raw_text
stringlengths
2
128k
tunde eso tunde eso tí a bí ní ọjọ́ 16 oṣù august ọdún 1977 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdẹ̀ nàìjíríà alásọyé nípa ọ̀rọ̀ àwùjọ àti olóòtú ìwé-ìròyìn findout ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ pdp tó díje dupò gómìnà ipinle osun ní ọdún 2018 eso ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ youthocracy ààrẹ fix nigeria group àti òǹkọ̀wé àwọn ìwé african security solu...
tam fiofori tam fiofori tí a bí ní ọdún 1942 tí a tún mọ̀ sí “ uncle tam ” jẹ́ ayàwòrán ìtàn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó gbajúgbajà fún àwọn àwo-orin rẹ̀ tí ń sọ ìtàn-àkọọ́lẹ̀ nàìjíríà fiofori tún jẹ́ òṣèré fíìmù òǹkọ̀wé alárìíwísí àti olùdámọ̀ràn lórí media àwọn kókó inú fíìmù rẹ̀ pẹ̀lú àwọn olórin nàìjíríà biodun olaku...
ado ahmad gidan dabino ado ahmad gidan dabino jẹ́ òǹkọ̀wé èdè hausa òǹkọ̀wé akéde oníròyìn olùṣe fíìmù olùdarí àti òṣèré fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kọ̀wé fún bíi ọgbọ̀n ọdún lórí àwọn àkọ́lé oríṣiríṣi ó ti ṣàgbéjáde àwọn ìwé ìtàn àròsọ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ member of the order of the niger mon ní ọjọ́ kọk...
shaibu husseini shaibu husseini tí a bí ní ọjọ́ 4 oṣù kejìlá ọdún 1970 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tún jẹ́ olórin alábòójútó àṣà pr àti agbaninímọ̀ràn lórí ẹ̀rọ ayélujára àti olùtọ́jú fíìmù ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ mass communication ní university of lagos ó sì ti kàwé ní lagos state university school o...
chris ihidero chris ihidero tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gún oṣù kẹta ọdún 1976 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó ń gbé fíìmù jáde òun ni olórí òǹkọ̀wé àti olóòtú mnet ìtàn ìgbésí ayé ẹ̀ ihidero kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ literature-in-english láti yunifásitì ìpínlẹ̀ èkó àti ní yunifásitì ìlú ìbàdàn ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ó ...
adewale maja-pearce adewale maja-pearce tí a bí ní ọdún 1953 jẹ́ òǹkọ̀wé akọ̀ròyìn àti lámèyítọ́ tó gbajúgbajà fún àwọn àròkọ rẹ̀ ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé bíi my father's country ní ọdún 1987 àti the house my father built ní ọdún 2014 àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé onítàn ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ adewale maja-pearce ní ...
may ellen mofe-damijo may ellen ezekial mofe-damijo 1956 - 1996 tí a tún mọ̀ sí mee jẹ́ akọ̀ròyìn àti òǹkọ̀wé tó ṣàtẹ̀jáde classique magazine ìwé-ìròyìn náà gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ akọ̀ròyìn bíi dele momodu ben charles obi àti rudolf okonkwo mofe-damijo tún kọ àwọn ìwé díẹ̀ bíi dream maker àti center spread
moky makura moky makura jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọ̀ròyìn òṣèrébìnrin àti oníṣòwòbìnrin tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí africa no filter èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí àyípadà tó ń bá ilè africa látàri ẹ̀rọ ayélujára ìgbésí ayé wọ́n bí makura ní èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìdílé akisemoyin èyí tó jẹ́...
joy ogwu joy uche angela ogwu tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1946 jẹ́ mínísítà nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí àti asojú nàìjíríà sí ẹgbẹ́ united nations ní new york láàrin ọdún 2008 sí 2017 òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti jẹ́ asojú sí egbẹ́ united nations làti orílẹ̀-èdè nàìjíríà kí ó tó di mínísítà ogwu tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀...
reubeni muoka reuben muoka jẹ́ olóòtú ìbánisọ̀rọ̀ fún vanguard newspaper nígbà kan rí ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà fún nigeria first mobile telephone operator lọ́wọ́lọ́wọ́ ó jẹ́ olùdarí public affairs fún nigerian communications commission ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ muoka kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ tíátà ní university of...
otosirieze obi-young otosirieze obi-young tí a bí ní ọdún 1994 jé òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria olóòtú àti akọ̀ròyìn ó jẹ́ olóòtú àgbà fún open country mag èyí tó jẹ́ ìwé-ìròyìn tó sọ nípa ilẹ̀ africa àti àwọ lítíréṣọ̀ rẹ̀ ó jẹ́ olóòtú ti folio nigeria èyí tó jẹ́ apá kan cnn tó ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́-ọnà orílẹ̀-èdè naiji...
reuben muoka reuben muoka jẹ́ olóòtú ìbánisọ̀rọ̀ fún vanguard newspaper nígbà kan rí ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà fún nigeria first mobile telephone operator lọ́wọ́lọ́wọ́ ó jẹ́ olùdarí public affairs fún nigerian communications commission ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ muoka kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ tíátà ní university of ...
ogechukwukanma ogwo ogechukwukanmawes ogwo jẹ́ olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti olóòtú orí rédíò tó ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi olóòtú ètò orí brilla fm lẹ́yìn tó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú raypower fm ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olóòtú ètò orí rédíò fún bíi ọdún méjìlá ó bẹlrẹ̀ pẹ̀lú ètò kan tọ́ pẹ̀ ní 'straight from the heart' lórí raypower fm n...
malcolm ohanwe malcolm ohanwe tí wọ́n bí ní ọdún 1993 ní munich jẹ́ akọroyin ará german-nigerian gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán eniyan media ati agbalejo tv ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ malcolm ohanwe tí wọ́n bí ní munich ní germany ìyá rẹ̀ jẹ́ ará palestine nígbà tí bàbá rẹ̀ sì jẹ...
chris okolie chris maduabrochukwu okolie tí wọ́n bí ní ọdún 1949 tí ó sì kú ní ọdún 2007 jẹ́ olùpolówó eré orin naijiria àti aṣàtẹ̀jáde ìwé tí ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ new breed organization àti aṣàgbéjáde ìwé-ìròyìn new breed ìgbésí ayé rẹ̀ okolie bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùpolówó orin ní àwọn ọdún 1960 tó ń ṣègbélá...
yusuph olaniyonu yusuph adebola olaniyonu jẹ́ akọroyin agbẹjọ́rò àti alábòójútó tó ń ṣiṣẹ́ bíi olùdámọ̀ràn pàtàkí lórí media àti ìpolówó sí ààrẹ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ naijiria bukola saraki ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ yusuph olaniyonu ni wọ́n bí sí ìlú èkó ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1966 ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ogun s...
dapo olorunyomi oyedapo oyekunle dapo olorunyomi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1957 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdẹ̀ naijiria òun ní olóòtú àgbà fún ìwé-ìròyìn premiun times èyí tí ń ṣe ìwé-ìròyìn ti ilẹ̀ nàìjíríà òun kan náà ni olùṣàkóso àgbà fún premium times fún investigative journalism ptcij òun ni olùdarí ...
kolade dominate olowu victor akolade olowu tí wọ́n bí ní ọjọ́ 8 oṣù october ọdún 1992 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó ń ṣịṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti oníṣòwò orí ẹ̀rọ ayélujára tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí kolade mr dominate ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bi ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹwàá ọdún 1992 ní ìlú ijebu ipinle ogun ní orílẹ̀-ede...
dj xclusive rotimi alakija tí á bí ní ọjó kérín-dín-lógún ósù kéwáà ọdún 1980 tí òpò mò sí́ dj xclusive ó jé disc jockey nàjíríà álágbéjádẹ ígbásílè ọrín átì olórìn álágbásílè ìbèrè áyé england ní á tí bí rotimi alakija sí ówó àwón óbí náìjíríà ní òdómódé ó pádá sí náìjíríà látì lépà èkó ní ílé èkó king's college ị̀lú ...
florence seriki florence seriki mfr tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1963 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2017 jẹ́ olùdásìlẹ̀ àti adarí ilé-isé omatek ventures plc ilé-isé nàìjíríà àkọ́kọ́ ní áfríkà láti ṣe èrọ kònpútà àti àwọn ẹ̀yà ara kònpútà ìpìlẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí seriki ní ìpínl...
akintunde popoola akintunde popoola jẹ biṣọọbu anglican ni naijiria o jẹ bishop ti diocese offa titi di ọdun 2018 o si jẹ aṣoju ti gusu ibadan bayi
nana asmaʼu nana asmaʾu gbogbo orúkọ rẹ̀ ni asmaʾu bint shehu usman dan fodiyo lárúbáwá ‎ 17931864 jẹ́ ọmọ ọba fula akéwì olùkọ́ àti ọmọ ọ̀lùdásílẹ̀ sokoto caliphate usman dan fodio ó jẹ́ ẹni tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yẹ́ sí ní apá àríwá nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ má ń fi ṣe àpèjúwe bí obìnrin ṣe le jẹ́ akọ̀wé tí yó sì wà láàyè ara rẹ̀ n...
iṣegbefabo
playboi carti jordan terrell cartera bi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1996 tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí playboi carti jẹ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹrika lati atlanta georgia
halle akorin halle orúkọ àbísọ rẹ̀ ni halle grace ihmordu a bi ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gún oṣù kejìlá jẹ́ òṣèrébìnrin akọrin àti oníjó ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ fún n3rd records iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2008 ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú fíìmù relentless 20082009 wọ́n padà ṣe àgbéjáde fíìmù náà ní bfi london film festival ...
gabriel akinbolarin akinbiyi gabriel akinbolarin akinbiyi a bi ni ojo karun osu kejila odun 1949 o se igbeyawo pelu iyaafin stella a akinbiyi ni nnkan bi odun merinlelogbon seyin ni odun 1956-1961 o lo si ile iwe st john's ti anglican oke igbo leyin na o pada lo si ile iwe local authority modern oke igbo ni ọdun 1962-1...
as aventuras de gui estopa as aventuras de gui estopa jẹ jara ti ere idaraya ará brasil tí wọ́n gbé jáde lọ́dún 2009
aso
ìró ati bùbá
monica friday nigerian film actress influencer realtor model and producer monica friday tí a bí ní ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lógún oṣù kẹrin ọdún 1988 jẹ́ òṣèré fíìmù ilẹ̀ nàìjíríà oní-ipa realtor model àti olùdarí ètò ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí monica ní badagry ó sì dàgbà ní ajégúnlẹ̀ àdúgbò tí ó wà ní ìlú èkó sínú il...
joshua olufemi joshua olufemi tí wọ́n bí ní ọjọ́ 22 oṣù keje ọdún 1983 jẹ́ oṣìṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùdásílẹ̀ ìmọ̀-ẹ̀rọ fún àwọn ará ìlú òun ni olùdásílẹ̀ dataphyte òun sì ni olùdarí ètò premiun times cntre for investigative journalism èyí tí wọ́n ń pè báyìí ní the centre for journalism in...
sam oritsetimeyin omatseye sam omatseye jẹ́ akéwì òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ akọ̀tàn fún eré oeí-ìtàgé àti akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria wọ́n bí sam ní ọjọ́ 15 oṣù june ọdún 1961 ipinle delta nigeria ni ó sì ti wá ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti ọdún 2019 fún national productivity order of merit npom ètò ẹ̀kọ́ sam omatseye lọ sí ilé-ẹ̀k...
sa'a ibrahim sa'a ibrahim jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òṣìṣẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó máa di alága broadcasting organisation of nigeria bon òun sì ni olùdarí àgbà fún ẹ̀rọ̀-amóhùn máwòrán ti abubakar rimi ìgbésí ayé rẹ̀ hajia sa'a ibrahim ni wọ́n bí sínú ìdílé malam ibrahim àti yalwa b...
nneka àkọrin nneka lucia egbuna tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1980 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà akọrin àti òṣèré bìnrin ó ma ń kọrin ní èdè gẹ̀ẹ́sì igbo àti èdè pidgin nàìjíríà ìpìlẹ̀ rẹ̀ a bí nneka lucia egbuna ní warri ìpínlẹ̀ dẹ́ltà nàìjíríà a sì tọ dàgbà ní ìlú kan náà ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède jẹ́m...
gbenga omotoso gbenga omotoso tí wọ́n bí ní ọjọ́ 11 oṣù november ọdún 1961 jẹ́ akọ̀ròyìn àti òǹkọ̀wé òun ni olóòtú ìwé-ilròyìn the nation títí tí wọ́n fi yàn án sípò commissioner tó ní ṣe pèlú lagos state ministry of information and strategy gómínà ìpínlẹ̀ èkó ìyẹn babajide sanwo-olu mu ṣèbúra láti wọ iṣẹ́ ní ọdún 2019...
chido onumah chido onumah tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10 oṣù april ọdún 1966 jẹ́ akọ̀ròyìn òǹkọ̀wé àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ó ti ṣiṣẹ́ fún bíi ogún ọdún gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn òǹkọ̀wé ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn àti oníṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ghana canada india orílẹ̀ èdè america caribbean àti europe ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè phd nínú ...
kate henshaw
tobore ovuorie tobore ovuorie jẹ́ akọròyìn olóòtú ọ̀rọ̀ ìlera àti olùṣèwádìí àgbà pẹ̀lú premium times ìgbésí ayé ovuorie ṣe àtẹ̀jáde ìwé àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ó bẹ̀rẹ̀ ìwádìí abélé kan tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ inside nigeria's ruthless human trafficking mafia ní ọdún 2013 èyí tí premium times gbé jáde ní ọdún ...
aisha salaudeen aisha salaudeen tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹríndínlógbọ̀n oṣù september ọdún 1994 jẹ́ gbajúgbajà akọ̀ròyìn ajàfún ẹ̀tọ́ obìnrin aṣàgbéjáde ìròyìn àti òǹkọ̀wé tó ń ṣiṣẹ́ ní cnn lọ́wọ́lọ́wọ́ ní oṣù kọkànlá ọdún 2020 ó gba àmì-ẹ̀yẹ future awards africa prize fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú ìjábọ̀ ìròyìn àti bí ó ṣe máa ń kọ ìt...
ijo kristiẹni ti a rà pada redeemed christian church of god rccg jẹ́ ìjọ pẹ́ńtíkọ́sítì ńlá kan ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà enoch adébóyè ti jẹ́ alábòójútó ìjọ náà láti ọdún 1981 ìjọ náà tó wà ní èkó ní àwọn olùjọ́sìn tó ń lọ bíi 50000 ní ọdún 2022 ìtàn rev josiah olufemi akindayomi tí wọ́n bí ní ọdún 1909 tó ...
redeemed christian church of god redeemed christian church of god rccg jẹ́ ìjọ pẹ́ńtíkọ́sítì ńlá kan ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà enoch adébóyè ti jẹ́ alábòójútó ìjọ náà láti ọdún 1981 ìjọ náà tó wà ní èkó ní àwọn olùjọ́sìn tó ń lọ bíi 50000 ní ọdún 2022 ìtàn rev josiah olufemi akindayomi tí wọ́n bí ní ọdún 19...
uzor osimkpa nigerian actress uzoma okwuchi osimkpa jẹ́ òṣèré obìnrin ti ile nàìjíríà tí a mọ̀ sí uzor osimkpa ó jáde ní ipò kárùn-ún ní àkókò kẹsàn-án nínú gulder ultimate search ti ọdún 2012 ìgbésí ayé ó gba òye nínú ètò ọrọ̀ ajé economics education láti yunifásítì ìpínlẹ̀ ábíá ní ilẹ̀ nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ iṣẹ́ ìṣèré uz...
najite dede najite dede jẹ́ òṣèrébìnrin àti adarí fíìmù ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ arábìnrin michelle dede àti richard mofe damijo àwọn mẹ́tẹ̀ta jẹ́ òṣèré ìdílé rẹ̀ orúkọ bàbá najite ni ogbeni brownson dede aṣojú nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí sí orílẹ̀-èdè ethiopia
hanshin tigers 甲子園 5066521146jpg tigers jẹ ẹgbẹ bọọlu afẹsẹgba japanese kan akopọ awọn tigers hanshin jẹ ẹgbẹ bọọlu afẹsẹgba olokiki julọ ti japan ati pe wọn ni atẹle nla kanti o ba ṣẹgun yoo mu ariwo kan wa si japan oludari ni eyan kan ti oruko re n je shofu okada ni alakoso ati pe o gbajumo ju awon agbabooluawọn alay...
angel unigwe nigerian actress born 2009 angel unigwe orúkọ àbísọ rẹ̀ ni angel onyinyechi unigwe tí a bí ní ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2005 jẹ́ òṣèré obìnrin ti ilẹ̀ nàìjíríà ó jẹ́ aláfiwé àti aṣètò tí ó tún ṣe ìfihàn nínú àwọn ìkéde tẹlifísàn olókìkí iṣẹ́ rẹ̀ ṣàfimọ̀ sí ilé-iṣẹ́ fíìmù nípasẹ̀ ìyá rẹ̀ unigwe b...
wendy lawal yewande lawal simpson jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ènìyàn mọ́ tẹ́lẹ̀rí sí yewande lawal adebisi òun ni ó jáwé olúborí nínú ìdíje miss lagos carnival pageant ní ọdún 2012 ìtàn rẹ̀ yetunde ni ọmọ karùn-ún nínú ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbí rẹ̀ bí lawal fẹ́ wanri simpson ní ọdún 2018 ó sì pàdánù ìyá rẹ...
suntrust bank nigeria limited suntrust bank nigeria limited stbnl jẹ́ ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ètò ìnáwó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó gba ìwé àṣẹ lọ́wọ́ banki gbogboogbò ilẹ̀ nàìjíríà ìyẹn central bank of nigeria àti olùṣàkóso ilé-ìfowopámọ́ orílẹ̀-èdè
diamond bank plc diamond bank plc j olùpèsè iṣẹ́ ìnáwó orílẹ̀-èdè nàìjíríà diamond bank gba nípasẹ̀ access bank ní òṣù kejìlá ọdún 2018 ósì kédè láti parí àwọn iṣówó tí àpapọ̀ ní kíkún ní ìdajì àkọ́kọ́ tí ọdún 2019 diamond bank ti dàpọ̀ ní kíkún pèlú access bank láti kọ́ ǹkan tuntun lákokò tí ó tọ́jú orúkọ access bank ...
child prostitution in nigeria child prostitution in nigeria jẹ́ ọ̀nà ìgba fífi àwọn ọmọdé ṣiṣẹ aṣẹ́wó iṣẹ́ aṣẹ́wo ti di iṣẹ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn rí gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọ̀ọ̀jọ́ wọn kódà tọmọdé àti tàgbà ló ní ṣíṣe yíì gẹ́gẹ́ bí ohun to ń fún wọn ní jíjẹ àti mímu àmọ́ èyí kì í ṣe ọ̀nà tó dára yorùbá bọ̀ wọ́n ní ọ̀nà kan...
ìfọmọdé ṣiṣẹ́ ipá ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
child abuse in nigeria
action against trafficking in persons and smuggling of migrants in nigeria
national agency for the prohibition of trafficking in persons national agency for the prohibition of trafficking in persons naptip je ajo agbofinro ti ijoba apapo ti nigeriawon daa le ni 2003 lati le koju gbigbe eniyan ati awọn iru iru awọn ẹtọ eda eniyan naptip wa lara awọn ile-ibẹwẹ ti o wa labẹ abojuto ti ile -iṣẹ f...
ẹrú ní nàìjíríà nàìjíríà ní ìtàn ìsìnrú ó sì ń kópa nínú òwò ẹrú ifiranṣẹ jẹ bayi arufin ni agbaye ati ni nigeria bibẹẹkọ ofin jẹ igbagbogbo aṣemáṣe pẹlu oriṣiriṣi aṣa aṣa ti o ti wa tẹlẹ eyiti o wo awọn iṣe kan yatọ ní nàìjíríà àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ kan àti àwọn àṣà ìsìn ti yọrí sí “ìforígbárí tí kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ láàá...
smuggling of migrants in nigeria ṣíṣe fàyàwó àwọn ènìyàn láti ìlú nàìjíríà sí òmíràn kì í ṣe ohun àjòjì ní àgbáyé kọ́dà kò yọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà sílẹ̀ àwọn obìnrin ọmọbìnrin ọmọdé àti àwọn ọ̀dọ́ ni wọ́n máa farakaáṣá ìwà ìgbéni lọ sí ìlú mìíràn ní ọ̀nà àìtọ́ àti òwò títa ènìyàn kì í ṣe òkè òkun nìkan ni wọ́n ń kó àwọn...
nigeria sexual offenders and service provider database nigeria sexual offenders and service provider database tí ó wà lábẹ́ ìṣàkóso naptip jẹ́ olùpèsè iṣẹ́ tó ní ojúṣe láti ṣe àtòjọ àti àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn èèyàn tí wọ́n ti fi ẹ̀sùn ìwà-ipá kàn àti ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn wọ́n gan-an àwọn èèyàn tó bá ti lòdì sí àwọn òfin t...
nigeria immigration service wọ́n ṣẹ̀dá àjọ nigeria immigration service nis àjọ aṣọ́bodè ìrìnkèrindò àwọn ènìyàn láti ara àjọ ọlọ́pàá the nigeria police np lóṣù kẹjọ ọdún 1958 ní ìbẹ̀rẹ̀ wọ́n ń pè wọ́n ní immigration department chief federal immigration officer cfio ni ó ń darí wọn nígbà náà ìdásílẹ̀ wọ́n dá ẹ̀ka aṣọ́bo...
talkam sọrọsoke talkam jẹ́ ìpilẹ̀sẹ̀ devatop centre for africa development ibùdó tó ń jà fún ètọ́ ọmọ ènìyàn tí ó gúnwá sí orí ìtàkùn ayélujára tí ó ń pèsè ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàyé àti dátà lórí kíkó àwọn ènìyàn ní ọ̀nà àìtọ́ àti jíjà fún ẹ̀tọ́ àwọn ẹgbẹ́ láwùjọ ilé -iṣẹ́ àwọn amòyè fún ìdàgbàsókè àwọn ajìjàgbara fún ẹ̀tọ́ ọmọ...
anthony ojukwu anthony okechukwu ojukwu je agbẹjọro ọmọ orilẹ-ede naijiria ati akowe agba ti national human rights commission ti naijiria ni ọdun 2021 o fun ni agbẹjọro agba ti nigeria san eko ni 1998 o pari masters degree llm ni ofin ni university of lagos akoka ojukwu tun pari eto international human rights training ...
olajumoke adenowo olukowe àti oluyaworan ní nàìjíríà ọlájùmọ̀kẹ́ adénọ́wọ̀ tí a bí ní ojó kerindinlogun osù kewa odun 196816 october 1968 jé ayaworan iléarchitect omo bíbi orílè-èdè nàìjíríà obere ilé isé tí ó ún yáwòrán ilé tí ósì ún se inú ilé loso rè ní odun 1994 orúko ilé isé náà ní ad consulting orúko oko rè ni ol...
edo state taskforce against human trafficking etaht edo state task force against human trafficking etaht jẹ́ àjọ-agbófinró orílẹ̀ èdè nigeria tí ìjọba ìpínlẹ̀ edó gbé kalẹ̀ láti dènà kíkó ọmọ ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ pẹ̀lú àwọn orúkọ burúkú tí ó pèlé e ní ìpínlè náà ní báyìí àwọn ìpínlẹ̀ mìíràn bí i oǹdó ọ̀yọ́ è...
devatop centre for africa development devatop centre for africa development jẹ́ àjọ tí àwọn olùdarí wọn jẹ́ ọ̀dọ́ tí àfojúsùn wọn ò dá lórí ajọ̀ àìlérè tó ń gbógun ti kíkó àwọn ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtọ́ ìwà ipá tí orísun jẹ́ ẹ̀yà-ìbí lílọ ọmọ ní lìlòkulò fífún àwọn ọmọ tí ó ní àǹfààní ẹ̀kọ́ ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ àti díd...
ìfini ṣòwò nàbì sex trafficking in nigeria ìkóniṣòwò nàbì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ ọ̀nà kan tí wọ́n fi ń kóni rìnrìn-àjò fini ṣòwò nàbì lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìkóni ṣòwò nàbì yi tun jẹ́ ọ̀nà ìfini ṣè òwò ẹrú ìgbàlódé tip ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà fí fini ṣòwò nàbì lọ́nà àìtọ́ yí ma ń mú ìpálára àti aburú tó ...
fatima waziri-azi fatima waziri-azi jẹ agbẹjọro ọmọ orilẹede naijiria ati olori ẹka ti ofin ara ilu tẹlẹ ni ile-ẹkọ giga ti ile-ẹkọ giga ti naijiria fatima je oluranlowo pataki fun aare orilede naijiria muhammadu buhari lati osu kejo odun 2019 ko je fije oga naptip agbẹjọro ẹtọ obinrin kan lodi si iwa-ipa abele ati iba...
national commission for persons with disability national commission for person with disabilities ncpd jẹ́ àjọ kan lòrìlẹ̀-èdè naijiria ọdún 2012 ni a gbé àjọ yìí sílẹ̀ èròńgbà àjọ yìí ni láti dẹ́kun ìwà yíya àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera sọtọ̀ àti láti jẹ́ kí irú àwọn èèyàn báyìí ní ẹ̀tọ́ àti àǹfààní kan náà pẹlú ...
ọjọ́ ìkéde lòdì sí kíkó àwọn ènìyàn lọ sí ìlú onílùú lọ́nà àìtọ́ ní orílẹ̀-èdè europe eu anti-trafficking day eu anti-trafficking day jẹ́ ọjọ́ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ láti kéde lòdì sí wíwọ ìlú lónà àìtọ́ ọjọ́ kejìdílógún oṣù ọ̀wàwà ni ọjọ́ ìyàsọ́tọ̀ fún ìpolongo yìí ìgbìmọ̀ europe ni wọn dá a sílẹ̀ pẹ̀lú èròngbà áti jẹ́ kí ...
eu anti-trafficking day
women advocate research and documentation centre women advocates research and documentation centre wardc je ajo ti kii se ti ijoba ti won da sile ni odun 2000 ti wo gbogun ti iwa ipa si obinrin ati awon eniyan gbogbo ni orilẹ-ede nàìjíríà it is registered with the cooperate affairs commission nigeria and has impacted i...
child labour in nigeria
child labour in nigeria ìfọmọdé ṣiṣẹ́ ipá
international and ibero-american foundation for administration and public policies àjọ international and ibero-american foundation for administration and public policies fiiapp ni ò jẹ́ àjọ gbogbo gbo tí wọ́n dá sílẹ̀ ni abe spanish state and a member institution of cooperación española lati ọwọ́ orílẹ̀-èdè spain àjọ y...
igbeyawo ipa igbeyawo ipa je ohun kan ti owopo ni ilu naijiria ni to ri wipe ijoba apapo ati ijoba ipinle o tii fi awon ofin lele lati daa duro ni eto omode wi ilu naijiria je ilu ti igbeyawo ipa wopo ju ni ile alawo dudu eto omo eniyan ofin eto awon omode lodi si igbeyawo omo ti ko to omo odun mejidini ogun olodi si o...
drug trafficking in nigeria òwò gbígbé oògùn-olóró lọ sí ilẹ̀ mìíràn láti tà á jẹ́ ẹ̀sẹ̀ tó lágbára ni orílé èdè nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ló rí iṣẹ́ yìí bí i òwò tó lérè lóri àwọn ọ̀daràn ènìyàn ló máa ń ṣiṣẹ́ yìí èyí fi hàn wí pé kò kì í ṣe àwọn nìkan lọ máa ń mú lọ sókè òkun láti fi ṣìwò burúkú yìí èyí ti di o...
ilokulo omo obinrin ni orile ede naijiriagirls child labour in nigeria ìlòkulò ọmọ obìnrin ní orílẹ èdè nàìjíríà jẹ́ ìsẹ̀lẹ̀ tó ń sẹlẹ̀ sí ọmọ obìnrin tó wà láàrin ọdún máàrún sí mẹ́rìnlá tó ń lọ́wọ́ sí akitiyan ọrọ̀ ajé yàtò sí ẹ̀kọ́ ìwé àti ̀igbà ìsinmi wọn lílo ọmọbìnrin ní ìlòkulò ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ti di ìwà ì...
bella disu oníṣòwò ní nàìjíríàwọ́n bi ní ọdun 1986 belinda bella ajoke olubunmi disu orúkọ baba rẹ̀ ni adenuga wọ́n bí ní 29 may 1986 jé obinrin onísòwò omo nàìjirià òun ni alaga abumet tnigeria limited ígbákejì alaga ilé ise globacom oun sì tún ni oga agba cobble stone property and estate limited ati alaga julius berg...
sex trafficking in nigeria
lara george lara george tí a bí ní 25th of june 1978 jé olorin ihinrere omo bíbí ìlú nàìjirià sùgbón tí ó ún gbé ní ìlú amerika àárò ayé rè a bí lara george ní june 25 1978 sí idile oluwole bajomo ni ipinle lagos ipin iṣakoso ti nigeria ìwè rè ó kàwé ni ilé-ìwé queen's college ni èkó tí ó tó di pé ó kàwé ní yunifásitì ...
killing of baby p
derek bentley case derek william bentley 30 osu kefa ọdun 1933 28 oṣu kini ọdun 1953 jẹ ọkunrin ara ilu gẹẹsi kan ti a pa nipa siso o ro titi emi fi bo ni enu re fun ipaniyan ọlọpa kan lakoko igbiyanju idigun jale kan christopher craig ẹni ọdun mokan din l'ogun ti o je ọrẹ ati alabaṣiṣẹpọ bentley ni a fi ẹsun ipaniyan ...
kíkó àwọn ọmọ wọ orílè-èdè mìíràn lọ́nà àìtọ́ trafficking of children form of human trafficking and is defined as the recruitment transportation transfer harboring and/or receipt of a child for the purpose of exploitationkíkó àwọn ọmọ lọ sí orílẹ̀-èdè mìíràn lọ́nà àìtọ́ jẹ́ ọ̀nà kị́kó àwọn ènìyàn wọ orilẹ̀-èdè mìíràn l...
trafficking of children
kòréà
tonye garrick tonye garrick tí a bí ní 27 august 1983 tí òpòlopò ènìyàn mò sí tonye jẹ́ olorin ọmọ orílè-èdè naijiria tí a bí bi sí orílè-èdè england orin accapella rè pèlú akole what about ustí ó ko ní odun 2010 ni wọ́n lò níbi ìjíròrò ààrẹ ọ̀dọ́ nàìjíríà lọ́dún 2011 ófi isé rè kalè gégé bi olubadamoran òwò ní odun 20...
the fox and the hound the fox and the hound jẹ fílmu ti ere idaraya ará amẹ́ríkà
don jazzy michael collins ajereh tí a bí ní ọjọ́ 26 oṣù kọkànlá ọdún 1982 tí a mọ̀ mọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i don jazzyjẹ́ aṣàgbéjáde rẹ́kọ́ọ̀dù ní nàìjíríà aṣojú fún àwọn ilé-iṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ ohùn ọ̀gá ilé-iṣẹ́ orin olórin olókòwò olùsọdimímọ̀ àti adẹ́rínpòṣónú òun ni olùdásílẹ̀ àti ọ̀gá ilé iṣẹ́ mavin records don jazzy...
202021 uefa champions league
babatunde yusuf olátúnjí
d'prince charles enebeli tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1986 tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ d'prince jẹ́ ọ̀kọrin afropop tí ilé naijiria ó jé olùdásílẹ̀ àti adarí ilé iṣé jonzing world ilé iṣẹ́ ìdárayá ti ó dásílẹ̀ ni ọdún 2019 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ìpínlẹ̀ èkó ni wọ́n bí charles enebeli sí ní ọjọ́ kẹtàlélógún ...
korede bello nigerian singer korede bello tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1996 ọ̀kọrin orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti akọrin sílẹ̀ ó tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú mavin records ní ọdún 2014 orin rẹ̀ godwin ló mu bọ́ sí gbangba ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé korede èyí tí ó túǹmọ́ ko ire wá jẹ́ ọmọ tí tí wọ́n bí sí ìlú èkó ibè náà ló tí ...
d prince
don jazzy
korede bello
mavin records mavin records tị́ a tún mọ̀ sí supreme mavin dynasty jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde ní ilẹ̀ nàìjíríà tí don jazzy tí ń ṣe olórin àti agbórinjáde dá sílẹ̀ ní 8th may 2012 ilé-iṣẹ́ náà bẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn tí òpin dé bá mo' hits records ilé-iṣẹ́ tí ń ṣe ti d'banj àti ti agbórinjáde tí a dárúkọ ṣaájú ilé-iṣẹ́ náà bí i i...
reminisce reminisce alaga ibile jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ ajilete ìbílẹ̀ gúúsù yewa ní ìpínlẹ̀ ogun apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù ṣẹẹrẹ ọdún 1981 ní ìpínlẹ̀ kaduna apá àríwá orílẹ̀-èdè nàìjíríànigerian rapper singer and songwritera bí rẹ̀mílẹ́kún khàlid sàfárù ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀...
zlatan ọmọ́níyì tèmídayọ̀ raphael bí ní ọjọ́ kọnkọ̀dínlógún oṣù kejìlá ọdún 1994 tí wọ́n mọ̀ ọ́ ní tiyì sí zlatan ìbílẹ̀ jẹ́ rápà akọrin akọ-orin olórin àti oníjó nàìjíríà láti èkìtì ijero local government area ìpínlẹ̀ èkìtì ó jẹ́ olórí àti olùdásílẹ̀ zanku records ní ọdún 2014 ó gba ipò àkọ́kọ́ tí ilé-iṣẹ́ airtel pàsè...
kcee kingsley chinweike okonkwo tí a mọ̀ sí kcee jẹ́ olórin nàìjíríà àti ẹni tí ó máa ń kọ orin ó ti fìgbà kan wà nínú ẹgbẹ́ orin hip hop tí wọ́n ń pè ní kc presh ó wá láti ìlú ní uli ní ìjọba ìbílẹ̀ ihiala ní ìpínlẹ̀ anambra nàìjíríà ní báyìí ó ní àdéhùn iṣẹ́ pẹ̀lú five star music ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú del b olùgbéjáde rẹ́kọ́...
kizz daniel oluwatobiloba daniel anidugbe tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí orúkọ ìtàgé rẹ̀ kizz daniel jẹ́ nàìjíríà olórin àti a-kọ-orin ó gbajúgbajà fún àwọn orin rẹ̀ woju and yeba orúkọ ìtàgé kiss daniel ni ó ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó yí i dà ní oṣù karùn-ún ọdún 2018 ó bọwọ́lùwé àdéhùn iṣẹ́ pẹ̀lú g-worldwide entertainment ní ọd...
lil kesh kẹ́ṣhiró ọlọ́ládẹ́ bí ní oṣù kẹ́ta ọjọ́ kẹtàdínlógún ọdún 1995 tí àwọn ènìyàn mọ sí lil kesh jẹ́ olórin rápà àti akọ-orin nàìjíríà ó di ìlú-mọ̀-ọ́-ká lẹ́yìn tó kọ orin shoki ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ kẹ́shinró ọlọ́láde jẹ́ bíbí àti dàgbà sí bàrígà agbègbè kan ní ìpínlẹ̀ èkó ní nàìjíríà ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó lọ sí stockbridge coll...
living in bondage 1992 nigerian filmliving in bondage gbígbé nínú ìgbèkùn apá kìn-ín-ní àti apá kejì jẹ́ eré àgbéléwò asaragágá orílẹ èdè nàìjíríà tí chris obi rapu jẹ́ olùdarí rẹ̀ a sì ti ọwọ́ kenneth nnebue àti okechukwu ogunjiofor kọ ọ́ aṣagbátẹrù erè yìí ni ogunjiofor jafac wine ló ṣe onígbọ̀wọ́ eré náà lára àwọn a...
sonia manzano sonia manzano june 12 1950 je osere ara amerika