdún 2008 agbẹjọ́rò jimoh ibrahim ra ìpín-ìdókòwò ilé...
motolani alake motolani olusegun alake tí a mọ̀ nípa iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí motolani alake jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ọ̀gá olórin oníṣòwò sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ akọ̀ròyìn olóòtú podcast àti olóòtú amóhùn-máwòrán ó sì tún jẹ́ alásọyé àṣà ìgbàlódé ó jẹ́ olóòtú àgbà ní pulse nigeria láti oṣù kẹta ọdún 2022 títí di oṣù kejìlá ọ...
stella din-jacob stella din-jacob jẹ alákóso media kan ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún jé oníròyìn ìgbóhùnsáféfé àti olóòtú ìròyìn ni tvc communications
sam amuka-pemu sam amuka pemu tí a bí ní oṣù kẹfà ojo ketala ọdún 1935 je oniroyin ni orile ede nàìjíríà òǹkọ̀wé ati òǹtẹ̀wéjádé aṣáájú nínú àwọn ìwé ìròyìn tí a mọ sì ìwé ìròyìn vanguard àti ti gbajumo ìwé ìròyìn punch ó jé ọmọ bibi ìlú sapele ni igobo to ìpínlè delta ni apa àríwá ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà gba owó olóògb...
ijeoma nwaogwugwu nigerian journalist ijeoma nwogwugwu jẹ́ òǹkọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ olùdásílẹ̀ alákòóso ti arise tv tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ìwé-ìròyìn thisday ó jẹ́ ayẹ̀ròyìn wò bákan náà ní ìwé-ìròyìn thisday ó jẹ́ òǹkọ̀ròyìn-bìnrin kejì nínú ìtàn ní o...
dusé mohamed ali dusé mohamed ali bey effendi 21 kọkànlá oṣù 1866 25 okufa 1945 دوسي محمد علي jẹ oṣere ara ilu sudan-egipti ati ajafẹtọ oloselu ẹniti o di olokiki fun ifẹ re ni orilẹ-ede afirika ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé eré òpìtàn oníròyìn olóòtú àti akéde ni ọdun 1912 o ṣẹda african times ati atunwo orient eyi ti a tun sọji ...
ikechukwu amaechi ikechukwu amaechi a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kínnií ọdún 1967 ó jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀ èdè naijiria akọ̀wé àti oníṣòwò ó jẹ́ olùdásìlẹ̀ ìwé ìròyiǹ theniche lórí aýe lujára ó wá láti ìjọba ìbílẹ̀ ahiazu-mbaise ní ìpínlẹ̀ imo naijiria ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí ikechukwu amaechi ní ọ...
mazi nwonwu nigerian author and journalist chiagozie fred nwonwu ẹni tí ó kọ̀wé lábẹ́ gègé orúkọ mazi nwonwu jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà alábòójútó àti ayẹ̀ròyìn wò ó pẹ̀lú àwọn olùdásílẹ̀ àti alákòóso ayẹ̀ròyìn wò ti omenana magazine ní ọdún 2017 wọ́n to orúkọ rẹ̀ wà lára ọ̀kan àwọn ènìyàn alágbára jàǹkàn-jàǹkà...
dusẹ́ mohammed ali
emotan emotan 15th century jẹ́ obìnrin olọ́jà tí ó ná ọjà oba ní ayé àtijó ní benin nígbà ìṣàkóso oba uwaifiokun àti omoba ogun ẹni tí ó sọ ara rẹ̀ ní oba ewuare the great lẹ́yìn tí ó di oba of benin òun ni ó bẹ̀rẹ̀ day care centre ní ìlú benin ìtàn àtenudẹ́nu sọ wípé ó ran oba ewuare lọ́wọ́ ní gbígba ìjọba benin lẹ́yì...
idia idia ni ìyá esigie ẹni tí ó jẹ́ oba àwọn ènìyàn edo láàrin ọdún 1504 sí 1550 àwọn onítàn mọ̀ pé idia wà láyé nígbà ogun idahogun náà wáyé láàrin ọdún 1515 sí 1516 nítorí ó kópa ribiribi láti mú ìṣẹ́gun benin wáyé ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì gbàgbọ́ pé òun ni igi lẹ́yìn ọgbà bí ọmọ rẹ̀ ṣe dé orí ìtẹ́ ó jẹ́ akíkanjú tó jà gidigid...
medina armino ethiopian long-distance runner medina deme armino jẹ elere sisa ti ọna jinjin ti órilẹ ede ethiopia ni ọdun 2019 ati 2020 medina yege ninu marathon ti xiamen to waye ni xiamen china àṣèyọri ni ọdun 2019 medina yege pẹlu wakati 22725 ni ọdun 2020 arabinrin gbiyanju lori wakati rẹ si 22612 ni ọ̀dun 2018 med...
leila aman leila aman ni a bini ọjọ kẹrin leelogun óṣu november ọdun 1977 ni arsi jẹ elere sisa ti ọna jinjin órilẹ ede ethiopia àṣèyọri ni ọdun 2003 leila kopa ninu ere gbogbo ilẹ afirica to waye ni abuja órilẹ ede naigiria ti arabinrin naa si gbè ipo kẹta ni ọdun 2004 leila kopa ninu marathon ti dubai ni bi ti arabin...
ivor agyeman-duah ivor agyeman-duah ti a bi òdún 1966 jẹ ọnmọwé ọ́mọ́ ilu ghana kan ònímọ̀-ọ́rọ́-àjé ònkọ́wé olòótú àtí ólúdárí fìímù ó tì ṣìṣẹ́ ní íṣẹ́ íjọ́bá ìlú ghana ó si ṣiṣẹ bi òlùdàmọ̀rán lórì ètò ìmùlò ìdàgbàsókè ígbésíàyé ábiị ivor agyeman-duah ni kumasi ghana ni ọdun 1966 à sì sọ́ l'orukọ lẹhin ọ̀rẹ́ baba rẹ ...
sin tax owó-orí ẹ̀ṣẹ̀ jẹ́ owó-orí tí a fúnni fún àwọn akitiyan tí a san ní pàtó lórí àwọn ẹrù kan tí a rò pé ó léwu sí àwùjọ àti àwọn ẹni-kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ọtí tábà oògùn àwọn adùn lílá àwọn ohun mímu àwọn oúnjẹ yára kọ́fì ṣúgà ayò àti àwọn àwòrán ìwòkuwò ní ìdákejì sí àwọn owó-orí pigovia èyítí ó ní láti sanwó fún ìb...
nwando achebe nwando achebe tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1970 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ajàfẹ́tọ́ obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni adarí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa kíkó ara ẹni mọ́ra ní college of social science tí ilé-ìwé michigan state university òun tún ni akọ̀ròyìn àgbà fún journal of west african history ìpìlẹ̀ rẹ̀ wọ́n bí...
ayoka olufunmilayo adebambo ayoka olufunmilayo adebambo jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òjògbón nínú títún àwọn àbùdá ẹranko ṣe àti ìmò ìṣiṣẹ́àbínimọ́ òun ni ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ìmò títún àbùdá ẹranko ṣe àti nínú ìmò ìsisẹ́àbínimọ́ ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2010 ó gba àmì-ẹ̀yẹ fellow of the anima...
laolu akande laolu akande jẹ́ akọ̀ròyìn olóòtú ọ̀mọ̀wé àti olùkọ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ òun ni agbẹnusọ fún igbákejì ààrẹ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìyẹn prof yemi osinbajo san ṣáájú kí ó tó di agbẹnusọ fún igbákejì ààrẹ akande ń jábọ̀ ìròyìn fún empowered newswire èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn kan tó wà ní orílẹ̀èdè amerika ó tún jẹ́...
elfrida o adebo elfrida o adebo tí orúkọ àbíso rẹ̀ jẹ́ olaniyan tí wọ́n sì bí ní ọdún 1928 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti núrsì ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1984 ó di ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ núrsì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ a bí adebo ní ìlú abeokuta ìpínlẹ̀ ògùn ní ọjọ́ kẹta osù kẹta ọdun 1928 ó bèrè ipa rẹ̀ nínú ...
folashade adefisayo folashade adefisayo jẹ́ olùkọ́ àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni kọmíṣọ́nà fún ẹ̀ka ìpínlè ẹ̀kọ́ tí ó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ ẹ̀tò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó lọ ilé ìwé yunifásítì ìlú ìbàdàn níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ bachelor nínú ìmò zoology lẹ́yìn náà ó te ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní yunifásitì ìpínlè èkó níbi tí ó ti...
kahina 7th century amazigh queen who resisted the umayyadsdihya tí wọ́n ń pè ní alkahinalárúbáwá ‎ jẹ́ ọbabìnrin ìlú berber ti aurès bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ olórí ẹ̀sìn àti olórí àwọn ológun tó tako muslim conquest of the maghreb agbègbè ti wọ́n pè ní numidia tẹlẹ̀ rí tí ó sì máa ń ṣégun àwọn ọmọ-ogun umayyad nínú ogun battle...
yennenga yennenga jẹ́ ọmọ-bìnrin àròsọ tí a kà sí ìyá ti àwọn ènìyàn mossi ti burkina faso arábìnrin olókìkí jagunjagun tí ó ṣe ìyebíye fún bàbá rẹ̀ naa gbewaa tàbí nedega olùdásílẹ̀ ìjọba dagbon ní báyìí ni ghana lónìí ṣùgbọ́n ọmọ-bìnrin ọba nífẹ̀ẹ́ sí àyànmọ mìíràn ó pinnu láti lọ kúrò ní ìjọba náà bí ó ti ń sáré pẹ̀...
anthonia adenike adeniji anthonia adenike adeniji tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1971 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ igbákejì ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò dídarí ọkọ òwò ní yunifásítì covenant ìpínlẹ̀ ogun nàìjíríà ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí adeniji ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-...
abubeker nassir abubeker nassir ahmed àmháríkì አቡበከር ናስር ti a bi 23 kínní 2000 jẹ agbabọọlu alamọdaju ara etiopia kan ti o ṣere bii iwaju fun mamelodi sundowns ni ajumọṣe bọọlu afẹsẹgba premier ati ẹgbẹ orilẹ-ede ethiopiao ṣe bọọlu tẹlẹ fun kofi etiopia ni ajumọṣe premier ethiopia
felicia adeyoyin felicia adebola adeyoyin tí a bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kọkànlá ọdún 1938 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ kínnií oṣù karùn-ún ọdún 2021 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní yunifásítì ìlú èkó àti ọmọ ọba ní ilé iji ní saki ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ òun ni ó kọ nigerian national pledge ìpìlẹ̀ rẹ̀ a bí felicia awujoola ní ọjọ́ kẹfà oṣù kọkànlá ...
women of owu
cordelia agbebaku cordelia ainenehi agbebaku tí a bí ní oṣù kínní ọdún 1961 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti adarí yunifásítì ambrose alli télèrí ìtàn ayé rẹ̀ wọ́n bí agbebaku ní ìlú ekpoma ní oṣù kínní ọdún 1961 ó kó nípa ìmọ̀ òfin ní yunifásitì bendel tí a mọ̀ sí yunifásitì ambrose alli lọ́wọ́ lọ́wọ́ agbebaku di adarí yunifásítì ambr...
anuket òrìṣà egypt àtijọ́ ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa òrìṣà egypt àtijọ́ fún ìtumọ́ míràn ẹ wo anuket ìṣojútùú anuket jẹ́ òrìsà àtijọ́ tí ô jẹ́ ọ̀kan láàárín àwọn òrìṣà orílè èdè egypt tí apá ilè nile àti ní ọwọ́ ìsàlẹ̀ gbogboògbò nubia èyí tí ó tún jẹ́ pé àwọn ará elephantine náà máa ń sìn etymology àwọn ará ilé egypt tàbí...
aqualtune aqualtune ezgondidu mahamud da silva santos fl 1665 jẹ́ ọmọ obìnrin tí ọba kàn tí wọn kò mọ orúkọ rẹ ní ìlú manikongo gẹ́gẹ́ bí àṣà ó jẹ́ ìyá ganga zumba ati ìyá tí ó bí ìyá zumbi ni ọdún 1665 aqualtune jẹ́ olórí ọmọ ogun ẹgbẹẹgbẹrun ọkunrin ati obinrin fún kongo lọsí ogun mbwila níbití ó tí ṣẹ́gun àwọn ọ̀ta ...
hiwot ayalew ethiopian long-distance runner hiwot ayalew yimer ni a bini ọjọ kẹfa óṣu march ọdun 1990 jẹ akọṣẹmọṣẹ elere sisa ti ọna jinjin to da lori steeplechase ti metres ẹgbẹrun mẹta ti órilẹ ede ethiopia hiwot ṣoju fun órilẹ ede ethiopia ninu ayẹyẹ ti olympics summer ti ọdun 2012 nibi to ti pari pẹlu ipo karun àṣè...
tigist assefa ethiopian long-distance runner tigist assefa tessema ni a bini ọjọ keji dinlọgbọn óṣu march ọdun 1994 jẹ elere sisa ọna jinjin lẹyin ti arabinrin naa kopa ninu marathon to waye ni oṣù kẹrin ọdun 2022 lo gbiyanju si lori iṣẹju meji dinlogun tigist kopa ninu marathon ti berlin nibi to ti gbe ipo karun àṣèyọ...
sofia assefa ethiopian long-distance runner sofia assefa ni a bini ọjọ kẹrinla óṣu november ọdun 1987 si ilu tenta south wollo jẹ elere sisa ti ọna jinjin to dalori steeplechase ti metres ẹgbẹrun mẹta sofia gba ami idẹ ọla ti silver ni summer olympics ti ọdun 2012 àṣèyọ̀ri sofia kopa ninu idije ilẹ afirica nibi to ti p...
meskerem assefa ethiopian runner colspan=3 style=text-aligncenter background-color#b0c4de| medal record colspan =3 meskerem assefa legesse wondimagegn ni a bini ọjọ ogun óṣu september ọdun 1985 si ilu robe arsi jẹ elere sisa ti ọna jinjin meskerem ṣọju fun órilẹ ede ethiopia ninu olympics ti ọdun 2008 ati 2012 àṣèyọri ...
lucy ameh lucy ameh tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà ọdún 1980 jẹ́ òṣeré àti oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣeré nínú ere braids on a bald head ní ọdún 2010 ayé àti èkọ́ rẹ̀ a bí lucy ní kaduna ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà ọdún 1980 ó bẹ̀rẹ̀ si ń ṣe eré ìtàgé nínú ilé ìjọsìn rẹ̀ nígbà tí ó sì ...
al-kahina 7th century amazigh queen who resisted the umayyads al-kahina lárúbáwá ‎ tí a mọ̀ sí dihya jẹ́ berber ọbabìnrin ti aurès àti adarí ẹ̀sìn àti àwọn ológun tí ó máa ń lé wájú àwọn aláàbò ọmọ ìlú sí muslim conquest of the maghreb ẹ̀sìn tí wọ́n padà mọ̀ sí numidia tí ó hàn pé wọ́n ń ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun umayyad ní...
rotimi williams rotimi williams jẹ́ àgbẹ̀ àti oníròyìn tẹ́lẹ̀ ó ní oko ìrẹsì kereksuk ni ipinle nassarawa tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìrẹsì ìṣowò kejì tí ó tóbi jùlọ ní orílẹ-èdè nàìjíríà nípasẹ̀ títóbi ilẹ̀ oko rẹ̀ èyítí ó wà ńi ìpínlẹ̀ nasarawa ní àríwá naìjíríà wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní àwọn saare 45000 àti pé ó gba bíi òṣìṣẹ́ 600 t...
anne bonny anne bonny8 oṣu kẹta ọdun 1697 - sọnu ni oṣu kẹrin ọdun 1721 igba kan anne bonney jẹ ajalelokun irish ti n ṣiṣẹ ni caribbean ati ọkan ninu awọn ajalelokun obinrin diẹ ninu itan-akọọlẹ ti o gbasilẹ ohun kekere ti a mọ nipa igbesi aye rẹ wa ni pataki lati inu iwe captain charles johnson's 1724 a general histor...
umar sani umar sani ọjọ́ karùn-úndínlọ́gbọ̀n oṣù ṣẹrẹ ọdún 1963 ní wọ́n bí i jẹ́ olùdámọ̀ràn àgbà lórí ìròyìn àti ìpolongo sí igbákejì olórí orílẹ̀-èdè nàìjíríà namadi sambo ó ti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ sí sambo's láti ọdún 2007 nígbà tí sambo jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà ní ìpínlè kaduna ó wà lára àwọn tí wọ́n tí wọ́n polo...
ernest okonkwo ernest okonkwo tí a bí ní ọdún 1936 jẹ́ akọ̀ròyìn eré ìdárayá àti oníròyìn tí ó ṣiṣẹ́ ní radio nigeria ó kú ní oṣù kẹjọ ọjọ́ 7 ọdún 1990
minna salami minna salami tí a bí ní 1978 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ nàìjíríà ará ìlú finland kan tí ó ti tan àlàyé lórí àwọn ọ̀ràn abo tí áfíríkà nípa àwọn orílẹ̀-èdè áfíríkà àti àwọn obìnrin nàìjíríà nípasẹ̀ búlọ́ọ̀gì tí ó gba ẹbun msafropolitan èyí tí ó ṣẹ̀dá àti tí n ṣatọ́kùn láti ọdún 2010 àwọn ọ̀ràn tí ó wà láàárín nínú b...
funmi wakama a bí funmi wakama ní ìlú èkó ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù keje ọdún 1966 gẹ́gẹ́ bíi olufunmilayo yetunde coker ó bẹ̀rẹ̀ iṣé akọ̀ròyìn rẹ̀ ní ọdún 1985 gẹ́gẹ́ bíi akọ́ṣẹ́ ní lagos television ltv 8 lagos kí ó tó lọ sí nigeria television authority abeokuta ní ọdún 2018 ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti ìlú og...
adebola williams adebola williams abíi ní ọdún 1986 ó jẹ́ ọmọ orile-èdè nigeria tí ó ń ṣe òwò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ akọ̀ròyìn olùgbaninímọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú àti olùsọ̀rọ̀-ìwúrí òun ni olùdarí-àgbà fún ẹgbẹ́ red | for africa ó jẹ́ olùjọdásílẹ̀ àti alámòjútó red africa ilé iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ó ṣe agbátẹrù àwon ọ̀dó jùl...
olukorede yishau olukorede s yishau jẹ́ òǹkọ̀wé àti akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà ó ti ṣe atokọ pípẹ́ fún ẹ̀bùn 2021 nà̀ij̀iríà fún litiréṣọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé re àti iṣẹ́ a bí yishau ni ṣomolu ní ̀ipínlẹ̀ èkó ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbánisọ̀rọ̀ púpọ̀ ní ambrose alli university ekpoma ó ti ṣiṣẹ́ bí oníṣẹ́ ìròyìn ní orísun ...
bayo onanuga bayo onanuga ọjọ́ ìbí ogún oṣù kẹfà ọdún 1957 jẹ́ oníròyìn ọmọ nàìjíríà ó dá ìwé ìròyìn thenews sílẹ̀ àti pé ó jẹ́ olùdarí ti news agency of nigeria nípasẹ̀ ààrẹ muhammadu buhari ní may 2016 ṣáájú èyí ó jẹ́ alákòóso àti olóòtú àgbà tí pm news àti thenews ìròyìn ìpìlẹ̀ a bí onanuga sí inú ìdílé apàṣẹ anikil...
tolu ogunlesi tolu ogunlesi jẹ́ ẹni tí a bí nínú ọjọ́ kẹ̀ta oṣù kẹ̀ta ọdún 1982 oníròyìn ti ìlu nigeria ni ń ṣẹ ó tún jẹ́ akéwì àti ayaworan akọ̀wé ẹ̀fẹ̀ àti ògbóntarìgì nínú lílo ayélujára ogunlesi jẹ́ ẹni ti ààrẹ muhammadu buhari yàn sí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olùṣe ẹ̀rọ ayélujára titun ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejì ọdún 201...
ruth osime ruth osime tí a bí ní ọjọ́ keje osù kejì ọdún 1964 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ́-èdè nàìjíríà ó ti figba kan jẹ́ olóòtú ìwe thisday style magazine ri ti o jẹ́ ìwé ìròyìn tí ó ní se pẹ̀lú oge síṣe ìgbésí ayé rẹ̀ ruth osime ni ọmọ chief grace osime o si ni awọn àbúrò obìnrin méjì grace osime àti omome osime-oloyede...
victor oladokun victor oladokun tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ victor bandele oladokun ó jẹ́ oníròyìn àti elétò ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ ní nigeria àti united kingdom ó jẹ́ olùdarí fún ìbánisọ̀rọ̀ àti ìbáṣepọ̀ àwọn ará ilẹ̀ òkèrè african development bank afdb ó sì tún jẹ́ aṣagbátẹrù àti olùgbàlejò fún gbajúgbajà ètò magasíìnì lórí a...
eniola akinkuotu eniola akinkuotu ọdún ìbí rẹ̀ ni 1986 jẹ́ akọ̀ròyìn àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní fásitì èkó university of lagos iṣẹ́ rẹ̀ iṣẹ́ akinkuotu gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn tàn káàkiri oríṣiríṣi ìlúó ṣe àtẹ̀jáde púpò lórí àwọn ìtàn tí ó rọ̀ mọ́ ọ̀ràn àti ìlòdì sí ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn láàárín ọdú...
adekunle ojora chief adekunle ojora tí a bí ní ọdún 1936 jẹ́ òṣìṣẹ́ ìṣọwó nàìjíríà kan tí ó jẹ́ alágà ìgbìmọ̀ ti agip nigeria limited láti ọdún 1971 títí di ìgbà tí unipetrol fi gbà ní 2002 ó bẹ̀rẹ̀ ìṣe-ṣíṣe gẹ́gẹ́ bíi oníṣẹ́ ìròyìn pẹ̀lú bbc ní ìbẹ̀rẹ̀ 1950s ní 1962 ó di aláṣẹ tí uac àti ní àkókò 1970s àwọn ọdún 1970 ...
neith neith ó jẹ́ èyí tí ó ba ni lẹ́rù coptic ⲛⲏⲓⲧ bákannáà jẹ́ èpè nit net tàbí neit jẹ́ àwọn ancient egyptian deity ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ wọ́n sọ pé ó alàkọ́kọ́ àti olú aṣẹ̀dá tí ó dà àgbáyé àti gbogbo àwọn ohun inú rẹ̀ tí ó sì ń ṣàkóso bí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ ó jẹ́ òrìṣàbìnrin fún àgbáyé àyàmọ̀ ọgbọ́n omi àwọn odò àwọn ìyá ọ...
richard akinnola richard akinnola jẹ́ on kàwé tí nàìjíríà onkowe agbejoro àti àjàrà gbàrà ó jẹ́ ayé ìwé wò tí ìwé ìròyìn vanguard àti adarí agbófinró tí ilé ìṣe centre for free speech organisation ó ṣe akojopo àwọn ìwé fún ilé ìṣe agbo ohùn fún afẹ́fẹ́ àti onkowe fún àwọn ìwé oríṣiríṣi
mason mount mason tony mount tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 1999 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílé-èdè england ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù olówó ààrin fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù chelsea nínú ìdíje premier leagu àti fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù 3 lions tí ìlu england mount bẹ̀ẹre sí gbá bọ́ọ̀lù àwọn àgbàlagb pẹ̀lu ìpìlẹ̀ a bí mason tony m...
arukaino umukoro nigerian journalist arukaino umukoro je akọ̀wé lá tí orílẹ̀de nàìjíríà tí a mọ fún bíborí cnn/multichoice africa journalist award ni ọdún 2015 ìwé kíkà umukoro kàwé gboyẹ̀ nínú industrial chemistry ni fáṣítì ti ìlú delta ó túbọ̀ lọ sí the nigerian institute of journalism tí ó sì sàsẹ́yege ìwé kíkà naa ...
richard akinnola
duro onabule duro onabule 27 september 1939 16 august 2022 jẹ́ akoroyin ọmọ nigeria tí ó jé olootu fún national concord láti ọdún 1984 sí ọdún 1985lẹ́yìn náà o di ìgbésíayé àti ise re a bí onabule ní ọdún 27 september 1939 ní ìjẹ̀bú- òde ó jáde ilé ìwé cms grammar school àti ilé ìwé journalism london isẹ àkọ́kọ́ rẹ jẹ́...
ruth osime
anne bonny
kọ́lá túbọ̀sún
sekhmet ancient egyptian goddess nínú àwọn ìtàn-àkọọlẹ ara egypt sekhmet tàbísachmis láti jẹ́ jagunjagun òrìṣà àti oníṣègùn oogun òrìṣà sekhmet jẹ́ òrìṣà tí oòrùn nígbà mìíràn à ń pè ní ọmọbìnrin tí òrìṣà ra bí àti pé ó nigba mìíràn ó ní nkán ṣẹ pẹ̀lú àwọn òrìṣà hathor àti bastet bibliography <templatestyles src=refbeg...
cleopatra cleopatra vii philopator jẹ́ ọbabìnrin ptolemaic tí orílẹ̀-èdè ẹ́gíptì ayéijọ́un láàrin ọdún 51 sí 30 bc ó jẹ́ ọmọ ìran ptolemaic àti ọmọ ẹni tí ó pilẹ̀ ìran náà ptolemy i soter ẹni tó jẹ́ ológun àti ọ̀rẹ́ alexander the great lẹ́yìn ikú cleopatra egypt di ọkàn lára àwọn orílẹ̀ èdè tí ó wà lábé ìjọba ìjọba róm...
journalism iṣẹ́ ìròyìn jẹ́ kíkọ àti pínpínká àwọn àpilẹ̀kọ bíi ìtàkurọ̀sọ ìṣẹ̀lẹ̀ òkodoro-ọ̀rọ̀ ìròrí àti àpilẹ̀kọ nípa àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹyọ nínú ìròyìn ojoojúmọ́ láti fi ṣe ìfitónilétí fún àwọn ènìyàn àwùjlóòrèkóòrè gbólóhùn ìròyìn jẹ́ ohun tí a lè fi sọrí àwọn tí wọ́n ń kó ohun tí a mọ̀ sí ojúlówó ìròyìn jọ kí et...
degitu azimeraw ethiopian long-distance runner degitu azimeraw asires ni a bini ọjọ kẹrin leelogun óṣu january ni ọdun 1999 jẹ elere sisa lóbinrin ti ọna jinjin órilẹ ede ethiopia àṣèyọri ni ọdun 2019 degitu kopa ninu marathon ti amsterdam nibi to ti gbe ipo akọkọ pẹlu akọsilẹ ti 21926 ni ọdun 2019 arabinrin naa kopa n...
workitu ayanu workitu ayanu gurmu ni a bini ọjọ kọkan dinlógun ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ ethiopia to da lori metres ẹgbẹrun marun àṣèyọri workitu kopa ninu idije agbaye ti iaaf cross country pẹlu ipo kẹrin ninu ere junior ti awọn óbinrin ni ọdun 2004 to si gbè pari pẹlu ipo kẹfa ni ọdun 2005 ati 2006 ni ọ...
wude ayalew ethiopian long-distance runner wude ayalew yimer ni a bini ọjọ kẹrin óṣu july ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ ethiopia ni ọdun 2009 arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ninu idije agbaye lori metres ẹgbẹrun mẹwa àṣèyọri ni ọdun 2006 wude kopa ninu idije agbaye ti cross country nibi to ti pari pẹl...
atsede bayisa ethiopian long-distance runner atsede bayisa tesema ni a bini ọjọ kẹrin dinlogun óṣu april ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ ethiopia to da lori ayẹyẹ sisa ere loju ọna bayisa yege ninu marathon ti chicago marathon ti boston ati marathon ti paris lẹẹmeji àṣèyọri atsede ṣoju fun órilẹ ede ethiopia...
grace o'malley pirate queen chieftain of the ó máille clan gráinne o'malley pípè rẹ̀ ní èdè irish ɡɾˠaːn̠ʲə 'grawn-ya' c 1603 tí wọ́n sì mò sí grace o'malley jẹ́ olórí ìjọba ó máille tí ìwọ̀-oòrùn ireland àti ọmọ eóghan dubhdara ó máille lẹ́yìn ìgbà tí bàbá rẹ̀ kú ó bẹ̀rẹ̀ sí ní máa ṣàkóso àwọn ilẹ̀ àti òkun bí ó tilẹ̀...
muhammad garba muhammad garba jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn nàìjíríà àti òṣèlú láti ìpínlẹ̀ kano tí ó jẹ́ kọmísọ́nà fún ìkéde àti ẹgbẹ́ kọmití international federation of journalists ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí muhammad ní ọjọ́ kejìlẹ́lógún oṣù kọkànlá ọdún 1965 ní agbẹ̀gbẹ̀ yakasi kano principal tí of ipinle kano ó lọ sí ilé-ìwé àk...
aisha abubakar abdulwahab dr aisha abubakar abdulwahab tí a bí ní ọdún 1971 jẹ́ ọlọ́pá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí unesco fún ní ẹ̀bùn owó láti ṣe ìwádìí nípa ààrùn ikó ààrùn tuberculosis ayé rẹ̀ a bí aisha abubakar abdulwahab ní ọdún 1971 ó sì dara pọ̀ mọ́ egbé ọlọ́pá nàìjíríà ní ọdún 1995 ó ní àmì ẹyẹ nínú ìmò veterin...
gbenga adefaye gbenga adefaye jẹ́ akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè nàìjíríà alákòóso àti ọ̀jọ̀gbọ́n ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn pẹ̀lú ìrírí fún ọgbọ̀n ọdún ní ilẹ̀-iṣẹ́ ìròyìn nàìjíríà òun ni olórí àwọn olóòtú fún vanguard media ìwé ìròyìn àti olórí ní nigerian institute of journalism àti wí pé ó ti fi ìgbà kan jẹ́ ààrẹ fún nigerian guild...
florence obi banku
alemitu bekele aga alemitu bekele aga ti a bini ọjọ kèji leelogun óṣu august ọdun 1976 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede ethiopia to da lori ere sisa ti idaji marathon àṣèyọri ni ọdun 1998 aga kopa ninu idija agbaye ti cross country ni marrakech morocco nibi to ti gbe ipo keji ninu idije ẹgbẹ ni ọdun 2008 arabinrin n...
alemitu bekele degfa turkish long-distance runner alemitu bekele degfa ni a bini ọjọ kejila óṣu september ọdun 1977 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ethiopia to da lori metres ti ẹgbẹrun marun àṣèyọri bekele pari pẹlu ipo keje ninu ere olympic ti ọdun 2008 ni ọdun 2009 arabinrin naa gba ami ẹyẹ ọla ti wura ninu idije ti...
mekdes bekele ethiopian steeplechase runner mekdes bekele tadese ni a bini ọjọ ogun óṣu january ọdun 1987 jẹ elere sisa lobinrin to da lori steeplechase ti ẹgbẹrun mẹta metres àṣèyọri ni ọdun 2006 mekdes kopa ninu idije agbaye ti junior ti beijing china to si gba ipo kẹta ninu metres ti ẹgbẹrun mẹta ni ọdun naa arabinr...
tadelech bekele ethiopian long-distance runner tadelech bekele ni a bini ọjọ kọkanla óṣu april ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ ethiopia àṣèyọri ni ọdun 2012 tadelech yege ninu idaji marathon ti české budějovice pẹlu wakati 11054 ni ọdun naa arabinrin naa yege ninu prague grand prix to jẹ ere ti ẹgbẹrun marun pẹ...
meseret belete meseret belete tola ni a bini ọdun kẹrin dinlọgbọn óṣu september ọdun 1999 jẹ elere sisa lobinrin arabinrin naa ṣóju fun ilẹ ethiopia ni ere ilẹ afirica ni ọdun 2019 ni rabat meseret gba ami ẹyẹ ọla ti idẹ ninu idaji marathon ti awọn óbinrin àṣèyọri ni ọdun 2018 meseret yege ninu idaji marathon ti gothen...
mimi belete ethiopian-born bahraini runner mimi belete gebregeiorges ni a bini ọjọ kẹsan óṣu june ọdun 1988 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede ethiopia to da lori ere sisa ti arin ati ọna jinjin arabinrin naa gba órukọ metres ti ẹgbẹrun marun ninu ere ilẹ asia ti ọdun 2010 àṣèyọri ni ọdun 2009 mimi yege ninu idije ti ...
ameyo adadevoh ameyo stella adadevoh tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ̀wá ọdún 1956 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ kàndínlọ́gún oṣù kẹjọ ọdún 2014 jẹ́ onímọ̀ ìṣẹ́gun òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ènìyàn ma ń ròyìn rẹ̀ fún ipa tí ó kó nínú mímú owó ààrùn ebola virus balẹ̀ ní nàìjíríà nípa mímú ẹni àkọ́kọ́ tí ó k...
ado ahmed gidan dabino hausa writer and director b 1964ado ahmad gidan dabino mon jẹ́ akọ̀wé èdè haúsá nàìjíríà òǹkọ̀wéatẹ̀wétàoníròyìn òǹtẹ̀-fíìmù jáde akojú fíìmù àti ọ̀ǹseré ó kọ eré fún bi ọgbọ̀n ọdún lórí àkorí oríṣiríṣi ó ti ṣe àtẹ̀wétà fún ìwé nóvẹ̀lì mẹ́ẹ̀dọ́gún ó gba oyè member of the order of the niger mon ẹ̀...
gelete burka ethiopian runner gelete burka bati ni a bini ọjọ kẹta leelogun óṣu january ọdun 1986 jẹ elere sisa lobinrin ilẹ ethiopia to da lori ere sisa ti arin ati ọna jinjin abi arabinrin naa si kofele zone ti arsi ni oromia àṣèyọri gelete kopa ninu idije agbaye ti iaaf ni ọdun 2006 arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti ọla ...
sinke biyadgilgn sinke dessie biyadgilgn ni a bini ọdun 1995 jẹ akọṣẹmọṣẹ elere sisa lóbinrin ta bisi órilẹ ede ethiopia to sin gbe ni washington d c àṣèyọri ni 2018 sinke kopa ninu marathon ti ibeji pẹlu wakati 23304 nibi to ti gba ẹbun owo ti 7500 ni ọdun 2016 sinke kopa ninu ere sisa ti mile maarun pẹlu wakati 2651
tadelesh birra ethiopian long-distance runner tadelesh birra ni a bini ọjọ kẹrin leelogun óṣu april ọdun 1975 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ ethiopia arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti marathon awọn óbinrin to da lori ere sisa to waye ni edmonton alberta canada ni ọdun 2001 àṣèyọri tadelesh yege ninu ere awọn óbinr...
irene ighodaro irene ighodaro ti a bi ni ojo kerindinlogun osu karun odun 1916 ti o si fi aye sile ni ojo kandinlogbon osu kokanla odun 1995 je omo eya croele ni orile ede siẹrra léònè ati onisegun oyinbo eni ti o je obinrin akoko lati di oníwòsàn ni orile ede siẹrra léònè
yolanda george-david yolanda george-david tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí aunt landa jẹ́ dókítá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ dókítà tó ní ìmọ̀ púpò nípa iṣẹ́ abẹ ọpọlọ ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ yolanda bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣisẹ́ láti ran àwọn ènìyàn lọ́wọ́ nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ó kàwé gboyè ní yunifásitì ti pittsburgh pittsb...
bezunesh bekele ethiopian long-distance runner bezunesh bekele sertsu ni a bini ọjọ kọkan dinlọgbọn óṣu january ọdun 1983 jẹ elere sisa lóbinrin órilẹ ede ethiopia to da lori marathon àṣèyọri bekele kopa ninu ere ti montferland ni ọdun 2004 ati 2005 ni ọdun 2006 arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti iaaf cross countr...
amane beriso ethiopian long-distance runner amane beriso shankule ni a bini ọjọ kẹtala óṣu october ọdun 1991 jẹ̀ elere sisa lobinrin ilẹ ethiopia ni ọdun 2022 arabinrin naa kopa ninu marathon ti valencia ni bi to ti gbe ipo kẹta aṣèyọri amane beriso yege ninu idaji marathon ti copenhagen ni ọdun 2014 ni ọdun 2015 amane...
summit university offa summit university offa
berhane adere ethiopian long-distance runner berhane adere debala ni a bini ọjọ kọkan leelogun óṣu july ọdun 1973 jẹ elere sisa lobinrin to ti fẹyinti ti órilẹ ede ethiopia to da lori metres ti ẹgbẹrun mẹwa ati marathon àṣèyọri ni ọdun 2001 ati 2005 berhane gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ninu idije agbaye ni ọdun 2002 ar...
ola brown olamide brown tí a bí ní ọdún 1986 jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílè-èdè nàìjíríà mọ́ ilẹ̀ọba britain oníṣòwò ọ̀lùdásílẹ̀ doctors healthcare investment group àti adarí greentree investment company flying doctors healthcare group jẹ́ ilé-isẹ́ tí ó ń ṣètò gbígbé àwọn ènìyàn tí ó nílò ìtójú ìlera ara ní kíákíá lọ sí...
ngozi alaegbu ngozi alaegbu jẹ́ akọròyìn àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ó ti ṣiṣẹ́ ní degue broadcasting network dbn television continental tvc lọ́wọ́lọ́wọ́ ó sì ń ṣịṣẹ́ pẹ̀lú arise tv ìgbésíayé rẹ̀ alaegbu kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ german ní university of hamburg germany ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ ṣíṣẹ iṣẹ́ pẹ̀l...
segun bucknor segun bucknor tí wọ́n bí ní 29 march 1946 tó sì kú ní 11 august 2017 jẹ́ olórin ilẹ̀ nàìjíríà àti akọ̀ròyìn láàárín ọdún 1960 àti 1970 ó jẹ́ ajẹdùrù àti atẹgìtá tó dájú lé àwọn ẹ̀yà orin ti tẹ̀mí pọ́ọ̀pù àti funk látàri iṣẹ́ kékeré wọn segun àti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin jọ ṣe àgbéjáde orin ẹlẹ́yàmẹyà tó dálé àṣ...
agnes yewande savage agnes yewande savage tí a bí ní ọjọ́ kànlẹ́lógún oṣù kejì ọdún 1906 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ keje oṣù kẹsàn-án ọdún 1964 jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti obìnrin àkọ́kọ́ ní ìwọòrùn áfíríkà láti di dókítá alábẹ́rẹ́ savage jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ áfríkà láti gba ...
lítíréso alohun litireso alóhùn litireso alóhùn ni àwọn ewì atenudenu tí a jogun láti enu àwọn bàbà ńlá wa ohùn ẹnu ni a fi ń gbé litireso jáde a kii kọ sílẹ̀ rara litireso alohun kún fún ọgbọ́n ìmò àti òye àgbà nígbà tí ìmọ mọọ - kọ mọọ - ka kò tíì dé ilẹ̀ wa oun ni àwọn baba ńlá wa ń lò litireso alohun pin si ona met...
amina bilali amina ally bilali jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède tanzania tí ó ṣeré ipò àárínlórí pápá fún yanga princess àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin tanzania isẹ́ òkè-òkun ally di olórí ẹgbẹ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin tanzania ní ìdíje cosafa women’s championship ti ọdún 2020 àti ìdíje cosafa women’s cham...
aisha masaka aisha masaka tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀wá oṣù kọkànlá ọdún 2003 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún bk häcken ní damallsvenskan àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti ilẹ̀ tanzania isẹ́ ẹgbẹ́ masaka ti ṣeré fún àwọn ọ̀dọ́ afirika ní tanzania isẹ́ òkè-òkun masaka ti sojú fún tanzania...
opah clement opah clement tukumbuke sanga tí a bí ní ọjọ kẹrìnlá osù kejì ọdún 2001 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún simba queens ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin simba ti ilẹ̀ tanzania àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin tanzania isẹ́ òkè-òkun clement ti sojú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀l...
janeth shija janeth shija simba jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó jẹ́ asọ́lé lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù simba queens àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti tanzania gbígbábọ́ọ̀lù fún orílẹ̀ èdè rẹ̀ ní ọdún 2019 shija darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn obìnrin tanzania tí ó wà lábẹ́ ogún ọdún fún ìdíje àkọ́kọ́...
asha rashid asha rashid jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó gbá ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin fún orílẹ̀-èdè tanzania
peter enahoro peter enahoro ojoibi 21 osu kinni 1935 je onise iroyin onkọwe onisowo ati akede naijiria tun mo nipa awọn pen orukọ ti peter pan nitori awọn gbajumo re iwe ni new african irohin labẹ ti orukọ a ti ṣe apejuwe rẹ gẹgẹbi “boya akọroyin agbaye olokiki julọ ni afirika igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ peter osajele aiz...