raw_text
stringlengths
2
128k
fatuma issa maonyo fatuma issa maonyo tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán osù kẹrin ọdún 1995 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó ṣeré ipò olùgbèjà lórí pápá fún simba queens àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin tanzania isẹ́ òkè-òkun ní oṣù keje ọdún 2018 maonyo borí ní bi ìdíje cecafa women's championship ti ọdún 20...
donisia minja donisia daniel minja tí a bí ní ọjọ́ kẹsán oṣù kẹjọ ọdún 1999 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún yanga princess àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin tanzania isẹ́ òkè-òkun ní ọdún 2018 minja mi àwọ̀n pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ta ní bi ìdíje cecafa women’s championship ti...
olusola momoh olúṣọlá momoh jẹ́ adarí àwọn ilé íròyìn kan ní nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ àti igbákejì alága ti àwọn channels media group ilé-iṣẹ́ tí ó ń darí channels tv momoh gboyè bsc ní mass communicatio láti yunifásitì ìlú èkó ó tún gba àmì ẹyẹ pí polongo ìròyìn ní yunifásitì ìlú èkó ní ọdún 2014 ó wà...
patricia kalesanwo patricia kalesanwo jẹ alamọdaju ibaraẹnisọrọ lorilẹ-ede naijiria oniroyin o tu je obinrin akọkọ ti o forukọsilẹ ti institute of journalism ti naijiria ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú eto ẹkọ agba communication arts lati yunifásítì ìlú ìbàdàn ibadan south west nàìjíríà arabinrin naa jẹ alaṣẹ ọran awọn ọmọ ile-i...
omololu falobi omololu falobi 1971-oṣù kẹwàá 5 2006 jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀ èdè naijiria ó sì jẹ́ ajìjàgbara àrùn aids ní ọdún 1997 ó ṣe ìdásílẹ̀ jaaids wọ́n ṣe ìdàsílẹ̀ ẹ̀yẹ ọmololu falobi ní orúkọ rè ní ọdún 1998 ó ṣe ìdásílẹ̀ jaaids tí ó jẹ́ àjọ tí kìí ṣe ti ìjọba pẹ̀lú èròńgbà láti kó àwọn oníṣẹ́ ìròyìn tí ó wà...
sophia mwasikili sophia edward mwasikili tí a bí ní ọjọ́ kẹrin osù kẹrin ọdún 1986 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó ṣeré ipò olùgbèjà lórí pápá àti asáájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin tanzania isẹ́ òkè-òkun mwasikili ti sojú orílẹ̀-ède tanzania ní ìpele àgbà ní bi ìdíje africa women cup of nati...
jaafar jaafar nigerian journalistjaafar jaafar jẹ́ akọ̀ròyìn ilẹ̀ nigerian ọ́ jé ọmọ bíbí ìlú kano state ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ daily nigerian ilé iṣẹ atẹ̀wéjáde orí ẹ̀rọ ayélujára èyí tí ó ṣe àgbéjáde àgbékúrú fídíò tó takọ gómìnà ìpínlẹ̀ kano abdullahi umar ganduje fún gbígba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ 5 million ní october 2018
james vivian clinton nigerian journalist james vivian clinton obe láti ọjọ́ kẹfà oṣù kejì ọdún 1902 - sí ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1973 jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ bíbí ìlú gold coast ní orílẹ̀-ède sierra leone ó jé olùgbé orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó wá láti ìdílé sierra leone creole ni apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè india àti...
hamza idris hamza idris tí a bí ní 27 july ọdún 1972 jẹ́ akọ̀ròyìn àti asàtúnse ilé-isé ìwé ìròyìn nigeria's daily trust newspapers òkàn lára àwọn ilé-isé ìwé ìròyìn tó ń síwájú ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni aláàmójútó ipò mèta ní ilé isẹ́ ìwé ìròyín tó ti ń sisẹ́ daily trust daily trust saturday and daily trust on sun...
eromo egbejule eromo egbejule j́ẹ oníṣẹ́ ìròyìn olùkọ̀wé àti oníṣẹ fíìmù ó j́ẹ́ olókìkí púpọ̀ jùlọ fún iṣẹ́ rẹ lórí ìkọlù boko haram àti àwọn ìjà mì́iràn ní iwọ-oorun àti central africa lọ́wọ́lọ́wọ́ ó jẹ́ olóòtú áfíríkà ní al jazeera english online abẹ́lẹ̀ ìlú sapele ní apá gúúsù nàíjíríà ni wọ́n ti bí egbejule ó ní àw...
mimi fawaz mimi fawaz jẹ́ akọròyìn eléré ìdárayá tí ilẹ̀ nàìjìríà-labanese olùdarí ètò àti olóòtú tí ó ń ṣiṣẹ́ gẹgẹ́ bíi olóòtú eré ìdárayá ní focus on africatí ìròyìn bbc ifètòlède fún bbc world news pẹ̀lú bbc africa àti bbc sports ó ti ṣiṣẹ́ fún cnn espn àti itv television network ní oṣù kìíní ọdún 2017 ó darí ètò ọd...
farooq kperogi nigerian academic columnist born 1973farooq adamu kperogi a bi ní ọdún 1973 ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ nàìjíríà àti amẹ́ríkà akọ̀wé born 1973 media scholarọ̀mọ̀wé ìgbóhùngbáwòrán sáfẹ́fẹ́ akọ̀ròyìn bílọ́gà àti ajìjàgbara ó jẹ́ afìròyìn léde àti aṣàtúnṣe ìròyìn ní ọ̀pọ̀ iwé ìròyìn ilẹ̀ nàìjíríà tí ó fi mọ́ dail...
tony momoh ọmọ oba tony momoh tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣu kẹrin ọdún 1939 tó sì kú ní ọjọ́ kínní oṣù kejì ọdún 2021 jẹ́ akọ̀ròyìn nàijíríà àti olóṣèlú kan tí ó jẹ́ mínísítà fún ìfitónilétí àti àṣà nàijíríà láti ọdún 1986 wọ 1990 lákòókò ìjọba ológun ti ọ̀gágun ibrahim babangida ìbí àti ẹ̀kọ́ a bí momoh ní ọjọ́ ...
robert campbell colonist robert campbell tí a bí ní 7 may 1829 19 january 1884 jẹ́ ọmọ bíbí orílè èdè jamaican tí ó fi ìgbà kan gbé ní orílè èdè united states kí ó tó lo sí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní àkókò ó kò ṣe lábẹ́ atèwéjáde kí ó tó kó ṣé láti di olùkọ́ ti èdè spéìn nígbà tí ó ri pé owó osù òun kéré nínú ìdàrúdàpò ọrọ...
simon kolawole simon kolawole jẹ́ akọ̀ròyìn aṣọ̀rọ̀-lórí-ìtàgé àti onímídíà aládàáni ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdarí ní cable newspaper limited lábẹ́ the cable iléeṣẹ́ ìwé ìròyìn orí afẹ́fẹ́ aládàáni ní ọdún 2012 àjọ ètò ọrọ̀-ajé lágbàáyé the world economic forum pe simon kolawole ní ọ̀kan lára àwọ...
wana udobang wana udobang tí a tún mọ̀ sí wana wana jẹ́ akọ̀ròyìn orile-èdè nàìjíríà ó tún jẹ́ akéwì oníròyìn òṣèré àti òṣìṣé amóhùnmáwòran iṣé rẹ̀ ti hàn ní orí bbc al jazeera huffington post bellanaija àti the guardian wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àwọn tó dáátọ́ lẹ́nu kí á sọ̀rọ̀ tó múná dóko
abidina coomassie nigerian journalist and newspaper publisher abidina coomassie jẹ́ akọ̀ròyìn àti atẹ̀wé-ìròyìn jáde ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀ coomassie ni ó dá today's communications ltd sílẹ̀ tí ó ń ṣàtẹ̀jáde ìwé-ìròyìn bí́i defunct today ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ ti abuja mirror àti èdè hausa a yau a ...
stumai abdalla stumai abdalla jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ agbábọ́ọ̀lù obìnrin tanzania ní ọdún 2019 ó jẹ́ asáájú fún ikọ̀ ẹgbẹ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nígbà tí wọ́n ń jà fún ife ẹ̀yẹ ìdíje
tejitu daba ethiopian-born long-distance runner colspan=3 style=text-aligncenter background-color#b0c4de| medal record women's athletics sport tejitu daba chalchissa ni a bini ọjọ ogun óṣu august ọdun 1991 jẹ elere sisa lobinrin to ṣoju fun bahrain daba gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura ninu idije ti ilẹ asia ere sisa ni ọdun...
matilda kerry matilda kerry jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó àti asọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ ìmóhùn máwòrán ó wà lára àwọn tí ó ń ṣe ètò the doctors ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ obìnrin tó rẹwà jù ní nàìjíríà ní ọdún 2000 ẹ̀kọ́ kerry lọ ilé ìwé federal girls college ti benin ibẹ̀ ni ó ti gba ìwé ẹrí waec rẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó parí ...
firehiwot dado ethiopian long-distance runner firehiwot tufa dado ni a bini ọjọ kẹsan óṣu january ọdun 1984 si assela arsi jẹ elere sisa lóbinrin ti ọna jinjin tufa yege ninu marathon ti new york city pẹlu wakati 22315 dado kopa ninu marathon ti rome city àṣèyọri dado kopa ninu ere awọn óbinrin ti casablanca ni ọdun 20...
birhan dagne birhan dagne ni a bini ọjọ kẹjọ óṣu april ọdun 1978 jẹ elere sisa lóbinrin jẹ ọmọ bibi ilẹ ethiopia ṣugbọn to gbe ni ilẹ british arabinrin naa da lori ere sisa ti ọna jinjin àṣèyọri dagne kopa ninu idije agbaye junior ti iaaf ti ọju ọna ni metres ti ẹgbẹrun mẹta ati metres ti ẹgbẹrun mẹwa birhan ṣoju fun b...
mamitu daska ethiopian long-distance runner colspan=3 style=text-aligncenter background-color#b0c4de| medal record colspan=3 | representing ethiopia colspan =3 mamitu daska molisa ni a bini ọjọ kẹrin lèèlogun óṣu october ọdun 1983 ẹ elere sisa lobinrin órilẹ ede ethiopia to da lo ri ti ayẹyẹ ere sisa ti oju ọna daska g...
bizunesh deba ethiopian long-distance runner bizunesh deba ni a bini ọjọ kẹjọ óṣu september ọdun 1987 jẹ elere sisa lobinrin ti ilẹ ethiopia to da lori ere sisa ti ọna jinjin arabinrin naa ṣè dada julọ ni ọdun 2014 ninu marathon ti boston pẹlu wakati 21959 àṣèyọri ni ọdun 2004 deba kopa ninu ere sisa ti ilẹ japan pẹlu ...
hamza idris
ramadan ramadan ramzan ramadhan tàbí ramathan jẹ́ oṣù kẹsàn-án nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run ẹ̀sìn ìmàle gbogbo ẹlẹ̀sìn islam ninwọ́n ma ń gba àwẹ̀ nínú oṣù ramadan jákè-jádò agbáyé tí wọ́n sì ma ń kún fún bíbẹ ọlọ́run púpọ̀ jùlọ gbígba awẹ̀ nínú oṣù ramadan lọ́dọọdún jẹ́ ìkan nínú àwọn òpó márùún ìmàle wọ́n ma ń gba awẹ̀ ní...
eleanor nwadinobi eleanor nwadinobi jẹ́ dókítà alábẹ́rẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ajà fún ètò ìlera tó péye fún àwọn obìnrin òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí a kọ́kọ́ yàn gẹ́gẹ́ bi ààrẹ medical women international association ìpìlẹ̀ rẹ̀ bàbá eleanor jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ ábíá nàìjíríà ìyá rẹ̀ sì wá láti orílẹ̀-èdè jamaica àwọn m...
mamman daura mamman daura tí á bí ní ọdún 1939 jẹ́ olóòtù ìròyìn ti nàìjíríà tí ó ṣé àtúnkọ tí ó padà ṣe ìṣàkóso nàìjíríà tuntun láti ọdún 1969 di 1975 ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí ààrẹ muhammadu buhari àti ọ̀kan gbòógì ọmọ ẹgbẹ́ kaduna mafia ẹgbẹ́ aláìmúnisìn oníṣòwò òṣìṣẹ́ ìlú ọ̀jọ̀gbọ́n àti olórí ológún láti ilẹ̀-àríwá náìjíríà...
meseret defar ethiopian long-distance runner meseret defar tola ni a bini ọjọ ọkan dinlọgbọn óṣu november ọdun 1983 jẹ elere sisa lóbinrin to da lori ayẹyẹ ti metres ẹgbẹrun mẹta ati metres ti ẹgbẹrun maarun àṣèyọri ni ọdun 2003 defar gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura ti metres ti ẹgbẹrun maarun ni ọdun 2004 defar kopa ninu o...
worknesh degefa ethiopian long-distance road runner worknesh degefa tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1990 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa ní nú eré sísá ti ọ̀nà jínjìn ní orílẹ̀-èdè ethopia arábìnrin náà jẹ́ ẹlẹ́ẹ̀kẹrin nínú àwọn tó lè sá eré jù àṣeyọrí ní ọdún 2016 worknesh kópa nínú marathon ti ìdajì ti prague ...
olayinka koso-thomas olayinka koso-thomas tí a bí ní ọdún 1937 jẹ́ dókítà alábẹ́rẹ́ tí a bí ní nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè sierra leone wọ́n mọ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè fún ipa rẹ̀ láti dá sí ṣẹ abẹ ojú ara àwọn ọmọbìnrin jòjòló dúró ní ọdún 1998 ó gba àmì-ẹ̀yẹ prince of asturias award fún iṣẹ́ rẹ̀
yihunlish delelecha yihunlish delelecha tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣu kẹwàá ọdún 1981 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínú eré-ìdárayá ti eré-sísá ní orílẹ̀-èdè ethiópíà arábìnrin náà kópa nínú ìdíje àgbáyé ti eré-sísá tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ti silver fún ilẹ̀ ethiopia àṣeyọrí ní ọdún 1998 delelecha kópa nínú ìdíje ti iaaf tó wá...
shure demise shure demise ware tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kìíní ọdún 1996 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínú eré-ìdárayá eré-sísá ní orílẹ̀-èdè ethopia tó sì ti kópa nínú ìdíje lóríṣiríṣi àṣeyọrí ní ọdún 2015 demise kópa nínú marathon ti dubai tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹrin ní ọdún 2015 demise kópa nínú marathon ti ilẹ̀ bo...
merima denboba merima denboba tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1974 ní ìlú arsi jẹ́ ọmọbìnrin eléré sísá tẹ́lẹ̀ rí tó dá lórí ẹgbẹ̀rúnmárùn-ún mítà àṣèyọri ni ọdun 2003 denboba yege ninu oeiras ti agbaye to si tun yege ninu cross internacional de itàlica ni ọdun naa arabinrin naa pada wa fun àṣèyọri keji ni ọ...
birhane dibaba birhane dibaba tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1993 jẹ́ ọmọbìnrin eléré sísá ti ọ̀nà jínjìn tó dá lórí ìdíje ti eré sísá ti ojú ọ̀nà àṣeyọrí ní ọdún 2014 dibaba kópa nínú marathon ti tokyo tó sì gbé ipò kejì láàárín wákàtí 22230 ní ọdún 2015 birhane kópa nínú marathon ti tokyo tó sì gbé ipò àkọ...
celestial church of christ benin - batism ceremony in cotonoujpg the celestial church of christ tí a tún mọ̀ sí ìjọ mímọ́ ti kristiccc jẹ́ ilé-ìjọsìn tí samuel oshoffa dá sílẹ̀ ní áfríkà ní ọjọ́ 29 oṣù kẹsàn-án ní ìlú porto-novo nih benin ó wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé pẹ̀lú orílẹ̀ èdè america àti àwọn orílẹ...
bosede bukola afolabi bosede bukola afolabi jẹ́ dókítà ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jẹ́ onímọ̀ nípa àìsàn ojú ara àwọn obìnrin òjògbón àti adarí ẹ̀ka àwọn olóyún àti àwọn àìsàn ti ojú ara obìnrin ní ilé ìwòsàn ti yunifásitì ìpínlẹ̀ èkó èkó nàìjíríà òun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti alága mrh maternal and reproductive health res...
aderonke kale aderonke kale jẹ́ dókítà ọpọlọ fún àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun nàìjíríà òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di majo general ẹgbẹ́ ọmọ ológun nàìjíríà ó wà lára àwọn adarí nigerian army medical corps iṣẹ́ rẹ̀ aderonke kale kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó ní kọ́lẹ́jì yunifásitì tí ó padà di yunifásítì ìlú ìbàdàn lẹ́yìn ...
ejegayehu dibaba ethiopian long-distance runner ejegayehu dibaba keneni ni a bini ọjọ kọkan leelogun óṣu march ọdun 1982 si bekoji jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ ethiopia àṣèyọri ni ọdun 2003 dibaba kopa ninu ere ti gbogbo ilẹ afirica ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura ni ọdun 2004 ejegayehu kopa ninu...
genzebe dibaba ethiopian middle and long-distance runner genzebe dibaba keneni ni a bini ọjọ kẹjọ óṣu february ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ ethiopia to da lori arin ati ọna jinjin àṣèyọri ni ọdun 2008 genzebe yege ninu idije agbaye u20 to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ninu mita ti ẹgbẹrun maarun lati ọdun 200...
mare dibaba ethiopian long-distance runner mare dibaba hurrsa ni a bini ọjọ ogun óṣu october ni ọdun 1989 jẹ elere sisa lóbinrin to da lori ọna jinjin àṣèyọri ni ọdun 2007 dibaba kopa ninu idije ti ilẹ ethiopia to si gbe ipo kẹfa ni bi to ti sare fun ọlọpa ti oromia ni ọdun 2008 dibaba kopa ninu idaji marathon ti new d...
betta edu betta c edu tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ́n oṣù kẹ̀wá ọdún 1986 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera ara ní ìpínlẹ̀ cross river àti alága ẹgbẹ́ àwọn kọmíṣọ́nà ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà
ọjọ́ ìbí ọjọ́ ìbí rẹ ni ìṣè-rántí ọjọ́ tí a bí ọ sáye ọjọ́ ìbí ni ajodun ojo pato ti a bi enikan gẹ́gẹ́ bí arákùnrin simon jacobson ti ṣé lálàyé ó dára kí a máa dunnú fún àwọn ohun ti a jẹ́ láyé àti ohun tí ati gbé ilé ayé ṣe sùgbón kí awá tó leè máa ṣe eléyìí a ní lati kọ́ mó rírì ìbí wa gan an ìbí ni ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí a...
michelle abueng michelle abueng tí a bí ní ọjọ́ kẹfà osù kaàrún ọdún 2001 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède botswana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù zambia fc yasa fc àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti orílẹ̀-ède botswana ó di ẹni tí ẹgbẹ́ zambia yasa queens mọ̀ nígbà tí ó ń gbábọ́ọ̀lù tako ...
nikan gaofetoge lone gaofetoge tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún osù keje ọdún 2001 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède motswana kan tí ó mú ipò olùgbèjà lórí pápá fún geronah àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède botswana
nondi mahlasela nondi mahlasela tí a bí ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1991 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède motswana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá fún prison àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède botswana
lesego moeng lesego gloria moeng tí a bí ní ọjọ́ kẹta osù kínní ọdún 1998 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède motswana kan tí ó mú ipò asọ́lé lórí pápá fún bdf àti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin orílẹ̀-ède botswana isẹ́ ẹgbẹ́ moeng ti gbábọ́ọ̀lù fún geronah ní botswana isẹ́ òkè-òkun moeng dúró fún botswana ní ìpele àgbà ní à...
olufunke adeboye olufunke adeboye jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ẹ̀ka fún ìtàn ní yunifásítì ìlú èkó nàìjíríà òun ni adarí faculty of arts ilé-ìwé náà lọ́wọ́ lọ́wọ́ àwọn ǹkan tí adeboye fẹ́ràn láti ma ṣe ìwádìí nípa ni ìtàn nàìjíríà kí ó ti pé àwọn òyìnbó amúnisìn ko nàìjíríà lẹ́rú nígbà tí wọ́n kọ lẹ́rú àti...
aisha lawal nigerian actress aisha lawal oladunni jẹ́ òṣèré nàìjíríà òǹkọ̀wé àti òṣèré fíìmù arábìnrin náà ni wọ́n yàn fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ yoruba ní ọdún 2014 city people entertainment awards òṣèré tí ó dára jùlọ nínú ìkópa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣáájú best actress in leading role - yoruba àmì ẹ̀yẹ ní ọdún 20...
christie ade ajayi christie ade ajayi tí a bí ní ọdún 1930 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń jà fitafita fún kíkó àwọn ọmọdé bí a ti ń kàwé láti ìgbà tí wón ti wà ní ọmọ jòjòló ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ní èdè gẹ̀ẹ́sì fún àwọn ọmọdé àwọn ìwé rẹ̀ sì jẹ́ ìwé nípa nàìjíríà ó tún jẹ́ olùkọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ó s jẹ́ ọmọ àw...
ummi ibrahim ummi ibrahim jẹ́ òṣèrébìrin kannywood an hausa language cinema tó di olókìkí nínú fíìmù jinsi níbi tí ó ti ní orúkọ rẹ̀ ní zeezee iṣẹ́ rẹ̀ àríyànjiyàn wà nípa òṣèré náà ní ilé-iṣẹ́ náà bí ó ṣe sọ pé òun lòún ga jùlọ èyí fa ifarapa láàrín àwọn ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ láti ìgbà tí wọ́n ti ríi kẹ́hìn ní kannywood ní ọdú...
ọláyẹmí ògúnwọlé
jasmine nwajei nigerian basketball playerjasmine nwajei tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdún 1995 ó jẹ́ ajubọ́ọ̀lù sápẹ̀rẹ̀ tí ikọ̀ first bank bc tí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó sì jẹ́ ajubọọlu sapẹrẹ tí ikọ̀ nàìjíríà nigerian national team ó ṣojú ikọ̀ nàìjíríà ní 2019 women's afrobasket wagner and syracuse statistics source
katherine obiang katherine obiang jé òsèrébìnrin ọmọ orílẹ-èdè nàìjíríà àti cameroon agbóhùn-sáféfé àti olóòtú ètò amóhùnmáwòran lákòókó ó sisé gégé bíi olóòtú ètò amóhùnmáwòrán fun nigerian television authority nta ni am express àti nigeria info 993fm ó bèrè sí ní se eré ó sì n kópa nínu sinimá àgbéléwò ó kópa nínu er...
chioma udeaja chioma udeaja tí a bí ní june 29 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n tó gbá bọ́ọ̀lù náà fún first bank àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọmọbìnrin yìí ni a tún mọ̀ sí elephant girl iṣẹ́ rẹ̀ lágbàáyé ó kópa nínú women's afrobasket tó wáyé ní ọdún 2017
mfon udoka nigerian-american basketball player and coach mfon sunday udoka tí a bí ní ọjọ́ kerin-dín-lógún oṣù kẹfà ọdún 1976 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà-amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀rí agbábọ́ọ́lù inú agbọ̀n tí ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ olùkọni fún ẹgbẹ́ bọ́ọ́lù inú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà d'tigress tí a bí ní portla...
ifeoma aggrey-fynn ifeoma iphie aggrey-fynn 8 june 1980 2 june 2015 known to most simply as iphie was a ghanaian-nigerian media personality writer and public speaker ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ́ baba tí ó bí aggrey-flynn jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè ghana nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n bí sílu nàìjíríà ó sí kẹ́...
sarah ogoke sarah ogoke tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1990 jẹ́ agbá bọ̀ọ́lù ọwọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti amerika fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ferroviário de maputo àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù owó orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kópa ní eré ijíde ti àwọn elégbé rẹ̀ obìnrin tí ó wáyé ní odún 2017 àti 2019 ogoke jé ọ̀kan lá...
linda ogugua linda ogugua tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1978 je agbá-bọọọlu sínú agbọ̀n ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó ń gba fún ẹgbẹ́ women's basketball center ogugua lọ sí fáṣítì ìlú california ní orílè-èdè amẹ́ríkà ódẹ̀ tún gbá bọọọlù pẹ̀lú the nigeria women's national basketball team ní 2004 summer olympics ayé ...
sadio mane sadio mané tí wọ́n bí ní oṣù kẹrin ọdún 1992 ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè senegal ó tún jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lọ́wọ́ iwájú fún ikọ̀ bayern munich nínú ìdíje bundesliga ó tún gbajú-gbajà àti ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tí ó dára jù lọ ní ilẹ̀ afrika wọ́n mọ̀ ọ́n fún eré-sísá ègé-gígé lórí pápá mane bẹ̀ẹ̀rẹ ère ...
mactabene amachree agbábọ́ọ́lù sínú ìwọn fún orílè-èdè naijiria mactabene amachree ọjọ́ ìbí jẹ́ ọjọ́ tí ó gbèyìn oṣù kínní ọdún 1978 ni ìpínlè port harcourt ní orílé èdè nàìjíríà jẹ́ agbábọ́ọ́lù sínú ìwọn fún orílè-èdè nàìjíríà ní ìgbà kàn rí tẹ́lẹ̀ ní ọdún 2001 òun yìí ní obìnrin àkọkọ́ tí ó sì wà láti orílè èdè nàìjí...
itoro umoh coleman american basketball player-coach itoro umoh-coleman ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 1977 jẹ́ òní ère ìdárayá ọmọ orílẹ̀-èdè amerika àti agbábọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá tẹ́lẹ̀rí fún ẹgbẹ́ wnba ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù clemson tigers ní ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé ó sì jé adarí ẹgbẹ́ náà n...
fade ogunro fade ogunro jẹ́ agbóhùn sáfẹfẹ́ ilé isé ìròyìn àti amóhùnmáwòrán olóòtú fíìmù àti aràsọ/amúnidára òun ni olùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé isé e bookings africa ilé isé kan fún pèsè kárdì fún lílọ ẹ̀rọ ayélujára ní ilẹ̀ áfríkà ó jẹ́ ọmọbíbí ìpínlẹ̀ ekiti ní apá ilà-oòrùn orílẹ́-èdè nàìjíríà ó ń sọ èdè gẹ̀ẹ́sì èdè ...
zina saro-wiwa zina saro-wiwa tí a bí ní ọdún 1976 port harcourt nigeria jẹ́ olórin fídíò àti onífíìmù tí ó gbé ní brooklyn ó ṣe àwọn fídíò àwọn ìwé àkọọ́lẹ̀ àwọn fídíò orin àti àwọn fíìmù àdánwò saro-wiwa ni olùdásílẹ fíìmù ti ẹgbẹ́ alt- nollywood ìgbìyànjú tí ó ńlò ìtan-àkọọ́lẹ̀ àṣà àti àwọn àpéjọ wíwò ti ilé-iṣẹ́ fí...
sarah imovbioh nigerian basketball playersarah imovbioh jẹ́ ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlelógùn oṣù karùn-ún ọdún1992ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá tí orílẹ̀-èdè náìjíríà fún peac-pécs àti nigerian national team
joanne aluka joanne aluka-white tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógbọ̀n oṣù kẹrin ọdun 1979 ní jackson mississippi orílẹ̀-èdè amerika jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria àti amẹ́ríkà igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ wọ́n bí i ní ìpínlẹ̀ mississippi ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó sì gba ẹ̀tọ́ ọmọ ìlú nàìjíríà lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ...
anita alaire afoke asuoha anita alaire afoke asuoha jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín alámì-ẹ̀yẹ ètò stand up òṣèré olóòtú ètò ìgbáfẹ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára àti atọ́nisọ́nà lórí ọ̀rọ̀ ayé àti ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ jẹ́ real warri pikin ìgbésí ayé rẹ̀ anita asuoha tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1990 ó sì d...
joanne alaku
bolanle olukanni orílẹ̀-èdè nàìjíríà isírẹ́lì amẹ́ríkà àti kẹ́ńyà ni wọ́n ti tọ́ bọ́láńlé bọ́láńlé olukanni lọ si st saviour's primary school ní ìlú eko fún ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ó tẹ̀ síwájú lọ sí queens college fún ilé-ẹ̀kọ́ gírámà olukanni tún lọ sí kenya níbití ó ti lọ sírosslyn academy ni nairobi kenya fún ...
nyma akashat zibiri nihmatallah akashat zibiri tí wón tún mọ̀ sí nyma jẹ́ agbẹjọ́rò àti olóòtú ètò tẹlifíṣọ̀nù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olóòtú ètò àràárọ̀ your view lórí tvc ìgbé ayé ó ṣetán nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin láti ilé-ìwé lagos university wọ́n sì pè é wọ nigerian bar aláṣedánwò mùsùlùmí nihmatal...
adora oleh nigerian tv hostadora oleh jẹ́ ọmọ bíbí ìlú bírítìṣì olóòtú telifísàn àti olóòtú àkọ́kọ́ tí mtn project fame èyí tí ó ṣe olóòtú rẹ̀ fún ọdún márùn-ún ni ọjọ́ àìkú 8 oṣù kejìlá ọdún 2013 adora oleh ní ó gba àmì ẹ̀yẹ fún olóòtú obìnrin tó gbajúmò ní nigeria broadcasters awards èyí tí ó wáyé ní ìlú èkó ó jé oló...
adora oleh
ìtọrọ umoh coleman
alexander abiodun adebayo bada alexander abiodun adebayo bada ọjọ́ ìbí ní ọjọ́ kẹrin osu kejìlá ọdún 1930- ojọ́ kẹjọ ọdún 2000 jẹ́ olùsọ́-àgùtàn kejì tí ilé ìjósìn tí amò sí celestial church of christ ccc tí ó tẹ̀lẹ́ olùdásílẹ̀ ilé ìjósìn náà ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ samuel biléhou joseph oschoffa ní oṣù kejìlá ọdún 1985 ìbẹ...
seye kehinde oluseye olugbemiga kehinde 21 osù kẹrin 1965 jẹ akọ̀ròyìn oríẹ-ède naijiria ti o jẹ olùdásílẹ̀ city people group limited igbesi aye ibẹrẹ a bí kẹ́hìndé ni ipinle iṣara ogun ni naijiria bí o tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn òbí rẹ méjèèjì jẹ òṣìṣẹ́ ìjọba ó ní ìwé ẹ̀rí nínú ṣíṣe àti ìfiròyìn lédè ó sì gba ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ...
sarah imovbioh
fade ogunro
linda ogugua
sarah ogoke
katherine obiang
tirunesh dibaba ethiopian long-distance runner tirunesh dibaba ni a bini ọjọ akọkọ óṣu june ọdun 1985 jẹ elere sisa lóbinrin to dalo ri ọna jinjin ati ere ti oju ona oke okun àṣèyọri tirunesh kopa ninu ere olympic to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura lẹẹmẹta ni ọjọ kẹfa ósu june ọdun 2008 dibaba kopa ninu ere ti bislett to...
dera dida ethiopian long-distance runner dera dida yami ni a bini ọjọ kẹrin dinlọgbọn óṣu october ọdun 1996 jẹ elere sisa lobinrin ti ilẹ ethiopia to da lori ọna jinjin àṣèyọri ni ọdun 2017 dera kopa ninu idije agbaye lori ere sisa ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa pẹlu wakati 315175 ni ọdun 2019dera gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver...
dihininet demsew jara dihininet demsew jara ni a bini ọjọ kaarun leelogun óṣu september ọdun 1994 jẹ elere sisa lóbinrin to da lori ayẹyẹ oju ọna aṣèyọri ni ọdun 2009 demsew kopa ninu marathon ti alaafia kosice to si pari pẹlu ipo karun pẹlu wakati 24803 ni ọdun 2016 demsew ṣoju fun órilẹ ede rẹ ninu idaji idije ti mar...
etenesh diro ethiopian long-distance runner etenesh diro neda ni a bini ọjọ kẹwa óṣu may ọdun 1991 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede ethiopia aṣèyọri etenesh kopa ninu olympics ti 2012 ati 2016 lori mita ti ẹgbẹrun mẹta ti steeplechase ni ọdun 2012 diro kopa ninu àṣekagba ere olympic to waye ni london pẹlu ipo kẹfa p...
lishan dula lishan dula gemechu ni a bini ọjọ kẹ̀ta dinlọgbọn óṣu february ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ti órilẹ́ ede ethiopia arabinrin naa da lori ọna jinjin to ṣoju fun bahrain àṣèyọri ni ọdun 2012 dula kopa ninu marathon ti olympics ti summer pẹlu wakati 23620
iyàrá ìdáná iyàra ìdáná jẹ́ ibi tí a tí n pèlò tí a sì ti n dáná se oúnjẹ yàra ìdáná jẹ́ ibìkan tí ayàsọ́tọ̀ nínú ilé ìgbé fun iṣé oúnjẹ sísè lóríṣíríṣi yàra ìdáná jẹ́ ibi tí a tí n pèlò tí a sì ti n dáná se oúnjẹ nítorí áwọn ohun èlò ìdána tí ó póríṣíríṣi tí an ṣe àmúlò àti pẹ̀lú onírurú ènìyàn tí o ń wọ iyàrá ìdáná m...
list of articles created from the 7th of april to the 30th of april april 2023 list of articles i created and edited on yoruba wikipedia from april 7th - april 30th 2023 list of articles created aisha lawal ummi ibrahim mfon udoka
yàrá ìdáná
ibiyinka a fuwape ibiyinka a fuwape tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1962 jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n físísì ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ẹni èkejì láti di adarí yunifásitì michael and cecilia ibru yunifásitì aládàáni kan ní nàìjíríà ìpìlẹ̀ a bí ibiyinka fuwape ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kejìlá ọdún 1...
richard brook
dupsy abiola modupeola dupsy abiola tí a bí ní oṣù kẹta ọdún 1982 jẹ́ agbẹjọ́rò àti oníṣòwò obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ilẹ̀ọba aṣọ̀kan ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdarí international airlines group iag òun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti adarí intern avenue ìpìlẹ̀ wọ́n bí dupsy abiola ní london orílẹ̀-èdè england òun ni ọm...
gbadebo rhodes-vivour use both this parameter and |birth_date to display the person's date of birth date of death and age at death -->|death_place=|death_cause=|body_discovered=|resting_place=|resting_place_coordinates=|burial_place=|burial_coordinates=|monuments=|nationality=nigerian|other_names=|siglum=|citizenship=|...
ashley battle ashley battle ti won bi ni ojo kokanlelogbon osu karun un odun 1982 jẹ akosemose agba boolu alapere eni ti o dara po mo iko agba boolu alapere seattle storm ọdun 2005 o bawon gba ifesewonse meji ki o to di pe won yọkuro o wa darapo mo new york liberty fun idije saa 2006 titi di 2009 o bawon kopa ninu idij...
chinyere kalu chinyere kalu mfr orúkọ àbísọ rẹ̀ ni onyenucheya jẹ́ obìnrin ọmọ orílẹ̀-edè nàìjíríà àkọ́kọ́ láti di awakọ̀ èrò ojú òfuurufú àti obínrin àkọ́kọ́ láti wa ọkọ̀ ojú òfurufú ní orílẹ̀-ede nàìjíríà ayé rẹ̀ ó jẹ́ ọmọ bíbí akwete ijoba ìbílẹ̀ ìwọ oòrùn ukwa ní ìpínlẹ̀ ábíá ìwọ oòrùn nàìjíríà kalu dàgbà lábé ìtọ́...
blessing liman blessing liman tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ọdún 1984 jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ajagun ojúòfurufú nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mọ́ gẹ́gẹ́ bi ọkàn lára àwọn obìnrin awa ọ̀kọ̀ ojú òfuurufú ti ológun tí ó dára jùlọ ní nàìjíríà ayé rẹ̀ wọ́n bí blessing liman ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì ọdún 1984 ní zangon kataf ìpínl...
hadiza lantana oboh hadiza lantana oboh ọdún 1959 sí 1998 jẹ́ awakọ̀ ojú òfuurufú ọmọ-orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun nìkan ni obìnrin tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi awakọ̀ ojú òfuurufú fún ilé ìṣẹ́ nigeria airways wọ́n ṣekú pá ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kejì ọdún 1998 àwọn afunrasí nínú ọ̀rọ̀ náà jẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ nínú ilé rẹ̀ tí wón jà lólè ay...
kalifọ́rníà
adeola ogunmola showemimo adeola sowemimo jẹ́ awakọ̀ ọ̀furufú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ adeola bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní sunrise aviation academy ní orílẹ̀ èdè amerika níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 2011 àwọn àṣeyọrí ní ọdún 2019 ó di obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àkọ́kọ́ láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú qatar airways ní ààrin...
tosin ajibade nigerian writer and blogger tosin olorisupergal ajibade oluwatosin ajibade tí a bí ní ọjọ́ kẹta-dín-lógún oṣù kejì ọdún 1987 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí a mọ̀ fún ojú òpó wẹ́ẹ̀bù eré ìdárayá àti ìgbésí ayé rẹ̀ olorisupergalcom àti láìpẹ́ ààyè ayélujára tirẹ̀ tosinajibadecom ó tún jẹ́ olùṣètò 'new media...
angela emuwa angela olufunmilayo emuwa jẹ́ adarí àwọn oníròyìn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ alága punch media foundation tí àwọn ìgbìmọ̀ punch nigeria limited yàn ní ọdún 2018 lẹ́yìn ikú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ gbadebowale wayne aboderin ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2018 kí wọ́n tó yàn án sípò gẹ́gẹ́ bí alága ó ti dara pọ̀ mọ́...